Early childhood Education Yoruba Language Syllabus Lagos State, Yoruba Scheme of work for Nursery 2 (Age 4). Kiko Alfabeeti Yoruba.
YORUBA SCHEME NURSERY TWO SAA KINNI (AGE 4)
OSE KINNI EDE
OKORI ORO
KIKO ALFABEETI YORUBA (a titi de e)
ERONGBA
Ni opin idanieko yi,
Awon akekoo yoo le
- Ko ati ka alfaabere Yoruba daradaro
- Se adamo awon leta pelu awonran
AKOONU
- Kioluko se ihansoro ata fe
- Akeeko jade se alhan leta a,d,e,e, si
Oju petaku kowe fun, kika, kiko ati damo
- Ki akeeko daruku awon aworan ti o omo
Awon leta a-e
AKOJOPO OGBON IKONI
- Ibanisoro ati Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati Oye
- Arojinle ati Yiyanju Isoro
- Eko Ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Ayoran fun apeere
- Aja/aga
- Bata/baba
- Dodo/doje
- Ejo/eti
e-eja/eye/enu
OKORI ORO
ONIKA YORUBA (1-5)
ERONGBA
Awon akekoo yoo le ke
AKOONU
Kiko ati onika Yoruba ati dokan de Aarun-nipelomi ije ati Ilo awon fun apeere
B.
1. eni bi eni
2. eji bi eji
3. eta-n tagba
4. erin woroko
6. arun –n gbodo
To o kilo si koo (Trace and write)
AKOJOPO OGBON IKONI
Ibanisoro ati Ajumose ise
Ogbon atinuda ati oye
Arojinle ati Yiyanju Isoro
– Eko Ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI
OSE KETA (3)
OKORI ORO
Dida Leta Al fabeeti Yoruba Mo (Identification of Yoruba alphabets) a-gb
ERONGBA
Awon akeloo yoo le da awon alfabeeti
Yoruba mo pelu aworan
AKONU
- Awon akeloo yoo se afihan awon alifabeeti Yoruba ni okookan.
- Akeeko yoo jumo se kika Ati kiko awon alifabeeti ede Yoruba
- Dida leta alifabeeti Yoruba mo pelu orin ati Aworan (identification of Yoruba Alphabets a-gb)
AKOJOPO OGBON IKONI
- Ibanisoro ati Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati Oye
- Arojinle ati Yiyanju Isoro
- Eko Ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Kaad pelebe
Kadibodu tenfe
Ti a ke alifabeeti
Yoruba si
Teep ti a ka Orin sinu re lit Alfabeeti Yoruba
OSE KERIN (4)
Asa Oruko JIJe Ni ile Yoruba lon Itakun ero Ayelujara (google)
ERONGBA
Awon akeeka yoo le:
- Daruko ara won ni kookan
- So oruko orile won Firi Yoruba ti oruko Amutorunwa , bi Taiwo ati
Kehinde fun awon ibeji
AKOJOPO OGBON IKONI
- Ibanisoro ati Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati Oye
- Arojinle ati Yiyanju Isoro
- Eko Ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Ideri oti
Ike omi kika
Igi ika
OSE KEFA (6) SINMI RAMPE – – – –
OSE KEJI (7)
KIKUN AWON AWORAN NI KOLO
- Fun apeere aja bata
IMOTO ARA -abbi
ERONGBA
Awon akekop yoo le
OKODUN
- Kun awon eda Aworan tioluko fun won daadaa
- Ki oluko se eda
Aworan awon leta yii si
Ihu iwe awon akekoo fun
Se-sise
- Kihun awon aworan ni kolo orisisi
Kolo oririsi
- aja ade
- bata baba
d. Dodo doje
e.Ejo, ewe
e eye, eyin
i. Bi a se le se loju ara nipe tito enu, iwe wiwe fifo aso
ii. kiko orin :
imotooto to le segun arun gbogbo
- we ki mo ge eekanna jeun to dara lasiko maa seun ju
AKOJOPO OGBON
- Ibanisoro ati Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati Oye
- Arojinle ati Yiyanju Isoro
- Eko Ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Orisi kolowale
a-e
eda aworan
iwe awon
akeiko
aworan omo new, ti o nfo enu, ti a nge eekanna fun
OSE KEJO (8)
OKORI ORO
DIDA ORUKU
NIKAN NINU
IYARA IKAWE (KILAASI)
ERONGBA
Awon akekoo yoo le
- Darolo awon nnkan
Ninu iyara ikawe
Daradara
- So iwulo awon
Nnkan ti awon daruko
AKOJOPO OGBON
- Ibanisoro ati Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati Oye
- Arojinle ati Yiyanju Isoro
- Eko Ero Ayelujara
OSE KESAN (9)
AWON AROFO KEEKEEKE
ERONGBA
Awon akeloo yoo le lo awon orin arofo
Keekeeke daradara
AKOONU
- Owo akeeko yoo ko orin wony
Bata re a dun ko ko ka
Bayi lawa nki ya w a la
Nki ya 2x
Kin ni n o fole se layeti
Mo wa 2x
AKOJOPO OGBON IKONI
- Ibanisoro ati Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati Oye
- Arojinle ati Yiyanju Isoro
- Eko Ero Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Orin kiko
iJo jijo
Atewo pipa
OSE KEEWI ATI
IKANKANLAA (11/12) –
ATUNYEWO EKOO
SAA KINNI (REVISION)
ERONGBA
Sise atunyewo ise lori
Ise saa kinni –ni asa ati litireso
AKOONU
Atunyewo eko saa kini lori ede
OHUN ELO IKONI
Sise amulo awon ohum elo amuseyen it a ti lo lati ibere saa yi.
12 & 12-
ERONGBA
Dawo
AKOONU
Idanwo dahun gbogbo ibeere lori ise saa yii.
Early childhood Education Yoruba Language Syllabus Lagos State, Yoruba Scheme of work for Nursery 2 (Age 4). Kiko Alfabeeti Yoruba.
YORUBA SCHEME NURSERY TWO (AGE 4) SAA KEJI
OSE KINNI (1)
ATUNYEWO EKO SAA KINNI
ERONGBA
Ni opin idamiloki yi awon akeloo yoo le se atunyewo ise saa kin-in
AKOONU
Atunyewo eko saa kinni
AKOJOPO OGBON IKONI
——–
OHUN ELO IKONI
Sise amuohun elo amuse yeni ti a loni saa kinni
OSE KEJI (2)
DADA LETA ALIFABEETI YORUBA MO (f – i)
ERONGBA
Awon akeloo yoo le
- Ka alifabeeti ede Yoruba lati leta (f – i)
- Da awon leta wonyii mo pelu eda aworan
AKOONU
Akeeko kookan yoo se afihan awon leta alifabeeti ede Yoruba (f – i)
- Pelu eda aworan awon leta si inu iwe awon akekoo.
f Fila
g gele
go gbaguda
h Hausa
i iwe igi
Awon akekoo yoo se afihan awon leta wonyi pelu aworan won.
IGBELEWON
- Ibanisoro ati Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati Oye
- Imo Arojinle ati Yiyanju Isoro
- Eko Imo Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Aworan ti oba awon Leta wonyi tan bi
f – file
g – gele abbi
OSE KETA (3)
TOO ONKA EDE YORUBA (TRACING 6 -10)
ERONGBA
Awon akekoo yoo le
- Ka onka ede fo uba Lati eefa ti de eewa (6-10)
- Ko orin igo meta fara ogrin
AKOONU
- Tito ati kika onka Yoruba lati eefa de eewa (6-10)
- Owo akeeko yoo lo OHUN ELO IKONI orika lati ka eefa de eewa
- Kiko orin igo mefa lara ogiri
IGBELEWON
- Ibanisoro ati Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati Oye
- Imo Arojinle ati Yiyanju Isoro
- Eko Imo Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Kaadi leta patelin
Kaadibooclu ti a ko onka si
Ike omoi fun orin igo mefa lara ogiri
OSE KERIN (4)
IWULO OMI
ERONGBA
Akekoro yoo le
- So Pataki omi lara
- Daruko awon ohun ti a n lo omi fun
- Ko orin Pataki julo ninu omi
Ninu omi
AKOONU
- Awon akekoo yoo se Adepewe iwulo omi.
Apeere fun mimi fifo abo, aso, sesi ounje, abbi.
IGBELEWON
- Ibanisoro ati Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati Oye
- Imo Arojinle ati Yiyanju Isoro
- Eko Imo Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Aworan eni ti o, mu omi, fo aso, fo abo abbL
OSE KAAPULE (5)
KIKO ATIKIKA ALIFABEETI EDE EDE YORUBA (f – i)
ERONGBA
Awon akekoo yoo i.e
- Ka alifaabeeti ede Yoruba daradara
- ko ni orin pelu ijo jijo ati lilo aworan idamo
AKOONU
- Owo akeeko yoo se ifihan leta f – .i pelu Kadi pelebe
- Kika ati kiko Alifabeeti ede Yoruba
IGBELEWON
- Ibanisoro ati Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati Oye
- Imo Arojinle ati Yiyanju Isoro
- Eko Imo Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Kaadi pelebe pelebe fun awon leta
Kaadi fen e fun awon leta
OSE KEFA (6)
ISINMI RAMPE
OSE KEJE (7)
ONKA ONKAYE LATI OOKANI TITI DE AARUN-UN (1-5) PELU AWORAN
ERONGBA
Awon akekoo yoo le:
- Ka onkaye lati ookan titi de
Aarun –un pelu eda aworan idamo won
AKOONU
Oluko yoo see eda aworan onka akaye
Sinu we awon akekoo,fun apeere,
Boolu kan – okan
Eja meji –meji
Igi meta –meta abbl
IGBELEWON
- Ibanisoro ati Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati Oye
- Imo Arojinle ati Yiyanju Isoro
- Eko Imo Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Aworan omo ti o kunle, dobale ki obi re
Omo ti o n ge koriko ayika gba abbl
OSE KESANI (9)
IMOTOTO
- ITOJU EYIN WA
- EWILORI IMOTOTO
ERONGBA
Awon akekco yoo le:
- ko orin jeyin jeyin ma beyin mije moji mo ro rin abbl
- salaye awon ohun elo itojueyin
- ke ewi lori imototo
AKOONU
Oluko yoo se alaye lori itoju eyin nipa fifo pelu eeru, eedu, orin
(pako) tabi ose ifonu ati buurosi omi.
Oluko yoo juwe bi a Se nfo eyin wa
Kiko ewi lori imototo fun awon akekoo
Imototo bori arun mole gege bi oye ti nborin ooru.
Bi afinju ba wa oja, a rin gbedemuke abbl
IGBELEWON
- Ibanisoro ati Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati Oye
- Imo Arojinle ati Yiyanju Isoro
- Eko Imo Ayelujara
OHUN ELO IKONI
- Aworan omo ti o nifo eyinle daadaa, buurosi ati ose ifoyin Pakolorin
- Kiko orin jeyin, jeyin, ma b eyin mi je, moji mo r’ orin abbi
- Aworan enitia mura daadaa
OSE KEEWA (10)
ATUNYEWO ISE LORI ASA ATI LITIRESO EDE YORUBA FUN SAAKEJI
ERONGBA
Awon akekoo yoo se atunyewo ise lori ede fun saa keji
AKOONU
Oluko yoo se
Atunyewo awon ise
Lori ede fun awon Akekoo
IGBELEWON
- Ibanisoro ati Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati Oye
- Imo Arojinle ati Yiyanju Isoro
- Eko Imo Ayelujara
OHUN ELO IKONI
lilo awon ohun ikoni ti ateyin wa fun ise saa keji lori asa ati litereso
OSE KOOKANLA (11)
ERONGBA
ATUNYEWO ISE LORI ASA ATI LITIRESO EDE YORUBA FUN SAA KEJI
ERONGBA
Awon akekoo yoo se
- Atunyewo ise lori asa ati litireso fun saa keji
Awon akekoo yoo se
- Dahun gbogbo ibeere lori ona meteeta
AKOONU
Oluko se aluyewo awon ise lori asa ati litireso ede Yoruba fun saa
Keji
OHUN ELO IKONI
lilo awon ohun ikoni ti ateyin wa fun ise saa keji lori asa ati litereso
OSE 12/13
IDANWO ATI AKOJOPO ESI IDANWO
ERONGBA
Dahun gbogbo ibeere Lori ise saa yii
AKOONU
IDANWO ATI AKOJOPO ESI IDANWO
Early childhood Education Yoruba Language Syllabus Lagos State, Yoruba Scheme of work for Nursery 2 (Age 4). Kiko Alfabeeti Yoruba.
YORUBA SCHEME OF WORK NURSERY TWO SAA KETA (AGE 4)
OSE KINNI (1)
AKORI ISE
- AGBEYEWO EKO SAA KEJI
- AGBEYEWO ALIFABEETI EDE YORUBAEKO
ERONGBA
Ni opin damiloyin yii, awon akekoo yoo:
Se atunyewo ise lori saa Keji pelu idantwo ikinni Kaabio si saa keta
AKOONU
- Agbeyewo eko pelu awon akekoo ise saa keji
- Ki oluko ati akekoo se agbeyewo ailfabeeti ede Yoruba lati leta ati dei.
- kika ati kiko leta a – I si etigho akekoo
- kioluko ka alifabeeti a-e ati f – j akekoo si ka tele won
IGBELEWON
- Ibanisoro ati Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati Oye
- Imo Arojinle ati Yiyanju Isoro
- Eko Imo Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Sise amulo awon ohun elo amuse yeni ti ati lo ni saa keji
Kaadiboodu/Kaadi pelenbe (Flash card) ti a ko leta a,b, d,e,f,g, gb,h, i
Aworan ti o fi pipe leta kookan han
- aja, aago
- boolu, bata
d -Doje dodo
e – Eye
f – Fila
g – Gele, gege
gb – Gbaguda
h – hausa
I – Igi
OSE KEJI (2)
AKORI ISE
EDE IMULO AWON NNKAN TI O W ANI YARA IKAWE (KILAASI)
ERONGBA
Owo awon akekoo yoo le
So Pataki iwulo awon nnkan ti o w ani yara ikawe daradara
AKOONU
Owo awon akekoo yoo
- Daruko ohun elo ni kilaasi
- Salaye iwulo awon nnikan ti o wa niyara ikawe (kilaasi) bi
aga – fun ijoko
abo – fun ifowo
efun – fun ikowe
tabiii – fun ikawe
patako – fun ikowe abbi
IGBELEWON
- Ibanisoro ati Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati Oye
- Imo Arojinle ati Yiyanju Isoro
- Eko Imo Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Aworan awon Nnkan ti o wa ninu Iyara ikawe (Kilaasi) bi aga
OSE KETA (3)
ASA-ORIN IREMOLEKUN
ERONGBA
Awon akekoo yoo le so orin iremolekun gege bi oluko ti ko won
AKOONU
Oluko yoo ko lana awon orin iremolekun wonyi
- Tani ba mi lumo mi o adende – kun o, Iya re lo ba wi o, adende-kun-de-kun o
- Ta lo ma o?
Eye ni o
So ko fun
O sa lo abbi
IGBELEWON
- Ibanisoro ati Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati Oye
- Imo Arojinle ati Yiyanju Isoro
- Eko Imo Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Aworan omode ati iya re to nkorin fun
Orin iremolekun
OSE KEERIN (4)
AKORI ISE
ERE IDARAYA (ASA)
ERONGBA
Owon awon akekoo yoo se awon ere idaraya wonyi daradara
- Ta lo wa ninu ogba naa
- Ekun meran, mee.
- Ina njo tori oke, e sare, e sare, abbi
AKOONU
Owo awon akeeko a ko orin awon ere idaraya wonyi:
- Ta lo wa ninu ogba naa
- Ekun meran mee
Ina njo lori oke e, e Sare, sere abbi
- Ko awon akekoo bo si ita ki won yipo bi osupa, eni kan yoo wa ni aarin.
- Ki won yipo nigba ti eniyan meji yoo maa sare yi awon akekoo yoo so owo won po
- Enikan yoo wa ninu ogba, okan nita, won yoo maa Ko orin patewo ati jo
IGBELEWON
- Ibanisoro ati Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati Oye
- Imo Arojinle ati Yiyanju Isoro
- Eko Imo Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Awon akeeko ati oluko
OSE
Ose Kaarun-un (5)
AKORI ISE
- EDE KIKO AWON ONKA EDE YORUBA
- EWI (LITIRESO) Adiye mi
ERONGBA
Awon akekoo yoo
i) Ka onka ede Yoruba hi aka gbadun.
ii) fi eda aworan idamao ka onka naa.
Awon akekoo yoo ka ewi Adiye mi.
-Saleye eko ti ewi naa ko wa.
AKOONU
Akeekoo elo onkaye ni ede Yoruba fun kiko ati kika
Onka fun
Apeere
Iwe kan
Iwe Kan
Iwe Meji
Aga meta
Aga merin
Oluk yoo se eda aworan ti o fe lo sinu iwe awon omo sibi kan fabi meji abbi
– Awon akekoo yoo
i)Ka ewi yi daradara
ii)mo itumo eko ti ewi naa kowa.
IGBELEWON
- Ibanisoro ati Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati Oye
- Imo Arojinle ati Yiyanju Isoro
- Eko Imo Ayelujara
OHUN ELO IKONI
- Eda aworan ti oluko fe lo sinu iwe awon akekoo.
- Aworan awon nnkan ti oluko lo fun onka won
-Aworan adiye
KAARUN –UN (6)
Isimi Ranpe
OSE KEJE (7 – 8)
AKORI ISE
EDE DIDA LETA (a – i) MO
ERONGBA
Awon akekoo yoo:
- Le da awon leta (a – i) mo
- Sise eda aworan idamo awon leta lati (a – i)
AKOONU
Dida alifabeeti ede Yoruba mo (a – i)
Le da awon leta (a – i)
- Ki oluko salaye awon leta wonyi fun awon akekoo pelu aworan
- Ki oluko beere kinni leta ti o bere oro ninu awon aworan wonyi?
IGBELEWON
- Ibanisoro ati Ajumose ise
- Ogbon atinuda ati Oye
- Imo Arojinle ati Yiyanju Isoro
- Eko Imo Ayelujara
OHUN ELO IKONI
Iwe fenfe ti a ko awon alifabeeti ede Yoruba si.
Aworan awon leta naa
OSE KESAN- AN (9)
AKORI ISE
ORISI ESO NILE WA
ERONGBA
Awon ake koo yoo:
AKOONU
Kiko ati didarukoawon eso jije ti o wa ni ayika wa
Logbon ati iwa rere apeere:
IGBELEWON
OHUN ELO IKONI
Aworan ti o se afihan orisirisi es jije ri ile Yoruba
Oriki kiko ijo jiji
Atewo pipa
OSE KEWAA (10)
AKORI ISE
ATUNYEWO ISE ISESAA KINNI TITI DE SAA KEJI
ERONGBA
Sise atunyewo ise lori ise saa keta (Efe)
AKOONU
OHUN ELO IKONI
Lilo awon ohun
Ikori amuseye ateyinwa fun aye akeeko
OSE KOOKANLA (11)
AKORI ISE
ATUNYEWO ISE LORI ASA ATI LITRESO EDE YORUBA FUN SAA KEJI
ERONGBA
Sise atunyewo ise lori asa ati litereso fun saa keji.
AKOONU
Ki Oluko ye awon ise lori asa ati litireso ninu saa meeta wo fun awon akeko kiwon ko awon orin ti o ba jeyo ninu awon ise naa.
IGELEWON
OHUN ELO IKONI
Lilo awon ohun ikonti atehin fun ise saa ke asa ati litereso
IKEJI LATI IKETALA 12/13
AKORI ISE
IDANWO ATI AKOJOPO ESI IDAWO
ERONGBA
Awon alekoo yoo Dahun gbogbo ibeere ti won bere ninu idanwo won daradara
AKOONU
IDanwo ati akojopo esi danwo