Yoruba Language Scheme of work for SSS 3. SS3 Schemes of Work Yoruba for Secondary School – Schemeofwork.com
SSS 3 Yoruba Language Scheme of Work First Term
EDE YORUBA AGBEYEWO ATE ETO TITUN OLODUN KETA (SS3) SA’A’ KI N-IN-NI
OSE | ORI ORO | ERONGBA | AKITIYAN | OGBON AMUSE | OHUN ELO AMUYENI |
1 | Ede Idanwo ranpe ikini kaabo | Lati je ki akekoo mo pe ise ti bere | Idanwo Ranpe/Ikinikaabo | Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro | Akosile ateyinwa |
Ede Itesjwaju eko lori isoro oro ise Alaye lori orisii ati ilo re ninu gbolohun | Ni opin Idanilekoo awon akekoo yoo i.So ki ni isoro oro je ii.Daruko orisirisi isoro oro to wa ninu gbolohun ede Yoruba iii.Lo won ni gbolohun kikun io.Dawon mo ninu gbolohun ti won ba tiba won pade o.Dahun ibeere lori | -Awon akekoo daruko awon isoro-oro ti o wa ninu gbolohun ede Yoruba. -Awon akekoo salaye ise ti isoro oro kookan n se ninu gbolohun -Awon akekoo se oniruuru apeere nipa lilo awon oro naa ni gbolohun -Awon akekoo dahun ibeere lokan-o-jokan. -Awon akekoo se akosile koko ise | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyan isoro. Ogbon Ajumose ati ibanisoro Eko Ajemawujo Eko Ero Ayelujara | Ate alagbeka ti a ya isoro oro ise si gege bi ekaigi Fidio Awon isoro oro Youtube KAPTO https://olukoniblogspot.eom https://m.faeebook.eom | |
Asa:Afiwe asa isinku abinibi ati eto isinku ode oni Ayipada to ti de ba asa isinku abinibi | Ni opin idanilekoo awon akekoo yoo le iSalaye eto isinku abinibi ati ti igbalode ii.se agbeyewo mejeeji iii.so iyato to ti de ba ilana isinki abinibi io.pa owe to ti inu asa isinku jade | -Awon akekoo salaye eto isinku abinibi -Awon akekoo jiroro nipa eto isinku ode-oni ni ilana Musululmi ati Kiritieni -Awon akekoo se afiwe isinku abinibi ati ode-oni Awon akekoo se akosilekoko ise | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro | Aworan posi Aworan oku ti a te sile https://pdfslide.net https://345peot.wordpress.eom https:olukoni.biogspot.eom |
2 | Ede itesiwaju eko lori isoro gbolohun gege bi ihun won Gbolohun eleyo oro ise Gbolohun olopo oro ise sise akojopo gbolohun Eleyo oro ise,Gbolohun olopo oro ise | Ni opin Idanilekoo le: i.Fun gbolohun ni oriki /so ohun to je ii.Da orisirisi gbolohun to wa mo iii.Salaye ohun ti gbolohun eleyo oro ise ati olopo ere ise je io.So ijora ati iyato to wa laarin won o.Dahun ibeere lori eko yii | -Awon akekoo salaye oriki `gbolohun ni kikun -Awon akekoodaruko eya gbolohun ti o wa -Awon akekoo jiroro nipa gbolohun eleyo oro-ise ni kikun -Awon akekoo toka si ijora ati iyato laarin gbolohun eleyo oro-ise ati olopo oro-ise -Awon akekoo se akosile koko ise | Ogbon Atinuda ayti Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro | Paali alagbeka ti ati ko apeere gbolohun eleyo oro ise ati olopo oro ise si. https://yo.m.wikipedia.org |
OSE | ORI ORO | ERONGBA | AKITIYAN | OGBON AMUSE | OHUN ELO AMUYENI |
Asa :Eto ogun jija.Awon iran tabi orile ti o maa n jagun ni ile Yoruba laye atijo Eeto aabo ilu atyi ipa ti awon ebinrin n ko ninu eto ogun. | Ni opin Idanilekoo awon akekoo yoo le: i.So bawo la se n jagun laye atijo ii.Salaye awon nnkan to n fa ogbun iii.Mo bi awon ara won lowo ogun io.Mo awon oloye ogun o.So ipa ti awon obinirin n ko ninu eto ogun jija oi.Dahun ibeere lori eko yii | –Awon akekoo salaye awon okunfa ogun -Awon akekoo daruko awon iran to n jagun laye atijo -Awon akekoo salaye bi a se n se eto aabo ati ipa ti awon aobinrin n ko ninu eto ogun -Awon akekoo daruko orisii awon ohun elo ogun jija laye atijo -Awon akekoo se akosile koko ise | Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro Eko Ajemawujo | Aworan olori ogun (balogun ti a ya. Aworan eroja ti a n lo fun ogun jija | |
Litireso: Agbeyewo iwe ti Ajo WAEE/NEEO yan. Itan onkowe ni soki,itan inu iwe naa ni soki ati awon ohun amuye miiran Egedida lati owo s.m. Raji (Estension publishers) | Ni opin Idanilekoo awon akekoo yoo le i.Se nipa eniti o ko iwe ti won n ka. ii.Mo itumo akori iwe naa. iii.Daruko awon eda inu itan naa io.fa koko ti itan naa dale yo o.Da iwe na ka ni akaja gaara | – Awon akekoo sero soki nipa onkowe litirese Ege dida ti S.M. Raji ko – Awon akekoo salaye iru ewi alohun ti Ege dida je ati ibi ayeye ti a ti n da ege – Awon akekoo jiroro nipa esin ti o ni ede dida lati ipile ki o to di gbogbogboo nibi ayeye – Awon akekoo se akosile koko ise | Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro Ogbon Idari Akekoo Eko Ajemawujo | Owe ti a n ka (Ege dida lati owo S.M Raji) Imo Ede, Asa Ati Litirese fun ile-eko Sekondiri Agba – Adewoyin, S.Y. Akekoo to mo ege da to n dege loju awon ako elegbe re |
3 | Ede: Itesiwaju lori ihun oro. Dida oro oruko ti aseda mo yato si eyi ti a ko seda. Itupale oro eniyan sise akojopo oro oruko | Ni opin Idanilekoo awon akekoo yoo le: i. Se awn ona ti a n gba seda oro oruko ninu ede Yoruba | – Awon akekoo daruko orisirisii oro-oruko nigba ti oluko n ko o soju patako ikowe – Awon akekoo pin apeere oro-oruko si ona meji – Awon akekoo sapejuwe awon ona ti a na gba lati seda oro- oruko. – Awon akekoo se akosile koko ise | Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro | Paali alagbeka ti ati ya orisi awon ona ti a n gba seda oro oruko si https://olukonibolgspot.eom https://m.faeebook.eom https://www.waoobiamas.ng.eom |
Asa: Itesiwaju eko lori Egbe Awo: i. Orisi egbe Awo ti o wa nile Yoruba ii. Alaye kikun lori ipa ti awon egbe wonuyi n ko ninu rto Oselu, Eto oro aje, Etutu ilu, awon oye inu egbe Awo ati imura won | Ni opin Idanilekoo awon akekoo yoo le: i. Salaye ki ni egbe awo ii. Mo bi won se n mura lokunrin/ obinrin iii. se pataki/ iwulo won laarin ilu. io. Soro nipa awon oloye egbe o. Mo eewo won / ofin to de egbe won | -Awon akekoo salaye itumo egbe awo ni ibamu si igbagbo Yoruba -Awon akekoo daruko orisiirisii awon egbe ao -Awon akekoo jiroro nipa ipa ti awon egbe awo n ko ninu eto oselu, oro aje, etutu ilu abbl | Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro Eko Ajemawujo | Aworan to n fi imura egbe Awo han ati ojubo |
OSE | ORI ORO | ERONGBA | AKITIYAN | OGBON AMUSE | OHUN ELO AMUYENI |
oi. Dahun ibeere lori eko yii | -Awon akekoo sero nipa awon oye to wa ninu egbe -won akekoo so awon eewo ati ofin to de omo egbe ninu awo -Awon akekoo se akosile koko ise | ||||
Litirese; Itupale Asayan iwe ti Ajo (WAEE/NEEO) yan | Ni opin Idanilekoo awon akekoo yoo le: i. Tesiwaju ninu kika iwe naa ii. Mo bi a se n dege sii ohun ti a n lo ohun ti a n lo fun-un | -Awon akekoo ka iwe Litirese Apileko Ege Dida -Awon akekoo salaye awon koko ti o suyo ninu iwe naa -Awon akekoo jiroro nipa awon koko ti won menuba -Awon akekoo se akosile koko ise | Ogbon Atinuda ayti Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro | Iwe ti a n ka. (Ege Dida- lati owo S.M Raji) Lilo eroredio lati ka ege lesi awon akekoo |
4 | Ede: Itesiwaju ninu Aaayan Ogbufo i. Ogbon ti a n ta fun Aaayan ogbufo lati ede geesi si ojulowo ede Yoruba ii. Fifi Oye itumo ayoka oloro geere to ta koko ju ti ateyinwa lo lati inu ede Geesi si ojulowo Yoruba ajumolo | Ni opin Idanilekoo awon akekoo yoo le: i. Se ekunrere alaye lori ohun ti Aayan Ogbufo je. ii. Da ilana ti a le tele lati se ogbufo ede kan si omiran. iii. Se iyato laarin ogbufo ewi ati oloro wuuru io.Dahun ibeere lori eko yii | Awon akekoo so itumo aayan ogbufo -Awon akekoo salaye ilana ati akitiyan lati tu tumo ede kan si omiran -Awon akekoo jiriri nipa orisii ogbufo ti o wa. -Awon akekoo sero lori awon ilana ti a gbodo tele nigba ti a ba n se ogbufo -Awon akekoo juwe iyato laarin ogbufo elewi ati oloro geere. -Awon akekoo se akosile koko ise | Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro | Paali alagbeka ti ati ko awon oro Geesi si ati itumo won ni ede Yoruba si https://www.worldeat.org https://m.faeebook.eom https://m.youtube.eom |
Asa: Itesiwaju nipa igbagbo awon Yoruba si aseyin-waye ati abami eda | Ni opin Idanilekoo awon akekoo yoo le: i.. So iha ti awon nsYoruba ko si Ajinde ii. Salaye awon ohun to fi idi eyi mule iii. Mo bi awon idid wonyi se ro mo aseyinwaye (ala, oju-oiri, Egungun, Akudaaya, Siso omo ni iyabo, yejide tabi Babarimisa, Babatunde abbl | -Awon akekoo salaye igbagbo awon Yoruba nipa ajinde ati awon ohnmiran ti o fi rinlo pe ajinde wa leyin iku. -Awon akekoo sero nipa awon ohun ti o ro mo aseyinwaye bi apeere ala lila, Oju oori,egungun, akudaaya, siso omo loruko bii iyabo, yejide tabi Babarimisa, Babatunde abbl. -Awon akekoo se akosile koko ise | Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro Eko Ajemawujo | Aworan oju sori, Aworan Egungun, eni to n je iyabo/Yetunde, Yejide tabi Babajide, Babarimisa lati so idi ti won fi sowon loruko yii https://Ambassadorseollege.eom.ng https://m.youtube.eom Ohun ti o wa leyin iku lati owo yorubaminbar |
OSE | ORI ORO | ERONGBA | AKITIYAN | OGBON AMUSE | OHUN ELO AMUYENI |
Litirese: Itesiwaju ni kika Asayan iwe ti Ajo WAEE/NEEO yan. Ege Dida- S.M Raji | Ni opin Idanilekoo awon akekoo yoo le: i. Tesiwaju ninu kika itan inu iwe ii. Salaye ona ti Ege Dida maa n tele iii. Mo koko to maa n jeyo ninu ege dida io. So ibi ayeye ti won ti le lo ege dida. o. Da iyato ati ijora Ege dida ati awon ewi alohun yoku. oi. So ilu tabi awon eya to ni ege dida nile Yoruba oii. Dahun ibeere lori koko eko | – Awon akekoo ka iwe litirese apileko Ege Dida ni kilaasi -Awon akekoo salayebi Ege Dida se jo rii agbegbe Egba -Awon akekoo to wa laarin Ege dida ati Orisa Oro -Awon akekoo se akosile koko ise | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro Ogbon Idari Akekoo Eko Ajemawujo | Iwe ti a n ka Ege dida lati owo S.M Raji Imo Ede, Asa ati Litirese Yoruba Adewoyin S.Y | |
5 | Ede: Itesiwaju, eko lori Akaye ayoka (Agbeyewo orisirisi akaye bii oloro geere, ewi ere onitan, fifi orisirisi ayoka danra) | Ni opin Idanilekoo awon akekoo yoo le: i. Salaye ohun ti akaye je ii. Mo orisi akaye to wa ati bi a se le ka won iii. Fa koko inu akaye yo io. Dahun ibeere abe akaye | -Awon akekoo salaye ohun ti akaye je ati isori akaye to wa -Awon akekoo ka akaye oloro geere ni kilaasi -Awon akekoo se itumo awon oro to ta koko ninu akaye naa. -Awon akekoo dahun ineere -Awon akekoo se akosile koko ise | Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro Eko Ajemawujo | Kaadi pelebe ti ati ko awon oro tuntun to suyo inu ayoka naa si Iwe idanwo WAEE ati NEEO ti o koja |
Asa: Itesiwaju eko lori eewo Awon eewo ti aisan mu wa. Akojiopo aisan ati eewo ti alaisan kookan ko gbodo deja Anfaani awon eewo fun alaisan | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. So nipa onkowe ii. Ka awon oriki orile naa ni akaye iii. oriki awon iran/eya Yoruba bii ologbeje, Arresa, opomulero abbl io. Da eewo ilu /iran kookan yo o. Dajun ibeere lori eko yii | -Awon akekoo salaye itumo eewo nile Yoruba -Awon akekoo daruko awon anfaani ti o wa ninu eewo -Awon akekoo salaye orisii eewo -Awon akekoo se akosile koko ise | Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro Eko Ajemawujo | Paali algbeka ti ati ko eewo si ni ibamu pelu iseri won https://m.faeebook.eom https://www.bbe.eom.yoruba https://youtube.eom.watehhooduaoieeteleoision | |
Litirese : Itupale asayan iwe ti ajo WAEE/NEEO yan (Awon oriki oriie mettadinlogbon Oju Ewe 112- 314) | Awon akekoo jiroro nipa onkowe -Awon akekoo ka oriki orile -Awon akekoo fa eko ti o wa ninu oriki-orile kookan yo -Awon akekoo se akosile koko ise | Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro | Iwe oriki onile metadinlogbon |
OSE | ORI ORO | ERONGBA | AKITIYAN | OGBON AMUSE | OHUN ELO AMUYENI |
6 | Ede: Atunyewo awon isori oro-oruko oro, Aropo | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Da awon isori oro to wa ninu ede Yoruba mo ii. Se ekunrere alaye lori okookan won. iii. Se ise ti okookan won n se ninu ise won io. Dahun ibeere lori koko eko | Awon akekoo daruko awon isori to wa ninu gbolohun -Awon akekoo sapejuwe gbolohun -Awoon akekoo se itupale oniruuru gbolohun ti oluko ko soju patako ikowe -Awon akekoo se akosile | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro | Aworan yi to peka isori oro inu ede Yoruba https://olukoni.blogspot.eom https://yo.m.wikipedia.org https://theyorubasoeialarena.blogspot.eom |
Asa: Itesiwaju eko lori oruko ile Yoruba oruko Amutorunwa, oruko abiso ati oriki inagije | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Mo iyato laarin oruko ile Yoruba ii. Salaye idi ti awon kan fi n je awon kan fi nje awon oruko kan iii. Da awon oriki abiso mo yato si oriki orile io. se akojo awon oruko wonyi o. Dahun ibeere lori eko yii | -Awon akekoo daruko amutorunwa -Awon akekoo mu orisirisi apeere oruko ti o jemo idile ati ise -Awon akekoo soro nipa orisii oruko inagije -Awon akekoo toka si oriki oruko abiso -Awon akekoo se akosile koko ise | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro | Paali algbeka ti ati ko eya awon oruko wonyi si https://books.google.eom https://www.nairaland.eom | |
Litirese: Itupale Asayan iwe ti Ajo WAEE/NEEO yan. Awon oriki orile metadinlogbon | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Tesiwaju ninu kika ewi naa ii. Mo oriki orile iran kookan ati idi ti awon koko kookan se jeyo iii. So idi ti Eewo se wa fun aiwon iran kan io. Dahun ibeere lori idanilekoo yii | -Awon akekoo so oro soki nipa onkowe -Awon akekoo soro nipa awon oriki ti o wa ninu iwe naa -Awon akekoo jiroro nipa eko inu awon oriki naa. -Awon akekoo se akosile | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati Ibanisoro Eko Ajemawujo | Aworan eni to n ki ode iran kan. Awon oriki orile metadinlogbon o.i. 117-314 |
7 | Ibewo awon obi si ile eko lati wo bi awon omo won se sesi ninu eko won ati ki ni ona abayo | Leyin abewo, obi ati oluko fikunlukun lori ona ti awon omo naa yoo se le se aseyori rere | Ibewo awon obi si ile eko lati wo bi awon omo won se sesi ninu eko won ati ki ni ona abayo | Leyin abewo, obi ati oluko fikunlukun lori ona ti awon omo naa yoo se le se aseyori rere | |
Olude idaji saa | Olude idaji saa | Olude idaji saa | Olude idaji saa | Olude idaji saa | |
8 | Ede: Iba Isele (Aseranwo oro-ise): i. Orisi Iba isele to wa Asetan, Aterere. Aisetan abbl. ii. Awon wuren ti o toka iba isele | Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Se kini iba isele fun iba isele loriki ii. Da orisi iba isele to wa mo iii. Fawon yo ninu gbolohun ede Yoruba | -Awon akekoo salaye orisi iba isele -Awon akekoo daruko awon wunren ti o n toka iba isele ninu gbolohun -Awon akekoo se apeere orisii iba-isele ninu gbolohun | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati | Paali alagbeka ti ati ko orisirisi eya iba isele to wa si https://yo.m.wikipedia.org |
OSE | ORI ORO | ERONGBA | AKITIYAN | OGBON AMUSE | OHUN ELO AMUYENI |
io. Lo won ninu gbolohun ede Yoruba io. Lo won ninu gbolohun kikun o.Mo awon atoka ti a fi le da awon iba isele wonyi mo yato si ara won oi. Dahun ibeere lori eko yii | -Awon akekoo se apeere orisii iba-isele ninu gbolohun -Awon akekoo se akosile koko ise | ibanisoro | https://infohub.syo.ng | ||
Asa: Itesiwaju eko nipa igbagbo ati ero Yoruba nipa Yoruba nipa oso ati Aje, Ero ati igbagbo awon eya miiran ni orile ede Naijiria ati orile ede miiran nipa Oso ati Aje | Ni opin idanilekoo awon akekoo yoo le i.Se nipa isesi awon Oso ati Aje orile ede miiran. ii.Won yoo le se ki ni igbagbo awon eya miiran nipa Oso ati Aje abi yato.. io.Se boya ipa kan naa ni awon Oso ati Aje n gba ronu abi o yato sira. o.Dahun ibeere lori eko yii. | -Awon akekoo salaye igbagbo ati ero Yoruba ni awujo wa -Awon akekoo jiroro nipa igbagbo ati ero awon eya miiran nipa ose ati aje -Awon akekoo satotonu nipa ijora ti iyato laarin igbalgbo ati ero Yoruba nipa Ose ati aje pelu aon eya miiran -Awon akekoo se akosile koko ise | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati Ibanisoro | Aworan to fi irisi awon Oso ati Ajehan. Aworan to fi irisi ibi ti won ti n se ipade han. | |
Litirese itupale Asayan iwe ti Ajo WAEE/NEEO yan | Ni opin idanilekoo yoo le: i.Tesiwaju ninu kika ewi naa. ii.Mo nipa oriki orile awon iran miiran iii.Se koko to han ninu oriki won io.Salaye bi eewo se jeyo ni iran won Se o.Dahun ibeere lori koko idanilekoo | -Awon akekoo ka iwe iwe Awon Oriki Orile Metadinlogbonbi Adeboye Babalola ko – Awon akekoo ka awon oriki wonyi i. Oriki Iran Olowu ii. Oriki Iran Oloye iii. Oriki Iran Olokun Esin Io. Oriki Iran Ajibogunde -Awon akekoo salaye ise iran ti a ka oriki won -Awon akekoo se akosile koko se. | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati Ibanisoro | Iwe oriki orile metadinlogbon. Stygoryseollege.eom.nfg | |
Ede Itesiwaju lori oro Agbaso i. Yiyi oro enu oloro si oro agbaso, fifi eti si sise, kika at jijabo iroyin ipade ii. Yiya afo agba oro si afo asafo | Lopin idanilekoo yoo le Salaye ohun i.e: Salaye ohun ti afo asafo ati afo agbara je. Da awon oro atoka afo agbaran mo i. Ko awon oro afo asafo jo. ii. Yiyi awon afo asafo si afo Agbara. iii.Da awon iso/ri oro ti iyipada maa ri de ba nigba ti a bar i yi afo asafo si efo agbaran. io. Mo awon oro atoka afo agbaran ti a maa ri o. Apeere pe, wipe, so pa, ni abbl o. Dahun ibeere lori eko yii. | -Awon akekoo salaye ohun ti afo asafo alti agbairan je – Awon akekoo yii afo asafo si agbaran ninu ijabo iroyin kan. – Awon akekoo yi afo agbaran si asafo -Awon akekoo toka si awon oro ti a ma n yi pada nigba ti a bar i se afo agba kiran -Awon akekoo se akosile koko ise | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati Ibanisoro | Ate ti ati ko oro enu oloro ti a yi fi afo agbaran si https://yo.unilateral.eom | |
Asa itesiwaju lori Eko Ile-imototo- itoju ara, Bi a se ri | Ni opin idanilekoo awon akekoo yoo le i. Ranti imo aleyinwa lori eko yii | Awon akekoo soro lori ikini igba, ise, ati akoko lorisirisi -Awon akekoo daruko | Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro | Aworan omo to n gbale ati omo to n tabo / Aso |
OSE | ORI ORO | ERONGBA | AKITIYAN | OGBON AMUSE | OHUN ELO AMUSEYENI |
Kini, oro siso:ounje sise ati | ii.Mo bi ase n kini ni orisirisi igba ati fun orisirisi ise. iii.So bi a se n se awon ounje Yoruba io.Mo bawo la se n ba agbalagba soro ati bi a se n soro lawujo o.Salaye bi a se n huwa lawujo oi.Dahun ibeere lori eko yii | Orisii ounje ile Yoruba ati bi a ti n se die ninu won -Awon akekoo sapejuwe bi a se le ba agbalagba soro lawujo -Awon akekoo so nipa bi a se n huwa irele lawujo -Awon akekoo se akosile koko ise | Ogbon Ajumose ati ibanisoro Ogbon Idari akekoo Eko Ajemawujo | ||
Litireso itupale Asayan iwe ti Ajo WAEE/NEEO yan | Ni opin idanilekoo awon akekoo yoo le: i.Tesiwaju ninu kika ewi inu iwe naa ii.Wa itumo si awon oro tuntun inu awon oriki naa. iii.Salaye koko to suyo ninu oriki iran kookan. io.Mo oriki iran won gan-an o.dahun ibeere lori eko yii | -Awon akekoo esiwaju ninu kika le Litireso ti ijoba yan -Se akosile awon koko ti o jeyo ninu awon oriki yii -So awon itan ti o ro mo oirun awon iran ti o ni oriki naa. -salaye eeko ti o jemo iran kookan -So nipa ise ti iran kookan n se -Awon akekoo se akosile koko ise | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro Ogbon idari Akekoo Eko Ajemawujo | Akekoo to lebun ewi jade la Iwe Awon Oriki orile Metadinlogbon- Adeboye babalola |
10 | Ede itesiwaju lori aroko oniroyin. i.Ijiroro kikun lori awon ori oro to je mo Aroko Oniroyin ii.Kiko ilapa ero | Ni opin Idanilekoo awon akekoo yoo le i.salaye bawo la se n ko aroko oniroyin ii.Da ori oro to je mo aroko oniroyin mo. ii.mo ilapa ero fun irufe aroko yii. io.so iyato to wa laarin aroko oniroyin ati orisi aroko yoku o.Dahun ibeere lori koko eko | -Awon akekoo se apere orisiinsii ori-oro to jemo aroko onirioyin/asotan -so nipa liana ti a gbodo samulo nipa kiko aroko onirioyin -So iyatoi laarin aroko oniroyin ati awon | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro | Apeere aroko oniyin ti enikan ti ko ri Aroko Lede Yoruba-Lawanson Olumuyiwa@okadabooks.eom |
Asa itesiwaju eko lori ojuse eni lawujo Pataki ojuse eni ile, laarin ebi, egbe Aladuugbo abbi.Bi apeere-pipa ofin ati iwa eni mo | Ni opin idanilekoo awon akekoo yoo le: i.So ipa ati ojuse agba, omode,obinrin okunrin ninu ile,laarin ilu egbe ati ilu ii.salaye Pataki pipa ofin mo yala ofin ninu ile tabi laarin ilu. iii.mo ojuse eni si oko/ aya eni.Obi eni io.Dahun ibeere lori eko yii o.So bi a se le pa ofin mo. | -Awon akekoo salaye ojuse obi si omo -soro nipa ojuse omo si obi -jiroro nipa ojuse oko si aya -ojuse awon ara ilu si ijoba -Awon akekoo se akosile koko ise | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro | Aworan obi to n fun omo re lowo iwe. Asatiwantiwablogspot.eom | |
Litireso: | Leyin idanilekoo awon | -Awon akekoo | Kaadi pelebepelebe ti | ||
OSE | ORI ORO | ERONGBA | AKITIYAN | OGBON AMUSE | ELO OHUN AMUSEYENI |
Itupale Asayan iwe ti Ajo WAEE/NEEO YAN | Akekoo yoo le i.Dangajia ninu kika oriki orile naa laiko won lenu ii.je ategun tabi awo kose fun awon to ni ebun ewi ninu awon akekoo iii.Mo oriki orile won itan inu re(yoo sile se atona bi won yoo se mo orirun won io.Da oriki orile won ka. o.Dahun ibeere lori koko eko | tesiwaju nninu kika iwe Awon Oriki Orile Metadinlogbon -salaye itan orirun orile won -Awon akekoo salaye ise ati eewo awon iran yii pelu ipo won lawujo -so ewi oriki orile ti o ba iran kookan mu ninu awon oriki ti won ka -Awon akekoo se akosile koko ise | Ogbon Arojinle ati yiyanju isero Ogbon Ajumose ati ibanisoro Ogbon Idari Akekoo Eko Ajemawujo | Ko awon oro ti itumo won farasin si | |
11 | Ede:iyato wa laarin oro apole ati apole ati apole Aponle i.Alaye kikun lori oro aponle Apola ii.Titoka si ilo oro aponle ninu gbolohun iii.Fifa oro Aponle ati Apola Aponle yo ninu gbolohun tabi ipinro io.Alopo mejeeji ninu gbolohun. o.Alopo mejeeji ninu gbolohun | Ni opin Idanilekoo awon akekoo yoo le: i.Salaye oro aponle ati Apola aponle ii.So iyato ati ijora to wa laarin oro aponle ati apola aponle. iii.Mo bi a se n lo oro ati apole Aponle mo ninu gbolohun io.Da oro aponle ati apola aponle mo ninu gbolohun o.Dahun ibeere lori koko eko yii | Awon akekoo se alaye lori oro aponla aponle -So iyato laarin oro aponle ati apola aponle -tokasi oro apole ninu gbolohun -fa apola aponle yo ninu gbolohun | Ogbon Arojinle ati yiyanju isero Ogbon Ajumose ati ibanisoro Ogbon Idari Akekoo | Aworan igi ti a fi oro aponle ati apola aponle. |
Asa: itesiwaju eko lori oran dida ati ijiya ti oto, ipa ti awon agbefoba ati agbofinro n) ko ninu sise eto idajo fun arufin ati odaran orisirisi eto idajo ati ona ti a o gba fi iya je odaran laye atijo ati ode oni | Ni opin idanilekoo,awon akekoo yoo le: i.Salaye orisirisi oran ti awon eniyan le da laye atijo ii.So ijiyato to wa fun orisirisi oran iii.Mo orisiri idajo to wa ati ona ti awon agbofinro fi n fiya je odaran io.dahun ibeere lori eko yii o.iyato to de ba oran dida ati ijiya to wa fun oran kookan laye atijo ati laye ode oni | -Awon akekoo salaye orisi oran dida laye atijo -so nipa ijiya ti o wa fun oran kookan. -so nipa idajo ti o wa fun oran dida ati ona ti aon agbofinro fi n fi iya je odaran -Awon akekoo so nipa liana ti a n gba fiya je odaran lode-onis -Awon akekoo se akosile koko ise | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isero Ogbon Ajumose ati ibanisoro | Aworan odaran ti awon agbofinro n foro wa lenu wo. | |
Litireso Ayewo finnifinni lori awon Asayan | Ni opin Idanilekoo awon akekoo yoo le i.So orisirisi owe to wa pelu apeere. | -Awon akekoo jiroro nipa itumo itandowe miiran yato si eyi ti oluko ko | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati | Ate ti o se afihan itandowe pelu itumo won |
OSE | ORI ORO | ERONGBA | AKITIYAN | OGBON AMUSE | ELO OHUN AMUSEYENI |
Itandowe siso ittandowe ati fifa owe inu won yo i.Titoka si owe ati asa to suyo ninu itan kookan ii.Isowo lo ede ninu itan to di owe kookan | ii.Se akojo orisirisi itandowe to Yoruba iii.Mo ki lo bi itan yii. io.Fa asa to suyo ninu awon itandowe wonyil. o.So iwulo owe oi.Dahun ibeere lori eko yii | won -fa asa Yoruba yo ninu itandowe -so ilwulo owe Yoruba lawujo -Awon akekoo se akosile koko ise | yiyanju isero Ogbon Ajumose ati ibanisoro | ||
12 | Idahun si ibeere lori aon ise saa.yii | Ni opin Idanilekoo, awon akekoo yoo le: i.Ranti imo ateyinwa lori awon eko yii ii.Beere ohun ti ko ba ye won to ninu eko yii iii.Mo bawo la se n dahun ibeere io.Gbaradi fun idanwo lai beru | -Awon akekoo dahun si ibeere lokan-o-jokan awon awon ise ti won ti ko ni saa yii. -Awon akekoo beere lowo oluko lori aon ise ti won ti ko ni saa yii | Ogbon Atinuda Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isero Ogbon Ajumose ati ibanisoro | |
13 | Akanse idanwo lori ise odun yii ninu Ede Asa ati litireso | Akanse idanwo lori ise odun yii ninu Ede, Asa ati litireso | Akanse idanwo lori ise odun yii ninu Ede, Asa ati litireso | Akanse idanwo lori ise odun yii ninu Ede, Asa ati litireso | Akanse idanwo lori ise odun yii ninu Ede, Asa ati litireso |
Yoruba Language Scheme of work for SSS 3. SS3 Schemes of Work Yoruba for Secondary School – Schemeofwork.com
Yoruba Language Scheme of Work SSS 3 Second Term
EDE YORUBA AGBEYEWO ATE ETO TITUN OLODUN KETA (SS3) S’A’ KEJI
OSE | ORI ORO | ERONGBA | AKITIYAN | OGBON AMUSE | OHUN ELO AMUSEYENI |
1. | Ede:Idanwo ranpo ikini kaabo | Lopin eko yii awon akekekoo yoo le: i.Mu gbogbo eko wa si iranti | Ede:Idanwo ranpe ikini kaabo | Ogbon Ajumose ati ibanisoro Ogbon Idari Akekoo | Imo ateyinwa ati akosile ateyinwa |
Ede Atunyewo Eko lori silebu ede Yoruba | Ni opin Ianilekoo,awon akekoo yoo le: *Rati Imo ateyinwa lori eko yii. So kini silebu? Orisi silebu melo lo wa ninu ede Yoruba Salaye bi a se n pin silebu ninu ede Yoruba Mo batani silebu ede Yoruba Si Idi ti konsonanti aranmupe n/m se le sise silebu Dahun ibeere lori eko yii | Awon akekoo salaye ohun ti silebu tumo si Awon akekoo sapejuwe awon batani silebu ti o wa pelu apeere. Awon akekoo pin awon oniruuru oro si silebu Awon akekoo se akosile ohun ti koko ise da le lori sinu iwe won lati oju patako. | Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Idari Akekoo | Ate alagbeka to n fi ihun silebu han ati bi a se n pin oro si silebu https://faeebook.eom learnyor.blo gspot.eom | |
Asa Atunyewo eko lori elegbegbe /iro-si-ro | Ni oipn idanilekoo awon akekoo yoo le: i.So ipa ti awon agba n ko lawujo ii.Mo anfaani to wa ninu ipa ti elegbegbe n ko ninu idagbasoke agbegbe,ilu ati orile ede ii.Dahun ibeere lori eko yii | Awon akekoo jiroro lori ipa ti awon agba n ko lawujo. Awon akekoo salaye awon awon anfaani to wa ninu ipa ti elegbejegbe n ko ninu idagbasoke agbegbe, ilu ati orile ede. Awon akekoo se akosile ohun ti koko ise da le lori sinu iwe won leti oju patako | Ogbon Arojinlee ati yiyanju Isorro Ogbon Ajumose ati ibanisoro Ogbon idari Akekoo Eko Ajemawujo | Aworan ti ati ya orisirisi ise elegbejegbe si to je ise ilu | |
Litirese: Atuyewo aawon Asayan iwe ti Ajo WAEE/NEEO yan i. Itan soki lori awon onkowe ii. Alaye lori awon eda | NI opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Ranti imo ateyinwa ii. Salaye koko to jeyo ninu awon itan naa iii. Soro lori awon eda itan ati ilu eda itan io. Mo sa Yoruba to suyo ninu itan naa o. Se awon ibudo itan | Awon akekoo se oruko se oruko awon iwer litirese rti Ajo WAEE/NEEO yan fun won ti won ti ka Awon akekoo jiroro nipa awon eda itan Awon akekoo salaye | Ogbon Arojinle ati yiyanju Isoro Ogbon Ajumose ati ibanisero Eko Ajemawujo | i. Awon akekoo to n kawe ii. Iwe ti a n’ka iii. Kadiboodu ti ati ko awon oro titun inu awon itan naa |
OSE | ORI ORO | ERONGBA | AKITIYAN | OGBON AMUSE | OHUN ELO AMUYENI |
Itan ati awon amuye itan yii | inu awon iwe naa oi. da isewo lo ede ionkowe koomo oii. Dahin ibeere lori eko yii | awon koko ati eko ti iwe yii da le lori Won jiroro nipa asa ati ise ile wa ti o suyo Won sero nipa awon ibudo itan | |||
2 | Ede:Atunyewo eko lori eko fonoloji ede Yoruba Apeere foniimu konsonanti,Faweli, ohun, konsonanti, aranmupe Asesilebu | Ni opin idanilekoo awon akekoo yoo le: i.Ranti imo ateyinwa lori eko fonoloji Yoruba ii.Beere ohun ti ko ba ye won to lori eko yii iii.Mo bi a se n dahun ibeere WAEE/NEEO ninu ede Yoruba io.Da foniimu konsonnanti aranmupe Asesilebu mo,konsonanti ati faweli mo o.Salaye foniimu ohun oi.Dahun ibeere lori eko yii | Awon akekoo jiroro nipa awon eko ti won ko lateyinwa Awon akekoo salaye awon koko ati eko ti iwe yii da le lori. | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro | Ate to n se afihan foniimu faweli konsonanti,ohun ati konsonanti aranmupe Asesilebu jigi |
Asa: Agbeyewo eko lori eko fonoloji ede Yoruba. Apeere Foniimu konsonanti,Faweli,ohun,konsonanti aranmupe Asesilebu | Ni opin idanilekoo awon akekoo yoo le i.So nipa awon orisa ile Yoruba ii.Mo nipa itan awon orisa wonyi iii.se orisa niwon lati ode orun abi eniyan to di orisa. io.Soro nipa ojubo won ati awon olusin won o.So ki ni eewo awon orisa wonyi. oi.Ta ni aworo won? oii.igba wo a n bowon ati bi ase n bo won mo iwulo won nile Yoruba. oiii.Dahun ibeere lori eko yii | -Awon akekoo daruko orisa ile Yoruba. -Awon akekoo so itan ti won ti gbo tele nipa orisa kookan. -Awon akekoo se apeere awon akoni ati akanda eniyan ti won di orisa akunlebo. -Awon akekoo so eewo awon orisa yii,igba ati akoko ti a maa n sodun awon orisa yii. -Ki awon se akosile koko eko sinu iwe won | Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro Eko Ajemawujo | Aworan awon orisa wonyi ti ati ya si ara paali alagbeka Aworan awon olusin won ati ohun ti a fi n bo won | |
Litireso itupale Asayan iwe Ajo WAEE/NEEO yan i.Yiye awon iwe ti ati ka seyin wo leyo kookan | Ni opin idanilekoo awon akekoo yoo le i.Salaye nipa orikowe ati koko ti itan naa dale ii.So nipa awon eda itan kookan pelu ipa ti won ko iii.se ere naa gege bi ere ori itage lati le ko tubwo ye won salaye awon koko to suyo ninu awon iwe naa. Dahun ibeere lori koko eko yii | -Awon akekoo ka okan ninu iwe litireso aplieko ti WAEE ati NEEO yan -Awon akekoo so itan inu iwe naa ni soki. -Awon akekoo so awon koko ati eko ti o suyo ninu iwe yii -Awon akekoo salaye ipa ti eda-Itan kookan ko. -Awon akekoo daruko awon asa ati ise to suyo | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro Ogbon Idari Akekoo Eko Ajemawujo | Gbogbo awon iwe ti ati ka seyin kaadi pelebepelepe ti ako awon oro tuntun to suyo si pelu itumo won |
OSE | ORI ORO | ERONGBA | AKITIYAN | OGBON AMUSE | OHUN ELO AMUYENI |
Wo ri oro mimu oro ayalo won inu ede Yoruba | Ni opin idanilekoo awon akekoo yoo le: i.Ranti imo ateyinwa lori eko yii ii.Salaye ohun ti oro ayalo je iii.So bi a se n ya oro lati inu ede miiran io.Da inu awon ede ti ati n ya oro mo o.Da awon ilana ti a n gba ya oro wo inu ede wa oi.Mo ofin tabi ifaramole ti awon oro oro ti a ya won inu ede wa gbodo tele. oii.Ki ni iwulo/anfaani oro ayalo. oiii.So awon nnkan marun-un to sokunfa Oro ayalo,(olaju,Eto oro aje,Ein,oselu/Eto | –Awon akekoo jiroro nipa oro-ayalo -Awon akekoo salaye awon ona ti a gbamu oro ayalo wo inu ede miiran. | Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro | https://feeebook.eom https://waeeonline.eom yorubaoloji.blogspot.eom | |
Asa Atunyewo Eko lori Eto ebi ati iserun Eni | Ni opin idanilekoo awon akekoo yoo le: i.Sobawo ni eto inu ebi se n. ii.Da ojuse baba ati iya mo iii.Mo ibasepo to wa laarin baba re ati awon aburo / egbon baba re io.Salaye ohun ti a n pe ni ebi ati iserun o.So iha /oju wo lo fi wo ipede yii (ohun ti egbon ba) ni, aburo lo ni) oi.Dahun ibeere lori eko yii | -Awon akekoo salaye itumo ebi ati iserun eni. -Awon akekoo salaye ibasepo ti iserun eni wa ninu ebi. -Awon akekoo salaye ojuse baba ati iya ninu ebi. | Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro | Aworan to n fi ajosepo han laarin ebi. Fidio You Tube ABNTO HOUSTON,TESAS https://m.faeebook | |
Litireso itupale Asayan awon iwe ti Ajo WAEE/NEEO yan | Ni opin idanilekoo awon yoo le:: Ranti koko ti iwe naa dale ii.Mo eto isowo ko ewi iii.Awon ewa ona ede inu ewi naa yo. io.je ategun fun akekoo to ba ni ebun ewi o.Beere ibeere lori ohun ti ko ba tun ye won | –Awon akekoo daruko iwe ewi apileko ti won ka seyin. -Awon akekoo salaye awon koko ti o jeyo ninu ewi naa. -Aon akekoo fa awon asa Yoruba jade ninu ewi naa. -Awon akekoo sapejuwe awon ona ede inu ewi naa | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro | Aworan eni to n kewi Iwe ti a n ka gan-an |
4 | Ede:Atunyewo kikan lori eko ihun oro ati iseda oro-oruko | Ni opin idanilekoo awon akekoo yoo le: i.Salaye lekunrere bawo la se n seda oro i.Mo awon ona ti a n gba seda oro nipa lilo Afomo ibeere &aarin, | –Awon akekoo salaye awon ona ti a n gba seda oro-oruko pelu apeere. -Awon akekoo fa awon oro-oruko ti a ko seda yo ninu apeere | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati | Ate ti ko awon oro ti a Seda si ati bi a se seda won pelu alaye. |
OSE | ORI ORO | ERONGBA | AKITIYAN | OGBON AMUSE | OHUN ELO AMUYENI |
Akanpo oro ise oro oruko Apetunpe abbi ii.Da awon oro ti a ko seda mo iii.Fa oro ti a seda yo ninu gbolohun Dahun ibeere lori eko yii | gbolohun a ko soju patako ikowe. | Ibanisoro | Hhtps://olukoniblogspot.eom https://m.faeebook.eom | ||
Asa Atunyewo kikun lori Eko iselu abinibi ati ode oni | Ni opin idanilekoo awon akekoo yoo le: i.Salaye eto iselu abinibi ati ti ode oni ii.so ijora ati iyato to wa laarin won.Do ipa ti oba ijoye ati akoda ko ninu eto iselu aye atijo iii.Beere ibeere lori ohun ti ko ye won io.Dahun ibeere lori eko yii | -Awon akekoo salaye eto oselu aye atijo -Awon akekoo salaye ijora ati iyato laarin oselu aye ati ode oni. -Awon akekoo ko bi ase n dahun ibeer ajo WAE ati NEEO | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro | Aworan oba to gunwa laafin re nibi to ti jiroro lori eto iselu |
5 | Litireso itupale Asayan awon iweti Ajo WAEE/NAEO yan | Ni opin idanilekoo awon akekoo yoo le: i.Ranti gbogbo eko ateyin wa ii.Beere ibeere lori ohun ti ko ye won. iii.Mo bawo la se le dahun ibeere ni ibamu bi WAEE/NEEO Se n fe | -Awon akekoo beere ibeere lori ohun ti won ka ninu iwe litireso -Awon akekoo dahun ibeere lori iwe ibeere WAEE ati NEEO ti won ti se koja lati mo bi won se koja lati mo bi won se le dahun ibeere ajo WAEE ati NEEO | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro | Awon iwe ti a ka Akojopo ibeere lori ede Yoruba |
Ede Atunyewo Eko lori isoro oro,oro-oruko oro Aropo oruko afarajoruko, oro ise. | Leyin idanlekoo awon akekoo yoo le i.Mo awon isori oro to wa ninu gbolohunede Yoruba ii.So ise /pataki awon isori oro wonyi ninu gbolohun. iii.Salaye ise ti oro oruko n se ninu gbolohun io.Da orisi oro ise to wa mo ati pataki oro ise ninu gbolohun. o.So ibasepo to wa laarin oro oruko ati oro Aropo afarajoruko pelu oro aropo oruko. | -Awon akekoo daruko awon isori-oro inu gbolohun. -Awon akekoo salaye ise awon isori oro kookan ninu gbolohun. -Awon akekoo daruko isori oro ti o wa ninu awon gbolohun ti won fun won fun ise sise. | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro | Awon to n se afihan eya oro ise ati isori oro oruko | |
Asa:Atunyewo Eko lorioge sise-Aso wiwo,itoju Ara,lla-kiko,irun didi abbi | Ni opin idanilekoo awon akekoo yoo le: i.Ranti imo ateyinwa lori eko yii ii.Mo awon ona ti Yoruba n gba soge iii.Soro lori okookan ona ti a n gba sara loge io.Mo bi a se re toju ara eni ati bi a se n soge | -Awon akekoo daruko awon oninuuru ona ti yoruba n gba soge laye atijo. -Awon akekoo so iyato ti o wa ninu oge sise aye atijo ati ode oni | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro Eko Ajemawujo | Aworn orisirisi iru didi ati gige fun awon okunruin Aworn to fi orisi aso wiwo ile wa han Aworn to fi orisirisi ila kiko han laarin Yoruba |
OSE | ORI ORO | ERONGBA | AKITIYAN | OGBON AMUSE | OHUN ELO AMUYENI |
o.Dahun ibeere lori eko yii | |||||
Litireso Atunyewo eko lori Alo Apamo Apagbe ati itandowe | Ni opin idanilekoo awon akekoo yoo le: i.Mo ki ni aio apamo ati apagbe ii.So ijora ati iyato to wa laarin won iii..Se akojo Alo Apamo ati Aagbe io.Salaye itandowe o.So ki lo n bi itandowe oi.Se akojo itandowe oii.Mo eko ti a ri ko ninu eko yii | Awon akekoo pa oninuuru alo apamo ati apagbe ni iyara ikekoo -Awon akekoo so iyato ti o wa laarin alo apamo ati alo apagbe. -Awon akekoo so itandowe kan yato si eyi ti oluko ti ko won ni yara ikekoo | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro Ogbon Idari Akekoo Eko Ajemawujo | Paali alagbeka ti ati ko Alo Apamo ati Apagbe si Aworan iya agba nibi ton so itandowe fun awon omo |
8 | Ede:Atunyew o Eko lori isori oro Apejuwe, oro Aponle,oro Asopo ati oro Atokun | Ni opin idanilekoo awon akekoo yoo le: i.Se ekunrere alaye lori awon isori oro wonyi ii.Da won mo ninu gbolohun ti won ba ti lo won iii.Mo ise ti awon isori oro wonyi n se ninu gbolohun io.Dahun ibeere lori eko yii | -Awon akekoo salaye itumo awon isoro oro apejuwe oro aponle,oro asopo ati oro atokun nipa ise ti won se ninu gbolohun. -Awon akekoo salaye iyato laarin isori oro wonyi. | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro | Ate alagbeka ti ati ko awon isori oro wonyi si ati bi a se le lowon. Fidio Youtube.EdueationLASG |
Asa Atunyewo kikan eko lori Asa igbeyawo ni ile Yoruba | Ni opin idanilekoo awon akekoo yoo le: i.Salaye lekunrere ohun ti igbeyawo je ii.Mo orisi igbeyawo to wa. iii.So igbese/ilana eto igbeyawo io.Mo itumo omoge, Adelebo,Alarina,balaga abbi. o.Daruko awon oun elo idana. oi.Mo bi ase n lo awon ohun elo idana lati fi sadura oii.Salaye ilana igbeyawo oiii.Beere ibeere lori ohun ti ko ba ye won to. | Awon akekoo salaye orisi asa igbeyawo ode-oni -Awon akeoko jiroro nipa ilana eto igbeyawo ile Yoruba -Awon akekoo daruko ohun elo idana iyawo ati bi a se n fi won sadura fun iyawo to n rele oko -Akekoo se ibere lori awon koko eko | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro | Kiko awon ohun elo idana wa si yara ikeko Kiko awon igbese to wa ninu igbeyawo si ara kadiboodu. https.//m.faeebook.eom asaatiowelleyoruba.blogspot,eom https://www.bbe.eom |
7 | Litireso itupale Asayan iwe ti Ajo WAEE/NEEO yan 1.Akojopo Alo ijapa Apa kinini lati owo Adeboye | Ni opin idanilekoo awon akekoo yoo le: i.Da awon iwe naa ka lai ko lona ii.Fa koko inu awon iwe naa yo iii.Da Dirama yato si aroso ati Ewi. io.Mo nipa itan awon onkowe to ko awon onkowe to ko awon iwe | -Awon akekoo daruko awon iwe litireso ti won ti ka seyin -Awonakekoo salaye soki ohun ti okookan litireso yii da le lori -Awon akekoo jiroro nipa koko ati eko to je yo | Ogbon Atinuda ati Oye Ogbon Arojinle ati yiyanju isoro Ogbon Ajumose ati ibanisoro Ogbon Idari Akekoo Eko Ajemawujo | Gbogbo awon iwe ti a ka Iweatumo ati ka adi pelebepelebe ti ati ko awon oro tuntun to suyo lati inu awon iwe naa. |
EDE YORUBA AGBEYEWO
OSE | ORI ORO | ERONGBA | AKITIYAN | OGBON AMUSE | OHUN ELO AMUSEYENI |
Babalola 2. Nitori owo (drama) lati owo Akinwunmi Isola. 3. Moremi Ajasoro) Prose Debo Awe. 4.Oroenu Akew (poetry) lati Owo Ayomide Akanji. 5. Ege Dida ati owo S.M Raji. 6. Awon oriki orile mesandinlogunn (oju Ewe 117-314) poetry. | WONYI v. Daruko awon ibuda gege bo se jeyo ninu won iwe naa vi. Mo isowo lo ede awon orikowe wonyi. vii. So oriki orije awon iran Yoruba kpokan vi. So eewo awon iran kpokan mo ati ohun to to eewo naa. vii. Dahun ibeere lori awon eko yin i liana WAEC ati INECO | -Awon akekoro salaye awon asa ati ise ile Yoruba ti o suyo. -Awçn akekoro sapeiuwe bi orikoye se samuko ona-ede ninu awon iwe itireso naa. -Awon akekoro daruko awon ibudo – itan ninu awon iwe itireso epi eko |
Agbalogbabo
Loyin gbogbo idanilekoo lori ede asa ati itireso ede Yoruba, awon akeköro ti le
• Lo ogbon arojinly aun yiysnju isoro Iati iwe won ohun ti o jemo Grama Ede Yoruba ati awon ohun ti o ro mo on.
• Se amulo ogbon arojinle ati yiyanji, isoro lati salaye awon eko ajemo-awujo
• Nipase ogbon ajumose a ibanise o lati iroro nipa ase Yoruba lekunrere
• See atotonu nipa itireso alohun ati epileko ni ibamu si awon eko abala naa ninu eyi ti a ti ri asa, ihun eko, ilo-ede
• La eko imo ero ayelujara a so ofintoto awon imo ode-oni . .