Yoruba Language Scheme of Work for SS 1 Federal

31 Min Read
yoruba language scheme of work
yoruba language scheme of work

FCT Senior Secondary Humanity Syllabus. Federal Yoruba Language Scheme of Work for SS 1. Sílébù èdè Yorùbá –Schemeofwork

YORÙBÁ SS 1 TÁÀMÙ KÌN-ÍN-NÍ

ÕSÊORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚÀMÚŚE IŚË  
1ÀŚÀ: Êkö Ilé   ÀKÓÓNÚ IŚË Oríkì êkö ilé Ìkíni ní oríśiríśi ônà d.   Iśë ilé śíśe e.   Ìbõwõ fágbà ç.   Ìmötótó f.   Ìbömôwí abblOLÙKÖ:       sô oríkì êkö ilé śàlàyé ní kíkún lórí oríśiríśi êkö ilé àti pàtàkì wôn láwùjô d.  śàlàyé ìkíni lóríśiríśi õnà e.  śàlàyé oríśiríśi õnà tí à ń gbà töjú ilé ç.  kô àwôn õrõ tó súyô sójú pátákó AKËKÕÖ: Tëtí sí àlàyé olùkö Śe àfihàn ìkíni lóríśiríśi õnà, ìwà ômôlúàbí, ìtöjú ilé. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Pátákó ìkõwéÀwòrán TéèpùTçlifísàn/ RédíòFíìmù
2.LÍTÍRÈŚÕ: Ìwé Kíkà: Ìtàn Àròsô Ôlörõ Geere   ÀKÓÓNÚ IŚË Kókó Õrõ Àhunpõ Ìtàn d.  Ôgbön ìsõtàn e.  Ibùdó ìtàn ç.  Êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá f.  Lílo èdè g. Ìjçyô àśà gb. Àmúyç àti àléébù OLÙKÖ: jë kí akëkõö ka ìwé ìtàn àròsô ôlörõ geere śàlàyé kíkún lórí kókó àkóónú iśë bí ó ti jçyô nínú ìtàn àròsô. ìsônísókí àhunpõ ìtànêdá ìtàn ôgbön ìsõtànìwúlò èdè ìjçyô õrõ àmúyç àti àléébù kô àwôn õrõ tí ó súyô sí ojú pátákó AKËKÕÖ:    a. Ka ìwé    b. Tëtí sí àlàyé olùkö    d.  Kô àwôn õrõ tó súyô pêlú ìtumõ wôn OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Pátákó ìkõwéÌwé ìtàn àròsô tí a yàn
3.ÈDÈ: Álífábëtì Èdè Yorùbá   ÀKÓÓNÚ IŚË Álífábëtì: a, b, d, e, ç, f, g, gb, h, i, j, k, l, m, n, o, ô, p, r, s, ś, t, u, w, y Köńsónáýtì: b, d, f, g, gb, h, j, k, l, m, n, p, r, s, ś, t, w, y      d.   Fáwëlì: a, e, ç, i, o, ô, u  OLÙKÖ: kô álífábëtì yorùbá lápapõ sára pátáko fún akëkõö kô àwôn lëtà tí ó dúró fún ìró köńsónáýtì àti ìró fáwëlì d.   pe wön lökõõkan fún akëkõö. AKËKÕÖ: fetí sí bí olùkö śe pe àwôn ìró köńsónáýtì àti fáwëlì náà. pe àwôn ìró köńsónáýtì àti fáwëlì náà bí olùkö ti pè wön d.  śe àdàkô àwôn lëtà ìró köńsónáýtì àti fáwëlì naa OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: kádíböõdù ńlá tí a kô álífábëtì Yorùbá sí. kádíböõdù ńlá tí ó ń śe àfihàn àwôn ìró Köńsónáýtì àti fáwëlì lötõõtõ. káàdì pélébé pélébé tí a kô àwôn lëtà náà sí.
4ÀŚÀ: Àwôn oúnjç ilê Yorùbá 
 
ÀKÓÓNÚ IŚË
a. Oríkì oúnjç
b. Oríśiríśi oúnjç
d.   bí a śe ń śe oúnjç kõõkan
e. ìpín sí ìsõrí àwôn oúnjç ilê Yorùbá bí i: sêmíró, ôlöràá, afáralókun, amáradán abbl
ç.   ìtöjú oúnjç àjçsëkù
f.   àfiwé oúnjç àtijö àti ti òde òní.
g. oúnjç tí ìlú/ agbègbè kõõkan fëràn
OLÙKÖ:
sô oríkì oúnjç
sô oríśìí oúnjç
d.  śàlàyé bí a śe ń śe oúnjç kõõkan
e.  kô àwôn oúnjç tí ó bö sí ìsõrí kan náà sára pátákó
ç.  sô bí a śe ń śe ìtöjú oúnjç tí ó bá sëkù
f.  sõrõ lórí àýfààní oúnjç láti oko àti ewu oúnjç inú agolo
g.  Ya àtç oúnjç ti ìlú/ agbègbè kõõkan fëràn sórí pátákó.
AKËKÕÖ:
a.    Tëtí sí àlàyé olùkö
b.    Sô èrò tiwôn lórí oúnjç
d.   Kô ohun tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé.
e.   Ya àtç tí olùkö yà sójú pátákó.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:
Oríśìíríśìí oúnjç tútù
Àwòrán
Ohun èlò oúnjç:
Ìkòkò, epo, iyõ irú, ewébê, sítóófù abbl
 

5.ÈDÈ: Sílébù èdè Yorùbá   ÀKÓÓNÚ IŚË Oríkì sílébù Ìhun sílébù [F, KF, N] d.   pínpín õrõ sí sílébùOLÙKÖ: sô oríkì sílébùśàlàyé ìhun sílébù d. śe õpõlôpõ àpççrç pínpín õrõ sí sílébù sójú pátákó AKËKÕÖ: Tëtí sí àlàyé olùkö Śe àpççrç pínpín õrõ sí sílébù fúnra rê d.   kô ohun tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: pátákó ìkõwé kádíböõdù tí ó śe àfihàn àwôn õrõ oní sílébù méjì, mëta abbl
6.LÍTÍRÈŚÕ: Lítírèśõ èdè Yorùbá   ÀKÓÓNÚ IŚË   Oríkì lítírèśõ  Êka lítírèśõ èdè Yorùbá AlohùnÀpilêkô d.   Àwôn ohun tí a lè fi dá ewì kõõkan    mõ: sísun, dídá, kíkô, pípa, pípè e.   Ìlò èdè inú ewìOLÙKÖ: śe àlàyé àwôn àbùdá pàtàkì lítírèśõ śe àfiwé lítírèśõ àpilêkô àti alohùn kô àpççrç lítírèśõ àpilêkô fún àwôn akëkõö. śàlàyé àwôn ìsõrí mëtêêta lítírèśõ àpilêkõ láti fi ìyàtõ wön hàn. sô àpççrç õkõõkan àwôn ìsõrí náà fún akëkõö. AKËKÕÖ: Tëtí sí gbogbo àlàyé olùkö dáradára Ya àtç láti fi ìyàtõ lítírèśõ àpilêkô àti alohùn hàn. kô àpççrç mìíràn fún ìsõrí kõõkan lítírèśõ àpilêkô. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Ìwé oríśiríśi Lítírèśõ àpilêkô: eré-oníśe, ewì àti ìtàn àròsô
7.LÍTÍRÈŚÕ: Ìtúpalê ewì alohùn (Àsàyàn ìwé kan)   ÀKÓÓNÚ IŚË   a. Àkóónú kókó õrõ àśà tó súyô ìhun lílé/ gbígbè, àdákô, àjùmõkô ìlò èdè: ônà èdè àti ìsôwölo-èdè ìjçyô àśà b.  Lítírèśõ alohùn mìíràn d. õgangan ipò àwôn akéwì: êśìn wön/ ìśe wôn, àkókò ìkéwì abblOLÙKÖ: jë kí akëkõö ka ewì alohùn löpõlöpõ ìgbà  śe àlàyé lórí kókó õrõ êkö, ìlò èdè, àmúyç àti àléébù inú ìwé àsàyàn ewì alohùn. AKËKÕÖ: fi etí sí ewì tí olùkö ń kà fún wôn. Gbìyànjú láti kéwì tí ó bá mõ d.   ka ìwé àsàyàn yìí OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Ìwé tó jçmö ewì alohùn Àwòrán tó bá ewì yìí mu Pátákó ìkõwé
8.ÌHUN ÕRÕ: a. Möfíìmù ní èdè Yorùbá b. Õnà tí a ń gbà śêdá õrõ-orúkô ÀKÓÓNÚ IŚË oríkì möfíìmù ìśêdá õrõ-orúkô –àfòmö ìbêrê (a-, on-, o, oní-, àì-, àti-, àfòmö àárin àpètúnpè (kíkún, çlëbç)OLÙKÖ: Śàlàyé oríśìí ìhun õrõ  Śàlàyé ìśêdá àwôn õrõ d.    Kô õpõlôpõ àpççrç oríśiríśi õrõ sórí pátákó. AKËKÕÖ: Sô oríśiríśi ìhun õrõ Sô bí a śe śêdá àwôn õrõ d.   Da õrõ-orúkô ìśêdá tí olùkö kô sójú pátákó kô sínú ìwé. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Śe àlàyé ìlò àfòmö ìbêrê onísílébù méjì láti śêdá õrõ-orúkô pêlú àpççrç.Kô õrõ ìpìlê mëta sílê d. Kô àpççrç õrõ ìśêdá alápètúnpè kíkún mëta àti alápètúnpè çlëbç

9.
IŚË ABÍNIBÍ i. Onírúurú iśë ilê Yorùbá bí i àgbê, alágbêdç, onídìrí, aśô híhun, aró dídá, awakõ abbl ii. Ìkíni àti ìdáhùn fún onírúurú iśë.   ÀKÓÓNÚ IŚË oríkì iśë abínibí àti àpççrç iśë: àgbê, ôdç, aśô híhun, aró dídá, epo fífõ, irun dídì, àyàn, olóólà, alágbêdç Bí a ti ń kö iśë d.    ìwúlò iśë kíkö e.   iśë ôkùnrin, obìnrin, tôkùnrin-tobìnrin ní àtijö àti lóde òní.OLÙKÖ: Sô oríkì àti ohun tí iśë abínibí jë Tö akëkõö sönà láti mô pàtàkì iśë śíśe àti bí a śe ń kö iśë kõõkan. d.    Sô àýfààní iśë kíkö e.    Kô ìjôra àti ìyàtõ tó wà nínú iśë abínibí àti tòde òní sójú pátákó AKËKÕÖ: Sô ohun tí o mõ nípa iśë śíśe àti ìdí tí ó fi yç kí ènìyàn śiśë Kô ohun tí olùkö kô sójú pátákó sínú ìwé rç. d.   Śe àfiwé iśë abínibí àti tòde òní. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Àwôn ohun-èlò iśë abínibí bí i: àdá, àkàtàýpò, ômô-owú, êmú, ôkö abbl Àwòrán çbu àti àwôn òśìśë.
10.ÀŚÀ: ÌGBÉYÀWÓ   Àkóónú iśë ìdí tí a fi ń gbéyàwó/ lökô oríśiríśi ìgbéyàwó tí ó wà láyé àtijö àti lóde òní, ìfômôtôrô, fífë níśulökà, àśàýte, śöõśì, kóòtù, mùsùlùmí, ôkô kan aya kan, aláya púpõ abbl d.  Ìgbésê inú oríśi ìgbéyàwó kõõkan láyé àtijö e.   ìgbésê inú oríśi ìgbéyàwó kõõkan lóde òní. ç.    Àýfààní àti ìśòro inú irú ìgbéyàwó kõõkan látijö àti lóde òní.OLÙKÖ: Śe àlàyé fún akëkõö lórí àýfààní tí ó wà nínú śíśe ìgbéyàwó Jë akëkõö jíròrò/ sô ìrírí rê; d.    kô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì sí ojú pátákó pêlú ìtumõ wôn AKËKÕÖ: Tëtí sí olùkö Jíròrò ní kíláásì/ sô ìrírí rç d.   Da àwôn õrõ tí olùkö kô sójú pátákó kô sínú ìwé OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Àwòrán ìgbéyàwó Fídíò Téèpù Tçlifísàn
11.ÈDÈ: ÒWE i. Oríśiríśi òwe  Ìtándòwe, òwe ajçmësìn, ìrírídòwe ii. ìwúlò òwe   ÀKÓÓNÚ IŚË Oríkì òwe Oríśiríśi òwe d.    Ìlò òwe/ ìwúlò òweOLÙKÖ: Sô ìtumõ òwe Jë kí akëkõö pa oríśiríśi òwe bí àpççrç: ìbáwí, ìkìlõ, ìmõràn abbl d. Kô ìbêrê àwôn òwe kan sójú pátákó fún akëkõö láti parí wôn e. Sô ìwúlò òwe AKËKÕÖ: Tëtí sí àlàyé olùkö Pa oríśiríśi òwe gëgë bí olùkö śe darí d.   kô ìparí àwôn òwe tí olùkö kô sí ojú pátákó sí inú ìwé wôn. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Ìwé òwe pêlú ìtumõ wôn Pátákó ìkõwé
12.ÀŚÀ: Oyún níní, ìtöjú oyún àti ìtöjú ômô láyé àtijö àti lóde òní.   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Ìgbàgbö nípa ômô bíbí àti àbíkú. b. Ohun gbogbo ló ní àsìkò, tôkô-taya ni oyún wà fún kì í śe àpön àti wúndíá. d. Õnà tí a lè gbà dín bíbí àbíkú kù láwùjô; b.a òye lórí onírúurú jënótáìpù êjê tó wà àti àwôn tó fë fëra wôn e. Aájò láti lè tètè lóyún: àýfààní kíkó ara çni ní ìjánu nípa ìbálòpõ, yíyçra fún ìlòkulò oògùn ìsëyún abbl ç. Bí a śe ń töjú aboyún f. Oúnjç aśaralóore g. Lílô fún ìtöjú ní ilé ìwòsàn (ìbílê/ ìjôba) gb. Oyún dídè h. ÀwêbíOLÙKÖ: a. Śàlàyé kíkún lórí ìgbàgbö Yorùbá nípa oyún níní, ìtöjú oyún àti àsìkò tó tö láti lóyún. b. Sõrõ lórí onírúurú jënótáìpù tó wà àti ìdí tí akëkõö fi gbôdõ mô tirê. d. La akëkõö lóye lórí jënótáìpù tó bá ara mu àti àwôn tó lè fëra wôn. e. Kô àwôn oúnjç asaralóore tí aláboyún lè jç sójú pátákó ìkõwé. AKËKÕÖ: a. Jíròrò nípa àwôn tóyún wà fún b. Sô ohun tí ó nípa oyún níní d. Sô jënótáìpù tìrç e. Dárúkô díê lára àwôn oúnjç aśaralóore ç. Dárúkô díê lára àwôn õnà tí a fi ń töjú aláboyún OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Àwòrán díê lára ohun èlò tí a fi ń töjú aláboyún ní ìlànà ti ìbílê: ìkòkò àgbo, ìsáàsùn, àśèjç, ìgbàdí abbl Àwòrán díê lára ohun tí a fi ń töjú aláboyún ní ìlànà Òyìnbó. Àtç tó ń fi oúnjç aśaralóore hàn.
  13.  ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ                   
  14.  ÌDÁNWÒ     

Federal Yoruba Language Scheme of Work for SS 1 –Schemeofwork

YORÙBÁ SS 1 TÁÀMÙ KEJÌ

ÕSÊORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚÀMÚŚE IŚË  
1ÈDÈ: Àkàyé:   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Ôgbön tí a ń ta fún àśeyege lórí àkàyé b. Kíka àyôkà d. Títúmõ àkànlò èdè, òwe àti ônà èdè tí ó jçyô nínú àyôkà ní ìbámu pêlú bí a ti lò ó. e. Dídáhùn ìbéèrè lórí àkóónú àyôkàOLÙKÖ: Śe àwárí àwôn àyôkà tó jçmö õrõ tó ń lô. Irú àyôkà bëê gbôdõ ní ìlò èdè tó dára. Jë kí akëkõö ka àyôkà náà dáradára d.  Tö akëkõö sönà láti dáhùn ìbéèrè nípa àyôkà e.   Tö akëkõö sönà láti sô ìtumõ òwe AKËKÕÖ: Tëtí sí àlàyé lórí àkàyé Ka àyôkà, dáhùn àwôn ìbéèrè lórí rê d.   śe àlàyé ìtumõ òwe, àkànlò èdè tí ó súyô ní ìbámu pêlú bí a śe lò wön. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:    Àyôkà oríśiríśi tí ó dá lé ìśêlê àwùjô.
2.LÍTÍRÈŚÕ: Àtúpalêàsàyànìwé eré-onítàn (ìwé méjì)   ÀKÓÓNÚ IŚË a.   Kókó Õrõ b.   Àhunpõ Ìtàn d.  ibùdó ìtàn e.  Êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá ç.  Ìlò èdè f.   Àmúyç àti àléébù OLÙKÖ: a.  jë kí akëkõö ka ìwé ìtàn eré-onítàn Śe àlàyé kíkún lórí ìjçyô àkóónú iśë nínú eré-onítàn àsàyàn:      Kókó õrõ ii.        Êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá ibùdó ìtàn ìlò èdèìjçyô àśà abbl d.   kô àwôn õrõ pàtàkì tí ó súyô sórí pátákó, kí o sì śàlàyé ìtumõ wôn. e.   Béèrè ìbéèrè löwö akëkõö AKËKÕÖ:    a. Ka ìwé eré-onítàn wá láti ilé àti nínú kíláásì    b. Tëtí sí àlàyé olùkö    d.  Kô àwôn õrõ tí olùkö kô sí orí pátákó sínú ìwé.    e.  Dáhùn ìbéèrè olùkö  OHUN-ÈLÒ: Ìwé eré-onítàn
3.ÀŚÀ: Àśà ìsômôlórúkô ní ilê Yorùbá   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Ìgbàgbö Yorùbá nípa pàtàkì orúkô (orúkô ômô ni ìjánu ômô) b.  Ètò ìsômôlórúkô b.a ifá lômô d.  Oríśiríśi orúkô àti ìtumõ wôn. i. Àbisô       ii. Àmútõrunwá      iii. Oríkì       iv. Ìnágijç   v. Ìdílé vi. Òde-òní abbl  OLÙKÖ: Kô oríśiríśi orúkô sí ojú pátákó Śàlàyé pàtàkì orúkô àti oríśiríśi orúkô d. Śàlàyé orúkô òde oni e. Darí àwôn akëkõö láti śe ìjìnlê eré ìsômôlórúkô. AKËKÕÖ: a. Tëtí sí àlàyé olùkö b. sô ohun tí wôn mõ nípa ìsômôlórúkô sáájú ìdánilëkõö d. sàwòkô orúkô tí ó wà lára pátákó e. kópa nínú ìśeré, ìsinjç ìsômôlórúkô.                     ç. śe àdàkô àwôn lëtà ìró köńsónáýtì àti fáwëlì naa. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: 1. Ohun èlò ìsômôlórúkô: oyin, atare, orógbó, obì, çja, omi 2. Kádíböõdù tí a to orúkô ômô àti ìtumõ wôn sí.
4.ÈDÈ: Aáyan Ògbufõ   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Ìtösönà lórí bí a śe ń śe aáyan ògbufõ b. Túmõ àwôn gbólóhùn kéékèèké láti èdè Gêësì sí Yorùbá   OLÙKÖ: a. Śàlàyé bí a śe ń śe aáyan ògbufõ b. Túmõ àwôn gbólóhùn láti èdè Gêësì sí Yorùbá d. Kô àwôn gbólóhùn àti àkànlò èdè tí a túmõ sí orí pátákó. AKËKÕÖ: a. Tëtí sí bí olùkö śe ń túmõ àwôn gbólóhùn b. Kô àwôn gbólóhùn àti àkànlò èdè tí olùkö kô sí ojú pátákó sí inú ìwé wôn. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Pátákó ìkõwé
5.LÍTÍRÈŚÕ: Àtúpalê ìwé ìtàn àròsô (ìwé méjì)   ÀKÓÓNÚ IŚË a. kókó õrõ b. ìfìwàwêdá d. Àhunpõ ìtàn e. Ibùdó ìtàn ç. ôgbön ìsõtàn f. êdá ìtàn g. ìlò èdè gb. Ìjçyô àśà h. Àmúyç àti àléébùOLÙKÖ: a. Jë kí akëkõö ka ìwé ìtàn àròsô. b. Śe àlàyé ní kíkún lórí ìjçyô àkóónú iśë lórí ìwé ìtàn: kókó õrõ, ìfìwàwêdá, àhunpõ ìtàn, ibùdó ìtàn, ôgbön ìsõtàn, àmúyç àti àléébù. d. Kô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì tó súyô sójú pátákó kí ó sì śàlàyé ìtumõ wôn. AKËKÕÖ:   a. Ka ìwé ìtàn àròsô wa láti ilé àti nínú kíláásì.   b. Tëtí sí àlàyé olùkö   d.  Kô àwôn õrõ tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Ìwé ìtàn àròsô
6.ÈDÈ: Àkànlò Èdè   ÀKÓÓNÚ IŚË: a. Oríkì àkànlò èdè b. Oríśiríśi àkànlò èdè  d. Ìlò Àkànlò èdè  OLÙKÖ: a. Sô ìtumõ àkànlò èdè  b. Jë kí akëkõö sô ìtumõ àwôn àkànlò èdè. AKËKÕÖ: a. Tëtí sí àlàyé olùkö b. Sô oríśiríśi àkànlò èdè d. Sô ìtumõ àkànlò èdè  OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Ìwé àkànlò èdè pêlú ìtumõ wôn Pátákó ìkõwé
7.ÈDÈ: a. Àròkô kíkô b. Ìgbésê fún àròkô kíkô   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Oríkì àròkô b. Àwôn ìgbésê tí a ń têlé láti kô àròkô kíkô d.  Oríśiríśi àwôn àròkô: i. Àròkô aláríyànjiyàn ii. Àròkô oníròyìn/ asõtàn    iii. Àròkô alálàyé iv. Àròkô ajçmö-ìsípayá v. Àròkô onísõrõýgbèsì vi. Àròkô asàpèjúwe vii. Lëtà Kíkô:     a. Lëtà gbêfê     b. Lëtà aláìgbagbêfê  OLÙKÖ: a. Sô ìtumõ àròkô b. Śàlàyé ìlapa èrò lórí àròkô kíkô d. Tö akëkõö sönà láti kô àròkô e. Yç ìśe akëkõö wò AKËKÕÖ: a. Tëtí sí àlàyé olùkö b. Kô àwôn àlàyé ojú pátákó sílê OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Pátákó ìkõwé
8.LÍTÍRÈŚÕ: Àtúpalê àsàyàn ewì àpilêkô (ìwé méjì)   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Kókó oro b. Ìhun ewì (ètò) d. Ìlò èdè e. Ijçyô àśà ç. Àmúyç àti àléébù OLÙKÖ: Jë kí akëkõö ka ìwé àsàyàn ewì àpilçkôŚe àlàyé ní kíkún lórí ìjçyô àkóónú iśë nínú ìwé àsàyàn ewì àpilêkô:Kókó õrõ Ìhun ewìÌlò èdè Ìjçyô àśàÀmúyç àti àléébù   d. Kô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì, kí o sì śàlàyé ìtumõ wôn.                                                                                                                                                                                       AKËKÕÖ: a. Ka ìwé àsàyàn ewì àpilêkô wá láti ilé àti nínú kíláásì b. Tëtí sí àlàyé olùkö d.  Kô àwôn õrõ tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Ìwé àśàyàn ewì àpilêkô
9.ÀŚÀ: Àśà ìtöjú ara lóde òní àti ewu tí ó rõ mö ô.                                           ÀKÓÓNÚ IŚË Ìtöjú ara çni b.a irun, èékánná, eyín, aśô: Ewu ìlòkulò oògùn olóró d.  ìtöjú ara lóde òní, àýfààní àti àléébù rê b.a i. Ètè kíkùn ii. irun díndín iii. Ihò méjì lílu sí etí kan iv. imú lílu      v. orin/ ewì nípa ìmötótóOLÙKÖ: Darí akëkõö láti sô õnà tí a lè gbà śe ìtöjú ara Śàlàyé ewu tó wà nínú àsìlò oògùn àti lílo oògùn olóró d.  Darí àwôn akëkõö láti kô orin/ ka ewì nípa pàtàkì ìmötótó AKËKÕÖ: Sô ìrírí rç nípa ewu tí àìtöjú ara lè fà. Kô orin tàbí ka ewì tí ó dá lórí pàtàkì ìmötótó d.  Śe àpççrç àwôn tí ó ti lo ìlòkulò oògùn olóró pêlú àyôrísí rê. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: 1. Pákò, búröõsì àti ôsç ìfôyín 2. Àwòrán õmùtípara, wèrè/ asínwín 3. Fíìmù tó śe àfihàn àtubõtán ìlòkulò oògùn àti oògùn olóró.
10.ÈDÈ: Àwôn ìsõrí õrõ nínú èdè Yorùbá     ÀKÓÓNÚ IŚË Õrõ-orúkô Õrõ-ìśe Õrõ-aröpò orúkô Õrõ-aröpò afarajorúkô Õrõ-àpönlé Õrõ-atökùn Õrõ-àsopõOLÙKÖ: Sô oríkì ìsõrí õrõ Śe àlàyé bí a śe lè dá ìsõrí õrõ kõõkan mõ nínú gbólóhùn. d.  Kô àwôn ìsõrí õrõ náà sí ojú pátákó. AKËKÕÖ: Tëtí sí àlàyé olùkö Kô àwôn ìsõrí õrõ tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé wôn OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Ìwé girama òde òní Ìwé èdè-ìperí Yorùbá Àwòrán àtç aröpò-orúkô àti afarajorúkô  
11.ÀŚÀ: Àwôn òrìśà ilê Yorùbá   ÀKÓÓNÚ IŚË Àwôn òrìśà ilê Yorùbá: ÔbàtáláÕrúnmìlàÒgún ÈśùŚàngóEgúngún OLÙKÖ: a. Śe àlàyé lórí àwôn òrìśà gëgë bí asojú Olódùmarè: b. Śàlàyé kíkún nípa: ìgbàgbö oríkì olùsìn àti abôrê ìsìn (ojoojúmö, õsõõśê, ôdôôdún) ohun èlò èèwõ ìmúra/ aśô abbl d. Kô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì sí ojú pátákó AKËKÕÖ: a. Tëtí sí àlàyé olùkö nípa àwôn òrìśà. b. Kô àwôn õrõ tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé d. kô ìparí àwôn òwe tí olùkö kô sí ojú pátákó sí inú ìwé wôn. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI:  a.  Àwòrán ojúbô àti abôrê  b. Àwôn ohun ètò fún ìsìn òrìśà b. a; aaja, kele Śàngó, ère òrìśà abbl
  12.  ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ     
  13.  ÌDÁNWÒ     

Federal Yoruba Language Scheme of Work for SS 1. Sílébù èdè Yorùbá –Schemeofwork

YORÙBÁ SS 1 TÁÀMÙ KËTA

ÕSÊORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚÀMÚŚE IŚË  
1ÀŚÀ: Oge Śíśe ní Ayé Àtijö àti Òde Òní   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Pàtàkì oge śíśe b. Oríśiríśi õnà tí a ń gbà śoge ní ayé àtijö. Ara fínfín Eyín pípa Tìróò lílé Làalì/ osùn kíkùn Irun dídì Ilà kíkô àti bëê bëê lô d. Irun fífá: irun gígê, irun dídì, irun kíkó e. Bàtà wíwõ lóríśiríśi ç. Ìyípadà tó dé bá àśà oge śíśe ní òde òní: Ètè kíkùn Irun díndín Ihò méjì lílu sí etí kan Imú lílu Aśô tó fara sílê Bàtà gogoro àti bëê bëê lôOLÙKÖ: a. Tö akëkõö sönà nípa ìdí tí àwôn Yorùbá fi ń śoge. b. Śe àfihàn ohun èlò oge śíśe d.  Tö akëkõö sönà láti dárúkô irúfë oge śíśe tí ó wà ní òde òní àti àléébù tí ó wà níbê fún ôkùnrin àti obìnrin. AKËKÕÖ: a. Sô ohun tí o ti śàkíyèsí nípa oge śíśe ní àwùjô àti ìdí pàtàkì tí àwôn ènìyàn fi ń śe oge. b. Sô irúfë oge śíśe tí wön mõ mö obìnrin śáájú ìdánilëkõö OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Ohun èlò gidi tìróò, bèbè ìdí, ìlêkê, làálì, osun, wíìgì, lëêdì, èékánnáÀwòrán oríśiríśi irun dídì, irun gígé àti bëê bëê lô.
2.ÈDÈ: Àròkô Ajçmö-Ìśípayá   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Kíkô àwôn ìlànà tí à ń gbà kô àròkô ajçmö-ìsípayá b. Ìlapa èrò àròkô ajçmö-ìsípayá  OLÙKÖ: a. Śe àpççrç ìlapa èrò àkôlé àròkô ajçmö-ìsípayá kan lójú pátákó ìkõwé b. Mú kí akëkõö śe ìlapa èrò àkôlé àròkô ajçmö-ìsípayá mìíràn d. Tö akëkõö sönà láti kô àròkô nípa lílo àwôn ìlapa tí ç śe ní kíláásì. e.  Yç iśë akëkõö wò.    AKËKÕÖ: a. Kíyèsí àpççrç ilapa èrò tí olùkö śe dáradára, sì dà á kô sínú ìwé rç b. Śe ìlapa èrò tìrç mìíràn d. Lo ìlapa méjèèjì tí ç śe ní kíláásì láti kô àròkô. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Pátákó ikõwé
3.ÌWÉ KÍKÀ: Àtúpalê Ìwé Eré-Onítàn   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Kókó õrõ: b. Àhunpõ ìtàn d. Ibùdó ìtàn e. Êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá ç. Ìlò èdè f. Ìjçyô àśà               g. Àmúyç àti àléébù  OLÙKÖ: a. Jë kí akëkõö ka ìwé eré-onítàn b. Śàlàyé ní kíkún lórí ìjçyô àkóónú iśë nínú ìwé eré-onítàn Kókó õrõÀhunpõ ìtàn AKËKÕÖ: a. Ka ìwé eré-onítàn wá láti ilé àti nínú kíláásì. b. Tëtí sí śàlàyé olùkö d. Kô àwôn õrõ tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Ìwé eré-onítàn
4.ÌSÕRÍ ÕRÕ: Õrõ-orúkô   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Oríkì õrõ-orúkô b. Oríśi õrõ-orúkô bí i: orúkô àdájë, orúkô àśeékà, orúkô aláìśeékà, orúkô afoyemõ àti bëê bëê lô.  OLÙKÖ: a. Kô àpççrç àwôn õrõ tí à ń pè ní õrõ-orúkô, õrõ-orúkô bí i ilé, igi, ojú, Ayõ. AKËKÕÖ: a. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí õrõ-orúkô     b. Kô àwôn àpççrç tí olùkö kô sókè d. Pe àwôn õrõ náà bí olùkö śe pè é.                                 OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Kô àwôn àpççrç ìsõrí õrõ sí ojú pátákó/ kádíböõdù
5.ÈDÈ: Ìhungbólóhùn nínú àpólà-orúkô, àpólà-ìśe, àpólà-atökùn   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Ìhun àpólà b. Iśë tí àpólà ń śe nínú gbólóhùn d. Àlàyé lórí oríśi àpólà tí ó wà: àpólà-orúkô, àpólà-ìśe, àpólà-atökùnOLÙKÖ: a. Àlàyé lórí oríśiríśi àpólà tí ó wà b. Fi iśë àpólà hàn nínú gbólóhùn d. Śe àfihàn àpólà àti awë-gbólóhùn AKËKÕÖ: a. Fi àpólà gbólóhùn wé awë-gbólóhùn láti lè mô ìyàtõ tó wà láàrin wôn b. Śe àpççrç àpólà oríśiríśi tí ó wà.  OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Pátákó ìkõwé Kádíböõdù tí ó ní àkôsílê àpólà õrõ-orúkô, àpólà atökùn, àpólà-ìśe.        
6.ÌSÕRÍ ÕRÕ: Õrõ-Ìśe   ÀKÓÓNÚ IŚË: Ìsõrí õrõ: õrõ-orúkô, õrõ-aröpò orúkô, õrõ-ìśe, õrõ-àpèjúwe, õrõ-atökùn, õrõ-asopõOLÙKÖ: Kô àpççrç àwôn õrõ tí ó wà lábë ìsõrí õrõ kõõkan. Bí àpççrç:   Õrõ-orúkô: ilé, igi, ojú, ayò, Akin, Adé. Õrõ-aröpò orúkô: mo, ó, a, mi, wa, wôn. AKËKÕÖ: Tëtí sí àlàyé olùkö lórí ìsõrí õrõ kõõkan Kô àwôn àpççrç tí olùkö kô sókè d.  pe àwôn õrõ náà bí olùkö śe pè é fún wôn   OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Pátákó ìkõwé                   Fídíò        Kádíböõdù
7.ÌSÕRÍ ÕRÕ: Õrõ-Aröpò Orúkô   ÀKÓÓNÚ IŚË Õrõ-aröpò orúkô Õrõ-orúkô afarajorúkô     OLÙKÖ: a. Kô àwôn õrõ aröpò orúkô sílê bí i: a, mo, ç, wôn, yin, ìwô àti bëê bëê lô. b. Kíkô õrõ aröpò orúkô afarajorúkô sílê, àwa, èmi, àwôn,êyin ati bëê bëê lô. d. Kô ipò tí a ti lè lo ìkõõkan àpççrç ipò çni kìn-ín-ín çyô tàbí õpõ.   AKËKÕÖ: a. Ka àwôn õrõ aröpò orúkô àti ti afarajorúkô sílê. b. Gbìyànjú láti mô ipò çnìkejì tàbí ìkëta çyô tàbí õpõ. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Pátákó ìkõwé Kádíböõdù
8.ÀWÔN ÊYÀ ARA FÚN ÌRÓ ÈDÈ PÍPÈ   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Kín ni àfipè? b. Oríśi àfipè tí ó wà d. Êyà ara àfipè àkànmölê àti àsúnsí e. Êyà ara àfipè tí a lè fi ojú rí àti èyí tí a kò lè fojú rí.  OLÙKÖ: a. Mënuba àwôn êyà ara tí ó wà. b. Sô ní sókí nípa êyà ara yòókù kí o sì śàlàyé lórí àwôn èyí tí à ń lò fún pípe ìró. d. Pín àwôn êyà ara tí a fi ń pe ìró náà sí ìsõrí wôn gëgë bí i; àfipè àsúnsí àti àfipè àkànmölê. e. Bákan náà ni olùkö yóò sô nípa àwôn àfipè tí a lè fojú rí àti èyí tí a kò lè fojú rí .                                                                                                                                                                                     AKËKÕÖ: a. Akëkõö yóò kô ohun tí olùkö kô sójú pátákó sílê  b. Yóò béèrè ìyàtõ tí ó wà nínú àfipè àsúnsí àti àkànmölê, àfipè tí a lè fi ojú rí àti èyí tí a kò le fojú rí. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Pátákó ìköwé Kádíböõdù  Àwòrán ènìyàn tí ó fi àwôn ibi ìpè ìró hàn.
9.ÌWÉ KÍKÀ                                            ÀKÓÓNÚ IŚË a. Śíśe àtúpalê ìwé eré-onítàn b. Wíwá àśà àti ìśe ilê Yorùbá jáde nínú ìwé náà. d. Śíśe àfihàn àwôn ìlò èdè àti çwà èdè inú ìwé náà.  OLÙKÖ: Olùkö yóò jë kí àwôn akëkõö ka ìwé eré-onítàn Sô díê nínú ìlò èdè àti çwà èdè tí ó súyô           AKËKÕÖ: a. Àwôn akëkõö yóò ní òye ohun tí ìtàn inú ìwé dálé. b. Wôn yóò lè dá çwà èdè mõ                          d. Wôn yóò sì lè töka sí àwôn àśà àti ìśe ilê Yorùbá.                 OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Pátákó ìkõwé                 Ìwé eré-onítàn tí a yàn             
10.ÊSÌN ÒDE ÒNÍ   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Oríśiríśi êsìn tí a ní nílê Yorùbá – êsìn àbáláyé b.Oríśiríśi êsìn òde òní bí i Kìrìsítíënì, Mùsùlùmí, Êkáńkà, Gúrúmàrajì, Búdà àti bëê bëê lô. d.  Õnà ìjösìn fún àwôn çlësìn.OLÙKÖ: a. Sísô nípa êsìn àbáláyé b. Àwôn òrìśà ilê Yorùbá àti bí a śe ń bô wön.  d. Àwôn oríśi êsìn tí a ní lóde òní.    AKËKÕÖ: a. Àdàkô ohun tí olùkö kô sójú pátákó. b. Mô àwôn õnà tí çlësìn kõõkan ń gbà jösìn.          d. Béèrè ìbéèrè lórí ohun tí a kö. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI: Pátákó ìkõwé       Àwòrán tí ó fi ìlànà êsìn kõõkan hàn.
  11.  ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ   
  12.  ÌDÁNWÒ 

Share this Article
Leave a comment