Yoruba Language Scheme of Work Primary 3 Federal

28 Min Read
yoruba language scheme of work
yoruba language scheme of work

Nigeria Language Syllabus, Yoruba Language scheme of work primary 3 Federal, awon okunrin ati obInrin n wo, Káàdì pélébé pélébé.

FIRST TERM YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK FOR PRIMARY THREE (3)

                        YORUBA PRIMARY 3 TAAMU KlN-IN-NI

OSE 1

ORI ORO/ AKOONU

ltan awon akoni ile Yoruba laye atijo ati ode onf

AKOONU ISE

1. Oruko akoni agbegbe akekoo n aye atijo ati n ode onti

2. Akitiyan awon akoni ti a ti daruko

AMUSE ISE

OLUKO

1. So ltan awon akoni kayefi

2. Ko akekoo lo s^ ibi pataki ti o jg mo ltan awon akoni wonyf

3. fi aworan awon akoni wony^ han akekoo

AKEKOO

1.Daruko awon akoni lokunrin ati lobinrin ti won mo

2.So ltan awon akoni naa

3.So irm won rnpa ohun ti won ri n ibi ti won lo.

OHUN-ELO IKONI

Aworan awon akoni ile Yoruba atijo ati ode onf.

OSE 2

ORI ORO/ AKOONU

OYKA: Ookanlelogbon de ogojl (31 – 40)

AKOONU ISE

  1. oyka Yoruba lati ookanlelogbon de ogojl.
  2. Aropo/ ayokuro awon oyka kan lati fun wa n oyka muran.
  3. Tftoka s^ awon oro to se patakl fun oyka (le ati dm).

AMUSE ISE

OLUKO

1. Atunyewo oyka lati ookan de ogbon

2. Ka oyka Yoruba lati ookanlelogbon de ogoji

Se aropo ati ayokuro awon oyka kan han akekoo.

AKEKOO

  1. Ka oyka lati ookan de ogbon.
  2. Ka oyka Yoruba lati ookanlelogbon de ogojl
  3. Teti sNe lati gbo b a ti n se aropo ati ayokuro oyka.

OHUN-ELO IKONI

1.Igi keekeeke, okuta wewe abbl

Aworan to n se afihan oyka onsinsi nykan

Dan akekoo lati ka ere-onfse

OSE 3

ORI ORO/ AKOONU

ERE – ONITAN KEEKEEKE

jjfroro lorf eko ti a n ko ati eda inu

AKOONU ISE

1. Wka Iwe ere -onfse  S^se ere-ornse  ltan

AMUSE ISE

OLUKO

Gba akekoo laaye lati daruko awon olu eda ltan

AKEKOO

Dan akekoo lati se ere

Salaye koko inu ere-ornse

  1. Feti sNe lati gbo ohun ti won n ka
  2. kopa nmu ere sfse
  3. So koko inu ere onfse 4. Daruko awon olu eda ltan

OHUN-EL0 1K0NI

1. Aso ere ati awon ohun elo mnran to ba ere mu.

OSE 4

ORI ORO/ AKOONU

Orin Omode Siwaju si i

AKOONU 1SE

1. Awon orin ati eko ti won n ko wa ba k ni n o fole se laye ti mo wa. Imototo lo le segun arun gbogbo    

we k o mo, ge eekanna rg, jgun to dara…

AMUSE ISE

OLUKO

1.Pe akekoo lati ko orin

2.Pe akekoo lati fa eko inu orin tire fun oluko

3. fa eko inu orin naa yo.

AKEKOO

1.Ko orin s^ etigboo oluko

2.Fa eko inu awon orin naa yo

3.Teti sf awon orin ti oluko n ko ati eko inu won

OHUN-EL0 1K0NI

1.Teepu ati kaseet! ti a ti gba orin sf

2.Aworan to jgmo orin naa

OSE 5

ORI ORO/ AKOONU

Owe Siwaju si i

AKOONU ISE

1. owe ati patak! re

2. Ttiumo owe ati lNoo loro b.a.

Agboju le ogun fi ara re fos! ta.

Owo omode ko to pgpg tagbalagba ko wo keygbe.

Agba k! ^ wa loja kon omo tuntun wo

AMUSE ISE

OLUKO

1. So ohun ti owe je ati patak! re laarin awon Yoruba

2. Pe akekoo lati pa owe ti won ti gbo ri.

3. Ko awon owe naa sf ara patako !kowe k o s! fe owe tire kun un

4. So !tumo owe k o s! lo won loro.

KEKOO

1.            Teti s^ oluko.

2.            Pa awon owe ti o mo

3.            So Itumo owe ti o pa

4.            Se akosNe awon owe ti oluko ko sara patako Ikowe

OHUN-ELO IKONI

  1. Teepu ti a ti gba owe sf inu re
  2. Aworan onsinsi rnpa awon owe tf a pa

OSE 6

ORI ORO/ AKOONU

APEKO AWON ORO LEDEE YORUBA

AKOONU ISE

Wko oro Yoruba keekeeke b.a. aga, tablll, Iwe, gyg, oju, gse, owo, on, imu, aye.

AMUSE ISE

OLUKO

ka awon oro naa fun akekoo

se s^pe^ awon oro pelu gnu

Pe awon oro Yoruba naa fun won lati ko

fi kaad! pelebe pelebe han akekoo

AKEKOO

  1. kopa nmu s^se s^pe^ gnufetf s^ ohun oluko n ka
  2. kopa nmu s^se s^pe^ gnu
  3. ko s^pe^ oro Yoruba ti oluko n pe
  4. wo kaad! pelebe pelebe ti oluko ko s^pe^ su

AKEKOO

1.fetf s^ ohun oluko n ka

2.kopa nmu s^se s^pe^ gnu

3.ko s^pe^ oro Yoruba ti oluko n pe

4.wo kaad! pelebe pelebe ti oluko ko s^pe^ su

OSE 7

ORI ORO/ AKOONU

Dfdaruko Nykan Siwaju sf i

AkOOnu ISE

Oruko awon nykan ti o wa n aarin Hu b.a. oja, ile, Iwosan, ile-Itaja nla kan ati keekeeke n orfsirfsi, aafin oba, ago olopaa, papa Isere nla, ile-lwe lorisirisi

AMUSE ISE

OLUKO

  1. Pe akekoo lati daruko awon ohun tf won fi maa n rln n aarin Ilu.
  2. So Iwulo awon ohun tf o wa n aarin Ilu.

AKEKOO

1.Daruko awon ohun tf o wa n aarin Ilu

2.So Iwulo awon ohun to n aarin Ilu won.

OHUN-EL0 1KONI

 Aworan awon ohun to wa n aarin Ilu.

OSE 8

ORI ORO/ AKOONU

ASO WIWO

AkOOnu ISE

  1. K ni aso w^wo?
  2. Aso awon okunrin b.a. sokoto, agbada, fi la abbl
  3. Aso awon obInrin: b.a. Iro, buba, yerI, dans^k^ abbl

AMUSE ISE

OLUKO

1.Salaye aso w^wo fun akekoo

2.Se alaye ona tf awon okunrin ati obInrin n gba n wo aso

3.Se afihan ati alaye Ilo aso w^wo

4.So irufe aso tf awon okunrin ati obInrin n wo ati patakI aso w^wo.

AKEKOO

1.Tetf s^ oluko rnpa aso wfwo

2.Salaye onsi aso tf awon okunrin ati obInrin n wo

3. So aleebu ti o wa nmu wfwo aso

OHUN-ELO IKONI

Buba, Yen, agbada, fi la, sokoto abbl

OSE 8

ORI ORO/ AKOONU

ITESIWAJU LORI ASO WIWO AKOONU ISE

1. Gbolohun keekeeke nfpa aso w^wO

b.a. mo de fi la, mama we gele, lo wo sokoto abbl

AMUSE ISE

OLUKO

1.Ko gbolohun sf ara patako.

2.ka a fun akekoo

3. Pan akekoo lati ka awon gbolohun naa.

AKEKOO

1.Feti s^ ohun ti oluko n so

2.farabale ka gbolohun naa Ohun-Elo Ikoni

Kadfooodu ti a ko awon gbolohun keekeeke sk

OSE 10

ORI ORO/ AKOONU

ISORI – Oro Gbolohun

AKOONU ISE

1. oro-oruko

2. oro aropo oruko

3. oro-ise

4.oro-apejuwe

5.oro-atokun

6. oro-asopo

AMUSE ISE

OLUKO

Ko apggrg awon oro ti o le wa labe ison oro

kookan. B apggrg:

1. oro-oruko – ile, igi, oju, ayo abbl

2. oro – ise: wa, jgun abbl

AKEKOO

  1. Teti sa alaye oluko lorf isorf oro kookan
  2. o awon apggrg ti oluko ko soke
  3. Pe awon oro naa b oluko se pe e fun won.

OHUN-EL0 1KONI

  • • K akekoo toka sa irufe oro ti o wa labe Ison kookan nmu gbolohun keekeeke tf oluko ko soju patako.

OSE 11

ORI ORO/ AKOONU

1SORI ORO: Oro-Oruko

AKOONU ISE

  1. Km ni oro-oruko?
  2. Idamo oro-oruko ati apggrg won

AMUSE ISE

OLUKO

  1. Salaye ohun ti oro-oruko je
  2.  Salaye ona ti a le gba da oro-oruko mo nmu gbolohun
  3. Daruko apggrg oro-oruko, b.a. ile, enlyan, igi, gyg, granko, Ilu abbl.

akekoo

  1. Teti s^ alaye oluko lorf oro-oruko
  2. Ko Idamo oro-oruko s^ oju patako
  3. Pe awon oro-oruko ti o jg mo enlyan tab granko
  4. Salaye awon ounjg ire oko fun akekoo

OHUN-ELO 1K0NI

Iwe pelebe pelebe ti a ko oro-oruko sf nmu

OSE 12

ORI ORO/ AKOONU

OUNJQ ILE YORUBA

AKOONU ISE

Itesfwaju awon ire oko ati ounjg ti a n fi won se.

AMUSE ISE

OLUKO

Ona ni a n gba se okookan won.

AKEKOO

1.Teti sf alaye oluko rnpa ounjg oko

2.Pe awon ounjg ile Yoruba, k o si so b won se n se okookan won.

OHUN-ELO IKONI

Isu, elubo egbodo, irgsi, ewa abbl

OSE 13: AtunyewA eko

OSE 14: IDANWO

SECOND TERM YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK FOR PRIMARY THREE (3)

                               YORÙBÁ PRIMARY 3 TÁÀMÙ KEJÌ

OSE 1

ORI ORO/ AKOONU

Sísô Nýkan Síwájú sí i

ÀKÓÓNÚ IŚË

1. Oríśiríśi iśë ômô: B. a: àwòrán yíyà, çní híhun, ìdí ìgbálê híhun, awô/ aśô ríran, ère gbígbë abbl.

2. Ohun èlò fún iśë kõõkan

AMUSE ISE

OLÙKÖ

1. Śàlàyé bí a ti ń śe àwôn iśë wõnyí.

2. fi àwôn ohun èlò han akëkõö

3. Tö akëkõö sönà lórí bí a ti ń śe àwôn iśë

wõnyí

4. kó akëkõö lô ibi tí wön ti ń śe èyí tí kò bá lè

śe nínú kíláásì.

AKËKÕÖ

1. Tëtí sí àlàyé olùkö

2. kópa nínú śíśe àwôn iśë náà

3. kópa níbi lílô tí a ti ń śe èyí tí olùkö kò bá lè

śe.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

1. Àwòrán tó ń śe àfihàn àwôn iśë wõnyí

2. Ohun èlò fún àwôn iśë náà

OSE 2

ORI ORO/ AKOONU

KÍKA GBÓLÓHÙN KÉÈKÈÈKÉ

ÀKÓÓNÚ IŚË Kíka gbólóhùn kéèkèèké

AMUSE ISE

OLÙKÖ

  1. Kô gbólóhùn sí ara pátákó
  2. . Kà á fún àwôn akëkõö
  3.  Darí akëkõö láti ka àwôn gbólóhùn náà

AKËKÕÖ

  1.  fetí sí ohun tí olùkö ń sô
  2.  fara balê kô gbólóhùn náà.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

 Kádíböõdù tí a kô àwôn gbólóhùn kéèkèèké sí

OSE 3

ORI ORO/ AKOONU

ÀLÖ ÀPAMÕ

ÀKÓÓNÚ IŚË

1. Àlö àpamõ kì í ní orin

2. máa ń jë ìbéèrè àti ìdáhùn b.a. kín ló kan ôba níkòó – abç

3. máa ń wáyé sáájú àlö onítàn

AMUSE ISE

OLÙKÖ

1. já àlö àpamõ tí olùkö pa.

2. pa àlö àpamõ fún akëkõö láti já

3. fún akëkõö láàyè láti pa àlö tirê

4. śàlàyé nípa êkö tí àlö náà ń köni

AKËKÕÖ

1. já àlö àpamõ tí olùkö pa

2. pa oríśiríśi àlö àpamõ

3. sô êkö tí àlö náà köni

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

1. Téèpù tí a gba àlö sí.

2. Àwòrán tó jç mö êdá inú àlö.

OSE 4

ORI ORO/ AKOONU

PÀTÀKÌ ÌWÀ RERE

ÀKÓÓNÚ IŚË

Àwôn ìpèdè tó ń fi ìwà rere hàn, b. a. “ìwà

rere lêśô ènìyàn” “ìwà lçwà ômô ènìyàn”

“oore lópé ìkà ò pé”. Çni tó ń śe rere kó

múra sí i, “Bí a bá da omi síwájú abbl

AMUSE ISE

OLÙKÖ

1. Śàlàyé ní kíkún lórí ìwà rere.

2. Sô oríśiríśi ìpèdè tó ń śe àfihàn ìwà rere

3. Sô pàtàkì tàbí àýfààní ìwà rere, b.a. ó máa

ń fa àlàáfíà láwùjô, ó ń mú ni jë çlësìn pípé tí yóò dé õrun rere/ àlùjánà.

AKËKÕÖ

1. Fi etí sí àlàyé olùkö

2. Sô oríśi ìpèdè mìíràn tí ó töka sí ìwà rere

3. Sô pàtàkì ìwà rere, yàtõ sí èyí tí olùkö tí sô

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

1. Fíìmù tó ń śe àfihàn ìwà rere pêlú èrè tó wà

níbê.

OSE 5

ORI ORO/ AKOONU

ÀŚÀ BÍ A ŚE Ń JÇUN

ÀKÓÓNÚ IŚË

1. Àwôn ìlànà tó tö láti têlé bí a śe ń jçun.

B.a. fô ôwö kí o tó jçun, máa sõrõ bí o bá ń

jçun, má dúró lósòó jçun, a kì í jçun láti inú ìkòkò.

2. Sô ìdí àwôn ìlànà wõnyí: láti pa òfin ìmötótó mö.

AMUSE ISE

OLÙKÖ

1. Śàlàyé àwôn ìlànà tí a gbôdõ têlé nígbà tí a bá ń jçun.

2. Sô ìdí tí a fi gbôdõ têlé e: b.a. láti pa òfin ìmötótó mö.

AKËKÕÖ

1. fi etí sí àlàyé tí olùkö ń śe.

2. sô ìdí mìíràn tí a fi gbôdõ pa òfin wõnyí mö yàtõ sí ti olùkö

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

 Àwòrán oríśiríśi tó ń śe àfihàn àwôn tó ń jçun pêlú ìlànà ìmötótó

OSE 6

ORI ORO/ AKOONU

OJÚŚE ÒBÍ SÍ ÔMÔ

ÀKÓÓNÚ IŚË

1. Ojúśe òbí sí ômô b.a.

  • ìpèsè – êkö tó yè kooro,
  • owó ilé-ìwé
  •  àlàáfíà pípé
  •  Aśô
  • ilé-ìgbë
  •  ààbò
  •  fi ìwà rere/ ìwà ômôlúàbí kö àwôn ômô nípa jíjë oníwàrere, nítorí çsin iwájú ni têyìn ń wò sáré
  • pa òfin orílê-èdè mö.

AMUSE ISE

OLÙKÖ

1. Sô ìtumõ ojúśe

2. Śàlàyé ojúśe òbí

3. Gba akëkõö láàyè kí ó sô ojúśe òbí rê

4. Darí akëkõö láti fi ojúśe òbí rê śeré.

AKËKÕÖ

1. Tëtí sí àlàyé olùkö

2. Sô ojúśe òbí tìrç

3. Kópa nínú eré

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

Àwôn ìdílé tó ó śe àfihàn ojúśe òbí

OSE 7

ORI ORO/ AKOONU

ÌWÉ KÍKÀ: Kíka Àśàyàn Ìwé

ÀKÓÓNÚ IŚË

1. ìsônísókí ìśêlê inú ìtàn

2. ìbáyému ìśêlê inú ìtàn

3. êkö àti kókó õrõ tó súyô

AMUSE ISE

OLÙKÖ

1. Ìfáàrà lórí òýkõwé àti ohun tí ìtàn dálé

2. Àlàyé lórí àwôn kókó õrõ tó súyô

3. Àlàyé êkö tó fë kí akëkõö kô nínú ìśêlê

4. Àkôsílê lórí ìdánilëkõö

AKËKÕÖ

1. Ka ìwé náà

2. Tún ìtàn náà sô ní sókí

3 Jíròrò lórí kókó õrõ inú ìwé náà

4. Kô àwôn ohun tí olùkö ti kô sí ojú pátákó inú

ìwé

5. ka ìwé náà láti ilé

OSE 8

ORI ORO/ AKOONU

ÊYÀ ARA ÈNÌYÀN

ÀKÓÓNÚ IŚË

Díê nínú àwôn êyà ara bí àpççrç irun, orí,

imú, çnu, àgbõn, ôrùn, apá, ikùn abbl

AMUSE ISE

OLÙKÖ

1. Jë kí akëkõö dárúkô àwôn êyà ara ènìyàn tí

ó mõ kí ó sì töka sí wôn.

2. Kô àwôn kókó inú êkö yìí sí ara pátákó kí

àwôn akëkõö lè kô ö sínú ìwé wôn.

AKËKÕÖ

1. Dárúkô êyà ara ènìyàn tí ó wà

2. Da àwôn kókó tí olùkö kô sí ara pátákó kô

sínú ìwé

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

 Kádíböõdù pélébé pélébé tí a kô orúkô

êyà ara kõõkan sí

OSE 9

ORI ORO/ AKOONU

ÌKÍNI FÚN ONÍRÚURÚ AYÇYÇ

ÀKÓÓNÚ IŚË

Ìkíni àti ìdáhùn láàrin ìnáwó śíśe: ìgbéyàwó,

ìsílé, ìkömô, ôjö ìbí abbl

  • ìgbéyàwó – ç kú ìnáwó ìyàwó, êyìn

ìyàwó kò ní mçni, àśç àti bëê bëê lô.

AMUSE ISE

OLÙKÖ

1. Darí akëkõö láti fi bí a śe ń kí ni śeré.

2. Fi àwòrán àwôn tó ń kí ara wôn han akëkõö

AKËKÕÖ

1. Sô ohun tí wôn mõ nípa àśà ìkíni sáájú

ìdánilëkõö.

2. Śe àpççrç àwôn oríśi ìkíni tí wön ti gbö rí

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

Àwòrán àwôn tó ń kí ara wôn.

OSE 10

ORI ORO/ AKOONU

ÌSÕRÍ ÕRÕ: Aröpò Orúkô

ÀKÓÓNÚ IŚË

1. Kí ni aröpò orúkô?

2. Ìdámõ aröpò orúkô àti àpççrç wôn:

Èmi, ìwô, êyin, àwôn, àwa, òun abbl

AMUSE ISE

OLÙKÖ

1. Śàlàyé ohun tí aröpò orúkô jë

2. Śàlàyé õnà tí a lè gbà dá aröpò-orúkô sí ojú

pátákó

3. Pe àwôn õrõ aröpò-orúkô.

AKËKÕÖ

1. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí aröpò-oruko

2. Kô ìdámõ aröpò-orúkô sí ojú pátákó

3. Pe àwôn õrõ aröpò-orúkô

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

 Ìwé pélébé pélébé tí a kô aröpò orúkô sí

nínú.

OSE 11: ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ

OSE 12: ÌDÁNWÒ

Nigeria Language Syllabus, Yoruba Language scheme of work primary 3 Federal, awon okunrin ati obInrin n wo, Káàdì pélébé pélébé.

THIRD TERM YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK FOR PRIMARY THREE (3)

                                         YORÙBÁ PRIMARY 3 TÁÀMÙ KËTA

OSE 1

ORI ORO/ AKOONU

KÍKÔ GBÓLÓHÙN KÉÈKÈÈKÉ

ÀKÓÓNÚ IŚË

Kíkô gbólóhùn kéèkèèké. B.a. Bádé lô

sí ilé-ìwé, Ayõ gé igi, Tèmítöpë mô ìwé

AMUSE ISE

OLÙKÖ

1. Kô gbólóhùn sí ara pátákó

2. Kà á fún akëkõö

3. Darí akëkõö láti ka àwôn gbólóhùn náà

AKËKÕÖ

1. fojú sí ohun tí olùkö ń kô.

2. farabalê láti kô gbólóhùn tirê.

3. Kô àkôsílê olùkö sínú ìwé rç

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

Kádíböõdù tí a kô àwôn gbólóhùn kéèkèèké

sí.

OSE 2

ORI ORO/ AKOONU

KÍKÔ SÍLÉBÙ

ÀKÓÓNÚ IŚË

1. Õrõ onísílébù kan b.a. K + F

d + e = de

w + a = wa

j + ç = jç

2. Õrõ onísílébù méjì b.a. F + KF

A + dé = Adé

I + kú = ikú

Ì + lú = ìlú

AMUSE ISE

OLÙKÖ

1. Śàlàyé bí a śe lè śêdá õrõ onísílébù kan

2. Śàlàyé bí a śe lè śêdá õrõ onísílébù méjì (K + F) KF

3. Lo káàdì pélébé pélébé tí a ti kô õrõ onísílébù kan tàbí méjì sí

4. Pe akëkõö ní õkõõkan láti pe àwôn õrõ náà

AKËKÕÖ

1. Tëtí sí àlàyé olùkö nípa ìśêdá õrõ onísílébù kan tàbí méjì

2. Sô àpççrç õrõ onísílébù kan tàbí méjì

3. Pe àwôn õrõ tó wà nínú káàdì tí olùkö fi hàn wön.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

1. Káàdì pélébé pélébé aláfihàn.

2. Àwòrán tó ń fi àwôn õrõ onísílébù kan tàbí méjì hàn.

OSE 3

ORI ORO/ AKOONU

Àlö Onítàn Síwájú sí i

ÀKÓÓNÚ IŚË

Àlö onítàn máa ń sábà ní orin àti

ègbè, ó ní àhunpõ ìtàn, ó ń köni

lögbön, b.a. àlö erin àti ìjàpá, ìjàpá àti

ajá, ìjàpá (Yán-níbo) àti babaláwo.

AMUSE ISE

OLÙKÖ

1. Pàlö fún akëkõö

2. Śàlàyé nípa êkö tí àlö náà ń köni

3. Gba akëkõö láàyè láti pa àlö onítàn

4. Sô ìyàtõ láàrin àlö onítàn àti àlö àpamõ

5. Kô àlö onítàn mìíràn bõ láti ilé

AKËKÕÖ

1. Tëtí sí àlö onítàn tí olùkö pa

2. kópa nínú gbígbe orin àlö 

3. pa àlö onítàn

4. Śàlàyé lórí àlö onítàn tí o pa.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

1. Àwòrán ohun tí àlö dá lé lórí tàbí ohun náà

gan-an b.a. (ìjàpá).

2. Téèpù tí a gba àlö sí

OSE 4

ORI ORO/ AKOONU

ERÉ ÔMÔDÉ SÍWÁJÚ SÍ I

ÀKÓÓNÚ IŚË

1. Oríśiríśi eré ômôdé (Ta ló wà nínú ôgbà náà, kí ni ń lëjê, çyç mélòó tolongo wáyé, çkùn mëran)

2. Bí a śe ń śe wön

3. Àýfààní àti ìwúlò wôn

4. Eré ômôdé śíśe

AMUSE ISE

OLÙKÖ

1. Śàlàyé lórí oríśiríśi eré ômôdé

2. sô àýfààní àti ewu tó wà níbê

3. Darí akëkõö ní ìsõrí ìsõrí láti śeré ômôdé

AKËKÕÖ

1. fi etí sí ohun tí olùkö ń sô

2. kópa nínú śíśe eré náà

3. sô oríśiríśi eré ômôdé mìíràn

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

 Àwòrán àwôn ômôdé tó ń śe oríśiríśi eré ômôdé.

OSE 5

ORI ORO/ AKOONU

ÀWÔN OHUN ÈLÒ INÚ ILÉ

ÀKÓÓNÚ IŚË         

1. Àwôn yàrá inú ilé b.a

  • Yàrá tí à ń sùn
  •  Yàrá ìgbàlejò
  •  Ilé ìdáná
  •  Ilé ìyàgbë
  •  Balùwê
  •  Yàrá ìkërù sí abbl

2. Ohun èlò tó wà ní yàrá kõõkan b.a.

sëêtì tábìlì, àga, êrô asõrõ-mágbèsì, amóhùnmáwòrán abbl.

AMUSE ISE

OLÙKÖ

1. Śàlàyé oríśiríśi yàrá tó máa ń wà nínú ilé

2. Sô àwôn ohun èlò tó máa ń wà ní yàrá kõõkan

3. Gba akëkõö láàyèlati sô àwôn ohun èlò tó

wà ní àwôn yàrá ní ilé e wôn.

AKËKÕÖ

1. Fetí sí ohun tí olùkö ń sô.

2. kópa nínú sísô àwôn ohun èlò inú ilé.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

 Àwòrán ilé àti ti oríśiríśi àwôn ohun èlò inú ilé

OSE 6

ORI ORO/ AKOONU

ÌTÀKURÕSÔ SÍWÁJÚ SÍ I

ÀKÓÓNÚ IŚË

1. Ìtàkurõsô lórí ààbò òpópónà ôkõ

2. Àýfààní tí ó wà nínú lílo afárá ìdátítì kôjá

3. rínrìn pêlú àkíyèsára

AMUSE ISE

OLÙKÖ

1. Olùkö béèrè ìdí tí wôn fi gbôdõ pa àwôn òfin

orí òpópónà mötò mö

2. Darí ìtàkurõsô nípa bíbéèrè ìbéèrè kí

akëkõö sì dáhùn

AKËKÕÖ

1. kópa nínú ìtàkurõsô

2. Dáhùn àwôn ìbéèrè olùkö lórí òfin tó de rírìn

ní òpópónà mötò.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

Àwòrán àwôn tó ń sôdá lópòpónà

OSE 7

ORI ORO/ AKOONU

ORÚKÔ OYÈ ÔBA ILÊ YORÙBÁ

ÀKÓÓNÚ IŚË

1. Oríśiríśi àwôn ôba ilê Yorùbá àti orúkô oyè wôn. B.a Ôõni ti Ilé-Ifê.

2. orúkô oyè ôba ìlú wôn

AMUSE ISE

OLÙKÖ

1. Sô oríśiríśi orúkô ôba ilê Yorùbá

2. fi àwòrán àwôn ôba wôn han akëkõö

AKËKÕÖ

1. Dárúkô àwôn ôba ilé Yorùbá tí wön mõ

2. Dárúkô ôba ìlú wôn àti ohun tí wôn mõ nipa rê

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

 Àwòrán ôba kan ní ilé Yorùbá.

OSE 8

ORI ORO/ AKOONU

ÌSÕRÍ ÕRÕ: Õrõ-Ìśe

ÀKÓÓNÚ IŚË

1. Kín ni õrõ-ìśe

2. Iśë wo ni õrõ-ìśe ń śe nínú gbólóhùn èdè Yorùbá.

AMUSE ISE

OLÙKÖ

1. Śe àlàyé õrõ-ise

2. kô õrõ-ìśe sí ara pátákó

3. Śàlàyé iśë tí õrõ-ìśe ń śe nínú gbólóhùn

AKËKÕÖ

1. Tëtí sí àlàyé olùkö.

2. Farabalê láti kô õrõ-ìśe tìrç

3. kópa nínú iśë tí õrõ-ìśe ń śe

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

Kádíböõdù tí a kô õrõ-iśë sí

OSE 9

ORI ORO/ AKOONU

ORÚKÔ OŚÙ NÍNÚ ÔDÚN

ÀKÓÓNÚ IŚË

1. Àwôn ośù nínú ôdún: śërë, èrèlè,

çrënà abbl

2. Kíkô orin tí ó bá ośù lô

AMUSE ISE

OLÙKÖ

1. Kô àwôn ośù wõnyí sí ara pátákó

2. Sô àwôn ośù wõnyí ní èdè wôn àti Yorùbá

3. Kô Gêësì ní orin fún àwôn akëkõö àti ní èdè

Yorùbá

4. Pe akëkõö láti sô àwôn ośù tí a kô sí ara

káàdì pélébé pélébé.

AKËKÕÖ

1. Pe àwôn ośù wõnyí têlé olùkö bí ó śe ń pè é

2. Dá àwôn ośù wõnyí mõ bí olùkö śe kô wôn

sínú káàdì pélébé pélébé

3. Fi ośù wõnyí kôrin bí olùkö śe kô wön.

OSE 10

ORI ORO/ AKOONU

ÀŚÀ ÌRANRA-ÇNI-LÖWÖ

ÀKÓÓNÚ IŚË

1. Kín ni àśà ìranra-çni-löwö?

2. Oríśi õnà tí a ń gbà ran ara çni löwö

ní ilê Yorùbá. Àpççrç, Àáró, õwê abbl

AMUSE ISE

OLÙKÖ

1. śe àlàyé lórí àśà ìranra-çni-löwö

2. sô oríśiríśi õnà tí a fi lè ran ara wa löwö

3. Töka sí àwôn àśà ìranra-çni-löwö kan.

4. sô èrè tàbí àýfààní tó wà nínú kí ènìyàn ran ara çni löwö

AKËKÕÖ

1. Fetí sí àlàyé nípa ìranra-çni-löwö.

2. kópa nínú sísô oríśiríśi õnà tí a lè gbà ran ara çni löwö

3. sô àwôn àýfààní tó wà nínú kí a ran ara çni

löwö.

Ohun-Èlò Ìköni

Àwòrán tó śàfihàn àwôn tó ń rolê nínú oko tí

wön ti ń śe àáró.

OSE 11

ORI ORO/ AKOONU

ÒÝKÀ YORÙBÁ

ÀKÓÓNÚ IŚË

1. òýkà Yorùbá láti oókanlélógójì dé

àádöta (41 – 50)

2. śíśe ìdámõ àwôn fígõ

AMUSE ISE

OLÙKÖ

1. Tö akëkõö sönà láti ka òýkà láti

oókanlélógójì dé àádöta

2. Pe akëkõö láti śe ìdámõ fígõ òýkà láti

oókanlélógójì dé àádöta

AKËKÕÖ

1. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí òýkà láti

oókanlélógójì dé àádöta

2. ka òýkà láti oókanlélógójì dé àádöta

3. Da òýkà tí a kô sí ojú pátákó/ ìwé pélébé

pélébé mõ ní õkõõkan.

OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI

Kádíböõdù àti ìwé pélébé pélébé tí a kô òýkà

kõõkan sí láti oókanlélógójì dé àádöta.

OSE  12: ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ

OSE  13: ÌDÁNWÒ

Share this Article
Leave a comment