Yoruba Language Syllabus for Early childhood Lagos State, Yoruba Scheme of work for Kindergarten (Age 5). Onika Yoruba. Schemeofwork.com
SCHEME OF WORK YORUBA KINDERGARTEN SAKA KINNI (AGE 5)
OSE
OSE KINNI (1)
AKORI ISE
Ede alifabeeti Yoruba (a titi de gb)
Litereso: Orin akonilogbon
ERONGBA
Ni opin idanileko yi, awon akeeko yoo le
- Ka alifaabeeti Yoruba lati (a – gb)
daradara
- Se afihan awon leta yi lafi ara iwe
Pelebe pelebe ti
Oluko ko won Si (flash cards)
iii. Da awon leta yi mo pelu eda aworan
Awon akekoo yoo. Ko orin akonilogbon ti oluko ko won daradara
AKOONU/ISE SISE
- ki oluko se alihan ara re niwaju awon akekoo
- kiluko lata a,b,d,e,e,f, g, gb, si oju patako ikowe.
- kika leta a, b, d, e,e, f, g, gb si etigbo awon akekoo
- ki oluko ka, a de, gb ki, awon akekoo si maa dahun
- ki akekoo ko awon leta (a- gb)
- ki awon akekoo fi aworan ti o ro mo awon leta( a-gb) han
- ki awon akekoo le, ko orin ati
- ijo jijoti oluko ti ko won
- fun apere
- iya oluko mi
- bata mi a dun koko ka
- ojo mo sere ninu ile abbi
IGBELEWON
-Ibanisoro ati Ajumose ise
-Ogbon atinuda ati oye
– Imo Arojinle ati yiyanju isoro
– Eko Ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Kaadi pelebe alafihan
(a-gb)
Kaadi tenfe (a-gb)
Aworan fun apeere
- aja
- bata
- Dodo
- Ejo/rti
- Fila
- Gele
- Gbaguda
Onn-kiko
Jo jio alewo pipa
Teepu ati kaseeli
Aworan to ni eriti on
Huwa omoluwahi han
OSE
KEJI (2)
AKORI ISE
Onika Yoruba (1-10)
ERONGBA
Awon akekooo yoo ka
Onika lati de awaa (1-10)
Ki won ko ni orin
Pelu ijo ije ati ilu
AKDONUISE SISI
Kiko ati kika onika Yoruba
Lati ookan de eewa pelu orin,
ijo ati ilu lilu atu=I ilo aworan
fun apeere
- Okan
- Eji
- Eta
- Enn
- Annu-un
- Efa
- Eje
- Ejo
- Esan-an
- Ewa
- Fun apeere
- Boolu meji aga meta abbi
- Ki akekoo ko orin igo lare ogin abbi
- Eni breni
- Eji be ej
- Eta ata fagba
- Enn woroko
- Arun n godo
- Efa tie le
- Biro n biro
- Iron beta
- Ogun d akesan
- Gbagba ewe
- Orika asonka fun apeere
D.
– alafori sale yi pelu or olio ye
1. ookan
2
3 eeta
4
5. Aarun-un
6
7. Eeje
8.
9. Eesan –an
IGBELEWON
– Ibanisoro ati Ajumose ise
_Ogbon atinuda ati oye
– Imo Arojinle ati yiyanju isoro
– Eko Imo ero -Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Kaadiboodu ti won
Ko onka ookan de
Eewe (1-10)
Kaadi pelebe
Pelebe won ko
Onika kookan si
Ideri oti
Okuta were
Igi isana
Igo tabi ike omi
Aworan OHUN ELO IKONI lori
- Ade kan
- Oju meji
- Aga meta
- Ife merin
- Ika marun-un
- Sibi meta
- Fila meje
- Ago mejo
- Isu mesan-an
- Ika mewa
OSE KETA (3)
AKORI ISE
EDE DIDA
ORUKO WOKAN
INNU IYARA
IKAME (KILAASI)
ERONGBA
Awon akeloo yo
- Daruko awon
Nnikan inu iyara
Kawe (kilassi) won
Daadara
- Ki won se jitopo kila at aworan
Won nipe dida oruko won
AKDONUISE SISI
- Titpaka si awon nikan to wa ni inu
- Iyara ikawe (kilasi) ati oruko won
- Fun apeere
- aga iwe latili ago ara ogon abbi
IGBELEWON
ibanisoro ati
Ajumose ise
Ogbon atinuda ati oye
Arojinle ati Yiyanju Isoro
– Eko Ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Aga ijoko oluko
- Tabili kowe awon akekoo
- Aago ile –iew abbi
- Aworan awon ohun ti o wa ninu kilassi
OSE
KERIN (4)
AKORI ISE
Asa ikini ati
Idahun in ile
Yoruba
Orin
ERONGBA
Awon akekoo yoo
- Ko orin kinni nile Yoruba
Se ahan bi omokunrin ati
Omobrin se nlo
Agbalagba
AKDONUISE SISI
Ki-awon akekoo le mo
iyatoo kilki mini igha kani –
akoko kookan
akoko kini Idahun
time greeting response
owuro ekaro Ekaaro o
osan E Ekaasan o
kasan
ireole E-ku-irole Ekale o
kika orin kini ati fifi aworan ikini han
owuro mi
osan mi
je ki o dara
Ale mi ko ma se baje
- Owura lawa
Eje ka sise
Tale ba de
Ka le nisimi
Ki awn akekoro se altife orin
Nkule afibi nibaje ki
Agbagba
IGBELEWON
– Ibanisoro ati Ajumose ise
– Ogbon atinuda ati oye
– Arojinle ati Yiyanju Isoro
– – Eko Ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Aworan Omodebinrin ti o Kunl tabi omokunrin ti o dobale ki agbalagba tabi obi re.
Teepu orin kiko fun apeere.
-Ewole fagba agba ni n gbani
Lomo nki baba o
Lomo nki yeye
Idobale ati ikunle
KLomo nki baba o
Lomo nki yeye
OSE KERUN (5)
AKORI ISE
ALIFEBEETI YORUBA (h-o)
ERONGBA
Awon akekoo yoo
i) Ka ailfabeereti
Yoruba lati (h-o)
ii) Fi aworan da awon alfaabeeti wonyi mo
AKDONUISE SISI
Ki oluko ko orin alifabeeti
Yoruba lati a-o fun apeere
Isa, tisa lo komi leede
a-aja,b –bata abbi
ki oluko ran akekoo leti lati
ka alifabeeti a gb ati kiko si ara patako
kika ati kiko alifabeeti h o’ fun awon akekoo pelu aworan
pipe akeeko meji tabi meta lati ka alifabeeti e-f-I ati a ti
f – – hi –k-m-o
IGBELEWON
- Ibanisoro ati Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati Oye
- Imo Arojinle ati yiyanju isoro
- Eko Ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Kaadi fihan ti a ko f, g, gb, h, i, si
Aworan ti o fi awon leta kookan han.
Fun apeera:
f – fila
g – gele
gb – gbaguda
h – hausa
i – igi
OSE KEFA (6)
IDANWO RANPE ISINMI
OSE KEJA (7)
AKORI ISE
Awon nkan tio wa ni Ayika ile eko
ERONGBA
Awon akekoo yoo
Daruko ailewon nnkan ti o wa ni ayika iwe won
AKDONUISE SISI
Kiko akekoo ni oruko ohun ti-o wa ni ayika pelu orin aworan fun apeere
Aworan
Igi
Oko
Aga
Tabil
abbi
kiko akekoo lati daruko awon nikan tio wa ni ayika lile –oko ati won,fun apeere
i. ile iwosan
ii eran osin bi aja, ewure, adiye
iii. oja
iv ile tosin –mosalasi, soosi
IGBELEWON
ibanisoro ati
Ajumose ise
Ogbon ainuda ati oye
Arojinle ati Yiyanju Isoro
Eko eo-ayelujara
OHUN ELO IKONI
i.Aworan nnkan ti o wa ni ile- eko bi aga, tabili, iwe, sibi, redio, ododo, igi, ferese abbi.
ii. Aworan nnkan ti d wa ni ayika ile – eko fun apeere, mooo ile.
Keke eran osin, aja ewebe, alupupu, aso,ata,eso, bata, ife,abb
Ohun eroja ati aworan fun orin kiko, ijo jiro.
Aworan awon ti won nse ere idaraya, abbl
OSE KERUN (8)
AKORI ISE
ALO APAMO
ERONGBA
Awon akekoo yoo le
i. so ilumo alo apamo
Daruko orisi
Alo ti owa
Ii dahun si ibeere ti alo gbe wa
AKDONUISE SISI
Ki oluko pa alo apamo fun awon akekoo ki awon akekoo
So idahun re
Bi apeere
Alo ol aalo
Ki lo koja nimaju ile oba ti ko ki oba kin ni o?
Idahun –agbara –ojo abbi
Ki awon akekoo le ke orinojo nro sere ninu ile abbi
Opa teere kanle o kan orun kinni o? idahun – Ojo,abbl
Ki awon akekoo le ko orin
Ojo nro sere ninu ile, abbI
IGBELEWON
ibanisoro ati
Ajumose ise
Ogbon ainuda ati oye
Arojinle ati Yiyanju Isoro
Eko eo-ayelujara
OHUN ELO IKONI
Aworan lori
Ojo nro
Awon omode lo nse ere daraya
OSE KESAN (9)
AKORI ISE
- Ede: awon eya ara eniyan
- Asa: Ere Idaraya
ERONGBA
Awon akekoo yoo le
i.Ke daruko awon eya ara eniyan
ii.Lilo won nipa kiko orin.
Awon akekoo yoo ko orin idaraya pelu atewo pipa daradara
AKDONUISE SISI
Kiko orin orimi ijeka orukun ese tire ni oluwa
Tire ni oluwa patapata
Kiko awon akekoo ni ere idaraya pelu orin ati ijo oun alewo pipa.
Bi apeere:
i.Eye meelo tolongo waye
ii.Ja itana to n tan
iii.Ta lo wa ninu ogba naa?
iv.E ma weyin o
v.Boju boju o
Ki awon akekoo ko orin ere idaraya kan ninu eyi ti a ti ko tabi eyi ti won ba fun mo
IGBELEWON
ibanisoro ati Ajumose ise
Ogbon ainuda ati oye
Arojinle ati Yiyanju Isoro
Eko eo-ayelujara
OHUN ELO IKONI
Aworan eya ara eniyan
Orin kiko, ijojijo alewo pipa
EDE:
ASE:
OSE KEWAA (10)
AKORI ISE
Awon Arofo keekeeke
ERONGBA
Awon akekoo yoo
Ko orin awon arofo keekeeke darada
AKDONUISE SISI
Ko awon akekoo awon arofo keekeeke bii
Adiye mi
Igo marun un lara ogiri
Akekooyoo kookan lara awon orin wonyi fun ise-sise
IGBELEWON
OHUN ELO IKONI
Orin kiko ijo jijo atewo pipa
OSE KOKANLA (11)
AKORI ISE
EDE ATUNYEWO EKO
ERONGBA
Sise atunyewo ise saa kin ni lori ede
AKDONUISE SISI
ATUNYEWO EKO SAA KINNI LORI ASA
IGBELEWON
Sisi amulo awon OHUN ELO IKONI
Amuseyeni ti a lori lati ibeere saayi
OHUN ELO IKONI
OSE KEJILA (12)
AKORI ISE
EDE ATUNYEWO
ERONGBA
Sise atunyewo
Ise lori ise saa
Kin-in lori ede ati litireso
AKDONUISE SISI
ATUNYEWO EKO SAA KINNI LORI ASA
IGBELEWON
Sise amulo awon OHUN ELO IKONI amuseyini ti a ti o lati ibeere saa yii
OHUN ELO IKONI
OSE KETALA (13)
AKORI ISE
IDANWO ISA
OSE KETALA (13)
AKORI ISE
ERONGBA
AKDONUISE SISI
IGBELEWON
OHUN ELO IKONI
SCHEME OF WORK YORUBA KINDEGARTEN SAA KEJI (AGE 5)
OSE KINNI (1)
AKORI ISE
AGBEYEWO
EKO
SAA KINI
ERONGBA
Sise agbeyewo ise saa kin-ni pelu idanwo.
Ikini kaabo si saa keji
ISE SISE
Agbeyewo eko pelu awon akekoo lori ise saa kinni
OGBON ISAFIBO AKITIYAN EKO
– Ibanisoro ati Ajumose ise
– Ogbon atinuda ati Oye
– Imo Arojinle ati yiyanju isoro
– Eko Imo ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI AMUSEYENI
Sise amulo awon OHUN ELO IKONI amuseyeni ti a loni saa kinni
OSE KEJI (2)
AKORI ISE
EDE: ALFABEETI YORUBA (p – y)
EWI
AKOSOR
ERONGBA
Awon akekoo yoo.
i)ka alifaabeeti Yoruba lati leta (p –y) daradara.
ii) Se afihan awon leta yi pelu aworan idamo won.
Awon akekoo yoo ko
Ornawonewi wonyi yekeyeke
ISE SISE
i. Ki oluko ko j, k, l, m, n, si ara patako.
ii.Ki awon akeedo ka leta j, k, l, m,n, o, o, p, r,s,s,t,u,w,y.
iii.Ki oluko to awon akekoo sona lori kika ati kiko alifabeeti.
iv.Pipe akekoo meji tabi meta jade lati ka alifabeeti a – o ati p – y.
v. Kiawon akekoo gbiyanju lati di alafo isale yii.
j — l — n –
vi. ki akekoo ka ati ko alifsbeeti a – y.
Ki akeeko ko ewi keekeeke ati eko to a ninure.
Fun apeere:
Ewure je eran ile to maa ni jiya pup nitor aigboran re abbl
Adiye mi eyi ti mo toju re. losan- an ojo kan emi ko mop e o ti je e lo abbl.
OGBON ISAFIBO AKITIYAN EKO
– Ibanisoro ati Ajumose ise
– Ogbon atinuda ati Oye
– Imo Arojinle ati yiyanju isoro
– Eko Imo ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI AMUSEYENI
Kaadi alafihan leta pelebe pelebe
Aworan ti o fi pipe leta kookan han bi apeere:
j – jagunjagun
k – kiniun
l – labalaba
m – malu
n – nomba/Naijiria abbl
Awon OHUN ELO IKONI ti ewi da le lon Teepu ati kaseeti.
OSE KETA (3)
AKORI ISE
EDE: ONKA YORUBA (1 -10) ati (11 – 20)
ERONGBA
Awon akekoo yoo;
i)Ka awon onkaa wonyi bo ti to ati bo seye
ii)Ko ni orin pelu
ISE SISE
Kiko ati kika onka ede Yoruba lati ookanla de ogun (11 – 20)
Kiko orisi orika
i.Onkaye sakala
11 – okanla
12 – eejila
13 – eetala
14 – eerinla
15 – aarundinlogun
16 – eerindinlogun
17 – eetadihlogun
18 – eejidinlogun
19 – ookandinlogun
20 – ogun
ii. Onkaye arika aworan:
11 – aga mokanla
12 – ile mejila
13 – iwe metala abbl
OGBON ISAFIBO AKITIYAN EKO
– Ibanisoro ati Ajumose ise
– Ogbon atinuda ati Oye
– Imo Arojinle ati yiyanju isoro
– Eko Imo ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI AMUSEYENI
– Tito igo tabi ike omi si ori
Tabii fun onka (11 – 20)
– Lilo igi isana
– Lilo ideri oti, okuta were
– Kika akekoo obinrin
– Kika akekoo okunrin
OSE KERIN (4)
AKORI ISE
OMI
ERONGBA
Awon akekoo yoo le:
i)So Pataki omilara
ii)So wulu omininu ile daradara
AKDONUISE SISI
- Kiko awon akekoyi iwolu apeere
- A maa nmu omi
- A maa o fi omi we
- A maa o fi omi we
- A man o fi omi fo aso
- A maa o fi omi pese ounje abbi
- K awon akekoo ko orin
Omiiablewe abbl
IGBELEWON
ibanisoro ati
Ajumose ise
Ogbon atinuda ati oye
Arojinle ati Yiyanju Isoro
– Eko Ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Omi
Aso,
IFe fun mimu omi abbl
Kiko orin omi labuwe ori
labumi enikan ki ba omi ise ota
OSE KARUN -UN (5)
AKORI ISE
Asa
ASA IKINNI NI ILE
YORUBA
ERONGBA
Awon akekoo yoo le
- So awon okoko fi kini maa
N wage
- Pataki ibowo fun
agba
ISE SISE
- Kiko awon akekoo bi ati n kini
- Ati dahun ni le Yoruba
- Kini nisiko odun o
- Idahun agi
- Kini opera la o se o
- Idahun –amiro
- Ki awon akekoo koju si ara
- Won kiwon ki ara wonni lara
- Kini ni ile Yoruba
OGBON ISAFIBO AKITIYAN EKO
ibanisoro ati
Ajumose ise
Ogbon atinuda ati oye
Arojinle ati Yiyanju Isoro
– Eko Ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI AMUSEYENI
- Aworan awon lumon ni ki ara
- Won
- Teepu ati kaseelifi won le
- Kini si eligboo awon akekoo
Lio akekoo oririn lati kunle
Ati ilo akekoo okurin lati fun
Dobale fun kini
OSE KEFA (6) – ISINMI RANPE
OSE KEJI (7)
AKORI ISE
EDE: ONKA AKAYE ATI SIRO ONIKA
LITIRESO: ALO APAGBE
ERONGBA
Awon akekoo yoo
- Ka onika akaye naa
Daradara
- Lio aworan lati fi se
Siro onikaye bi gi meji
Osan merin abbi
Awon akekoo yoo so
i) Onin fun afo apagbe
ii)So eko ti a ni ko ninu Alo apagbe naa
ISE SISE
- Ki oluko ka onika akaye fun awon
- Akeloo
- Ki awon akekoo le fi onika se isiro
- Ki awon akekoole fi onika se isiro
Fun apeere
Okan – osan kan
– osan meji
Osan kan ati osan meji yoo fun wa ni
Osan kan ati osan meji yoo fun wa ni
Osanmeta abbi
- Ki oluko pa alo aladun kan fun awon
Akekoo
- Ki oluko ko orin inu ati maa daradara
Fun awonakekoo
- Ki awon akeeko si le mo oni alo raa ko
Daradara
- Ki oluko eko ti alo naa ko wa
- Fun apeere alo ijapa ati aja
- Nibi ajalimu jaba lo si inu okoloo fi
- Won ti to ji-su-wa ijeba ati si fi quokoro
- Ati wa okan juwa ti ware injuwonba sui lo
Le edagbelo
Aja lin se to nwajub ti japa si in ko orin
Pe ki aja wa ran oun ni enu
Oni aja
Lile aja, aja duroramenu maa ke soloko
Agbo
Egbe anjaa ko je abbi
OGBON ISAFIBO AKITIYAN EKO
- ibanisoro ati
- Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati oye
- Arojinle ati Yiyanju Isoro
- – Eko Ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI AMUSEYENI
–Kabooodu ti won ko onka
-Akaye si lara lati aworan ifihan Onka lati ookan le eewa (1-10)
-Kaati peebe pelele wn o unka kookan si Den ati okuta were gi abbi.
Teepu ati kaseel fia Abbi
-Teepu ati kaseeh fi a
Ni nlo naa si
-Aworan en fo nna acrati
– Awon ti an pa ab fun
-Awon ijapa ati Aja
OSE KEJO (8)
AKORI ISE
- Ede: Orin keekeere
- Akomogbon
ERONGBA
- Awon akekoo yoo
- Ko awon omo
- Akomoluko eko lawo
- Orin akamogbon ko wa
ISE SISE
- Kiku aworan ake won orin ile
- Ikori ogbon ati wa iyebiye
- Mototo segun anu gbogbon
- Omota moyere oju o
- Iya olugbonwon abbi
OGBON ISAFIBO AKITIYAN EKO
- ibanisoro ati
- Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati oye
- Arojinle ati Yiyanju Isoro
- Eko Ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI AMUSEYENI
- Aworan ohun eeje un
- Kiko awon pipa maa tio
- Nile Yoruba
OSE KESAN (9)
AKORI ISE
- Aso koniwon ile Yoruba
ERONGBA
Awoni akeeko yoo le;
i) Daruko awon onsi Aso wiwo nie aso Yoruba Paba wiwo aso Okuni ati borin
ii) Wiwo aso awelesi Akoni ati obiri naa
ISE SISE
- Ki oluko so onrisi as wiwo nlie
Yoruba
Kakeeko le salaye afaanrin owe
Ninu aso wiwo
Ki akeesoko wo aso tabi aworan
Ti aso oku nin ati aso se e wotinu aso
Abbi
Ma ki cawon akekoo yii
Wiwo onsiri aso ibi si
Buba –blouse
Iro wrapper
Sokoto – trousers
Agbada – flowing gown
Kaba – gown
Agbeko –lady’s under wears abbi
OGBON ISAFIBO AKITIYAN EKO
- ibanisoro ati
- Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati oye
- Arojinle ati Yiyanju Isoro
- – Eko Ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI AMUSEYENI
- Aworan/ orisisi aso ibile ni
- iIe Yoruba bi
- Buba
- Iro
- Sokoto
- Agbada
- Kaba
- Agbeko abbi
OSE KEWA (10)
AKORI ISE
AWO (COLOURS)
ERONGBA
Awon akekoo yoo le
- Daruko orisi awon ni
Ede Yoruba
- Ilo awo aso fi awon
Ekekoo wo la ti fid a
Awon awo mo daradara
ISE SISE
- Kiko orisiri awon ti o wa ni ayika fun
Awo — aworan
Awo funfun –Owu-wool-white
Awo dudu — Eedu charcoal –black
Awo pupa — Eje-blood –red
Awo eweko — Ewe –leaf-green
- Ki awon akeere da won awon dumo si
- Ara wonpelu aworan
- Ki awon akeeko dariko awon yi okookan
OGBON ISAFIBO AKITIYAN EKO
- ibanisoro ati
- Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati oye
- Arojinle ati Yiyanju Isoro
- – Eko Ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI AMUSEYENI
- Baa funfun
- Aso funfun
- Baba dudu
- Aso dudu
- Baba alawo eweko
- Aso alawo eweko
- Fila alawo dudu
- Gele alawo pupa
- Gel alawo pupa
OSE KOKANLA (11)
AKORI ISE
ATUNYEWO ISE
SAAKEJI LORI EDE
ERONGBA
Sise agbe jewo se saa
Keji lori ede
ISE SISE
Ki oluko se atunyewo awon ise ti o ti ko awon akekoo lati bere saa keji lori ede
OHUN ELO IKONI AMUSEYENI
Lilo awon OHUN ELO IKONI amuseyeni ti oluko ti fi ko won lawon ise naa tele
OSE KEJILA (12)
AKORI ISE
Atunyewo ise
Sayeji ilori
Asaati litireso
ERONGBA
Sise atunjewo ise saa
Keji ori asa ati litreso
ISE SISE
Ki oluko atunjewo awon ise a tiko Awon akekoo lati ibere saa keji lori asa ati litreso
OHUN ELO IKONI AMUSEYENI
- Lilo awon OHUN ELO IKONI amuseyeni
- Ti Oluko ti fi nko won lawon ise naa lele
OSE KETALA (13)
DAWON ATI AKOJOPO ESI IDANWO
Ki awon akekoo dahun
Gbogbo ibere lori
Saa keji daradara
Yoruba Language Syllabus for Early childhood Lagos State, Yoruba Scheme of work for Kindergarten (Age 5). Onika Yoruba. Schemeofwork.com
SCHEME OF WORK YORUBA KINDEGARTEN SAA KETA (AGE 5)
OSE
OSE KINNI (1)
ORI ORO
AGBEYEWO ISE
SAA JEJI
Ede alifabeeti
Yoruba (a-s) (a-y)
ERONGBA
Ni opin idaileko yi
Awon akekoo yoo le
Dahungbogbo ibeere
Lori saa keji daradara
ISE-SISE
Agbe yeworeko pelu awon
Akekoo lori ise saa keji
- Ki-olukoalifabeeti a-s ati a-y awon
Akekoo meji si meta jade lati
Ka leta 0-s ati a-s
- Pipe akekoo meji si meta jade lati
Ka leta 0-s ati a-s
Ki akekoo gbiyaju lati di alafo isale y1
0
- Afihan kaadi pelebe lori alifapeeti
Jumi kika ati kiko alifabeeti Yoruba
Aarin awon akekoo
OGBON ISAFIBO AKITIYAN EKO
———
OHUN ELO IKONI
Sise amulo awon ohun
Amuseyeri ti a ti lo mi saa
Keji
Kaadi alalihan pelebe
Pelebe ti ako 0, p, e, at s, si
Aworan ti o fi pipe leta
Kookan han
o- owo (money)
o-ogede (banana)
p- pepeye –duck)
r- redio –radio)
s- salubata (sanda)
OSE KEJI (2)
ORI ORO
Ede
Ojo ti owa
Ninu ose (days of the week)
ERONGBA
Awon akekoo yoo
Daruko awon ojo ninu
Ose
Kiko awon ojo ninu
Ose pelu orin
ISE SISI
Ki oluko ko orin ojo ose fun
Awon akekoo fun apeere
Ojo marun –un la nlo nile iwe
Aiku aje isegun ojotu ojobo eti
Abameta
Pe akekoolokokan lati pea won
Ojo-naa
Sunday-Aiku
Monday- aje
OGBON IASFIBO AKITYAN
KITIYAN EKO
- ibanisoro ati
- Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati oye
- Arojinle ati Yiyanju Isoro
- – Eko Ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Kaadi pelebe pelebe ile
Ko ojo lio wa ninu ose
Kalenda
Teepu ati kaseeli orin
Meji to wa ninu ose
OSE
KETA (3)
LITRESO ORIN
KEEKEEKE
AKOMNNWA
AKOMOLOGBON
ERONGBA
Awon akekoo yoo
Ko awon onin
Akomniwa ati
Akomologbon daradara
ISE SISI
kiko awon akekoo ni orin keekeeke
Fun apeere
Ja itanna to n tan, to lutu to si gara
Ma duro dojo ola, okoko sure tele
Labe igi orogbo ibela igbe in sere wa
Inu wa dun, ara waya labe igi omomo
Eye meo lolongoikaye lolongo abbi
IGBELEWON
- ibanisoro ati
- Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati oye
- Arojinle ati Yiyanju Isoro
- – Eko Ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Orin kiko
Ijo jijo
Ilo-ilo
Atewa pipa
Teepu ati kassli orin
OSE
KERIN (4)
ERONGBA
EDE IRO FAWEL ATURO
KONSONANTI
Awon akeloo yoo
Da awon leta tiwon je
Iro fawel mo.
Mo onsii iye fawel je
So awon iro konsonnati ni ede
Yoruba
ISE SISI
Kika ati kiko fawel
Fawell Yoruba a,e,e,i,o,o,u
Kika ati kikokonsonanti ede Yoruba
b,d,f,g, gh, k,j,m,n,p,I,s, s,t w,y,r
ki oluko fi mo fawel ko orin a, e, e, o,o,u
IGBELEWON
- ibanisoro ati
- Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati oye
- Arojinle ati Yiyanju Isoro
- – Eko Ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Kadibodu pelebe
Li a, ko
Leta fawel ati
Konsonanti si
Kadibodu ako ewiyi si
Teepu ati
Kaseeti ti a ka ewi yii si
Onn kiko alewo
Pipa ilu
Ilubewi kike ati ijo ijo
LITIPRESO EWI KEEKEEKE
ERONGBA
Awon akekoo yoo yii
Ka awon ewi naa ni
Aka gbadun daradara
So awon ewi wonyi ko wa
ISE SISI
Ki oluko ewi keekeeke
Akomologbon quaro ikowe
Fun apeere
Ewure je eran ile adiye mi
La itana torin han abbi
Akeeko oluko awon ewi keekeeke pulu
Orin ati ijo
OSE
KAPURIN (5)
EDE SISO FAWEL
ATI
KONSONANTI PO
ERONGBA
Awon akekoro yoo yoo
So iro konsonanti ati iro
Well fawel po fun silebu
Kan tabi meji
ISE SISI
Kiko akekoo bi a lih se amulo
Iro consonanti ati iro fawel lati seda
Oro onislebu kan tabi silebu meji
Fun apeere
a e e i o o
b ba be be bi bo o
a da de de di do o
f fa fe fe f fo fo
g ga ge ge gi go g
gb gba gbe gbe gbi gbo g
h ha he he hi ho h
j ja je je ji jo jo
k ka ke ke ki ko k
abbi
IGBELEWON
- ibanisoro ati
- Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati oye
- Arojinle ati Yiyanju Isoro
- – Eko Ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Kadiboodi ti a Yoruba
To se
Alihan amulo awon
Konsonanti ati mo
Wonyi si
Aworan ti se
Afihan awon oro wonyi
OSE
KEFA (6)
SINMI RAMPE
OSE KEJE (7)
EDE OPOONISILEBU IKEJI
ERONGBA
Awon akekoo yoo le
Ko oro oni silebu meji
daradara
ISE SISI
Kiko ati fifi aworan han awon
Akekoo bi a tin ko oro o ni
alfabeeti meta
fun apeere
o-ba –king
o-wo- money
a-ga-chair
o-mo-child
i-we-book
i-le-house
e-ja-fish
a-be-knife
e-li-ear
IGBELEWON
- ibanisoro ati
- Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati oye
- Arojinle ati Yiyanju Isoro
- – Eko Ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Aworan ti o se
Afihan awon
Oro wonyi
Oba
Owo
Aga
Iwe
Omo abbi
OSE
KEKO (8)
ASA OUNJE ATI ESO
ERONGBA
Awon akekoo yoo le
- Danuko awon ounje
Ile wa
- Piri awon ounje
Wonyi si isori pelu ise
Ti won nse ni ago ara
ISE SISI
Kiko atididaruko awon ounje ile wa
Didaruko awon ire-oko ati ounje
Won ni fi won se
Pin punjesi son ati se ti won nise lara
Ko die sile ninu ire-okoati ounje
Akekoo yoo daruko onsii ounje ile wa
Fun apeere
Eba, amala, eko, koko,isu, iyan, abbi
Kiko ati didararuko awon ti o je jije
Ayi ti o wa ni ayika
Sp iwulo eso jije lala
Ko die sile ninu awon eso ile Yoruba
Fun apeere
Onono osan orange
ibepe –paw-paw
ogede –banana
asala – walnut
ope oyino –pineapple
akekoo yoo se alifan eso ile Yoruba
tabi pelu aworan
IGBELEWON
- ibanisoro ati
- Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati oye
- Arojinle ati Yiyanju Isoro
- – Eko Ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Orisiri –oko
Aworan
Awon to n toju ounje
Orsirisi ounje bi eba
Amala, iyan eko, monmoir abbi
Aworan ti o se afiran
Orisinsi esojije ni ile
Yoruba bii ibepe
Ogede, osan, abbi
OSE
KESANAN (9)
LITPESO
ARAENIYAN
ERONGBA
Awon akekoo yoo le
Ke daruko
Eniyan han pelu
Atewo pipa daradara
ISE SISI
Kiko akekoo orin ijo
Ati atewo pipa
Fun apeere
On ni-my head
Ejika –my sholders
Orinkun –knees
Ese –legs
Tire ni oluwa patapata
IGBELEWON
- ibanisoro ati
- Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati oye
- Arojinle ati Yiyanju Isoro
- – Eko Ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Aworan ti o se alifan
Ati gbogbo orikeeri
Orin kike ijo jijo alewo pipa
Titoka si awon eya ara
Aworan eye ara
OSE
Kewaa (10)
OSE AWON ERAN
OSIN
ERONGBA
Awon akekoo yoo
- So ilumo oran osin
- Daruko orisis eran
Osin to wa
- Pataki awon eran osin wonyi
ISE SISI
Ki oluko salaye fun awon eran
osin ni awon nnikan elemi
li owa fun jije ti o n gbe laarin ile
pelu eniyan
o ile eranti tabi eye fun apeere
eure –goat
agunla –sheep
ologbo –cat
maalu –caw
igbiri –snail
elede – pig
aja-dog
eye-bird
adiye hen
pepeye –duck abbi
IGBELEWON
- ibanisoro ati
- Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati oye
- Arojinle ati Yiyanju Isoro
- – Eko Ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Aworan li o se afihan awon
Eranko yi lolokan oyo-
Teepu li o ni kaseetiti
Gba ohun orin wonyi sile
OSE
KOKANLA (11)
EDE ATUNYEWO
EKO SAA Yii
ERONGBA
Awon akekoo yoo se
Alunyewo ise ion ede
ISE SISI
Ki oluko ran awon akekoo awon
Ise ti o ti ko won ati ibeere saa eko
Lori ede ati litireso
IGBELEWON
Kia won akekoo se
Iranti awon eko ti
Won ti ko lati ibeere
Faamu lori ede ati
Litreso
OHUN ELO IKONI
Ki oluko se amulo awon
Ohan elo amuseyan li o
Fi ko won lawon ise naa
OSE
KEJILA (12)
ERONGBA
Sise alunyewo iselori
Ase ati lititrso
ISE SISI
Ki oluko muu wa si iranti awon
Akekoo nipa awon-ise ti o ti ko won
Lati ibeere taamu ion asa
IGBELEWON
Ki awon akekoo le
Se iranti awon ise ti won
Ti ko
OHUN ELO IKONI
Ki oluko se amuwo awon
OHUN ELO IKONI ti o fin ko
Awon akekoo ni awon ise
Yii bo lati ibeere taamu
OSE IDANWO IDANWO IDANWO
KETALA