Nigeria Syllabus, Yoruba Language scheme of work primary 2 Federal, álífábëêtì èdè Òyìnbó àti èdè Yorùbá, sílébù, gbólóhùn kéèkèèké.
FIRST TERM YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK FOR PRIMARY TWO
YORÙBÁ PRIMARY 2 TÁÀMÙ KÌN-ÍN-NÍ
ÕS Ê 1
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ÌTÊSÍWÁJÚ NÍNÚ KÍKA ÁLÍFÁBËÊTÌ
YORÙBÁ
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Kíkô álífábëêtì Yorùbá sí ara pátákó ìkõwé
2. Śíśe àfihàn álífábëêtì tí ó jë fáwëlì
3. Kíkô köńsónáýtì sí ojú pátákó
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1. Kô álífábëêtì Yorùbá sí ara pátákó ìkõwé
2. Ka fáwëlì álífábëêtì àránmúpè àti àìránmúpè fún akëkõö
3. Ka köńsónáýtì fún akëkõö
4. Pe akëkõö bí i méjì láti kà á.
AKËKÕÖ
1. Fi etí sílê bí olùkö śe ń ka fáwëlì àti köńsónáýtì
2. Pè é têlé olùkö bí ó śe ń kà á
3. Śe ìdámõ àránmúpè àti àìránmúpè ní ara pátákó ìkõwé
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1. Pátákó Ìkõwé
2. Káàdì aláfihàn
3. Pátákó çlëmõö
ÕS Ê 2
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ÌTÊSÍWÁJÚ LÓRÍ KÍKA ÁLÍFÁBËÊTÌ YORÙBÁ
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Ìyàtõ álífábëêtì èdè Òyìnbó àti èdè Yorùbá: ABC ní à pè ní álífábëêtì èdè Òyìnbó nígbà tí ABD jë álífábëêtì èdè Yorùbá abbl.
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1. Kô álífábëêtì sí ojú pátákó ìkõwé.
2. Kô ìyàtõ tí ó wà nínú álífábëêtì èdè Òyìnbó àti èdè Yorùbá síta.
AKËKÕÖ
1. Ka álífábëêtì ara pátákó
2.Fa ìyàtõ tí ó wà nínú álífábëêtì èdè Òyìnbó àti èdè Yorùbá síta
3.Dá àwôn lëtà náà mõ löõkõkan.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1.Kádíböõdù tí a kô álífábëêtì sí.
2.Káàdì pélébé pélébé tí ó śe ìdámõ álífábëêtì náà
ÕS Ê 3
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ÒÝKÀ YORÙBÁ:Oókanlélógún dé ôgbõn(21 – 30)
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Kíka òýkà láti oókanlélógún dé ôgbõn
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1.Tö akëkõö sönà láti ka òýkà oókanlélógún dé ôgbõn
2.Śe àlàyé ìgbésê òýkà ní kíkún bí àpççrç: 21 – 24 àròpõ 25 – 29 àyôkúrò 30 -ìsôdipúpõ
AKËKÕÖ
1.Ka òýkà láti oókanlélógún títí dé ôgbõn
2.Dá òýkà ti ojú pátákó mõ ní õkõõkan
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1.Kádíböõdù tí a kô òýkà oókanlélógún dé ôgbõn sí.
2.Káàdì pélébé pélébé tí a kô òýkà kõõkan sí.
ÕS Ê 4
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ÌMÖTÓTÓ ÀYÍKÁ
ÀKÓÓNÚ IŚË
1.Ìtöjú ilé àti àyíká: ríro oko êgbë ilé àti àyíká ilé.
2.Ewu tó wà nínú àìtöjú àyíká wa
3.Orin àti ewì tó jçmö ìmötótó b.a. ìmötótó ló lè śëgun àrùn gbogbo abbl.
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1.Śe àlàyé ní êkúnrërë nípa ìmötótó ní àyíká ilé àti ilé-êkö
2.Fi àwôn ohun èlò fún ìmötótó ilé àti àyíká hàn.
3.Sô ewu tí àìtöjú àyíká ilé lè fà
4.Kô orin àti ewì tí ó jçmö ìmötótó
5.Tö akëkõö sönà láti sô àkíyèsí àyíká, kí wôn sì śe àtúnśe.
AKËKÕÖ
1.Sô bí a śe lè śe ìmötótó àyíká wa.
2.Sô àwôn ewu àìtöjú ilé àti àyíká lè fa.
3.Kô orin àti ewì ìmötótó.
4.Kópa nínú títún àyíká śe.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1.Ìgbálê gígùn
2.ôkö
3.àdá
4.Réèkì
5.Apêrê ìdalênu
6.ìkólê
ÕS Ê 5
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ÌTÊSÍWÁJÚ LÓRÍ DÍDÁRÚKÔ NÝKAN
ÀKÓÓNÚ IŚË
1.Ilé – tçlifísàn, rédíò abbl
2.Ilé-êkö, – çfun, àga abbl
3.Òpópónà ôjà – mötò, ènìyàn abbl
4.ôjà – iśu, ata abbl
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1.Pe akëkõö láti dárúkô àwôn ohun tí ó wà ní àyíká rê
2.Sô ìwúlò wôn
3.Pe akëkõö láti fi àwôn ohun tí ó wà ní àyíká wôn kôrin
AKËKÕÖ
1.Dárúkô àwôn ohun tí ó wà ní àyíká rç
2.Sô ìwúlò wôn
3.Fi àwôn ohun tó wà ní àyíká wôn kôrin
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
Àwòrán àwôn ohun tó wà ní àyíká tàbí nýkan náà gan-an
ÕS Ê 6
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ÌRÓ ÈDÈ (ÀMÌ OHÙN)
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Kín ni àmì ohùn?
2. Oríśi àmì ohùn:
Ohùn àárin(a kì í fihàn)
Ohùn òkè
Ohùn ìsàlê
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1.Śàlàyé ohun tí à ń pè ní ìró ohùn
2.Kô àwôn àpççrç ìró ohùn sójú pátákó
3.Pè wön fún àwôn akëkõö
AKËKÕÖ
1.Tëtí sí àlàyé olùkö lórí àwôn àmì ohùn mëtêêta
2.Pe àwôn ohùn náà têlé olùkö,
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
•Kádíböõdù tí ó ń śe àfihàn àwôn àmì ohùn.
ÕS Ê 7
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ÌTÊSÍWÁJÚ LÓRÍ ÌRÓ ÈDÈ (ÀMÌ OHÙN)
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Fáwëlì àti oríśiríśi àmì ohùn kõõkan
lórí fáwëlì. B.a. à, a, á, e,è, é, ç, ê, ë abbl.
2. Àmì ohùn lórí õrõ onísílébù kan, b.a. bá, bà, ba abbl
3. Àmì ohùn lórí õrõ onísílébù méjì, b.a. ôkö, ôkô, õkõ abbl
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1. Kô àwôn fáwëlì pêlú àmì ohùn orí wôn àti àwôn õrõ onísílébù kan àti onísílébù méjì.
AKËKÕÖ
1. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí àwôn àmì ohùn onísílébù kan àti onísílébù méjì
2. Pe àwôn fáwëlì àti õrõ náà bí olùkö śe pè wön.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
Kádíböõdù tí ó ń sse àfihàn àwôn àmì ohùn lórí fáwëlì onísílébù kan àti onísílébù méjì.
ÕS Ê 8
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
KÍKA SÍLÉBÙ
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Àlàyé ohun tí sílébù jë (Ègé õrõ)
2. Gígé àwôn õrõ onísílébù b.a Bàbá – ba/ba, Bàtà – bà/tà abbl
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1. Śe àlàyé sílébù
2. Kô àwôn õrõ sí ara pátákó kí o sì pín wôn sí ègé õrõ.
AKËKÕÖ
1. Tëtí sí olùkö
2. Pe àwôn õrõ náà têlé olùkö
3. Kópa nínú kíkô sílébù sí ara pátákó ìkõwé
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
Káàdì pélébé pélébé tí a kô àwôn õrõ tí a pín sí ègé sí.
ÕS Ê 9
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ERÉ ÒŚÙPÁ
ÀKÓÓNÚ IŚË
1.Ìtàn sísô bí àpççrç: bojúbojú abbl
2.Orin erémôdé
3.Êkö tí a rí kö
• Ní ìmõ kíkún nípa àyíká wôn
• Mô orin kô, mô õrõ inú orin àti kíkà wôn
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1.Kô àwôn orin náà.
2.Tç àwôn orin náà tí ó ti gbà sí inú téèpù fun
3.Kô àpççrç àwôn orin náà.
AKËKÕÖ
1.Kí akëkõö kô èyí tí wôn mõ
2.Fetí sí téèpù tí a ti gba irú orin bëê sílê
3.Kô àpççrç orin tí wön gbö.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1.Àwòrán tí ó jç mö orin náà
2.Téèpù
3.Ìlù
ÕS Ê 10
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ÌWÉ KÍKÀ: Kíka Ìwé Àśàyàn
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Àyôkà tí ìmõ rê kò ju ti ôjö-orí akëkõö lô
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1.Śe àwárí àwôn àyôkà tí ó jçmö õrõ tó ń lô
2.Jë kí akëkõö ka àyôkà, kí ó sì dáhùn ìbéèrè
AKËKÕÖ
1. Tëtí sí àlàyé lórí àkàyé
2.Ka àyôkà, sì dáhùn àwôn ìbéèrè lórí rê
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
• Àyôkà oríśiríśi tí ó dálé ìśêlê àwùjô.
ÕS Ê 11
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
AÁYAN ÒGBUFÕ
ÀKÓÓNÚ IŚË
1.Kín ni aáyan ògbufõ?
2.Títúmõ àwôn õrõ b.a Come – wá, dog – ajá, food – oúnjç abbl
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1.Śàlàyé títúmõ aáyan ògbufõ
2.Kô àwôn õrõ sí ojú pátákó fún akëkõö
3.Kô àpççrç õrõ aáyan ògbufõ kí akëkõö sì kà wön
AKËKÕÖ
1.Tëtí sí àlàyé lórí aáyan ògbufõ
2.Ka àpççrç aáyan ògbufõ kí o sì pè é têlé olùkö
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
•Kádíböõdù pélébé pélébé tí a kô aáyan ògbufõ sí nínú.
ÕS Ê 12
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ÌTÊSÍWÁJÚ LÓRÍ AÁYAN ÒGBUFÕ
ÀKÓÓNÚ IŚË
Títúmõ õrõ bí i: Pencil – Pëńsù
Biro – Báírò Chair – àga abbl
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1.Śàlàyé lórí àwôn õrõ kookan
2.Kô àwôn õrõ sí ojú pátákó
3.Kô àpççrç õrõ aáyan ògbufõ
AKËKÕÖ
1.Tëtí sí àlàyé olùkö lórí àpççrç aáyan ògbufõ.
2.Pe àwôn aáyan ògbufõ náà têlé olùkö.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
Kádíböõdù tí ó ń śe àfihàn aáyan ògbufõ.
ÕS Ê 13 : ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ
ÕS Ê 14: ÌDÁNWÒ
Nigeria Syllabus, Yoruba Language scheme of work primary 2 Federal, álífábëêtì èdè Òyìnbó àti èdè Yorùbá, sílébù, gbólóhùn kéèkèèké.
SECOND TERM YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK FOR PRIMARY TWO
ÕS Ê 1
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ÌTÊSÍWÁJÚ LÓRÍ ÌKÍNI
ÀKÓÓNÚ IŚË
1.Pàtàkì ìkíni ní ilê Yorùbá
2.kíni ní onírúurú ìgbà àpççrç ìgbà ôdún.
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1.Àlàyé ní êkúnrërë lórí pàtàkì ìkíni àti ìdáhùn
2.ìkíni àti ìdáhùn fún onírúurú ìgbà tó wà nínú ôdún, ìgbà òjò, ìgbà êêrùn àti ìgbà ôyë. Ç kú òjò abbl
AKËKÕÖ
1.Sô ohun tí wôn mõ nípa àśà ìkíni sáájú ìdánilëkõö
2.Kópa nínú eré bí a śe ń kí ni.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
Àwòrán àwôn tí ó ń kí ara wôn
ÕS Ê 2
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ÌTÊSÍWÁJÚ NÍNÚ KÍKÔ ÁLÍFÁBËÊTÌ ÈDÈ YORÙBÁ
ÀKÓÓNÚ IŚË
1.Kíkô álífábëêtì èdè Yorùbá.
2.Dídá àwôn ìró álífábëêtì náà mõ. Àpççrç ìró fáwëlì àti ìró köńsónáýtì
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1.Kô álífábëêtì Yorùbá sókè fún àwôn akëkõö.
2.Kô àwôn lëtà tí ó dúró fún ìró õrõ köńsónáýtì, fáwëlì àránmúpè àti àìránmúpè lötõõtõ sójú pátákó.
3.Pè wön lökõõkan fún akëkõö köńsónáýtì
AKËKÕÖ
1.Śe àwòkô àtç álífábëêtì Yorùbá.
2.Śe àwòkô àwôn lëtà ìró köńsónáýtì, fáwëlì àránmúpè àti àìránmúpè.
3.Pe àwôn fáwëlì àti köńsónáýtì náà bí olùkö śe pè wön.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1.Kádíböõdù ńlá tí a kô álífábëêtì Yorùbá sí.
2.Kádíböõdù ńlá tí ó ń śe àfihàn àwôn fáwëlì àti köńsónáýtì lötõõtõ
3.Káàdì pélébé pélébé tí a kô àwôn lëtà náà sí.
ÕS Ê 3
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ÌTÊSÍWÁJÚ LÓRÍ ÌRÓ ÈDÈ (ÀMÌ OHÙN)
ÀKÓÓNÚ IŚË
1.Àmì ohùn lórí õrõ onísílébù kan. Àpççrç; ba, bá, wá abbl
2.Àmì ohùn onísílébù méjì. Àpççrç; adé – a/dé, bàbá – bà/bá abbl
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1.Śe àlàyé lórí oríśi ohùn mëtêêta
2.Kô àwôn fáwëlì pêlú ohùn orí wôn àti àwôn õrõ onísílébù méjì sára pátákó.
3.Pè wön fún àwôn akëkõö
AKËKÕÖ
1.Tëtí sí àlàyé olùkö lórí àwôn àmì ohùn mëtêêta
2.Śe àwòkô fáwëlì àti àwôn õrõ tí olùkö kô
3.Pe àwôn fáwëlì àti õrõ náà bí olùkö śe pè wön.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
•Kádíböõdù tí ó ń śe àfihàn àwôn àmì ohùn
lórí fáwëlì õrõ onísílébù kan àti onísílébù
méjì.
ÕS Ê 4
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
KÍKÔ SÍLÉBÙ
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Kín ni sílébù?
2. Kíkô sílébù, çja, ewúrë, ìlú, agolo
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1.Śe àlàyé sílébù
2.Kô àwôn õrõ sí ara pátákó, kí o sì pín wôn sí ègé õrõ.
3.Tö akëkõö sönà láti kô sílébù sí ara pátákó ìkõwé
AKËKÕÖ
1.Tëtí sí olùkö.
2.Gbìyànjú láti kô sílébù sí ara pátákó.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
•Káàdí pélébé pélébé tí a kô àwôn õrõ tí a pín sí ègé sí.
ÕS Ê 5
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ÒWE KÉÈKÈÈKÉ
ÀKÓÓNÚ IŚË
1.Kín ni òwe?
2.Pípa àwôn òwe kéèkèèké. Àpççrç. Bámi na ômô mi kò dénú ôlömô, màlúù tí kò nírù Ôlörun ôba ló ń lé esinsin fún un.
3. Bí ômôdé śe ń pa òwe níwájú àgbà
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1. Śe àlàyé òwe.
2.Sô bí ômôdé śe ń pa òwe níwájú àgbà. Bí àpççrç, “tótó, ó śe bí òwe, êyin àgbà náà ni ç máa ń sô pé”
3.Pe akëkõö láti pa àwôn òwe tí wôn ti gbö rí
4.Kô àwôn òwe náà sí ara pátákó
AKËKÕÖ
1.Tëtí sí àlàyé olùkö
2.Pa àwôn òwe tí o mõ
3.śe àkôsílê àwôn òwe tí olùkö kô sí ojú pátákó ìkõwé sínú ìwé wôn.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1.Téèpù tí a ti gba òwe sí inú rê
2.Ìwé tó dá lórí òwe Yorùbá
3.Àwòrán oríśiríśi nípa àwôn òwe tí a pa.
ÕS Ê 6
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ERÉ ÔMÔDÉ
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Kín ni eré ômôdé?
2. oríśi õnà méjì tí eré ômôdé pín sí.
Àpççrç i. Àwôn tí ó jçmö pípagbo tàbí tí tò lësççsç
ii. Àwôn tó jç mö àkösórí
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1.Śe àlàyé eré ômôdé
2.Sô oríśi õnà méjì tí eré ômôdé pín sí
3.Śàlàyé lórí oríśiríśi eré ômôdé
AKËKÕÖ
1.Tëtí sí àlàyé olùkö lórí eré ômôdé .
2.Sô oríśiríśi eré ômôdé mìíràn
3.Kópa nínú eré śíśe náà
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
•Àwòrán àwôn ômôdé tó ń śe oríśiríśi eré
ômôdé.
ÕS Ê 7
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ÌTÊSÍWÁJÚ LÓRÍ ERÉ ÔMÔDÉ
ÀKÓÓNÚ IŚË
1.Àýfààní eré ômôdé.
2.Oríśiríśi àpççrç eré ômôdé. Àpççrç; Çkùn mëran, Çyç mëta tolongo wáyé, bojúbojú, eni bí eni.
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1. Sô àýfààní àti àléébù síśeré ômôdé
2.Darí àwôn akëkõö ní ìsõrí láti śeré ômôdé
3.Kó akëkõö lô sí ibi tí wön ti ń śeré kõõkan
AKËKÕÖ
1.Tëtí sí àlàyé olùkö lórí àýfààní àti àléébù tó wà nínú eré śíśe.
2.Kópa nínú síśe àwôn eré náà.
3.Lô sí ibi tí wôn ti le fi ojú rí śíśe àwôn eré náà.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1.Àwòrán àwôn ômô tó ń śe oríśiríśi eré ômôdé
2.Òkòtó
ÕS Ê 8
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
OÚNJÇ ILÊ YORÙBÁ: Oúnjç ôlöràá àti oúnjç amáradán
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Oríśi oúnjç ôlöràá – Bötà, õrá çran, epo pupa, òróró, abbl
2. Oríśi oúnjç amáradán – çyin, êwà, çran, çja abbl
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1.Śàlàyé lórí àwôn oúnjç ôlöràá
2.Kô àwôn oúnjç amáradán.
3.Sô àýfààní tí õkõõkan wôn ń fún ara
AKËKÕÖ
1.Tëtí sí àlàyé olùkö lórí oúnjç ôlöràá
2.Pe àwôn oúnjç amáradán náà têlé olùkö
3.Kópa nínú àýfààní tí àwôn oúnjç wõnyí ń śe fún ara.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
•Káàdì pélébé pélébé tí a kô àwôn oúnjç ôlöràá àti amáradán sí.
ÕS Ê 9
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ÌTÊSÍWÁJÚ LÓRÍ OÚNJÇ ILÊ YORÙBÁ:
Oúnjç Afáralókun
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Oúnjç afáralókun bí àmàlà, êbà, iyán, ìrçsì, búrëdì abbl
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1.Sô àwôn oúnjç afáralókun fún akëkõö
2.Sô iśë tí wôn ń śe nínú ara
AKËKÕÖ
1.Tëtí sílê láti gbö ohun tí olùkö ń sô
2.Kô àkôsílê olùkö sínú ìwé rç.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
•Kádíböõdù tí a kô àwôn oúnjç sêmíró sí.
ÕS Ê 10
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ÌTÊSÍWÁJÚ LÓRÍ OÚNJÇ ILÊ YORÙBÁ:
Oúnjç Sêmíró
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Oúnjç bí i wàrà, õgêdê, èso lóríśiríśi abbl
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1.Kô àwôn oúnjç sêmíró sára pátákó.
2.Kà á fún akëkõö
3.Darí akëkõö láti ka oúnjç náà
AKËKÕÖ
1.Fojú sí ohun tí olùkö ń kö.
2.farabalê láti kô oúnjç tìrç
3.Kô àkôsílê olùkö sínú ìwé
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
•Kádíböõdù tí a kô àwôn oúnjç sêmíró sí.
ÕS Ê 11: ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ
ÕS Ê 12: ÌDÁNWÒ
Nigeria Syllabus, Yoruba Language scheme of work primary 2 Federal
THIRD TERM YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK FOR PRIMARY TWO
YORÙBÁ PRIMARY 2 TÁÀMÙ KËTA
ÕS Ê 1
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
OLÚ ÌLÚ ILÊ YORÙBÁ
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Àwôn Ìlú bí Ìfê, Öyö Ìbàdàn, Ìjêbú, Àbéòkúta, Àkúrë Èkìtì Òsogbo àti bëê bëê lo.
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1.Kô àwôn Olú Ìlú ilê Yorùbá sára pátákó
2.Kàá fún akëkõö
3.Darí akëkõö láti kaa Olú Ìlú ilê Yorùbá
AKËKÕÖ
1.Fôjú sí óhun ti olùkö ń sô.
2.Farabalê láti ko Olú ìlú tirê.
3.Kô àkôsílê olùkö sínú ìwé rç
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
•Kádíbödù tí a kô àwôn olú ìlú ilê Yorùbá sí.
ÕS Ê 2
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ÌPOLÓWÓ ÔJÀ
ÀKÓÓNÚ IŚË
1.Kínni ìpolówó ôjà.
2.Àýfààní tó wà nínú ìpolówó ôjà.
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1.Śe àlàyé ìpolówó ôjà.
2.Sô àýfààní ìpolówó ôjà.
3.Darí akëkõö láti śe ìpolówó ôjà.
AKËKÕÖ
1.Tétí sí àlàyé olùkö.
2.Sô àýfààní ti o wa láàrin ìpolówó ôjà.
3. Kó pa nínú ìpolówó ôjà
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
•Àwòrán ti o fi çni tí ó ń polówó ôjà hàn
ÕS Ê 3
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ÌTÊSÍWÁJÚ LÓRÍ ÌPOLÓWÓ ÔJÀ
ÀKÓÓNÚ IŚË
1.ìpolówó ôjà láyé àtijö àti òde òní. Àpççrç
2.Ayé àtijö: ojúlé sí ojúlé, inú ôjà abbl
3.Òde òní: rédíò, tçlifísàn àti ìwé ìròyìn
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1.Śàlàyé bí a śe ń śe ìpolówó ôjà
2.Sô bí a śe ń polówó ôjà ní ayé àtijö fún akëkõö
3.Sô bí a śe ń polówó ôjà ní ayé òde òní fún àwôn akëkõö
AKËKÕÖ
1.fi etí sí àlàyé olùkö
2.sô oríśi õnà mìíràn tí à ń gbà polówó ôjà láyé àtijö
3.sô ìrírí wôn nípa ôjà títà tàbí ìpolówó.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
•Ìwé ìròyìn tí ó śe àfihàn ibi tí wôn ti polówó ôjà
ÕS Ê 4
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ÌTÊSÍWÁJÚ NÍNÚ ÌTÀKURÕSÔ
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. orúkô çni tí ó ń pàdé fún ìgbà àkökö, ìlú rê, ôjö orí rê, ilé-ìwé tí ó ń lô, irú oúnjç tó fëràn jù.
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1.Tö àwôn akëkõö sönà láti le dáhùn àwôn ìbéèrè náà bí ó ti tö àti bí ó ti yç
2.Jë kí àwôn akëkõö béèrè ìbéèrè.
AKËKÕÖ
1.Fún olùkö ní ìdáhùn tó bá ìbéèrè rê mu
2.kí akëkõö béèrè ìbéèrè.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
Śíśe àmúlò àwôn akëkõö láti béèrè ìbéèrè löwö ara wôn.
ÕS Ê 5
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ERÉ-ONÍŚE ONÍJÓLÓRIN
ÀKÓÓNÚ IŚË
1.Orin kíkô
2.Oríśiríśi orin. Àpççrç orin ìgbéyàwó, orin arçmôlëkún, orin ìkömôjáde, orí ìwà rere àti orin ìdárayá
3.Pàtàkì orin
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1.Darí àwôn akëkõö láti lo orin náà fún ìśeré
2.Śàlàyé lórí oríśiríśi orin
3.Sô pàtàkì orin
AKËKÕÖ
1.Kô orin têlé olùkö
2. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí oríśiríśi orin
3. kópa nínú ìjíròrò pàtàkì orin kíkô
ÕS Ê 6
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ÌTÊSÍWÁJÚ LÓRÍ ERÉ ONÍŚE
ONÍJÓLÓRIN
ÀKÓÓNÚ IŚË
- ijó jíjó
- ìfarasõrõ
- ìjupájusê
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1. Darí olùkö láti lo àwôn orin náà fún ìśeré.
2. Láti fi ôwö àti çsê śe àpèjúwe bí wön śe ń jó
AKËKÕÖ
1.Kô orin têlé olùkö
2.Kópa nínú ijó jíjó
3.Fi êyà ara bí i ôwö, çsê, ojú śe àpèjúwe
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1.Aśô eré àti ohun èlò mìíràn tó bá ìśêlê inú orin mu
2.Ìlù
ÕS Ê 7
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ÀLÖ ONÍTÀN
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Àlö onítàn – àlö ìjàpá àti ajá
2. Àlö olórogún, àlö asõdí-abáj, àlö ìjàpá àti ìgbín, àlö àkùkô àti kõlõkõlõ
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1. Fún akëkõö ní àpççrç ìtàn bëê
2. Śàlàyé àlö ìjàpá àti àlö olórin
3. Sô êkö tí a rí kö.
AKËKÕÖ
1. sô ìtàn tìrç
2. Fa êkö inú ìtàn rê yô.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1. Ohun tí ìtàn dálé (bí a bà lè rí i)
2. Àwòrán ohun tí ìtàn dálé
3. Téèpù
ÕS Ê 8
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
ÌFARA-ÇNI-SÍPÒ ÔMÔLÀKEJÌ
ÀKÓÓNÚ IŚË
1. Àśà ìwà ômôlúàbí, àpççrç kín ni àwôn ìwà ômôlúàbí – ìrànlöwö, ìbánikëdùn, ìfë, ìlawösí, ìfira çni jì, àánú abbl
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1. Śàlàyé ohun tí fífi ara çni sípò ômôlàkejì túmõ sí.
2.Sô pàtàkì àti àýfààní rê láwùjô b.a. fún ìgbésí ayé rere àti àlàáfíà.
3.Tö akëkõö sönà láti jíròrò lórí ìwà rere bí ìrànlöwö, ìfë abbl
AKËKÕÖ
1. Tëtí sí olùkö
2. Sô nípa àýfààní àti ìwúlò fífi ara çni sípò ômôlàkejì
3. Kópa nínú ìjíròrò
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1. Fíìmù tó ń śe àfihàn àwôn tí ìyà ń jç tí wön nílò àánú
2. Àwòrán tó ń śe àfihàn àwôn tó nílò ìrànlöwö.
ÕS Ê 9
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
GBÓLÓHÙN KÉÈKÈÈKÉ
ÀKÓÓNÚ IŚË
1.Kín ni gbólóhùn?
2.Kíkà àti kíkô gbólóhùn kéèkèèké
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1.Śe àlàyé ohun tí gbólóhùn túmõ sí
2.Kô gbólóhùn sí ara pátákó
3.Kà á fún akëkõö
4.Darí akëkõö láti ka àwôn gbólóhùn náà
AKËKÕÖ
1.Fetí sí ohun tí olùkö ń sô
2.Fara balê ka gbólóhùn náà.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
Kádíböõdù tí a kô àwôn gbólóhùn kéèkèèké sí.
ÕS Ê 10
ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ
GBÓLÓHÙN ABÖDÉ
ÀKÓÓNÚ IŚË
1.Kín ni gbólóhùn abödé?
2.Kíkà àti kíkô gbólóhùn abödé. Àpççrç: Mo fë jçun, Mo fë lô ilé, Mo fë sùn abbl
ÀMÚŚE IŚË
OLÙKÖ
1.Śàlàyé gbólóhùn abödé
2.Kô gbólóhùn abödé sí ara pátákó
3.Kà á fún akëkõö
4.Darí àwôn akëkõö láti kà á.
AKËKÕÖ
1.śe àkôsílê gbólóhùn abödé tí olùkö kô sójú pátákó sínú ìwé rç.
2.kà á têlé olùkö bí ó śe ń kà á.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
•Kádíböõdù tí a kô àwôn gbólóhùn abödé sí.
ÕS Ê 11: ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ
ÕS Ê 12: ÌDÁNWÒ