Yoruba Language Scheme of Work for SS 2 Federal

28 Min Read
yoruba language scheme of work
yoruba language scheme of work

FCT Senior Secondary Humanity Curriculum. SS 2 Yoruba Language Scheme of Work Federal Schemeofwork.com

YORÙBÁ SS 2 TÁÀMÙ KÌN-ÍN-NÍ

ÕSÊORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚÀMÚŚE IŚË  
1ÈDÈ: Àròkô Aláríyànjiyàn   ÀKÓÓNÚ IŚË Kíkô àwôn ìlapa èrò àròkô aláríyànjiyàn Àròkô aláríyànjiyàn kíkôOLÙKÖ: a. Śe àlàyé ìgbésê inú ìlapa èrò àkôlé àròkô aláríyànjiyàn kan ní kíkún. b. Tö akëkõö sönà láti lo ìlapa èrò yçn láti kô àròkô. d. Yç iśë akëkõö wò e. Darí akëkõö láti śe àríyànjiyàn lórí orí-õrõ tí wön yàn ní kíláásì. AKËKÕÖ: a. Tëtí sí àlàyé olùkö kí o sì kíyèsí àwôn ìgbésê ìlapa èrò tí olùkö kô sílê. b. Kô àwôn àlàyé ojú pátákó sílê. d. Lo ìlapa èrò tí olùkö śe láti kô àròkô. e. Kópa nínú śíśe àríyànjiyàn lórí orí-õrõ ní kíláásì. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Ìwé tí ó ní ìlapa èrò nínú àti àpççrç àròkô aláriiyànjiyàn.
2.LÍTÍRÈŚÕ: Àtúpalê Ìwé Eré-Onítàn   ÀKÓÓNÚ IŚË Kókó õrõ Ìfìwàwêdá d.  Àhunpõ ìtàn e.  Ibùdó ìtàn ç.  Êdá ìtàn f.  Ìlò-èdè g. Ìjçyô àśà gb. Àmúyç àti àléébùOLÙKÖ: a. Tö akëkõö sönà láti kà ìwé eré-onítàn. b. Śe àlàyé ní kíkún lórí ìjçyô atótónu iśë nínú ìwé eré-onítàn: kókó õrõ Ìfìwàwêdá Àhunpõ ìtàn Ibùdó ìtàn Êdá ìtàn Ìlò èdè Ìjçyô àśà Àmúyç àti àléébù d. Kíkô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì tó súyô sí ojú pátákó kí o sì śàlàyé ìtumõ wôn. AKËKÕÖ: a. Ka ìwé eré-onítàn wá láti ilé àti nínú kíláásì. b. Tëtí sí àlàyé olùkö d. Kô àwôn õrõ tí olùkö kô sí ojú pátákó ìwé OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Ìwé eré-oníśe
3.ÀŚÀ: Ìsìnkú   ÀKÓÓNÚ IŚË oríśiríśi bí ikú ti ń pani: àìsàn, ìjàýbá lóríśiríśi, ikú àìtöjö, fífôwö-rôrí-kú Ìtúfõ d.  Ìtöjú òkú e.  Títë òkú ní ìtë êyç ç.  Ìbánikëdùn f.  Bí a śe ń sin òkú ní ayé àtijö g. Ìsìnkú abàmì êdá; abuké, çni ti odò gbé, çni tó pokùnso, çni tó jábö lórí õpç. gb. Òkú ríró h.  Śíśe eegun òkú/ àgõ fífà abblOLÙKÖ: a. Śe àlàyé kíkún nípa oríśiríśi ikú tí ń pani b. Śe àlàyé bí a ti ń sin oríśiríśi òkú àti ètùtù tí ó rõ mö ôn. d. Kô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì sí ojú pátákó ìkõwé. e. Śe àlàyé kíkún lórí ìsìnkú àgbà. AKËKÕÖ: a. Tëtí sí àwôn àlàyé olùkö. b. Kô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì tí olùkö kô sojú pátákó ìkõwé sínú ìwé rê OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Pátákó Rédíò Ìwé kíkà lórí ewì alohùn tó jçmö ìsìnkú Oríśiríśi àwòrán tí ó jçmö ìsìnkú.
4.ÈDÈ: Gbólóhùn   ÀKÓÓNÚ IŚË Oríkì gbólóhùn Àlàyé ìpín gbólóhùn nípa ìhun d.  Alábödé e.  Oníbõ ç. AlákànpõOLÙKÖ: a. Kô oríśiríśi àpççrç gbólóhùn sí ojú pátákó ìkõwé. b. Sô fún akëkõö láti fa ìlà sí abë õrõ-ìśe àti olùwà nínú gbólóhùn d.  Śe àlàyé àbùdá gbólóhùn alábödé, oníbõ àti alákànpõ. AKËKÕÖ: a. Tëtí sí àlàyé olùkö b. Śe àwòkô àwôn àpççrç gbólóhùn tí olùkö kô sójú pátákó. d. Fa ìlà sí abë õrõ-iśë àti olùwà rê. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Pátákó ìkõwé
5.ÀŚÀ: Eré Ìdárayá   ÀKÓÓNÚ IŚË Oríśiríśi eré ìdárayá Eré òśùpá bí i – bojúbojú, sa-n-sálùbö d.  Eré abëlé e.  Eré ìta gbangba bí i; òkòtó, àrìn, ìjàkadì/ çkç, ògò gbígbõn abbl.OLÙKÖ: a. Śe àlàyé bí a ti ń śe díê nínú eré ìdárayá tí ó mënuba. b. Tö àwôn akëkõö sönà láti śe àwôn eré ìdárayá. d. Kô àwôn orin inú eré ìdárayá náà sójú pátákó AKËKÕÖ: a. Sô ohun tí o mõ nípa eré ìdárayá sáájú ìdánilëkõö. b. Dárúkô díê nínú eré ìdárayá mìíràn tí o mõ. d. Tëtí sí àlàyé olùkö. e. Kópa nínú eré ìdárayá tí olùkö kô sójú pátákó. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Ôpön ayò Ômô ayò Òkòtó Àrìn abbl
6.LÍTÍRÈŚÕ: Àtúpalê Ewì Alohùn (Àsàyàn ìwé kan)   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Àkóónú Kókó õrõ, àśà tó súyô Ìhun Lílé/ gbígbè, àdákô, àjùmõkô abblÌlò èdè: ônà èdè àti ìsôwölo-èdè Ìjçyô àśà b.Lítírèśõ alohùn mìíràn d. Õgangan ipò àwôn akéwì, êsìn/ ìśe wôn, àkókò ìkéwì abbl  OLÙKÖ: a. Jë kí àwôn akëkõö gbìyànjú láti ka ewì alohùn löpõlôpõ ìgbà. b. Śe àlàyé lórí kókó õrõ, êkö, ìlò-èdè àmúyç àti àléébù inú ìwé àsàyàn ewì alohùn. AKËKÕÖ: a. Fi etí sí ewì tí olùkö ń kà fún wôn. b. Gbìyànjú láti kéwì tí o bá mõ. d. Ka ìwé àsàyàn yìí. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Ìwé tó jçmö ewì alohùn Àwòrán tó bá ewì yìí mu. Pátákó ìkõwé Téèpù
7.ÀŚÀ: Ètò Ìśèlú   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Ààtò agbo ilé Iśë baálé ilé Iśë ìyálé iléIśë obìnrin iléIśë ômô ilé Ètò oyè jíjçOyè ìdíléOyè ìfidánilöláOyè êsìnOyè ògbóniOyè ológunOLÙKÖ: a. Śe àlàyé lórí ààtò agbo-ilé àti ààtò oyè jíjç. b. Śe ètò eré-oníśe lórí àśà ìfinijoyè d. Fi fídíò ayçyç ìfinijoyè han àwôn akëkõö AKËKÕÖ: a. Tëtí sí àlàyé olùkö b. Kópa nínú eré-oníśe lórí àśà ìfinijoyè d.  Wo fídíò ìfôbajç OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Àwòrán Fídíò ayçyç ìfinijoyè, ìdájö ní köõtùìbílê abbl. 
8.ÈDÈ: Àròkô Oníròyìn   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Àròkô oníròyìn Ìròyìn jàýbá ôkõ kan tó sojú mi pàtóÌròyìn eré böõlù tí ó sojú miÌrìn-àjò ojúmitó sí Àgö ôlöpàáOLÙKÖ: Śe àlàyé ìgbésê àròkô Śe àlàyé ìfáàrà d.  Śe àlàyé ìpín afõ e.  Śe àlàyé ìfàmìsí ç.  Śe àlàyé ìgúnlê f.  Śe àlàyé ìlò èdè AKËKÕÖ: Ka àròkô oníròyìn tí ó pegedéKô àròkô oníròyìn nípa títêlé ìgbésê tí olùkö ti śàlàyé rê OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Ìwé àpilêkôlórí àròkô Ìwé iśë àti pátákó ìkõwé
9.ÀŚÀ: Ètò Ôrõ-Ajé (Ìpolówó Ôjà) a. Ìdí tí a fi ń polówó ôjà b. Bí a śe ń polówó ôjà, b.a êkô tútù, ç ç jçran êkô d. Ôgbön ìpolówó ôjà ní ayé àtijö àti òde òní, b.a ìpolówó lórí rédíò, tçlifísàn, ìwé ìròyìn, ìkiri abbl OLÙKÖ a. Tç ìpolówó ôjà tí a ti tê sórí téèpù fún àwôn akëkõö gbö. b. Fún àwôn akëkõö ní àýfààní láti śe ìpolówó ôjà ní kíláásì. d. Kó akëkõö lô śe àbêwò sí ôjà tàbí ìdíkõ. AKËKÕÖ a. Tëtí sí téèpù tí olùkö tê b. Kópa nínú śíśe ìpolówó ôjà nínú kíláásì d. Śe àbêwò sí ôjà tàbí ìdíkõ láti gbö oríśiríśi ìpolówó ôjà. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI ÀtçFídíò RédíòÊrô agbõrõ sílê TéèpùTçlifísànÌpolówó ôjà lóríśiríśi nínú ìwé ìròyìn abbl.
10.LÍTÍRÈŚÕ: Itêsíwájú Àtúpalê Ewì Àpilêkô kókó õrõ Àśà àti ìśe tó súyô nínú ìwé náà d.  Ètò/ Ìhun e.  Ìlò èdè ç.  Àmúyç àti Àléébù OLÙKÖ a. jë kí akëkõö ka ewì àpilêkô b. śe àlàyé ní kíkún lórí ìjçyô àkóónú d. kô bí ó śe jçyô nínú ewì àpilêkô àsàyàn: kókó õrõ ìhun (ètò) ìlò èdè àmúyç àti àléébù d.  Kô àwôn õrõ tí ó śe pàtàkì pàtàkì sí ojú pátákó ìkõwé, śíśe àlàyé lórí ìtumõ wôn. AKËKÕÖ Ka àsàyàn ewì ní àkàsínú àti àkàsíta Tëtí sí àlàyé olùkö d.  Da àwôn õrõ tí olùkö kô sójú pátákó kô sínú ìwé. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Àsàyàn ìwé ewì àpilêkô Àwòrán tó bá ewì kõõkan mu. 
11.ÈDÈ: Õrõ Àyálò a. Àlàyé lórí õrõ àyálò b. Òfin tí ó de õrõ àyálò d. Okùnfà õrõ àyálò–Êsìn, Ètò ôrõ-ajé àti bëê bëê lô. e. Ìlànà õrõ àyálò (àfojúyá àti àfetíyá)OLÙKÖ a. Śe àlàyé kíkún lórí õrõ àyálò b. Śe àlàyé okùnfa õrõ àyálò d. Śe àlàyé fún àwôn akëkõö lórí ìlànà õrõ àyálò àfojúyá àti àfetíyá.   AKËKÕÖ  a. Tëtí sí àlàyé olùkö  b. kô kókó ìdánilëkõö sílê. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Pátákó ìkõwé Kádíböõdù tí ó śe àfihàn õrõ àyálò tí a yá wô inú èdè Yorùbá.
12.ÈDÈ: Õrõ àgbàsô (Afõ asafõ àti afõ Agbàrán) a. Ìtumõ õrõ àgbàsô b. Àlàyé lórí afõ asafõ àti afõ agbàrán d. Àwôn atöka õrõ àgbàsô. e.  Àwôn ìsõrí õrõ tí ó máa jçyô nínú õrõ àgbàsô.OLÙKÖ a. Śe àlàyé ìtumõ õrõ àgbàsô fún àwôn akëkõö. b. Jë kí akëkõö mô ìyàtõ láàrin afõ asafõ àti afõ agbàrán. d. Kô àwôn atöka àgbàsô fún akëkõö e. Kô àwôn ìsõrí õrõ tí ó máa ń jçyô nínú õrõ àgbàsô sí ojú pátákó ìkôwé. AKËKÕÖ a. Tëtí sí àlàyé olùkö. b. Kí akëkõö śe àgbàsô õrõ láàrin ara wôn. d. Kô àwôn õrõ tí ó śe pàtàkì tí olùkö kô sí ojú pátákó sí inú ìwé. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Pátákó ìkõwé Kádíböõdù tí ó śe àfihàn õrõ atöka õrõ àgbàsô.
  13.    ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ     
  14.  ÌDÁNWÒ     

FCT Senior Secondary Humanity Curriculum. SS 2 Yoruba Language Scheme of Work Federal Schemeofwork.com

YORÙBÁ SS 2 TÁÀMÙ KEJÌ

ÕSÊORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚÀMÚŚE IŚË  
1.ÈDÈ: Àròkô (Lëtà gbêfê)   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Àdírësì b. Ìkíni d. Àkôlé e. Déètì ç. Kókó õrõ f. ÀsôkágbáOLÙKÖ: a. Tö akëkõö sõnà láti kô àròkô b. Gbìyànjú láti kô àròkô tí olùkö bá yàn fún wôn AKËKÕÖ: a. Têlé ìlànà olùkö láti kô àròkô. b. Gbìyànjú láti kô àròkô tí olùkö bá yàn fún wôn OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Ìwé àpilêkô lórí àròkô Àpççrç lëtà gbêfê tó múná dóko pátákó ìkõwé
2.ÌWÉ KÍKA: Àtúpalê Ìtàn Àròsô   ÀKÓÓNÚ IŚË Akëkõö yóò le śe àtúpalê    a. Kókó õrõ b. Àhunpõ ìtàn àti ìfìwàwêdá d. Ibùdó ìtàn e. Ôgbön ìsõtàn ç. Ìlo èdè f. Àśà tó jçyô nínú ìtàn àròsôOLÙKÖ: a. Jë kí akëkõö ka ìwé ìtàn àròsô ní àkàyé b. Śe àlàyé tó kún lórí ìwé ìtàn àròsô d. Kô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì tí ó jçyô jáde sójú pátákó AKËKÕÖ: a. Ka ìwé ìtàn àròsô wa láti ilé àti nínú kíláásì b. Tëtí sí àlàyé olùkö d. Da àwôn õrõ tí olùkö kô sójú pátákó kô sínú ìwé rç. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Fídíò Téèpù Tçlifísàn Êrô agbõrõ sô
3.ÈDÈ: Aáyan Ògbufõ   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Títúmõ àyôlò ewì ní èdè Gêësì kan sí èdè Yorùbá b. Títúmõ ewì ní èdè Yorùbá sí èdè Gêësì.OLÙKÖ: a. Tö akëkõö sönà láti túmõ ewì kúkurú kan ní èdè geeai sí Yorùbá. b. Tö akëkõö sönà láti túmõ ewì Yorùbá sí èdè Gêësì. AKËKÕÖ: a. Túmõ àyôlò ewì kúkurú kan ní èdè Gêësì àti Yorùbá b. Túmõ ewì kúkurú ní èdè Yorùbá sí èdè Gêësì OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Ìwé ewì àpilêkô ní èdè Gêësì àti Yorùbá. pátákó ìkõwé ìwé atúmõ èdè
4.ÈDÈ: Ìhun Gbólóhùn – oríśiríśi awë gbólóhùn a. Ìhun awë-gbolohun b. Iśë tí awë-gbólóhùn ń śe nínú gbólóhùn OLÙKÖ: a. Śe àlàyé ìyàtõ láàrin àpólà àti awë-gbólóhùn. b. Śe àlàyé àbùdá awë-gbólóhùn. d. Śe àlàyé olórí awë-gbólóhùn e. Śe àlàyé awë-gbólóhùn afarahç ç. Fi ìyàtõ han láàrin olórí gbólóhùn àti awë-gbólóhùn afarahç.   AKËKÕÖ: a. Fi àpólà gbólóhùn wé awë-gbólóhùn láti le mô ìyàtõ tó wà láàrin wôn. b. Sô àbùdá awë-gbólóhùn afarahç OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Pátákó ìkõwé Kádíböõdù tí ó ní àkôsílê àpólà õrõ-orúkô, àpólà-atökùn, olórí awë-gbólóhùn àti awë-gbólóhùn afarahç
5.ÀŚÀ: Ètò Ogún jíjç   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Ìtumõ ogún àti ohun tí à ń jç lógún b. Ìyàtõ láàrin ogún ìyá àti ogún baba d. Õnà tí à ń gbà pín ogún e. Àwôn tó ní êtö sí ogún ç. Wàhálà tí ó rõ mö ogún pínpínOLÙKÖ: a. Śe àlàyé ohun tí ogún jíjç jë fún àwôn akëkõö. b. Tö àwôn akëkõö sönà láti śe eré oníśe lórí ètò ogún pínpín nínú kíláásì. d. Śe àlàyé ìyàtõ ogún ìyá àti ogún baba e. Jë kí akëkõö wo/ tëtí sí ètò ogún pínpín lórí ètò ìyanjú aáwõ lórí tçlifísàn àti rédíò. AKËKÕÖ: a. Tëtí sí àlàyé olùkö b. Kópa nínú eré ètò ogún pínpín nínú kíláásì d. Wo ètò ogún pínpín ní kóòtù OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Àwòrán ohun tí à ń jogún; ilé, ilê, aśô abbl Fídíò tí ó fi ibi tí a ti ń pín ogún hàn.
6.ÈDÈ: Pípajç àti ìsúnkì   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Oríkì ìpajç b. Òfin ìpajç d. Fáwëlì pípajç e. Köńsónáýtì pípajç ç. Ìyöpõ fáwëlì f. Oríkì ìsúnkì g. ìbáśepõ tí ó wà láàrin ìpajç àti ìsúnkìOLÙKÖ: a. Sô oríkì ìpajç àti ìsúnkì àti ìjçyôpõ b. Sô òfin tó de ìpajç, ìsúnkì àti ìyöpõ fáwëlì d. Sô oríśiríśi ìpajç tí ó wà e. Béèrè ìbéèrè löwö akëkõö ç. Dáhùn ìbéèrè àwôn akëkõö f. Yan kókó sójú pátákó AKËKÕÖ: a. Tëtí sí olùkö. b. Béèrè ìbéèrè löwö olùkö d. Dáhùn ìbéèrè olùkö e. Śe àkôsílê sínú ìwé rç. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Pátákó ìkõwé
7.LÍTÍRÈŚÕ: ÌtêsíwájúÀtúpalê Ewì Alohùn   ÀKÓÓNÚ IŚË kókó õrõ Êsìn/ ìśe tí ewì rõ mö d.  Ìlù, ijó, orin tí ó jç mö ewì e.  Ìjçyô àśà àti ìśe ç.  Ìlò èdè f. Àmúyç àti àléébù nínú ewì náàOLÙKÖ: a. Śe àlàyé àwôn kókó õrõ inú ewì náà b. Śe àlàyé ààtò d. Śe àlàyé ônà èdè àti ìsôwö-lo-èdè tó jçyô e. Kô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì tí ó súyô sí ojú pátákó AKËKÕÖ: a. Fi ara balê ka àsàyàn ìwé ewì alohùn b. Śe àkôsílê àwôn kókó õrõ śíśê-n-têlé d. Töka sí ônà èdè àti ìsôwö-lo-èdè e. Kô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì ojú pátákó ìkõwé sílê OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Àsàyàn ìwé ewì alohùn Àwòrán ohun tí ewì alohùn dálé Êrô agbõrõsílê àti téèpù
8.ÀŚÀ: Ètò Ìdájö   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Õnà tí a fi ń śe ìdájö látijö ni õdõ; baálê, ìjòyè ìlú, ôba. Ipa çmçsê/ ìlàrí b. Ìdájö lóde òní: ilé çjö ìbílê, ilé çjö gíga, ilé çjö kò-të-mi-lörùn, ilé çjö tó ga jù. Ìgbìmõ elétíigbáròyé, ipa aködà, ôlöpàá, wödà abbl.OLÙKÖ: a. Śe àlàyé ètò ìdájö látijö àti lóde oni b. Śe àlàyé ewu tó wà nínú dídájö èké àti àýfààní ìdájö òdodo AKËKÕÖ a. Sô ohun tí o mõ nípa ètò ìdájö b. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí ètò ìdájö d. Béèrè ìbéèrè tí ó bá rú ô lójú OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Àwòrán tí ó fi ètò ìdájö hàn Fíìmù àti fídíò ibi tí wôn ti ń fi ìdájö hàn.
9.ÈDÈ: Àrànmö   ÀKÓÓNÚ IŚË Oríkì àrànmö Àrànmö ohùn d. Àrànmö Fáwëlì e. Àrànmö iwájú ç. Àrànmö êyìn f. Àrànmö aláìfòró àti àrànmö afòró OLÙKÖ a. Śe àlàyé fún àwôn akëkõö ohun tí àrànmö jë b. Sô oríśiríśi àrànmö tí ó wà pêlú àpççrç tí ó múná dóko d. Béèrè ìbéèrè löwö akëkõö e. Śe àkôsílê sójú pátákó AKËKÕÖ a. Tëtí sí olùkö b. Béèrè ìbéèrè löwö olùkö d. Dáhùn ìbéèrè olùkö e. Śe àkôsílê sínú ìwé rç OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Pátákó ìkõwé
10.ÈDÈ: Wúnrên onítumõ gírámà   ÀKÓÓNÚ IŚË a. oríkì wúnrên onítumõ àdámö b. Ibá-ìśêlê ôjö iwájú d. Ibá-ìśêlê löwölöwö e. Ibá-ìśêlê atërçrç ç. Ibá-ìśêlê aśetán f. Ibá-ìśêlê bárakúOLÙKÖ a. Olùkö yóò śàlàyé fún akëkõö ohun tí à ń pè ní wúnrên onítumõ gírámà. b. Olùkö yóò kô àwôn wúnrên yìí sílê: yóò, máa, ti, ń, àti bëê bëê lô d. Olùkö yóò kö àwôn akëkõö ní ibá yìí; ôjö iwájú, löwölöwö, aśetán, atërçrç àti bárakú. AKËKÕÖ a. Akëkõö yóò tëtí sí olùkö b. Akëkõö yóò dáhùn ìbéèrè d. Akëkõö yóò kô àkôsílê sínú ìwé rê OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Pátákó ìkõwé Kádíböõdù tí olùkö ti kô àwôn õrõ tí ó śàfihàn àwôn ibá yìí nínú gbólóhùn láti ilé.
11.ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ 
12.ÌDÁNWÒ 

FCT Senior Secondary Humanity Curriculum. SS 2 Yoruba Language Scheme of Work Federal Schemeofwork.com

YORÙBÁ SS 2 TÁÀMÙ KËTA

ÕSÊORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚÀMÚŚE IŚË  
1.ÈDÈ: Àtúnyêwò Àròkô Ajçmö-ìsípayá   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Ìlànà èrò àròkô ajçmö-ìsípayá b. Àkôlé d. Ìfáàrà e. Kókó àròkô ç. Àgbálôgbábõ f. Àtúntò àwôn ìpín afõ g. Kíkô àròkô lórí àkôlé bí i ôjà, omi, ìwé-ìròyìn, ààwê abblOLÙKÖ a. Rán akëkõö létí ìlànà tí wön ní láti têlé láti kô àròkô ajçmö-ìsípayá b. Śe àlàyé àwôn ìlapa èrò lórí àròkô ajçmö-ìsípayá d. Tö akëkõö sömà layi kô àròkô AKËKÕÖ a. Tëtí sí àlàyé olùkö b. Lo ìlapa èrò olùkö láti kô àròkô ajçmö-ìsípayá OHUN-ÈLÒ IKÖNI Pátákó ìkõwé
2.ÀŚÀ: Ìranra-çni-löwö   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Èsúsú 2. Àjô 3. Õwê 4. Àáró 5. Àrokodóko 6. Gbà- mi-o-rà-mí 7. Çgbë AláfôwösowöpõOLÙKÖ a. Śe àlàyé oríśiríśi àśà ìranra-çni-löwö àti àýfààní wôn. b. Śe àlàyé ipò àśà ìranra-çni-löwö nínú iśë àjùmõśe àti ôrõ-ajé d. Darí akëkõö láti jíròrò lórí çgbë aláfôwösowöpõ e. Kó akëkõö lô sí ìdí çbu níbi tí wön ti jô ń fôwösowöpõ śiśë AKËKÕÖ a. Tëtí sí àwôn àlàyé olùkö sì śe àkôsílê kókó kókó õrõ bí ó ti yç b. Śe ìbéèrè lórí ohun tí kò bá yé ô d. Kópa nínú ìjíròrò tí olùkö darí lórí çgbë aláfôwösowöpõ OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Fídíò Fíìmù Àwòrán 
3.ÈDÈ: Õrõ Àyálò   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Àlàyé lórí õrõ àyálò b. Òfin tí ó de õrõ àyálò d.  Okùnfà õrõ àyálò – Êsìn, Ètò ôrõ-ajé àti bëê bëê lô. e.  Ìlànà õrõ àyálò (àfojúyá àti àfetíyá)OLÙKÖ a. Śàlàyé kíkún lórí õrõ àyálò b. Śàlàyé okùnfa õrõ àyálò d. Śàlàyé fún àwôn akëkõö lórí ìlànà õrõ àyálò àfojúyá àti àfetíyá AKËKÕÖ  a. Tëtí sí àlàyé olùkö  b. kô kókó ìdánilëkõö sílê. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Pátákó ìkõwé Kádíböõdù tí ó śe àfihàn õrõ àyálò tí a yá wô inú èdè Yorùbá.
4.ÈDÈ: Àròkô Alápèjúwe   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Kókó õrõ b. Ìlapa èrò d. Ètò kókó e. Ìfáàrà ç. Èdè f. ÌkádìíOLÙKÖ a. Olùkö śàlàyé orí-õrõ àròkô alápèjúwe fún àwôn akëkõö bí i – Ilé-Ìwé Mi, Títì Márosê Èkó sí Ìbàdàn, Õgá Yorùbá Mi abbl b. Olùkö yóò kö àwôn akëkõö bí a śe ń śe ìlapa èrò wa lórí àròkô yìí. d. Olùkö yóò kö àwôn akëkõö bí wôn yóò śe śe ètò kókó tí wön ní láti kô sílê AKËKÕÖ a. Akëkõö yóò tëtí sí olùkö b. Akëkõö yóò śàpèjúwe bí olùkö Yorùbá wôn śe rí d. Akëkõö yóò kô kókó inú ìdánilëkõö sílê OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Pátákó ìkõwé Kádíböõdù tí ó śe àpèjúwe títì márosê.  
5.ÀŚÀ: Õnà Ìbánisõrõ   ÀKÓÓNÚ IŚË 1a. Lílo êyà ara fún ìbánisõrõ b. Śíśe ni ni èékánná d. Orí gbígbõn e. Ojú sísë ç. Títçnimölê f. Imú yínyín 2. Ìpàrokò a. Ìbánisõrõ ayé òde òní bí àpççrç ìwé ìròyìn, tçlifísàn, rédíò abblOLÙKÖ a. Śàlàyé õnà ìbánisõrõ ní ayé àtijö b. Śàlàyé õnà ìbánisõrõ ní ayé òde òní d. Śàlàyé ohun èlò ìbánisõrõ ní ayé àtijö àti òde òní AKËKÕÖ a. Śàlàyé nípa õnà ìbánisõrõ yálà ayé àtijö tàbí òde òní b. Sô nípa ohun ìbánisõrõ tó mõ d.  Śàlàyé bí a śe ń fi ìpàrokò bánisõrõ OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Ìwé àśà tó jçmö õnà ìbánisõrõ Tçlifóònù Kõýpútà
6.ÈDÈ: Ìhun gbólóhùn   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Àpólà õrõ-oruko b. Àpólà õrõ-ìśe d. Àpólà õrõ-atökùnOLÙKÖ a. Tö àwôn akëkõö sönà láti dá àwôn àpólà-orúkô mõ nínú gbólóhùn . b. Śe àlàyé fún àwôn akëkõö lórí fönrán inú àpólà, ìhun wôn àti ìśesí wôn nínú gbólóhùn AKËKÕÖ a. Tëtí sí ìdánilëkõö olùkö b. Kô àwôn àpççrç tí olùkö kô sí ojú pátákó sí inú ìwé wôn OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Ìwé Gírámà òde òní Ìwé Èdè Ìperí Yorùbá 
7.ÀŚÀ: Owó yíyá àti gbèsè gbígbà   ÀKÓÓNÚ IŚË 1a. Àlàyé lórí owó yíyá b. Ìdí tí a fi ń yáwó d. Onídùúró 2. Àlàyé lórí bí a śe ń gba gbèsè  a. Dídógò  b. Òsómàálò abbl 3. Owó yíyá òde òní OLÙKÖ a. Àlàyé kíkún lórí owó yíyá b. Olùkö yóò śàlàyé àwôn ìdí tí a fi ń yáwó fún akëkõö d. Àlàyé lórí bí a śe ń gba gbèsè e. Jíròrò pêlú àwôn akëkõö ç. Śàlàyé owó yíyá ní òde òní fún àwôn akëkõö AKËKÕÖ a. Tëtí sílê b. Kô kókó ìdánilëkõö sílê d. Kópa nínú ìjíròrò bí a śe ń yáwó. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Fíìmù àwòrán bí a śe ń yáwó Pátákó ìkõwé
8.ÈDÈ: Òýkà Èdè Yorùbá láti Çgbàá dé Àádöta Õkë   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Kín ni òýkà? b. Òýkàa Çgbàá dé Àádöta õkë d. Ìlò òýkà    OLÙKÖ a. Śàlàyé ohun tí òýkà jë b. Sô ìwúlò òýkà d. Tö àwôn akëkõö sönà láti kô òýkà láti çgbàá títí dé àádöta õkë e. Śe àlàyé ìgbésê õnà ní kíkún b.a. i. 20 + 10 =    àròpõ ii. 13 – 18 =    àyôkúrò iii. 10 x 5 =    ìsôdipúpõ AKËKÕÖ a. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí òýkà àti ìwúlò rê b. Ka òýkà láti çgbàá dé àádöta õkë OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Kádíböõdù tí a kô òýkà láti çgbàá títí dé àádöta õkë Kádíböõdù tí a kô òýkà kõõkan sí 
9.ÈDÈ: Àmì Ohùn   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Irú èdè wo ni èdè Yorùbá: Èdè olóhùn b. Àmì tí ó wà nínú èdè Yorùbá d. Àmì òkè e. Àmì àárin ç. Àmì ìsàlê 2. Àwôn õrõ onísípëlì kan náà tí àmì yà sötõ – agbôn, ôkô, aya abbl OLÙKÖ a. Olùkö yóò śàlàyé bí èdè Yorùbá śe jë èdè olóhùn b. Olùkö yóò śàlàyé oríśi àmì ohùn tí a ní nínú èdè Yorùbá d. Olùkö yóò jë kí o yé àwôn akëkõö pé ìró fáwëlì ni ó máa ń gba àmì lédè Yorùbá àyàfi köńsónáýtì aránmú aśesílébù AKËKÕÖ a. Akëkõö yóò tëtí sí olùkö. b. Akëkõö yóò kô kókó ìdánilëkõö sínú ìwé wôn d. Jíròrò pêlú olùkö lórí bí a śe ń lo àwôn àmì yìí. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Ôwö fífi śe àpèjúwe àwôn àmì náà Kádíböõdù tí olùkö ti śe àfihàn àmì ohùn mëtêêta sí láti ilé.
10.FÓNËTÍÌKÌ: Àpèjúwe Ìró Köńsónáýtì   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Kín ni fónëtíìkì? b. Alífábëêtì Yorùbá d. Ìró Köńsónáýtì e. Àpèjúwe ìró Köńsónáýtì i. ibi ìsçnupè ii. õnà ìsçnupè iii. ipò tán-án-ná ç. Ìró köńsónáýtì jë méjìdínlógúnOLÙKÖ a. Olùkö yóò kí oríkì fónëtíìkì fún àwôn akëkõö b. Olùkö yóò śàlàyé bí a śe ń śàpèjúwe ìró köńsónáýtì d. Olùkö yóò śàlàyé ìró akùnyùn àti ìró àìkùnyùn AKËKÕÖ a. Akëkõö yóò tëtí sí ohun tí olùkö ń wí b. Akëkõö yóò kô kókó ìdánilëkõö sí inú ìwé wôn d. Akëkõö yóò kópa nínú ìjíròrò OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Kádíböõdù tí olùkö tí kô àwôn ìró köńsónáýtì àti àpèjúwe wôn sí Pátákó ìkõwé
11.FÓNËTÍÌKÌ: Àpèjúwe ìró fáwëlì   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Kín ni ìró fáwëlì? b. Àpèjúwe ìró fáwëlì i. Ipò ètè – pçrçsç, roboto ii. Ipò ahön – iwájú, êyìn àti àárin ahön iii. Ipò àfàsé – Àránmú àti Àìránmú – ìró fáwëlì jë méjeOLÙKÖ a. Olùkö yóò śàlàyé oríkì fáwëlì fún àwôn akëkõö b. Olùkö yóò śàlàyé ipò ètè, ipò àfàsé àti ipò ahön nígbà tí a bá ń pe ìró fáwëlì. d. Olùkö yóò śàlàyé oríśi fáwëlì tí a ní. AKËKÕÖ a. Akëkõö yóò tëtí sí ohun tí olùkö ń kö wôn b. Kô kókó ìdánilëkõö sínú ìwé wôn d. Béèrè ìbéèrè löwö olùkö OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Fídíò Êrô agbõrõ Pátákó ìkõwé 
  12.  ÀTÚNYÊWÒ IŚË       
  13.  ÌDÁNWÒ       

Share this Article
Leave a comment