Yoruba Language Scheme of Work for JSS2 Federal

37 Min Read
yoruba language scheme of work
yoruba language scheme of work

Education Resource Centre Yoruba Language Scheme of work for JSS2 Federal. Yoruba JSS2. –Schemeofwork.com

YORÙBÁ JSS 2 TÁÀMÙ KÌN-ÍN-NÍ

ÕSÊORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚÀMÚŚE IŚË  
1.ÈDÈ: Sílébù Èdè Yorùbá   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Oríkì sílébù . 2. Ìhun sílébù (F, KF, Kos (N) 3. Pípín õrõ sí sílébù OLÙKÖ 1. Sô oríkì sílébù  2. Śe àlàyé ìhun sílébù 3. Sç õpõlôpõ àpççrç pínpín õrõ sí sílébù sójú pátákó AKËKÕÖ 1. Têtì sí àlàyé olùkö 2. Śe àpççrç pípín õrõ sí sílébù fúnra rê 3. Kô ohun tí olùkö kô saju pátákó sínú ìwé OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Pátákó ìkõwé.
2.ÀŚÀ: Êsìn Ìbílê Yorùbá   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Pàtàkì Êsìn Láwùjô Yorùbá 2. Ìgbàgbö Àti Èrò Àwôn Yorùbá Nípa Olódùmarè 3. Ipò Olódùmarè 4. Òrìśà Ilê Yorùbá 5. Êsìn òde òní: * Mùsùlùmí * Ômôlëyìn Jésù  OLÙKÖ 1. Śe àlàyé ipa ti êsìn ń kó láwùjô 2. Śe àlàyé ipò Olódùmarè nínú êsìn 3. Śàlàyé nípa àwôn òrìśà ilê Yorùbá àti bí a ti ń sìn wön. 4. Śe àlàyé àjôśe àárin àwôn çlësìn ìbílê, Mùsùlùmí àti Ômôlëyìn Jésú
AKËKÕÖ 1. Sô ohun ti wön mõ nípa êsìn ìbílê Yorùbá àti êsìn ìgbàlódé 2. Jíròrò nípa àjôśe Olódùmarè, àwôn òrìśà àti olùsìn wôn. 3. Jíròrò lórí ìjà êsìn àti bí a śe lè dékun rê.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Àwòrán àwôn çlësìn oríśìí mëtêêtà níbi ìsìn. 2. Fídíò 3. Sinimá
3.LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn Ìwé Ìtàn Àròsô Ôlörõ Geere   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Ìsônísókí ìśêlê inú ìtàn abáyému 2. Êkö àti kókó õrõ tó súyô àti ìbáyému õrõ tó ń lô láwùjô, (bí àpççrç ipò/ ìpín obìnrin láwùjô, ìkôlura êsìn, ômôlúàbí, ìtöjú àyíká, ìlera, ààrùn éèdì/ rômôlöwölësê abbl) 3. Êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá 4. Ìlò èdè: (a) Ônà èdè – Àfiwé – òwe – Àkànlò èdè (b) Àwítúnwí – Ìfìrómõrísí – ìfohungbohùn abbl  OLÙKÖ 1. Śe ìfáàrà lórí òýkõwé àti ohun tí ìtàn náà dálé. 2. darí akëkõö láti tún ìtàn sô 3. Śe àlàyé lórí àwôn kókó-õrõ tó súyô àti ìbáyému wôn 4. Śe àlàyé nípa àwôn êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá wôn 5. darí ìjíròrò nípa ìlò èdè nínú ìtàn náà.
AKËKÕÖ 1. Ka ìwé náà 2.  tún ìtàn náà sô ní sókí 3. jíròrò lórí kókó-õrõ inú ìwé náà àti ìbáyému wôn 4. Tëtí sí àlàyé olùkö nípa êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá wôn. 5. Kópa nínú ìjíròrò lórí ìlò èdè.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Ìwé tí a yàn fún kíkà. 2. Àwòrán díê lára ìśêlê tó köni lëkõö nínú ìwé náà.
4.ÒÝKÀ: Oókanléláàádöjô dé igba (151 – 200). Kíka owó Náírà   ÀKÓÓNÚ IŚË Òýkà láti Oókanléláàádöjô dé igba (151-200). Òýkà owó náírà b.a. náírà kan, náírà méjì, ogún náírà, ôgbõ náírà abbl.OLÙKÖ 1. Tö àwôn akëkõö sönà láti ka òýkà – Oókanléláàádöjô dé igba (151 – 200). 2. Śe àlàyé ìgbésê òýkà ní kíkún. 3. Tö akëkõö sönà láti ka owó náírà pêlú òýkà Yorùbá. AKËKÕÖ  1. Ka òýkà láti Oókanléláàádöjô dé igba (151 – 200). 2. Dá òýkà tí a kô sójú pátákó mõ  ní õkõõkan 3. Dá owó náírà mõ àti bí a śe ń pè wön ní ìlànà òýkà Yorùbá 4. Kô òýkà tí olùkö kô sójú pátákó sínú ìwé. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Kádíböõdù tí a kô òýkà láti Oókanléláàádöjô dé igba (151 – 200). 2. Káàdì pélébé pélébé tí a kô òýkà kõõkan sí. 3. Owó náírà lóríśiríśi.
5.ÈDÈ: Oríśiríśi Gbólóhùn (Ìhun)   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Oríkì Gbólóhùn 2. Oríśiríśi Gbólóhùn * Alábödé * Alákànpõ * OníbõOLÙKÖ 1. Fún gbólóhùn ní oríkì 2. Śe àlàyé ìhun õkõõkan àwôn oríśi gbólóhùn mëtêêta 3. Śe àpççrç õkõõkan irú àwôn gbólóhùn náà, kô wön sára pátákó, kí o sì kà wön fún akëkõö. 4. Darí akëkõö láti śe àwôn àpççrç mìíràn yàtõ sí èyí tí olùkö śe. AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö nípa oríkì gbólóhùn àti ìhun õkõõkan àwôn oríśi gbólóhùn mëtêêta náà. 2. Da àwôn àpççrç tí olùkö kô sára pátákó kô sínú ìwé rç. 3. Pe àwôn gbólóhùn náà têlé olùkö 4. Śe àwôn àpççrç mìíràn yàtõ sí èyí tí olùkö śe. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Kádíböõdù tí a kô àpççrç gbólóhùn alábödé, oníbõ àti alákànpõ sí.
6.ÈDÈ: Àmì Ohùn   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Oríkì àmì ohùn 2. Àlàyé lórí oríśi ohùn Yorùbá mëtêêta àti àmì wôn i. Ohùn àárin – (a kì í fi í hàn lórí õrõ) ii. Ohùn ìsàlê – iii. Ohùn òkè –     3. Fáwëlì àti oríśiríśi àmì ohùn kõõkan lórí fáwëlì kõõkan. Bí àpççrç: à, a, á, è, e, é, abbl 4. Àmì ohùn lórí õrõ onísílébù kan. B.a: bá, dà, kan abbl.OLÙKÖ 1. Fún àmì ohùn ní oríkì 2. Śe àlàyé oríśi àmì ohùn mëtêêta 3. Kô àwôn fáwëlì pêlú ohùn orí wôn 4. Kô õrõ onísílébù kan àti ôlöpõ sílébù sára pátákó 5. pè wön fún akëkõö. AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí oríkì àmì ohùn àti àwôn àmì mëtêêta. 2. Śe àdàkô fáwëlì àti àwôn õrõ tí olùkö kô. 3. Pe àwôn fáwëlì àti õrõ náà bí olùkö śe pè wön. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Kádíböõdù tí ó ń śe àfihàn àwôn àmì ohùn lórí fáwëlì, õrõ onísílébù kan àti ôlöpõ sílébù.
7.ÀŚÀ: Ìranra-çni-löwö   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Èsúsú 2. Àjô 3. Õwê 4. Àáró 5. Àrokodóko 6. Çgbë aláfôwösowöpõ òde òní.OLÙKÖ 1. Śe àlàyé oríśiríśi àśà ìranra-çni-löwö àti àýfààní wôn 2. Śe àlàyé ipò àśà ìranra-çni-löwö nínú iśë àjùmõśe àti ôrõ-ajé 3. Darí akëkõö láti jíròrò lórí çgbë aláfôwösowöpõ. 4. Kó akëkõö lô sô ìdí çbu níbi tí wön ti ń jô fôwö-so-wöpõ śiśë AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àwôn àlàyé olùkö, sì śe àkôsílê kókó-õrõ bí ó ti yç. 2. Śe ìbéèrè lórí ohun tí kò bá yé e. 3. Kópa nínú ìjíròrò tí olùkö darí lórí çgbë aláfôwösowöpõ lóde òní 4. Têlé olùkö lô sí çbu láti lô wo àwôn òśìśë bí wön śe ń śiśë. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Fídíò 2. Fíìmù 3. Àwòrán
8.LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn ìwé eré-onítàn   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Ibùdó ìtàn 2. Àhunpõ ìtàn 3. Àśà tó súyô 4. Kókó-õrõ 5. Ìfìwàwêdá 6. Ìlò èdè   OLÙKÖ 1. Darí akëkõö láti ka eré-onítàn náà. 2. Śe ìfáàrà lórí òýkõwé àti ohun tí eré náà dá lé. 3. Fa àwôn kókó õrõ yô 4. Jíròrò lórí êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá wôn 5. Śe àfiwé ìśêlê inú ìtàn pêlú õrõ tó ń lô láwùjô. 6. Śe àlàyé lórí ìlò èdè 7. Darí ìśeré ní kíláásì, ìbá à jë ìran kan àbí méjì AKËKÕÖ 1. Ka eré-onítàn náà. 2. Ìjíròrò lórí ìśêlê tí wön ti gbö rí/ kà rí, tí ó fi ara pë èyí tí wön kà. 3. Fa êkö tí wön rí kö yô. 4. Töka sí oríśiríśi ìlò èdè 5. Jíròrò lórí àwôn êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá wôn 6. Kópa nínú ìśeré tí olùkö darí ní kíláásì. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Ìwé ìròyìn  2. ìwé ìròyìn tí ìśêlê tó fara pë ti inú ìwé ti wáyé. 3. fíìmù tó bá eré mu (tí ó bá wà) 4. Aśô eré 5. Ohun èlò ìśeré
9.ÀŚÀ: Òýkà ôjö àti ośù ní ilê Yorùbá   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Òýkà àwôn ôjö tí ó wà nínú õsê. Ìtàn tí ó rõ mö ôn. Ôjö Ajé, Ìśëgun, Ôjörú, Ôjöbõ, Çtì, Àbámëta. 2. Àwôn ośù tí ó wà nínú ôdún: Śërë, Èrèlé, Erénà, Igbe, Èbìbí, Okúdù, Agçmô, Ògun, Ôwëwê, Õwàrà, Belu, Õpç.OLÙKÖ 1. Śe àlàyé iye ôjö tí ó wà nínú õsê fún akëkõö 2. Kö akëkõö láti kô orin tí ó rõmö àwôn ôjö tó wà nínú õsê 3. Śe àlàyé iye ośù tí ó wà nínú ôdún fún akëkõö. 4. Darí akëkõö láti kô orin tí ó rõmö àwôn ośù tó wà nínú ôdún. AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àwôn àlàyé olùkö nípa iye ôjö tí ó wà nínú õsê àti iye ośù tí ó wà nínú ôdún. 2. Kópa nínú orin tí olùkö darí ní kíláásì. 3. Śe àkôsílê ohun tí olùkö kô sójú pátákó sí inú ìwé. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Kádíböõdù tí a kô àwôn ôjö tí ó wà nínú õsê àti ośù tí ó wà nínú ôdún sí. 2. Káàdì pélébé pélébé tí a kô àwôn ôjö àti ośù sí
10.ÈDÈ: Aáyan Ògbufõ   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Oríkì aáyan ògbufõ 2. Ìtönisönà lórí bí a śe ń śe aáyan ògbufõ 3. Śíśe aáyan ògbufõ çlëyô õrõ láti èdè Gêësì sí Yorùbá 4. Túmõ gbólóhùn kéèkèèké láti èdè Gêësì sí Yorùbá.  OLÙKÖ 1. Fún aáyan ògbufõ ní oríkì. 2. Śe àlàyé bí a śe ń śe aáyan ògbufõ. 3. Śe aáyan ògbufõ çlëyô õrõ láti èdè Gêësì sí Yorùbá. 4. Túmõ gbólóhùn kéèkèèké láti èdè Gêësì sí Yorùbá AKËKÕÖ 1. Tëtí sí bí olùkö śe ń túmõ àwôn çyô õrõ àti gbólóhùn 2. Kô àwôn çyô õrõ àti àwôn gbólóhùn tí olùkö kô sí ojú pátákó sí inú ìwé wôn. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Pátákó ìkõwé Śíśe àmúlò àwôn ohun èlò tó wà nítòsí bí i owó, àga, omi, pátákó ìkõwé, síbí, abbl
11.ÀŚÀ: Oúnjç Ilê Yorùbá   ÀKÓÓNÚ IŚË Oríkì oúnjç Oríśiríśi oúnjç Bí a śe ń śe oúnjç kõõkan. ìsõrí ìsõrí oúnjç afáralókun àti amáradán Àfiwé oúnjç àtijö àti ti òde òní.OLÙKÖ 1. Sô oríkì oúnjç 2. Sô oríśiríśi oúnjç 3. Śe àlàyé bí a śe ń śe oúnjç kõõkan 4. Kô àwôn oúnjç tí ó bö sí ìsõrí kan náà sójú pátákó 5. Sõrõ lórí àýfààní oúnjç láti oko àti ewu oúnjç inú agolo AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö. 2. Sô èrò tiwôn lórí oúnjç 3. Kô ohun tí olùkö kô sójú pátákó sínú ìwé. 4. Ya àtç tí olùkö yà sójú pátákó. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Oríśiríśi oúnjç tútù Àwòrán Ohun èlò ìśeunjç: ìkòkò, epo, iyõ, irú, ewébê, sítóòfù àdògán abbl
12.ÈDÈ: Gbólóhùn   ÀKÓÓNÚ IŚË Ìbéèrè Àlàyé ÀśçOLÙKÖ 1. Śe àlàyé ìhun õkõõkan àwôn oríśi gbólóhùn mëtêêta náà. 2. Da àwôn àpççrç tí olùkö kô sójú pátákó kô sínú ìwé rç 3. Pe àwôn gbólóhùn náà têlé olùkö 4. Śe àwôn àpççrç mìíràn yàtõ sí àwôn èyí tí olùkö ti śe OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Kádíböõdù tí a kô àpççrç gbólóhùn ìbéèrè, àlàyé àti àśç sí.
  13.  ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ   
  14.  ÌDÁNWÒ     

Education Resource Centre Yoruba Language Scheme of work for JSS2 Federal –Schemeofwork.com

YORÙBÁ JSS 2 TÁÀMÙ KEJÌ

ÕSÊORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚÀMÚŚE IŚË  
1.LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn ìwé (Ewì Àpilêkô)   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Àwôn ewì tó wà nínú ìwé tí a yàn 2. Kókó õrõ b.a. ìwà ènìyàn; àwôn êdá mìíràn tí kì í śe ènìyàn, õrõ tó ń lô láwùjô,, ìkôlura êsìn, ipò obìnrin, ètò ôrõ-ajé, ìśakô/ ìśabo – gbogbolômô, éèdì. Àkíyèsí: Ó pôn dandan láti yan ìwé ewì tí ó ní àwôn àkóónú kókó õrõ wõnyí 3. Ônà èdè àti ìsôwölo-èdè.OLÙKÖ 1. Ka ewì sí etígbõö àwôn akëkõö 2. Śe àlàyé lórí ewì tí a kà 3. Kô àwôn kókó õrõ jáde 4. Śe àlàyé ní kíkún lórí; * ônà èdè àti ìsôwölo-èdè. * kókó õrõ * Êkö tó köni * Darí ìjíròrò nípa àwôn kókó inú êkö yìí ni kíláásì AKËKÕÖ 1. ka ewì tí olùkö kà fúnra rç 2. kô àwôn kókó tí olùkö kô sójú pátákó sínú ìwé 3. kópa nínú ìjíròrò tí olùkö śe nínú kíláásì. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Ìwé tí a yàn 2. Àwòrán àwôn ohun tí ewì dá lé lórí.
2.ÀŚÀ: Ogun àti Àlàáfíà   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. kí ni ogun? Kí sì ni ìdí tí ó fi máa ń wáyé? 2. Ogun Yorùbá láyé àtijö – orúkô ogun b.a. jálumi, kírìjí abbl – Àwôn jagunjagun b.a. Ìbíkúnlé, Ògúnmölá, Ògèdèýgbé abbl – Ohun èlò ogun b. a. ôfà, ôkõ, idà, ìbôn, oògùn. 3. Àýfààní ogun jíjà; õnà ìdáàbòbo ìlú çni, láti kó ìlú çni lërú, abbl 4. Àléébù ogun nípa ôsë tó ń śe – Dá õtá sílê – Run ìlú – Fa ìyàn, abbl 5. Õnà láti dëkun ogun jíjà. – Yíyàgò fún aáwõ.OLÙKÖ 1. Śe àlàyé ohun tí ogun jë àti ìdí tí ó fi máa ń wáyé 2. Śe àlàyé nípa oríśiríśi ogun Yorùbá 3. Śe àlàyé àýfààní tí ó wà nínú ogun jíjà. (jë kí akëkõö mõ pé èyí mô níba. Àwôn ènìyàn péréte sì ni ó máa ń sábà kàn). 4. Śe àlàyé àléébù tí ó wà nínú ogun (jë kí akëkõö mõ pé èyí máa ń kan ènìyàn púpõ ju ti àýfààní rê lô). 5. Śe àlàyé pé kò sí ìfõkànbalê àti ìdàgbàsókè ní àkókò ogun. AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àwôn àlàyé olùkö 2. śe àkôsílê sínú ìwé rç bí ó ti yç. 3. Wo àwòrán fíìmù, fídíò abbl tí olùkö fihàn 4. kópa nínú ìjíròrò tí olùkö darí OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Téèpù 2. kásëêtì 3. Fídíò 4. fíìmù 5. Àwòrán 6. Tçlifísàn
3.ÈDÈ: Àtúnyêwò Ìsõrí Õrõ – Õrõ-Orúkô àti Õrõ-Ìśe   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Àlàyé lórí õrõ-orúkô 2. Iśë tí õrõ-orúkô ń śe nínú gbólóhùn 3. Àlàyé lórí oríśiríśi õrõ-orúkô 4. Àlàyé lórí õrõ-ìśe 5. Iśë tí õrõ-ìśe ń śe nínú gbólóhùn.OLÙKÖ 1. Śe àlàyé lórí õrõ-orúkô 2. Śe àlàyé iśë tí õrõ-orúkô ń śe nínú gbólóhùn. B.a olùwà, àbõ àti êyán. 3. Dárúkô oríśiríśi õrõ-orúkô pêlú àpççrç wôn. B.a, orúkô ènìyàn, çranko, aśeékà, çlëmìí abbl. 4. Śe àlàyé lórí õrõ-ìśe 5. Śe àlàyé iśë tí õrõ-ìśe ń śe nínú gbólóhùn. (jë kí akëkõö mõ pé òun ni òpómúléró àti kókó gbólóhùn) AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí ìsõrí õrõ-orúkô àti õrõ-ìśe. 2. Kô àwôn àpççrç tí olùkö śe sínú ìwé. 3. Śe àwôn àpççrç tìrç lábë ìdarí olùkö. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. kádíböõdù  2. káàdì pélébé pélébé.
4.ÀŚÀ: Òýkà- Õtàlénígba-ó-dín mësàn-án dé õödúnrún   ÀKÓÓNÚ IŚË Òýkà láti Õtàlénígba-ó-dín mësàn-án dé õödúnrún (251 – 300). Kíkà 260 = Õtàlénígba 280 = Õrìnlénígba 300 = ÕödúnrúnOLÙKÖ 1. Tö akëkõö sönà láti ka òýkà láti Õtàlénígba-ó-dín mësàn-án dé õödúnrún (251-300) 2. Śe àlàyé ìgbésê òýkà ní kíkún. AKËKÕÖ 1. ka òýkà láti Õtàlénígba-ó-dín mësàn-án dé õödúnrún (251 – 300) 2. Dá òýkà tí a kô sójú pátákó mõ ní õkõõkan. 3. kô òýkà tí olùkö kô sójú pátákó sínú ìwé. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. kádíböõdù tí a kô òýkà láti Õtàlénígba-ó-dín mësàn-án dé õödúnrún (251 – 300) sí. 2. káàdì pélébé pélébé tí a kô òýkà kõõkan sí.
5.ÈDÈ: Fónëtíìkì – Àpèjúwe ìró Köńsónáýtì    ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Köńsónáýtì: b, d, f, g, gb, h, j, k, l, abbl 2. Àpèjúwe ìró köńsónáýtì – ibi ìsçnupè – õnà ìsçnupè Ipò tán-án-náOLÙKÖ 1. Kô köńsónáýtì Yorùbá lápapõ sójú pátákó fún akëkõö 2. Śe àpèjúwe ìró köńsónáýtì fún akëkõö lórí àtç köńsónáýtì  – ibi ìsçnupè b.a. Àfèjì-ètèpè, Àfàfàsépè, àfèrìgìpè abbl – õnà ìsçnupè b.a. àréhön, àfúnnupè, àśenupè abbl – ipò tán-án-ná b.a akùnyùn tàbí àìkùnyùn AKËKÕÖ 1. fetí sí bí olùkö śe pe àwôn ìró köńsónáýtì náà 2. pe àwôn ìró köńsónáýtì náà bí olùkö śe pè wön. 3. Ya àtç ìró köńsónáýtì tí olùkö fi śe àpèjúwe ibi ìsçnupè, õnà ìsçnupè àti ipò tán-án-na 4. Śe àdàkô àwôn ohun tí olùkö kô sójú pátákó sínú ìwé  OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Kádíböõdù tí ó śe àfihàn àwòrán êyà ara ifõ 2. Káàdì pélébé pélébé tí a kô àwôn lëtà sí.
6.ÀŚÀ: Ogun àti Àlàáfíà   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Àýfààní ogun jíjà; õnà ìdáàbò bo ìlú çni, láti kó ni lërú abbl 2. Àléébù ogun nípa ôśë tí ó ń śe – Dá õtá sílê – Run ìlú – Fa ìyàn abbl 3. Õnà láti dëkun ogun jíjà – Yíyàgò fún aáwõ.OLÙKÖ 1. Śe àlàyé àýfààní tí ó wà nínú ogun jíjà. (jë kí akëkõö mõ pé èyí mô níba. Àwôn ènìyàn péréte sì ni ó máa ń sábà kàn). 2. Śe àlàyé àléébù tí ó wà nínú ogun (jë kí akëkõö mõ pé èyí máa ń kan ènìyàn púpõ ju ti àýfààní rê lô). 3. Śe àlàyé pé kò sí ìfõkànbalê àti ìdàgbàsókè ní àkókò ogun. AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àwôn àlàyé olùkö 2. śe àkôsílê sínú ìwé rç bí ó ti yç. 3. Wo àwòrán fíìmù, fídíò abbl tí olùkö fihàn 4. kópa nínú ìjíròrò tí olùkö darí OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Téèpù 2. kásëêtì 3. Fídíò 4. fíìmù 5. Àwòrán 6. Tçlifísàn
7.ÈDÈ: Òwe   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Oríkì òwe 2. Oríśiríśi òwe 3. ìlò òwe 4. Ìwúlò òweOLÙKÖ 1. Sô ìtumõ owe 2. jë kí akëkõö pa oríśiríśi òwe. B.a. ìbáwí, ìkìlõ, ìmõràn abbl 3. Kô ìbêrê àwôn òwe kan sójú pátákó ìkõwé fún àwôn akëkõö láti parí wôn 4. Śe àlàyé ìwúlò òwe fún akëkõö; b.a òwe ń jë kí èdè Yorùbá dùnún gbé kalê, ó wúlò fún láti sõrõ àśírí abbl. AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö 2. Pa oríśiríśi òwe gëgë b olùkö śe darí 3. kô ìparí àwôn òwe tí olùkö kô sí ojú pátákó sí inú ìwé wôn. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Ìwé owe 2. pátákó ìkõwé
8.ÈDÈ: Àtúnyêwò ìsõrí õrõ-ìśe   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Iśë tí õrõ-ìśe ń śe nínú gbólóhùn * õrõ- ìśe çlëlà * õrõ-ìśe aláìlëlà * õrõ-ìśe agbàbõ * õrõ-ìśe aláìgbàbõ * õrõ-ìśe alápèpadà * õrõ-ìśe aśèbéèrè, abblOLÙKÖ 1. śe àlàyé iśë tí õrõ-ìśe ń śe nínú gbólóhùn fún àwôn akëkõö b.a. òun ni kókó inú gbolohun. 2. Śe àkôsílê oríśiríśi õrõ-iśë pêlú àpççrç fún õkõõkan wôn. Bí àpççrç; Õrõ-ìśe alápèpadà – Ç rò mi ro ire AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí iśë tí õrõ-ìśe ń śe àti àwôn oríśiríśi õrõ-ìśe tí ó wà. 2. kô àwôn àpççrç tí olùkö śe sínú ìwé 3. śe àwôn àpççrç tìrç lábë ìdarí olùkö.   OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Kádíböõdù 2. Káàdì pélébé pélébé
9.ÈDÈ: Fónëtíìkì – Àpèjúwe Ìró Fáwëlì   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Fáwëlì: * Àránmúpè – an, çn, in, un, ôn * Àìránmúpè – a, e, ç, i, o , ô, u 2. Àpèjúwe ìró fáwëlì * ipò ahön * ipò ètè * ipò àfàséOLÙKÖ 1. kô fáwëlì Yorùbá lápapõ sójú pátákó fún akëkõö 2. śe àpèjúwe ìró fáwëlì fún àwôn akëkõö lórí àtç ìró fáwëlì. Bí àpççrç: – ipò ahön: iwájú ahön, àárin ahön àti êyìn ahön – ipò ètè: pçrçsç tàbí roboto – ipò àfàsé: Àránmúpè àti Àìránmúpè AKËKÕÖ 1. Fetí sí bí olùkö śe pe àwôn ìró fáwëlì náà. 2. pe àwôn ìró fáwëlì náà bí olùkö śe pè wön. 3. Ya àtç ìró fáwëlì tí olùkö fi śe àpèjúwe ìró fáwëlì àìránmúpè àti àránmúpè 4. śe àdàkô àwôn ohun tí olùkö kô sójú pátákó sínú ìwé. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. kádíböõdù tí ó śe àfihàn àtç ìró fáwëlì àránmúpè àti àìránmúpè 2. káàdì pélébé pélébé tí a kô àwôn lëtà sí.
10.ÀŚÀ: Ìpolówó Ôjà   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Ìdí tí a fi ń polówó ôjà 2. Bí a śe ń polówó ôjà: b. a. êkô tútù, ç ç jçran êkô. 3. Ôgbön ìpolówó ôjà ní ayé àtijö àti òde òní. B.a. ìpolówó ôjà lórí rédíò, tçlifísàn, ìwé ìròyìn, ìpàtç, ìkiri abbl.OLÙKÖ 1. Tç ìpolówó ôjà tí a ti tê sórí téèpù fún àwôn akëkõö gbö. 2. fún àwôn akëkõö ní àýfààní láti śe ìpolówó ôjà ní kíláásì. 3. kó akëkõö lô śe àbêwò sí ôjà tàbí ìdíkõ. AKËKÕÖ 1. Tëtí sí téèpù tí olùkö tê 2. kópa nínú śíśe ìpolówó ôjà nínú kíláásì. 3. śe àbêwò sí ôjà tàbí ìdíkõ láti gbö oríśiríśi ìpolówó ôjà. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Àtç 2. Fídíò 3. Rédíò 4. Êrô agbõrõ sílê 5. Téèpù 6. Ìpolówó ôjà lóríśiríśi nínú ìwé ìròyìn abbl.
  11.  ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ   
  12.      ÌDÁNWÒ 

YORÙBÁ JSS 2 TÁÀMÙ KËTA

ÕSÊORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚÀMÚŚE IŚË  
1.ÀŚÀ: Ìsômôlórúkô   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Ìgbàgbö Yorùbá nípa bí orúkô śe śe pàtàkì tó (orúkô ômô ni ìjánu ômô, orúkô a máa ro ômô) orúkô rere. 2. Ètò ìsômôlórúkô b.a lílo ìrèké, oyin, àádùn, abbl (àwôn ohun èlò ìsômôlórúkô).OLÙKÖ 1. Śe àlàyé ìgbàgbö Yorùbá nípa pàtàkì orúkô. 2. Dárúkô àwôn ohun-èlò ìsômôlórúkô bí i àádùn, orógbó, ataare, oyin abbl fún àwôn àfihàn swo èyí tí ó bá wà ní àröwötó. 3. Dari àwôn akëkõö láti śe eré ìsômôlórúkô nínú kíláásì AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö nípa pàtàkì orúkô àti ètò ìsômôlórúkô, sì śe àkôsílê kókó kókó õrõ bí ó ti yç. 2. Sô ohun tí wön mõ nípa ìsômôlórúkô sáájú ìdánilëkõö 3. Dárúkô àwôn ohun-èlò ìsômôlórúkô pêlú dídá õkõõkan wôn mõ 4. Śe eré ìsômôlórúkô OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Ohun èlò ìsômôlórúkô; oyin, ataare, orógbó,obì, çja, omi, ìrèké 2. Àwòrán ohun èlò ìsômôlórúkô 3. Fídíò ètò ìsômôlórúkô.
2.ÈDÈ: ìsõrí õrõ Õrõ aröpò orúkô àti õrõ aröpò afarajorúkô.   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Oríkì õrõ aröpò-orúkô 2. Àbùdá õrõ aröpò-orúkô 3. Àlàyé lórí õrõ aröpò-afarajorúkô àti wúnrên rê.OLÙKÖ 1. Fún õrõ aröpò-orúkô ní oríkì. Õrõ aröpò-orúkô ni àwôn õrõ tí a lò dípò õrõ-orúkô nínú gbólóhùn. 2.Śe àlàyé  àbùdá õrõ aröpò-orúkô fún akëkõö. Bí i, ó máa ń töka sí iye (çyô àti õpõ), ó töka sí ipò (çnìkínní, kejì, këta). B.a. Mo jç êbà: çnìkínní çyô 3. Śe àlàyé lórí õrõ aröpò-afarajorúkô àti àwôn wúnrên rê fún akëkõö. (jë kí akëkõö mõ pé ó ń töka sí iye àti ipò). Wúnrên tàbí õrõ atoka rê ni; Èmi, ìwô, êyin, òun àti àwôn. AKËKÕÖ 1. Śe àdàkô àwôn gbólóhùn tí olùkö kô sójú pátákó sí inú ìwé wôn. 2. Tëtí sí àlàyé olùkö. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Kádíböõdù tí a kô àpççrç gbólóhùn tí a ti lo õrõ aröpò-orúkô àti õrõ aröpò-afarajorúkô sí. 2. Àwòrán àtç õrõ aröpò-orúkô àti õrõ aröpò-afarajorúkô.
3.ÒÝKÀ: Õödúnrún dé Êëdëgbêta (300 – 500)   ÀKÓÓNÚ IŚË Òýkà láti Õödúnrún dé Êëdëgbêta (300– 500) 320 = Okòólélöõödúnrún 400 = Irínwó 460 = Õtàlénírínwó, abblOLÙKÖ 1. Tö akëkõö sönà láti ka òýkà Õödúnrún dé Êëdëgbêta (300 – 500). 2. Śe àlàyé ìgbésê òýkà ní kíkún. AKËKÕÖ 1. Ka òýkà láti Õödúnrún dé Êëdëgbêta (300 – 500) 2. Dá òýkà tí a kô sójú pátákó mõ ní õkõõkan. 3. kô òýkà tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Kádíböõdù tí a kô òýkà Õödúnrún dé Êëdëgbêta (300 – 500) sí. 2. Káàdì pélébé pélébé tí a kô òýkà kõõkan sí.
4.ÀŚÀ: Ìsômôlórúkô   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Ètò ìsômôlórúkô, bí a śe ń lo àwôn ohun èlò ìsômôlórúkô bí i obì, orógbó, ataare, oyín, ìrèké abbl fún ìwúre 2. Oríśiríśi orúkô * Àbísô * Àmútõrunwá * Oríkì * Àbíkú * Ìnágijç, abbl.OLÙKÖ 1. śe àlàyé ètò ìsômôlórúkô fún àwôn akëkõö 2. kô oríśiríśi orúkô sí ojú pátákó 3. Darí akëkõö láti śe eré ìsômôlórúkô nínú kíláásì AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö nípa ètò ìsômôlórúkô àti bí a śe ń lo õkõõkan àwôn ohun èlò ìsômôlórúkô fún ìwúre, kí ó sì kô àwôn kókó kókó õrõ b ó ti yç 2. śe àwòkô orúkô tí ó wà lójú pátákó 3. śe eré ìsômôlórúkô OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Ohun èlò ìsômôlórúkô bí i obì, orógbó, ataare, oyín, ìrèké, àádùn 2. Kádíböõdù tí a to orúkô ômô àti ìtöjú wôn sí. 3. Fídíò ètò ìsômôlórúkô.
5.ÈDÈ: Aáyan Ògbufõ (ôlörõ geere àti ewì)   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Títúmõ àyôlò ôlörõ geere kéèkèèké ní èdè Gêësì sí èdè Yorùbá 2. Títúmõ àyôlò ôlörõ geere ní èdè Yorùbá sí èdè Gêësì. 3. Títúmõ ewì ní èdè Gêësì sí èdè Yorùbá.OLÙKÖ 1. Tö akëkõö sönà láti túmõ àyôlò ôlörõ geere kéèkèèké ní èdè Gêësì sí èdè Yorùbá. 2. Tö akëkõö sönà láti túmõ àyôlò ôlörõ geere kéèkèèké ní èdè Yorùbá sí èdè Gêësì. 3. Tö akëkõö sönà láti túmõ ewì kúkurú ní èdè Gêësì sí èdè Yorùbá. AKËKÕÖ 1. Túmõ àyôlò ôlörõ geere kéèkèèké ní èdè Gêësì sí èdè Yorùbá. 2. Túmõ àyôlò ôlörõ geere kéèkèèké ní èdè Yorùbá sí èdè Gêësì. 3. Túmõ ewì kúkurú ní èdè Gêësì sí èdè Yorùbá. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Ìwé àyôkà ôlörõ geere ní èdè Gêësì sí èdè Yorùbá. 2. Ìwé àpilêkô ní èdè Gêësì àti Yorùbá 3. Pátákó ìkõwé 4. Ìwé atúmõ èdè

6.LÍTÍRÈŚÕ: Lítírèśõ Alohùn   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. õgangan ipò: – ìtumõ – Àbùdá rê Akópa (òśèré/ olùgbö) Àkókò ìśeré Ibi ìśeré Ìwúlò Ohun èlò – orin Ìśêlê Ìfarafojúsõrõ 2. Õrõ-ìśe tí a fi gbé wôn jáde bí i pípè, sísun, kíkô, dídá, mímu abbl. OLÙKÖ 1. Śe àlàyé pé akëkõö nílò láti ní ìmõ nípa àwôn àbùdá õgangan ipò lítírèśõ alohùn kan bí àgbéyêwò rê tó kún. 2. Śe àlàyé nípa àbùdá õgangan ipò lítírèśõ alohùn díê bí àpççrç (ìjálá, çkún ìyàwó, àlö onítàn). 3. Śe àlàyé õrõ-ìśe tí wön fi máa ń gbé àwôn ewì alohùn kan jáde. Bí àpççrç; Ìjálá – sísun, Ègè – dídá, orin – kíkô abbl AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö 2. Śe àkôsílê kókó inú àlàyé náà 3. Béèrè ohun tí ó ná rú ô lójú 4. Śe àpççrç àbùdá õganganipo lítírèśõ alohùn mìíràn yàtõ sí èyí tí olùkö śe. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Fíìmù 2. Rédíò 3. Téèpù 4. Kásëêtì 5. Ìwé lítírèśõ alohùn àdàkô.

7.ÈDÈ: Ìsõrí – Õrõ Õrõ-Atökùn àti õrõ-àsopõ   ÀKÓÓNÚ IŚË Õrõ-Atökùn Õrõ – àsopõ Àwôn wúnrên õrõ-àsopõOLÙKÖ
1. Śe àlàyé õrõ-atökùn àti àwôn wúnrên rê fún akëkõö bí àpççrç; si, ni abbl
2. Sô ìtumõ õrõ-àsopõ fún akëkõö
3. Dárúkô àwôn wúnrên õrõ-àsopõ bí i; pêlú, òun, śùgbön, àyàfi abbl fún akëkõö.
4. Śe àlàyé bí a śe lè dá ìsõrí õrõ kõõkan mõ nínú gbólóhùn. AKËKÕÖ
1. Tëtí sí àlàyé olùkö.
2. Kô àwôn ìsõrí õrõ tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé wôn.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1. Ìwé gírámà òde-oni
2. Ìwé Èdè-Ìperí Yorùbá 3. Kádíböõdù tí a kô àpççrç àwôn wúnrên õrõ-àsopõ àti õrõ-atökùn sí

8.9.
ÌBÁŚEPÕ LÁÀRIN ÈDÈ ÀTI ÀŚÀ
 
ÀKÓÓNÚ IŚË
Ìwúlò èdè
Èdè gëgë bí òpómúléró àśà
OLÙKÖ
1. Śe àlàyé ìwúlò èdè fún akëkõö (jë kí akëkõö mõ pé mö-yà-mí ni èdè àti àśà jë fún àwùjô àti pé bí kò sí èdè àwùjô kò sí).
2. Śe àlàyé fún akëkõö pé bí èdè śe ń dàgbà ni ìgbélárugç ń bá àśà.
3. Jë kí akëkõö mõ pé èdè ni a fi ń sõrõ tí a fi ń gbé èrò inú çni jáde.
AKËKÕÖ
1. Tëtí sí àlàyé olùkö
2. Kô ohun tí olùkö kô sí ojú pátákó sí inú ìwé rç.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1. Pátákó ìkõwé
2. Àwòrán tí ó śe àfihàn àśà ìgbéyàwó tàbí ìsômôlórúkô.

9.ÌBÁŚEPÕ LÁÀRIN ÈDÈ ÀTI ÀŚÀ   ÀKÓÓNÚ IŚË Ìwúlò èdè Èdè gëgë bí òpómúléró àśàOLÙKÖ 1. Śe àlàyé ìwúlò èdè fún akëkõö (jë kí akëkõö mõ pé mö-yà-mí ni èdè àti àśà jë fún àwùjô àti pé bí kò sí èdè àwùjô kò sí). 2. Śe àlàyé fún akëkõö pé bí èdè śe ń dàgbà ni ìgbélárugç ń bá àśà. 3. Jë kí akëkõö mõ pé èdè ni a fi ń sõrõ tí a fi ń gbé èrò inú çni jáde. AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö 2. Kô ohun tí olùkö kô sí ojú pátákó sí inú ìwé rç. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Pátákó ìkõwé 2. Àwòrán tí ó śe àfihàn àśà ìgbéyàwó tàbí ìsômôlórúkô.
10.ÀŚÀ: Oge Śíśe   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Pàtàkì oge sis 2. Oríśiríśi õnà tí a ń gbà śoge Ayé àtijö; Ara fínfín Eyín pípa Tìróò lílé Làálì/ osùn kíkùn Irun dídì, irun fífá, irun gígé, irun kíkó Ilà kíkô abbl 3. Oge śíśe lóde òní; Ètè kíkùn Irun díndín Ihò méjì lílu sí etí kan Imú lílu Aśô tó fara sílê Bàtà gogoro abblOLÙKÖ 1. Tö akëkõö sönà nípa ìdí tí àwôn Yorùbá fi máa ń śoge. 2. Śe àfihàn ohun èlò oge śíśe 3. Tö akëkõö sönà láti dárúkô irúfë oge śíśe tí ó wà ní òde òní àti àléébù tí ó wà níbê fún ôkùnrin àti obìnrin. AKËKÕÖ 1. Sô ohun tí o śàkíyèsí nípa oge śíśe ní àwùjô àti ìdí pàtàkì tí àwôn ènìyàn fi ń śe oge. 2. Sô irúfë oge śíśe tí wön mõ mô obìnrin sáájú ìdánilëkõö. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Ohun èlò gidi bí i; tìróò, làálì, bèbè-ìdí, ìlêkê, osùn,wíìgì, lëêdì, èékánná abbl 2. Àwòrán oríśiríśi irun dídì, irun gígé abbl 3. Àwòrán tí ó śe àfihàn àwôn ilà ojú tí àwôn Yorùbá máa ń kô.
11.ÈDÈ: Ìsõrí Õrõ Õrõ-àpönlé àti õrõ-àpèjúwe   ÀKÓÓNÚ IŚË Oríkì õrõ-àpönlé iśë tí õrõ àpèjúwe ń śe nínú gbólóhùn.OLÙKÖ 1. Sô oríkì tàbí ìtumõ õrõ-àpönlé fún akëkõö, kí o sì fi àpççrç rê han nínú gbólóhùn. Bí àpççrç: Igi náà ga fíofío. 2. Śe àlàyé iśë tí õrõ-àpèjúwe ń śe nínú gbólóhùn fún akëkõö. B.a.      Aśô pupa ni Böla wõ   AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö 2. Kô àwôn ìsõrí õrõ tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé. 3. Śe àpççrç àwôn gbólóhùn mìíràn tí ó ní õrõ-àpönlé àti õrõ-àpèjúwe yàtõ sí èyí tí olùkö kô. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Ìwé gírámà òde òní 2. pátákó ìkõwé Káàdì pélébé pélébé tí a kô õrõ-àpönlé àti õrõ àpèjúwe sí.
  12.  ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ   
  13.  ÌDÁNWÒ   

dddd

hhh



YORÙBÁ JSS 2 TÁÀMÙ KEJÌ

dffffff

Share this Article
Leave a comment