Nigeria Language Syllabus, Yoruba Language scheme of work primary 4 Federal, eré oníṣe, oríkì lẹ́tà gbẹ̀fẹ́,àwọn àpẹẹrẹ, Schemeofwork.com
FIRST TERM YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK FOR PRIMARY FOUR
TEACHING SCHEME PRIMARY FOUR -YORUBA -TAAMU KINNI
ÕS Ê 1 :
ORÍ ÕRÕ
EDE
ÀKÓÓNÚ
Fònẹ́ìkì- ìtẹ̀síwájú lórí álifábẹ́ẹ̀0 Èdè Yorùbá
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
Kíkọ álífábẹẹ́ ̀7 èdè Yorùbá lápapọ̀ sójú pátákó ìkọ̀wé
– Kíkọ lẹ́tà ó
dúró fún ìró
kọ́nsónáǹ7
– Kíkọ lẹ́tà ó
dúró fún fáwẹ̀lì.
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Akẹḱ ọ̀ọ́ yóò tẹ́ sí bí olùkọ́ ṣe pe àwọn ìró náà.
– Yóò pe àwọn ìró kọ́nsónáǹ7 à0
fáwẹ̀lì bí olùkọ́ ṣe pè wọ́n.
ÕS Ê 2
ORÍ ÕRÕ
LÍTÍRÉṢỌ
ÀKÓÓNÚ
Eré onìṣe
– oríkì eré oníṣe
– pàtàkì à0 ìwúlò eré oníṣe
– àǹfààní à0 àléébù eré oníṣe
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
Sọ oríkì eré oníṣe fún akẹḱ ọ̀ọ́
– Kọ àwọn pàtàkì à0 ìwúlò eré oníṣe
– Sọ àwọn àǹfààni
à0 àléébù eré oníṣe
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Yóò lè sọ nípa eré oníṣe
– Mọ pàtàkì eré oníṣe ní ̀àwùjọ
– Sọ àǹfààní à0 àléébù eré oníṣe.
ÕS Ê 3
ORÍ ÕRÕ
ONKÀ
ÀKÓÓNÚ
Oǹ̀kà lá0 oókànléláàdọ́ta
dé ọgọ́rùn ún.
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
Kaoǹkà fún àwọn akẹḱ ọ̀ọ́ lá0 oókànléláàdọ́ta dé ọgọ́rùn ún
– ṣíṣe àlàyé kíkún nípa oǹkà àpẹẹrẹ
60-5=55 (àárùn dín lọ́gọ́ta)
– kọ oǹkà fún àwọn akẹḱ ọ̀ọ́.
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Ka oǹkà lá0 ààdọ́ta dé ọgọ́rùn ún
– fojú sí bí a ṣe ṣe àròpọ̀ à0 àyọkúro oǹkà.
ÕS Ê 4
ORÍ ÕRÕ
ÀRÒSỌ
ÀKÓÓNÚ
rọ kọ̀m̀ pútà, ọ̀tá òṣìṣẹ́ ni bí?
– Kín ni ẹ̀rọ kọ̀m̀ púta?
– Kín ni ìwúlò ẹ̀rọ kọ̀m̀ pútà?
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
Sísọ oríkì ẹ̀rọ kọ̀m̀ pútà
– Sọ ìwúlò ẹ̀rọ kọ̀mọpútà
láwùjọ
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Mímọ oríkì ẹ̀rọ kọ̀m̀ pútà
– Sísọ ìwúlò ẹ̀rọ kọ̀m̀ pútà
ÕS Ê 5
ORÍ ÕRÕ
LẸTÀ KÍKỌ
ÀKÓÓNÚ
Oríkì lẹ́tà kíkọ
– Oríṣiríṣi lẹ́tà
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
Kọ oríkì lẹtà kíkọ
– ṣe àlàyé àpẹẹrẹ lẹ́tà ní oríṣiríṣi
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Tẹ́7 sí àlàyé olùkọ́
– lè mẹ́nuba oríṣiríṣi lẹ́tà kíkọ
ÕS Ê 6
ORÍ ÕRÕ
ÀKÀYÉ
ÀKÓÓNÚ
Sọ ìtúmọ̀ àkàyé
– ka ìwé àṣàyàn ọlọ́rọ̀ geere ní èdè Yorùbá
– – dáhùn ìbéèrè lórí àkàyé náà
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
ṣàlàyé oríkì àkàyé
– Kíka àyọkà kan nínú àkàyé
– Pe akẹ́kọ̀ọ́ lá0 kàá
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Yóò mọ oríkì àkàyé
– Tẹ́ sí àlàyé olùkọ́
– Ka àkàyé ní àkàsínú.
ÕS Ê 7
ORÍ ÕRÕ
ÀṢÀ
ÀKÓÓNÚ
Oríkì àṣà
– Pàtàkì àṣà làwùjọ
Oríṣiríṣi àṣà yorùbá
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
Sọ oríkì àṣà
– ṣàlàyé pàtàkì àṣà láwùjọ
– mẹ́nuba oríṣiríṣi àṣà yorùbá
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Akẹḱ ọ̀ọ́ yóò ní òye ohun
àṣà yorùbá jẹ́
– yọ́ò tẹ́ sí àlàyé olùkọ́.
ÕS Ê 8
ORÍ ÕRÕ
ÌTÀN ÀRÒSỌ
ÀKÓÓNÚ
Oríkì ìtàn àròsọ ọlọ́rọ̀ geere
– àlọ́ onítàn kò ní orin
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
Sọ oríkì ìtàn àròsọ ọlọ́rọ̀ geere
– pa àlọ́ onítàn kò ní orin
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Mọ oríkì ìtàn àròsọ ọlọ́rọ̀
geere
– mọ àpẹẹrẹàlọ́ onítàn kò ní orin
ÕS Ê 9
ORÍ ÕRÕ
PỌNTUÉṢÀN
ÀKÓÓNÚ
Oríṣiríṣi àmì pọntuéṣàn gẹ́gẹ́ bí àpẹẹrẹ àmì ìdánudúro,
àmì ìyàlẹnu
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
ṣàlàyé oríṣiríṣi àmì pọntuéṣàn
– kọ wọ́n sí ara pátákó ìkọ̀wé
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Tẹ́ sí àlàyé olùkọ́
– kíkó pa nínúkíkọ
àpẹẹrẹ sí ojú
pátákó ìkọ̀wé.
ÕS Ê 10
ORÍ ÕRÕ
EWÌ
ÀKÓÓNÚ
Kín ni Líréṣọ̀ ewì?
– Kókó ọ̀rọ̀ ó jẹ mọ́ ohun ó ń lọ láwùjọ
bíi ètò ọrọ̀ ajé, òṣèlú
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
Ka ewì sí akẹḱ ọ̀ọ́ lé
– ṣe àlàyé ewì akà
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Ka ewì náà sínú
– ṣe àmì sí a ̀wọn ọ̀rọ̀ ó ta kókọ́.
ÕS Ê 11
ORÍ ÕRÕ
ÌSỌ RÍ ÒRỌ
ÀKÓÓNÚ
Oríṣiríṣi ìsọ̀rí ọ̀rọ̀
– oríkì ọ̀rọ̀ orúkọ
– – oríṣiríṣi ọ̀rọ̀ orúkọ
– àpẹẹrẹ orúkọ ènìyàn, ẹranko, ìlú,
nǹkan à0 bẹ́ẹ̀ lọ
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
Dárúkọ oríṣi ìsọ̀rí ọ̀rọ̀
– sọ ohun ọ̀rọ̀ orúkọ jẹ́
– mẹ́nu ba oríṣiríṣi ọ̀rọ̀ orúkọ ó wà
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Mọ ìsọ̀rí ọ̀rọ̀ èdè yorùbá
– mọ oríkì ọ̀rọ̀ orúkọ
– – ṣe àpẹẹrẹ oríṣiríṣi ọ̀rọ̀ orúkọ
ÕS Ê 12
ORÍ ÕRÕ
ERÉ ONÍTÀN KÉKÈÈKÉ
ÀKÓÓNÚ
Kíka ìwé eré oníṣe
– ṣíṣe eré oníṣe
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
Darí akẹḱ ọ̀ọ́ lá0 ka ìwé eré oníṣe
– Darí akẹḱ ọ̀ọ́ lá0
ṣe eré oníṣe
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Fe sílẹ̀ lá0 gbọ́ ohun à ń kà
– Kópa nínú eré oníṣe
– Sọ kókó inú eré oníṣe
– Dàrúkọ àwọn ẹ̀dá ìtàn.
ÕS Ê 13: ÀTÚYẸWÒ Ẹk Ọ
ÕS Ê 14: ÌDÁNWÒ
Nigeria Language Syllabus, Yoruba Language scheme of work primary 4 Federal, eré oníṣe, oríkì lẹ́tà gbẹ̀fẹ́,àwọn àpẹẹrẹ, Schemeofwork.com
SECOND TERM YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK FOR PRIMARY FOUR
TEACHING SCHEME PRIMARY FOUR -YORUBA – TÁÀMÙ KEJÌ
ÕS Ê 1
ORÍ ÕRÕ
LẸTÀ KÍKỌ
ÀKÓÓNÚ
Lẹtà gb ́ ẹ̀fẹ́
– Oríkì lẹ́tà gbẹ̀fẹ́
– – ìgbésẹ̀ lẹ́tà gbẹ̀fẹ́
– Àpẹẹrẹ lẹtà ́ gbẹ̀fẹ
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
Sọ oríkì lẹ́tà gbẹ̀fẹ́
– ṣe àlàyé ìgbésẹ̀ lẹ́tà gbẹ̀fẹ́
– kọ àpẹẹrẹ lẹ́tà gbẹ̀fẹ
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Tẹ́ sí àlàyé olùkọ
– sọ àwọn ìgbésẹ olùkọ́
kọ sójú patákó sínú ìnú wọn.
ÕS Ê 2
ORÍ ÕRÕ
ẸRỌ KỌ M PÚTÀ
ÀKÓÓNÚ
Dídá ẹ̀yà ara kọ̀m̀ pútà mọ̀
– ya àwòrán kọ̀m̀ pútà
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
Dárúkọ àwọn ẹ̀yà ara
kọ̀m̀ pútà
– ya àwòrán kọ̀m̀ pútà sí ojú pátákó
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Dárúkọ àwọn ẹ̀yà ara
kọ̀m̀ pútà
– ya àwòrán kọ̀m̀ pútà sínú ìwé wọn
ÕS Ê 3
ORÍ ÕRÕ
EWÌ
ÀKÓÓNÚ
Òwe
-ṣe àlàyé lórí ìtumọ̀ òwe
– pàtàkì òwe láwùjọ yorùbá
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
Sọ ohun òwe jẹ́
– sọ pàtàkì òwe ní àwùjọ yorùbá
– – pa òwe pẹ̀lú ìtumọ̀ rẹ̀ fún àwọn akẹḱ ọ̀ọ
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Tẹ́ sí olùkọ́
– Pa àpẹẹrẹ òwe o mọ̀
– – kọ àwọn àpẹẹrẹ náà sílẹ
ÕS Ê 4
ORÍ ÕRÕ
PỌNTUÉṢÀN
ÀKÓÓNÚ
Ìtẹ̀síwájú lórí àwọn àmì pọntuéṣàn
– Ìwúlò àmì pọntuéṣàn nínú gbólóhùn yorùbá
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
ṣe àlàyé ìtẹ̀síwájú lórí àmì pọntuéṣàn à0 ìlò rẹ̀
– Tọ́ akẹ́kọ̀ọ́ sọ́nà lá0 kọ àmì náà sí ojú pátákó
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Tẹ́ sí àlàyé olùkọ́
– Kópa ní kíkọ àmì pọntuéṣàn sí ara pátákó
– – ṣe àdàkọ àwọn àpẹẹrẹ náà sínú ìwé wọn.
ÕS Ê 5
ORÍ ÕRÕ
ÀṢÀ
ÀKÓÓNÚ
Ìwà rere à0 ìwà
búburú
– àpẹerẹ ìwà rere
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
ṣe àlàyé lórí ìwà rere
– sọ àǹfààní a lè rí gbà nínú ìwà rere
– – ìfẹ́ sí orílẹ̀ èdè ẹni
– – darí akẹḱ ọ̀ọ́ lá0 ṣe eré ó fi ìwà rere
hàn
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Tẹ́ sí àlàyé olùkọ́
– ṣe àlàyé lórí ìfẹ́ sí orílẹ̀ èdè ẹni
– – jíròrò lórí ọ̀nà a lè gbà _ ìfẹ́ hàn sí orílẹ̀
èdè ẹni.
ÕS Ê 6
ORÍ ÕRÕ
ÌSỌ RÍ Ọ RỌ
ÀKÓÓNÚ
Òrọ̀ arọ́pò orúkọ à0 afarajorùkọ
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
Sọ oríkì ọ̀rọ̀ arọ́pò
orúkọ
– Àpẹẹrẹ ọ̀rọ̀
arọ́pò orúkọ
– Oríkì ọ̀rọ̀
afarajorúkọ
– Àpẹẹrẹ ọ̀rọ̀
afarajorúkọ
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Ki oríkì ọ̀rọ̀ arọ́pò
orúkọ
– Kọ àpẹẹrẹ ọ̀rọ̀
arọ́pò orúkọ
– Ki oríkì ọ̀rọ̀ afarajorúkọ
– Àpẹẹrẹ ọ̀rọ̀ afarajorúkọ.
ÕS Ê 7
ORÍ ÕRÕ
Ọ RỌ ÀTI ÍDÀKEJÌ
ÀKÓÓNÚ
Òrọ[ à0 ìdàkejì
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
Kọ àpẹẹre ọ̀rọ̀ à0
ìdàkejì
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Mọ ìtumọ̀ àwọn ọ̀rọ̀ à0 ìdàkejì
ÕS Ê 8
ORÍ ÕRÕ
ÌTÀN ÀRÒSỌ
ÀKÓÓNÚ
Àlọ́ onítàn kò ní
orin.
– Àpẹẹrẹ àkùkọ à0
kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀, bí
igún ṣe pá
lórí
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
pa àpẹẹrẹ álọ́ onítàn
kò ní orin fún
akẹḱ ọ̀ọ́
– Darí akẹḱ ọ̀ọ́
lá0 pa àlọ́
onítàn kò
lórin 0 wọn
mọ̀
– Fa ẹ̀kọ́ inú
àwọn àlọ́
onítàn náà yọ
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Tẹ́ sí àwọn àpẹẹrẹ olúkọ́ ń fún wọn
– Pa àlọ́ onítàn 7rẹ
– – sọ ẹ̀kọ́ ìtàn náà kọ́ wọn.
ÕS Ê 9
ORÍ ÕRÕ
ÀKÀYÉ
ÀKÓÓNÚ
Ìwé kíkà
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
ṣàlàyé lórí kókó àyọkà
– Ka àyọkà náà
fún akẹḱ ọ̀ọ́
– Jẹ́ kí akẹḱ ọ̀ọ́
kà á ní àkà
sínú
– ṣàlàyé àwọn
ọ̀rọ̀ ó ta
kókó nínú
àyọkà náà
– – béèrè
ìbéèrè lọ́wọ́
akẹḱ ọ̀ọ́ nípa
àyọkà náà.
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Tẹ́ sí àlàyé olùkọ̀
– Ka àyọkà ní
àkà sínú
– Dáhùn ìbéèrè
olùkọ́
– Sọ ìtumọ̀
àwọn ọ̀rọ̀ ó
ta kókó.
ÕS Ê 10
ORÍ ÕRÕ
OǸKÀ
ÀKÓÓNÚ
Ka ọ̀kànlélọ́gọ́rùn ún
dé àádọ́jọ
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
Ka òǹkà fún àwọn
akẹḱ ọ̀ọ́
– ṣe àlàyékíkún
nípa oǹkà
gẹ́gẹ́ bí
àpẹẹrẹ
110 = àádọ́fà
=(20×6-10)
– ṣe àròpọ̀ à0
àyọkúrò oǹkà
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Ka oǹka lá0 ọgọ́rùn ún
dé àádọ́jọ
– fojú sı bí a 0 ń ́́
ṣe àròpọ̀ à0
àyọkúrò.
ÕS Ê 11: ÀTÚNYẸWÒ ẸK Ọ
ÕS Ê 12: ÌDÁNWÒ
THIRD TERM YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK FOR PRIMARY FOUR
TEACHING SCHEME PRIMARY FOUR -YORUBA – TÁÀMÙ KẸTA
ÕS Ê 1
ORÍ ÕRÕ
LẸTÀ KÍKỌ
ÀKÓÓNÚ
Lẹtà àìgb ́ ẹ̀fẹ
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
Ki oríkì lẹ́tà àìgbẹ̀fẹ́
– ṣàlàyé ìlapa èrò lẹ́tà àìgbẹ̀fẹ́
– – ṣe álàyé oreṣ́ Iọ̀nà a lè gbà gbé lẹtà àìgb ́ ẹ̀fẹ́ kalẹ̀
– Tọ́ akẹ́kọ̀ọ́ sọ́nà lá0 kọ lẹtà
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Tẹ́ sí àlàyé olùkọ́
– Da ìlapa èrò olùkọ́ kọ sójú pátákó kọ sínú ìwé
– Kọ àpẹẹrẹ lẹ́tà 7rẹ,kí o tẹ̀ lé ìlànà 0 olùkọ́ .
ÕS Ê 2
ORÍ ÕRÕ
ÌTÀN ÀRÒSỌ
ÀKÓÓNÚ
Àlọ́ onítàn ó ni orin
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
Sọ àpẹẹrẹ àlọ́ onítàn ó ní orin fún akẹḱ ọ̀ọ́
– Darí akẹḱ ọ̀ọ́ lá0 pa àlọ́ onítàn oórin wọ́n mọ̀
– fa ẹkọ́ ó wa nínú àwọn àlọ́ onítàn náà yọ
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Tẹ́ sí àwọn àpẹẹrẹ olùkọ́ ṣe
– Pa àlọ́ onítàn olórin 7rẹ
– Sọ ẹ̀kọ́ a rí kọ́ ninú àwọn ìtàn náà.
ÕS Ê 3
ORÍ ÕRÕ
ÌTẸSÍWÁJÚ LO RÍ ÀWỌN ÌLÒ ÀMÌN
ÀKÓÓNÚ
Pọntuéṣàn
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
ṣe àlàyé oríṣiríṣi àmì pọntuéṣàn à0 ìlò wọn
– Kọ wọ́n sí ojú pátákó ìkọ̀wé pẹ̀lú àpẹẹrẹ
– – tọ́ akẹ́kọ̀ọ́ sọ́nà lá0 kọ àwọn àmì náà sójú pátákó ìkọ̀wé.
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Tẹ́ sí àlàyé olùkọ́
– Kópa nínú kíkọ àwọn àmì pọntuéṣàn náà sájú pátákó ìkọ̀wé
– ṣe àdàkọ iṣẹ́ ojú pátákó sínú ìwé rẹ̀
ÕS Ê 4
ORÍ ÕRÕ
ÌTÀN ÀRÒSỌ
ÀKÓÓNÚ
Aáwọ̀ yíyanjú ní ilẹ̀ Yorùbá
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
ṣe àlàyé ìtumọ̀ aáwọ̀
– sọ àwọn ohun ó má a ń fa aáwọ̀
– àárín àwọn wo ni aáwọ̀ 0 máa ń ṣẹlẹ̀?
– Yóò sọ àwọn ọ̀nà a lè gbà yanjú aáwọ
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Tẹ́ sí àlàyé olùkọ́
– Mọ àwọn ohun ó máa ń fa aáwọ[
– Òye àwọn aáwọ̀ máa ń wáyé láàárín wọn yóò yé e
– Yóò mọ àwọn ọ̀nà a lè gbà yanjú aáwọ̀ ní ilẹ̀ Yorùbá.
ÕS Ê 5
ORÍ ÕRÕ
EWÌ
ÀKÓÓNÚ
Òwe : oríṣịríṣi òwe
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
ṣe ìtúmọ̀ ò̀̀we à0 lílò rẹ Tẹ́ sí olùkọ
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
– àpẹẹrẹ ẹṣin ìwájú ni tẹ̀yìn ń wò sáré.
– ilé ọba tó jó ẹwà ló bù si.
– sọ oríṣiríṣi òwe a ní ní ilẹ̀ yorùbá
– pe akẹḱ ọọ́ lá0 pa òwe wọ́n gbọ́ rí
Pa àwọn òwe o mọ
– ṣe àkọsílẹ̀ àwọn òwe
olùkọ́ kọ sára pátákó.
ÕS Ê 6
ORÍ ÕRÕ
ÀṢA
ÀKÓÓNÚ
Aṣọ wíwọ
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
Yóò fi oríṣiríṣi aṣọ ilẹ̀
yorùbá à0 àwòrán wọn
han akẹḱ ọ̀ọ́
– sọ àǹfààní à0
àléébù aṣọ
ìgbàlódé díẹ
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Dárúkọ oríṣiríṣi aṣọ ilẹ̀ yorùbá
– dárúkọ oríṣiríṣi aṣọ
ìgbàlódé
– sọ àǹfààní à0 àléébù
aṣọ ìgbàlódé.
ÕS Ê 7
ORÍ ÕRÕ
ÀRÒKỌ
ÀKÓÓNÚ
Àrùn kògbóògùn éèdì
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
ṣàlàyé ìtumọ̀ àròkọ
– ṣàlàyé kíkún lórí arùn kogbóogun éedi
– ṣàlàyé ìdìtÍ àrùn yií fi jẹ́ kògbóògùn
– ìmọ̀ràn fún àwọn ó ní àrùn éèdì
– ìmọ̀ràn rẹ̀ fún àwọn kò ì ní àrùn éèdì
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Tẹ́ sí àlàyé olùkọ́
– mọ ìdí àrùn éèdì fi jẹ́ kògbóògùn
– mọ ìmọ̀ràn a lè fún ẹni ó ní àrùn éèdì à0 ẹni kò ní.
ÕS Ê 8
ORÍ ÕRÕ
AKÀYÉ
ÀKÓÓNÚ
Ìdíje bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
ṣàlàyé lóri kókó àyọkà
– ka àyọkà náà fún àwọn akẹḱ ọ̀ọ́
– jẹ́ kí akẹḱ ọ̀ọ́ ka àyọkà ní àkà sínú
– ṣàlàyé àwọn ọ̀rọ̀ ó ta kókó nínú àyọkà náà
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
ṣàlàyé lórí kókó àyọkà
– ka àyọkà ní à kà sínú
– dáhùn ìbéèrè olùkọ́
– sọ ìtumọ̀ àwọn ọ̀rọ̀ ó ta kókó.
ÕS Ê 9
ORÍ ÕRÕ
ÌTẸSÍWÁJÚ
LÓRÍ ÀṢÀ
ÀKÓÓNÚ
A̧ṣà ouń́jẹ jíjẹ
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
ṣàlàyé oríṣiríṣi ouńjẹ àwọn yorùbá ń jẹ
– ṣàlàyé lórí ìsọ̀rí ouńjẹ pẹ̀lú àpẹẹrẹ
– mẹ́nu ba àwọn ouńjẹ ó wà fún ìpanu
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Tẹ́ sí àlàyé olùkọ́
– sọ àpẹẹrẹ ouńjẹ mìírànlábẹ́ ìsọ̀rí
kọ̀ọ̀kan yàtọ̀ sí 0 olùkọ́.
ÕS Ê 10
ORÍ ÕRÕ
ÌSỌ RÍ Ọ RỌ
ÀKÓÓNÚ
ọ̀rọ̀ ìṣe
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
ṣàlàyé ìtumọ̀ ọ̀rọ̀ ìṣe
-ṣàlàyé iṣẹ́ ọ̀rọ̀ ìṣe ń ṣe nínú gbólóhùn èdè yorùbá
– sọ àpẹẹrẹ ọ̀rọ̀ ìṣe
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Mọ ìtumọ̀ ọ̀rọ̀ ìṣe
– ṣe àlàyé lórí àwọn iṣẹ́ ọ̀rọ̀ ìṣe ń ṣe nínú gbólóhùn èdè yorúbá
– mọ àpẹẹrẹ ọ̀rọ̀ ìṣe
ÕS Ê 11
ORÍ ÕRÕ
OǸKÀ
YORÙBÁ
ÀKÓÓNÚ
Ka àádọ́jọ dé igba
ÀMÚŚE IŚË OLUKO
Ka oǹkà fún akẹḱ ọ̀ọ́ lá0
àádọ́jọ dé igba
– ṣe àlàyé kíkún
nípa oǹkà
– kọ oǹkà fún
akẹḱ ọ̀ọ́ lá0
àádọ́jọ dé igba.
ṣe àròpọ̀ à0
àyọkúrò oǹkà
ÀMÚŚE IŚË AKEkOO
Ka oǹkà lá0 àádọ́jọ dé igba
– fojú sí bí a 0 ń ṣe
àròpọ̀ à0 àyọkúrò
oǹkà.
ÕS Ê 11: ÀTÚNYẸWÒ ẸKỌ
ÕS Ê 12: ÌDÁNWO