Yoruba Language Scheme of Work for JSS1 Federal

34 Min Read
yoruba language scheme of work
yoruba language scheme of work

Education Resource Centre Yoruba Language Scheme of work for JSS1 Federal. Yoruba JSS1. –Schemeofwork.com

YORÙBÁ JSS 1 TÁÀMÙ KÌN-ÍN-NÍ

ÕSÊORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚÀMÚŚE IŚË
1.Ìtàn ìśêdálê àti ìtànkálê ômô Yorùbá   Àwôn ôba ilé Yorùbá àti orúkô oyè wôn. Bí àpççrç (Aláàfin ti ìlú Õyö, Ôõni ti Ilé-Ifê abblOLÙKÖ   Śe àlàyé àwôn agbègbè tí êyà Yorùbá tàn dé ní àgbáyéFi ìtàn àti àwòrán máàpù śe àlàyé bí Yorùbá śe śê àti bí wôn śe dé ibi tí wön wà
 ÀKÓÓNÚ IŚË   Ìśêdálê Yorùbá láti õdõ Odùduwà   Ìtànkálê Yorùbá lëyìn ikú Odùduwà: Owu, Sabçç, Kétu, Pópó, Õyö Ìjêśà, Ìjêbú, Êgbá abbl   d. Lákòókò òwò çrú: Sàró, Amëríkà, Brazil, Trinidad àti Tobago. Àwôn Erékùsù Karebia. Àwôn ìlú àti orúkô ôba pêlú oyè wôn.báyìí.
3. Dárúkô àwôn ôba ilé Yorùbá àti orúkô oyè wôn
AKËKÕÖ
1. Dárúkô díê lára àwôn agbègbè tí êyà Yorùbá tàn dé.
2. Tún ìtàn bí Yorùbá śe śe, àti bí wôn śe tán ka sô, kí ó sì kô ö sílê
3. Dárúkô àwôn ôba díê ní ilê Yorùbá àti orúkô oyè wôn.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
1. Máàpù Áfíríkà àti ilê Lárúbáwá
2. Máàpù Nàìjíríà àti agbègbè tí ó śàfihàn ìtànkálê Yorùbá
3. Àwôn ôba aládé dier ní ilê Yorùbá
2.ÌRÓ ÈDÈ: Alífábëêtì àti köńsónáýtì èdè YorùbáOLÙKÖ 1. Kô alífábëêtì Yorùbá lápapõ sára pátákó fún akëkõö.
 ÀKÓÓNÚ IŚË 
   Köńsónáýtì: b, d, f, g, gb, h, j, k, l, m, n, p, r, s, ś, t, w, y.Fáwëlì àìránmúpè: a, e, ç, i, o, ô, uFáwëlì àránmúpè: an, in, ôn, un, çnKö àwôn lëtà tí ó dúró fún ìró köńsónáýtì, fáwëlì àìránmúpè àti àránmúpè lötõõtõ fún akëkõö.Pe wön lökõõkan fún akëkõö.
  AKËKÕÖ   Fétí sí bí olùkö śe pe àwôn ìró köńsónáýtì àti fáwëlì náà.Pe àwôn ìró köńsónáýtì àti fáwëlì náà bí olùkö ti pè wön.Śe àdàkô àwôn lëtà ìró köńsónáýtì àti fáwëlì náà OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI   Kádíböõdù ńlá tí a kô alífábëêtì Yorùbá si   Kádíböõdù ńlá tí ó ń śe àfihàn àwôn köńsónáýtì àti fáwëlì lötõõtõ.Káàdì pélébé pélébé tí a kô àwôn lëtà náà sí.
3.ÀWÔN ÊYÀ YORÙBÁ ÀTI ÊKA ÈDÈ  WÔN   ÀKÓÓNÚ IŚË   Díê nínú àwôn êyà tó wà b.a Êgbá, Ìbõlö, Yewa, Òýdó, Ìjêśà, Ifê, Òýkò, Õyö, Èkìtì, Ìbàràpá, Ègùn, Ìgbómìnà, Ìkálê, Àkókó, Àwórì, Õwõ abblOLÙKÖ   Jë kí akëkõö dárúkô àwôn êyà Yorùbá tí ó mõ kí ó sì töka sí çkùn tí a ti lè rí êyà kõõkan nínú máàpùKô àwôn kókó inú êkö yìí sí ojú pátákó kí àwôn akëkõö le kô ö sínú ìwé wôn.     AKËKÕÖ   1. Dárúkô àdúgbò tí o ti wá àti àwôn mìíràn tí
  o mõ ní ilê Yorùbá àti ohun tí o mõ nípa êyà kõõkan. Da àwôn kókó tí olùkö kô sí ojú pátákó kô sínú ìwé. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI   Máàpù ilê Yorùbá.Kádíböõdù pélébé pélébé tí a kô orúkô êyà kõõkan sí.
4.ÒÝKÀ – Ohun tí ó śe okùnfà òýkà.OLÙKÖ   Tö akëkõö sönà láti ka àwôn nýkan díê ní àyíká wôn.Sô ìtàn bí òýkà kíkà śe bêrê. AKËKÕÖKô ohun tí olùkö kô sílê.   Tëtí sí ìtàn tí olùkö sô nípa òýkà àti owó çyô. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI   Kádíböõdù tí a kô òýkà díê kan sí.
 Àlàyé lórí ètò pàsípàrõ àti owó çyô.
   ÀKÓÓNÚ IŚË
 Àlàyé lórí bí òýkà śe bêrê àti bí ètò pàsípàrõ àti owó çyô śe bêrê ní ìbêrê pêpê.
5.ÌRÓ ÈDÈ: Àlàyé lórí fáwëlì èdè Yorùbá –OLÙKÖ
 fáwëlì àránmúpè àti àìránmúpèKô àwôn lëtà tí ó dúró fún ìró fáwëlì àránmúpè
  àti àìránmúpè.
 ÀKÓÓNÚ IŚË 
  AKËKÕÖ
 Fáwëlì àránmúpè – an, çn, in, un,ôn Fáwëlì àìránmúpè – a, e, ç, i, o, ô, u.Pe àwôn ìró fáwëlì náà bí olùkö ti pè wön. Śe àdàkô àwôn lëtà ìró fáwëlì náà OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI   Káàdì pélébé pélébé tí a kô àwôn lëtà náà sí
6.ÌKÍNI: Ìkíni ní onírúurú ìgbà àti àkókòOLÙKÖ   Darí akëkõö láti fi bí a śe ń kí ni śeré   Fi àwòrán àwôn tó ń kí ara wôn han akëkõö AKËKÕÖSô ohun tí wôn mõ nípa àśà ìkíni sáájú ìdánilëkõö.Śe àpççrç àwôn oríśi ìkíni tí wôn ti gbö rí. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNIÀwòrán àwôn tó ń kí ara wôn.
   ÀKÓÓNÚ IŚË
 1. Ìkíni ní onírúurú ìgbà àti àkókò. Ìkíni ní ìgbà òjò, ìgbà êrùn tàbí õgbçlê, ìkíni ní ìgbà ôyë abbl.
 2. Ìkíni àti ìdáhùn láàrin ôjö: àárò, õsán àti alë: ç káàárõ, ç káàsán, ç káalë.
7.ÀKÀYÉOLÙKÖ
   ÀKÓÓNÚ IŚË   Àyôkà tí ìmõ rê kò ju ti ôjö orí akëkõö.Ìbéèrè lórí àyôkà nípa òye õrõ àti ìlò èdè rê1. Pèsè àyôkà tí ó jçmö õrõ tó ń lô láwùjô (b.a. Ewu lílo oògùn olóró, ìjà çlëyàmêyà/ çlësìn mêsìn, ààbò lójú pópó, Êtö obìnrin, ômôdé àti ômônìyàn abbl. AKËKÕÖ
  1. Ka àyôkà tí olùkö pèsè sile
  2. Dáhùn ìbéèrè lórí àyôkà náà
  Tëtí sí àlàyé olùkö lórí àwôn àkànlò èdè àti õrõ tí ó ta kókó OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI   Àwòrán tí ó jçmö õrõ inú àyôkà
8.ÌKÍNI   ÀKÓÓNÚ IŚË   Ìkíni fún onírúurú ayçyç àti bí a śe ń kí àwôn ôba àti ìjòyè.Ìkíni àti ìdáhùn fún onírúurú iśëOLÙKÖ   1. Darí akëkõö láti fi bí a śe ń kí ni ní onírúurú ayçyç śeré. AKËKÕÖ   Śe àpççrç àwôn oríśi ìkíni tí wön ti gbö rí níbi ayçyç, ìjòyè àti iśë OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Àwòrán tí ó jçmö irú ìkíni tí ìdánilëkõö dá lé lórí
9.ÀRÒKÔ KÍKÔ   ÀKÓÓNÚ IŚË   Àlàyé lórí oríśiríśi àròkôÌgbésê tí à ń têlé láti kô àròkôOLÙKÖ   Kô kí ó sì śàlàyé ní sókísókí lórí oríśiríśi àròkôTö akëkõö sönà láti kô àwôn ìgbésê tí à ń têlé láti kô àròkô AKËKÕÖ   Tëtí sí àlàyé olùkö.   kópa nínú kíkô àwôn ìgbésê tí à ń têlé láti kô àròkô
  OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Kádíböõdù tí ó ń śàfihàn oríśiríśi àròkô àti àwôn ìgbésê tí à ń têlé.
10.ÀŚÀ: ÌgbéyàwóOLÙKÖ
  1. Śe àlàyé lórí ètò ìgbéyàwó ìbílê Yorùbá
 ÀKÓÓNÚ IŚË 
  2. Darí àwôn akëkõö láti śeré ìgbéyàwó
 1. Ìlànà àśà ìgbéyàwó ìbílê: ìfojúsóde, alárinà,     ìjöhçn/    ìsíhùn,     ìtôrô,                 ìdána, ìgbéyàwó  3. Fún akëkõö láàyè láti kôrin ìgbéyàwó/ sun çkún ìyàwó
 Ìgbéyàwó   lóde    òní:    Kóòtù,       Śöõśì, MösálásíÀfiwé tìbílê àti ti òde òníTö akëkõö láti jíròrò nípa ìgbéyàwó òde òní   mú kí akëkõö jíròrò lórí àýfààní inú ìkóra- çni-ní-ìjánu àti ewu àìlèkóra-çni-ní-ìjánu śáájú ìgbéyàwó.
 4.      Àýfààní      ìkóra-çni-ní-ìjánu         śáájú ìgbéyàwó  AKËKÕÖ
 5. Ewu àìlekóra-çni-ní-ìjánu śáájú ìgbéyàwó – oyún òjijì, bíba ilé-ômô  jë, àrùn ajçmö-ìbálòpõ, àtõsí, jeèríjeèrí, éèdì (AIDS)Tëtí sí àlàyé olùkö.   Śe eré ìgbéyàwó   Jíròrò lórí ìgbéyàwó òde òní
 – Ìgbéyàwó àìròtëlê/ àpàpàndodo.4. Jíròrò lórí àýfààní inú ìkóra-çni-ní-ìjánu àti ewu àìlèkóra-çni-ní-ìjánu śáájú ìgbéyàwó.
  OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
  1. Àwòrán ohun tí ó wà nínú çrù ìgbéyàwó àti ohun ìdána
  Àwòrán lórí àśà ìgbéyàwó   Ìwé lórí àśà ìgbéyàwó   Àwòrán aláìsàn éèdì.
11.LËTÀ KÍKÔ   ÀKÓÓNÚ IŚË   Lëtà gbêfê àti Aláìgbêfê   Ìyàtõ àárin wôn   Ìlapa kíkô lëtà gbêfê   ÀdírësìDéètìKíkô õrõ inú lëtà, kí a sì pín in sí ègé afõ bí ó ti yç.Àsôkágbá/ àgbálôgbábõ/ ìgúnlêÌlapa kíkô lëtà àìgbagbêfê   Àdírësì méjìDéètìÀkôléÕrõ inú lëtà tí a pín in sí ègé afõ bí ó ti yç.OLÙKÖ   Sô oríśi lëtà méjì tí ó wà fún akëkõö.   Śe àlàyé ìyàtõ láàrin méjèèjì   Lo ìlapa kíkô lëtà gbêfê àti àìgbagbêfê láti töka sí ìyàtõ wôn bí i àdírësì, ìkíni, àkôlé àti àsôkágbá abblTö akëkõö sönà láti kô oríśi lëtà méjèèjì AKËKÕÖTëtí sí àlàyé olùkö   Kô ìlapa kíkô oríśi lëtà gbêfê àti àìgbagbêfê bí olùkö śe śàlàyé rê/ kô sára pátákó.Têlé ìtösönà olùkö láti kô lëtà méjèèjì OHUN-ÈLÒ ÌKÖNIPátákó çlçmôô àti kádíböõdù tí a kô ìlànà méjèèjì sí.
12.ÀKÔTÖ   ÀKÓÓNÚ IŚËOLÙKÖ   Śe àlàyé ohun tí àkôtö je   Sô ìtàn ní sókí nípa bí èdè Yorùbá śe di
 Àlàyé ohun tí àkôtö jë   Bí èdè Yorùbá śe di kíkô sílê   Àfiwé àkôtö àtijö àti ti òde òní:   fáwëlì   aiye – ayé, yio – yo/ yóò, enia – ènìyàn abbl köńsónáýtì:  Oshogbo  –  Òśogbo,  Iffô – Ifõ   Àmì ohùn: õgun – oogun, Alãnu – Aláàánú   Yíyán õrõ nídìí: ẹ – ç, ṣ – ś,   Pínpín õrõ: wipe – wí pé, nigbati – nígbà tíkíkô sílê   Kô àkôtö àtijö àti ti òde òní sí ara pátákó   Śe àlàyé kíkún lórí ìyàtõ méjèèjì láti fi ìdí tí ti òde òní fi péye hàn AKËKÕÖ   Tëtí sí àlàyé olùkö nípa ohun tí àkôtö jë àti ìtàn bí àkôtö śe bêrê/ bí èdè Yorùbá śe di kíkô sileKô àwôn àpççrç àkôtö tí olùkö kô sílê sínú ìwé.Béèrè ìbéèrè lórí ohun tí kò bá yé ô lórí àlàyé tí olùkö śe. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Kádíböõdù tí a kô àkôtö òde òní àti ti àtijö si.
  13.  Àtúnyêwò Êkö 
  14.  Ìdánwò 

YORÙBÁ JSS 1 TÁÀMÙ KEJÌ

ÕSÊORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚÀMÚŚE IŚË
1.ÈDÈ: Àròkô Oníròyìn   ÀKÓÓNÚ IŚË   Àkôlé   Ìlapa èrò   Àtúntò ìlapa èrò   Ìfáàrà   Ìpín afõ   Kókó õrõ inú àròkô   Ìgúnlê/ ÀsôkágbáOLÙKÖ   Śe àlàyé ìgbésê àròkô   Śe àlàyé ìfáàrà   Śe àlàyé ìpín afõ   Śe àlàyé ìfàmìsí ç. Śe àlàyé ìgúnlêŚe àlàyé ìlò èdè   Tö akëkõö sönà láti kô àròkô nípa lílo ìlapa tí ó śe. AKËKÕÖ   Ka àròkô oníròyìn tí ó pegedé   Kô àròkô oníròyìn nípa títêlé ìgbésê tí olùkö ti śàlàyé rê OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI   Ìwé àpilêkô lórí àròkôÌwé iśë àti pátákó ìkõwé
2.ÀŚÀ: Àśà ÌgbéyàwóOLÙKÖ   1. Śe àlàyé lórí ètò ìgbéyàwó ìbílê Yorùbá
 ÀKÓÓNÚ IŚË   Ìlànà àśà ìgbéyàwó ìbílê: ìfojúsóde, alárinà, ìjöhçn/ ìsíhùn, ìtôrô, ìdána, ìgbéyàwóÌgbéyàwó lóde òní: Kóòtù, Śöõśì, MösálásíÀfiwé tìbílê àti ti òde òní   Àýfààní ìkóra-çni-ní-ìjánu śáájú ìgbéyàwóEwu àìlekóra-çni-ní-ìjánu śáájú ìgbéyàwó – oyún òjijì, bíba ilé-ômô  jë, àrùn ajçmö-ìbálòpõ, àtõsí, jeèríjeèrí, éèdì (AIDS) – Ìgbéyàwó àìròtëlê/ àpàpàndodo.Darí àwôn akëkõö láti śe eré ìgbéyàwó   Fún akëkõö láàyè láti kôrin ìgbéyàwó/ sun çkún ìyàwóTö akëkõö sönà láti jíròrò nípa ìgbéyàwó òde òníMú kí akëkõö jíròrò lórí àýfààní inú ìkóra-çni- ní-ìjánu àti ewu àìlèkóra-çni-ní-ìjánu śáájú ìgbéyàwó. AKËKÕÖ   Tëtí sí àlàyé olùkö.   Śe eré ìgbéyàwó/ sun çkún ìyàwó.   Jíròrò lórí ìgbéyàwó òde òní   Jíròrò lórí àýfààní inú ìkóra-çni-ní-ìjánu àti ewu àìlèkóra-çni-ní-ìjánu śáájú ìgbéyàwó. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI   Àwôn ohun tí ó wà nínú çrù ìgbéyàwó àti ohun ìdánaÀwòrán lórí àśà ìgbéyàwó   Ìwé lórí àśà ìgbéyàwó   Àwòrán aláìsàn éèdì.
3.ÒÝKÀ:   Oókanléláàádöta dé ôgörùn-ún (51 – 100)   ÀKÓÓNÚ IŚË   Oókanléláàádöta dé ôgörùn-ún (51 – 100)OLÙKÖ Tö akëkõö sönà láti ka Oókanléláàádöta dé ôgörùn-ún (51 – 100) AKËKÕÖ Ka òýkà láti Oókanléláàádöta dé ôgörùn-únDá òýkà tí a kô sójú pátákó mõ ní õkõõkanKô òýkà tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNIKádíböõdù tí a kô òýkà láti Oókanléláàádöta dé ôgörùn-ún (51 – 100).Káàdì pélébé pélébé tí a kô òýkà kõõkan sí.
4.LÍTÍRÈŚÕ   ÀKÓÓNÚ IŚË   1. Kí ni lítírèśõ?   – Êka tí lítírèśõ Yorùbá pín sí (Lítírèśõ alohùn àti àpilêkô 2. Ìsõrí lítírèśõ, àpilêkô   Ewì   Ìwé ìtàn àròsô   Eré-onítànOLÙKÖ   Śe àlàyé àwôn àbùdá pàtàkì lítírèśõ   Śe àfiwé lítírèśõ àpilêkô àti alohùn   Kô àpççrç lítírèśõ àpilêkô fún akëkõö   Śe àlàyé àwôn ìsõrí mëtêêta lítírèśõ, àpilêkô láti fi ìyàtõ wôn hànSô àpççrç õkõõkan àwôn ìsõrí náà fún akëkõö AKËKÕÖ   1. Tëtí sí gbogbo àlàyé olùkö dáradára.
  Ya àtç láti fi ìyàtõ lítírèśõ àpilêkô àti alohùn hàn.Kô àpççrç mìíràn ìsõrí kõõkan lítírèśõ, àpilêkô OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI   Ìwé oríśiríśi lítírèśõ, àpilêkô Eré-oníśe, ewì àti ìtàn àròsô
5.ÈDÈ: Ìsõrí õrõ     OLÙKÖ
   ÀKÓÓNÚ IŚË     1. Śe àlàyé kíkún lórí ipò àti iśë kõõkan nínú gbólóhùn
 1. Õrõ-orúkô     2. Śe õpõlôpõ àpççrç lórí õkõõkan fún akëkõö
 2. Õrõ-aröpò orúkô     3. Darí akëkõö láti śe àpççrç tirê
 3. Õrõ-ìśe     AKËKÕÖ
 4. Õrõ-àpèjúwe     1. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí ìsõrí õrõ kõõkan
 5. Õrõ-atökùn     2. Kô àwôn àpççrç tí olùkö śe sínú ìwé
 6. Õrõ-àsopõ     3. Śe àwôn àpççrç tìrç lábë ìdarí olùkö
 Àlàyé kíkún lórí gbólóhùn.ipòàtiiśëwônnínúOHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
       1. Kádíböõdù
       2. Káàdì pélébé pélébé
6.LÍTÍRÈŚÕ (Ìwé Kíkà): Kíka ìwé lítírèśõ àpilêkô   ÀKÓÓNÚ IŚË   kókó õrõ   àhunpõ ìtàn àti ìfìwàwêdá   Ibùdó ìtàn   ôgbön ìsõtàn ç. Ìlò-èdèÀśà tó jçyô nínú ìtàn àròsô.OLÙKÖ   Jë kí akëkõö ka ìwé ìtàn àròsô ní àkàyé   Śe àlàyé tó kún lórí ìwé ìtàn àròsô   d. Kô àwôn õrõ pàtàkì pàtàkì tí ó jçyô jáde sójú pátákó. AKËKÕÖ   Ka ìwé ìtàn àròsô wá láti ilé àti nínú kíláásì   Tëtí sí àlàyé olùkö   d. Da àwôn õrõ tí olùkö kô sójú pátákó kô sínú ìwé rç OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI   FídíòTéèpùTçlifísànÊrô agbõrõ sô
7.ÌSÕRÍ ÕRÕ   ÀKÓÓNÚ IŚË   Kí ni õrõ-orúkô?Oríśi õrõ-orúkô méjì: àìśêdá àti èyí tí a śêdá, pêlú àpççrçÀlàyé kíkún lórí oríśiríśi õnà ìśêdá õrõ-orúkô pêlú àpççrçOLÙKÖ   Śe àlàyé ohun tí õrõ-orúkô jë   Śe àlàyé oríśi õrõ-orúkô méjì: àìśêdá àti èyí tí a śêdá, pêlú àpççrç – çja, ejò, ìyá, ôwö, adé. AKËKÕÖ   1. Tëtí sí àlàyé olùkö
 4.  Àlàyé kíkún lórí iśë tí õrõ-orúkô ń  śe nínú gbólóhùnŚe àpççrç õrõ-orúkô tí a kò śêdá mìíràn   Śe àpççrç àwôn oríśiríśi õrõ-orúkô tí a śêdá mìíràn yàtõ sí èyí tí olùkö ti śe.Kô àwôn àpççrç náà sílê. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Kádíböõdù tí a kô oríśiríśi àpççrç sí.
8.ERÉ ÌDÁRAYÁOLÙKÖ
   ÀKÓÓNÚ IŚËa. Śàlàyé bí a śe ń śe díê nínú eré ìdárayá tí a mënubà
 oríśiríśi eré ìdárayá   eré òśùpá bí i – bojúbojú, san-n-sa lubôb. Tö àwôn akëkõö sönà láti śe àwôn eré ìdárayá náà
 d. eré ìta gbangba bí i – òkòtó, àrìn, ìjàkadì/ çkç ogod. Kô àwôn orin inú eré ìdárayá náà sójú pátákó
  AKËKÕÖ
  a. Sô ohun tí o mõ nípa eré ìdárayá sáájú ìdánilëkõö
  b. Dárúkô díê nínú eré ìdárayá mìíràn tí o mõ
  d. Tëtí sí àlàyé olùkö
  e. Kópa nínú śíśe eré ìdárayá tí olùkö kô sójú pátákó kô ö sínú ìwé rç
  OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
  ôpön ayòômô ayòòkòtóàrìn abbl
9.ÀŚÀ: Ètò Ôrõ-Ajé   ÀKÓÓNÚ IŚË   ìdí tí a fi ń polówó ôjà   bí a śe ń polówó ôjà b.a. êkô tútù, ç ç jçran êkô d. ôgbön- ìpolówó ôjà ní ayé àtijö àti òde òní b.a. ìpolówó lórí rédíò, tçlifísàn, ìwé ìròyìn, ìpàtç, ìkiri abblOLÙKÖ   Tç ìpolówó ôjà tí a ti tê sórí téèpù fún àwôn akëkõö gbö.Fún àwôn akëkõö ní àýfààní láti śe ìpolówó ôjaní kíláásì d. Kó akëkõö lô śe àbêwò ní ôjà tàbí ìdíkõ AKËKÕÖ Tëtí sí téèpù ti olùkö têKópa nínú śíśe ìpolówó ôjà nínú kíláásì d. Śe àbêwò sí ôjà tàbí ìdíkõ láti gbö oríśiríśi ìpolówó ôjà OHUN- ÈLÒ ÌKÖNI ÀtçFídíòRédíòÊrô agbõrõ sílêÌpolówó lóríśiríśi nínú ìwé ìròyìn abbl.
10.ÈDÈ: Àkôtö   ÀKÓÓNÚ IŚËOLÙKÖ   a. Śe àlàyé ohun tí àkôtö jë.
 Àlàyé ohun tí àkôtö jë   Àfiwé àkôtö àtijö àti ti òde òní   Fáwëlì:   aiye – ayé   yio – yo/ yòó/ yóò enia – ènìyàn abbl köńsónáýtì: oshogbo – Òśogbo Offa – ÕfàÀmì Ohùn:   õgùn – òógùn alãnu – aláàánú Yíyán õrõ:   ẹ – ç   ṣ – ś   Pínpín õrõ wipe – wí pé nigbati – nígbà tí Bíótilêjëwípé – Bí ó tilê jë wí péb. Kô àkôtö àtijö àti ti òde òní sára pátákó   d. Śe àlàyé kíkún lórí ìyàtõ méjèèjì ní õkõõkan láti fi ìdí tí ti òde òní fi péye hàn. AKËKÕÖ   Tëtí sí àlàyé olùkö   Kô àwôn àpççrç àkôtö tí olùkö kô sí ara pátákó sí inú ìwé. d. Béèrè ìbéèrè löwö olùkö nípa ohun tí kò bá yé ô nínú àwôn àlàyé rê. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI   Kádíböõdù tí a kô àkôtö òde òní àti ti àtijö sí.   Àwôn àśàyàn ìwé tí a fi àkôtö òde òní kô.
 B, Õrõ àti ìdàkejì rê, b.a Bàbá – Ìyá Êgbön – Àbúrò   Òkè – Ilê abbl 
      11.      Àtúnyêwò Êkö 
      12.      Ìdánwò 

Education Resource Centre Yoruba Language Scheme of work for JSS1 Federal. Yoruba JSS1. –Schemeofwork.com

YORÙBÁ JSS 1 TÁÀMÙ KËTA

ÕSÊORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚÀMÚŚE IŚË
1.ÈDÈ: Fónëtíìkì   ÀKÓÓNÚ IŚË   Àwôn êyà ara fún ìró pípè   Oríśi àfipè   Àfipè àsúnsí b.a, ètè ìsàlêÀfipè àkànmölê b.a, ètè òkèOLÙKÖ   Kô àwôn êyà ara tí ó wà fún ìró èdè pípè fún àwôn akëkõö lójú pátákó.Dárúkô oríśi àfipè   Àfipè àsúnsí b.a, ètè ìsàlê, iwájú ahön, êyìn ahönÀfipè àkànmölê b.a, ètè òkè, eyín òkè, àjà çnu. AKËKÕÖ   Tëtí sí àlàyé olùkö   Kô àpççrç àfipè àsúnsí àti àkànmölê sí inú ìwé   d. Lo àwôn êyà ara àfipè láti pe àwôn ìró kan. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Yíya àwòrán tí ó śe àfihàn êyà ara tí ó wà fún ìró èdè pípè sínú kádíböõdùGíláàsì
2.ÀŚÀ: Eré Ìdárayá   ÀKÓÓNÚ IŚË   a. oríśiríśi eré ìdárayáOLÙKÖ   a. Śe àlàyé bí a ti ń śe díê nínú eré ìdárayá tí a mënubà
 b. Eré òśùpá bí i bojúbojú, sa-ń- sálùbö d. Eré abëléb. Tö àwôn akëkõö sönà láti śe àwôn eré ìdárayá náà. d. Kô àwôn orin inú eré ìdárayá náà sójú pátákó AKËKÕÖ Sô ohun tí o mõ nípa eré ìdárayá sáájú ìdánilëkõö.Dárúkô díê nínú eré ìdárayá mìíràn tí o mõ.   d. Tëtí sí àlàyé olùkö   e. Kópa nínú śíśe eré tí olùkö sójú pátákó OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Ôpön ayòÔmô ayòÒkòtóÀrìn abbl.
e. Eré ìta gbangba bí i òkòtó, àrìn, ìjàkadì/ çkç, ogo gbígbõn.
3.ÈDÈ: Ìsõrí õrõOLÙKÖ
   ÀKÓÓNÚ IŚË1. Śe àlàyé kíkún lórí ipò àti iśë kõõkan nínú gbólóhùn
 1. Õrõ-orúkô2. Śe õpõlôpõ àpççrç lórí õkõõkan fún akëkõö
 2. Õrõ-aröpò orúkô3. Darí akëkõö láti śe àpççrç tirê
 3. Õrõ-ìśeAKËKÕÖ
 4. Õrõ-àpèjúwe  1. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí ìsõrí õrõ kõõkan
 5. Õrõ-atökùn 
 6. Õrõ-àsopõ Àlàyé kíkún lórí ipò àti iśë wôn nínú gbólóhùn.Kô àwôn àpççrç tí olùkö śe sínú ìwé   Śe àwôn àpççrç tìrç lábë ìdarí olùkö. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNIKádíböõdù   Káàdì pélébé pélébé
4.LÍTÍRÈŚÕ: Kíka ìwé lítírèśõ àpilêkô   ÀKÓÓNÚ IŚË   Kókó õrõ   Àhunpõ ìtàn   Ibùdó ìtàn   Êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá   Ìlò èdè   Ìsúyô àśà abblOLÙKÖ Śe àlàyé àbùdá kõõkan àti bí a śe lè mú u lò fún ìsõrí lítírèśõ kõõkanŚe õpõlôpõ àpççrç láti inú ìsõrí lítírèśõ kõõkanŚàlàyé pé inú àwôn lítírèśõ tí a fi sô ìtàn nìkan ni a ti lè śe àgbéyêwò àhunpõ ìtàn, êdá ìtàn àti ibùdó ìtàn. AKËKÕÖ Tëtí sí àlàyé olùkö, kí o sì śe àkôsílê rê sínú ìwéŚe àpççrç tirê tí ó yàtõ sí ti olùkö OHUN-ÈLÒ ÌKÖNIÌwé ewì, eré-onítàn àti ìtàn àròsô
5.ÌSÕRÍ ÕRÕ   ÀKÓÓNÚ IŚË   1. Kí ni õrõ-orúkô?OLÙKÖ Śe àlàyé ohun tí õrõ-orúkô jëŚe àlàyé oríśi õrõ-orúkô méjì: àìśêdá àti èyí tí a śêdá, pêlú àpççrç – çja, ejò, ìyá, ôwö, êrín, adé,
 2. Oríśi õrõ-orúkô méjì: àìśêdá àti èyíàbõ, jíjç, alaalë. 3. Śe àlàyé kíkún lórí oríśiríśi õnà ìśêdá õrõ-orúkô pêlú àpççrç
AKËKÕÖ Tëtí sí àlàyé olùköŚe àpççrç õrõ-orúkô tí a kò śêdá mìírànŚe àpççrç àwôn oríśiríśi õrõ-orúkô tí a śêdá mìíràn yàtõ sí èyí tí olùkö ti śe.Kô àwôn àpççrç náà sílê. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNIKádíböõdù tí a kô oríśiríśi àpççrç sí.
tí a śêdá, pêlú àpççrç
3. Àlàyé kíkún lórí oríśiríśi õnà ìśêdá
õrõ-orúkô pêlú àpççrç
6.ÒÝKÀ:    OLÙKÖ Tö akëkõö sönà láti ka òýkà, Oókanlélögörùn-ún dé àádöjô (101–150)Śe àlàyé ìgbésê òýkà ní kíkún AKËKÕÖKa òýkà láti Oókanlélögörùn-ún dé àádöjô (101 – 150) Dá òýkà tí a kô sójú pátákó mõ ní õkõõkanKô òýkà tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNIKádíböõdù       tí       a      kô      òýkà      láti Oókanlélögörùn-ún dé àádöjô (101  – 150)
 Oókanlélögörùn-únàádöjô(101
 150)    
   ÀKÓÓNÚ IŚË    
 Oókanlélögörùn-únàádöjô(101
 150)    
  sí. Káàdì pélébé pélébé tí a kô òýkà kõõkan sí.
7.ÀŚÀ: Oyún níní àti ìtöjú Aláboyún   ÀKÓÓNÚ IŚË   Ìgbàgbö Yorùbá nípa àgàn, ômô bíbí àti àbíkúÀwôn tí oyún níní wà fún (tôkôtaya)   Õnà tí a lè gbà dín bíbí àbíkú kù láwùjôoríśiríśi jënótáìpù êjê tó wà àti àwôn tó lè fëra wôn.Aájò láti lè tètè lóyún – àýfààní kíkóra- çni-níjàánu nípa ìbálòpõBí a śe ń töjú aboyún látijô àti lóde òní: Àtijö;   Oyún    dídè,     èèwõ             aláboyún, àsèjç, àgbo abbl Òde òní   Oúnjç aśaralóore, lílô fún ìtöjú ní ilé ìwòsàn (ìbílê/ ìjôba) abblOLÙKÖ
 1. Śe àlàyé ní kíkún lórí ìgbàgbö àwôn Yorùbá nípa oyún níní, ìtöjú oyún àti àsìkò tó tö láti lóyún
 2. Śe àlàyé onírúurú jënótáìpù êjê tí ó wà àti èyí tí ó bára mu
 3. Kô àwôn oúnjç aśaralóore tí aboyún lè jç sára pátákó ìkõwé
 4. Śe àlàyé bí a śe ń töjú aláboyún látijö àti lóde òní
 5. Śe àlàyé nípa pàtàkì ìkóra-çni-ní-ìjánu sáájú ìgbéyàwó fún çni tí ó bá tètè fë ômô bí
 AKËKÕÖ
 1. Sõrõ nípa àwôn tóyún wà fún
 2. Sô ohun tí o mõ nípa oyún
 3. Sô jënótáìpù tìrç
 4. Dárúkô díê lára àwôn oúnjç aśaralóore
 5. Dárúkô díê lára àwôn õnà tí a fi ń töjú aláboyún látijô àti lóde òní
 6. Tëtí sí àwôn àlàyé olùkö
 OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
  Àwòrán aboyúnÀwòrán díê lára ohun-èlò tí a fi ń töjú aláboyún ní ìlànà ti ìbílê: ìkòkò àgbo, ìśaasùn àśèjç, ìgbàdí abblÀwòrán díê lára ohun tí a fi töjú aláboyún ní òde òníÀtç tí ó ń fi oúnjç aśaralóore hàn.
8.ÈDÈ: Ìśêdá õrõ-orúkôOLÙKÖ Śe àlàyé oríśiríśi ìhun õrõŚe àlàyé ìśêdá àwôn õrõKô õpõlôpõ àpççrç oríśiríśi õrõ ìśêdá sójú pátákó AKËKÕÖ Sô oríśiríśi ìhun õrõSô bí a śe śêdá àwôn õrõ.Da õrõ-orúkô ìśêdá tí olùkö kô sínú ìwé. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNIPátákó ìkõwéKádíböõdù tí a ya àtç oríśiríśi õrõ ìśêdá sí.
   ÀKÓÓNÚ IŚË
 1. Ìhun õrõ onísílébù kan; a, e, ç, wön,
 lô, gbö, rìn, abbl
 2. Ìhun õrõ ôlöpõ sílébù b.a agbádá,
 kõýkõsõ, gbangbayíkítá, abbl.
 3. Ìśêdá õrõ-orúkô – àfòmö ìbêrê (a, òý,
 ò, oní, àì, àti b.a. àti + jç = àtijç. Àfòmö
 àárin: àpètúnpè (kíkún, çlëbç) b.a. jí + jç
 = jíjç, ômô + kí + ômô = ômôkömô.
9.LÍTÍRÈŚÕ: Kíka ìwé lítírèśõ àpilêkôOLÙKÖ
  1. Śe àlàyé àbùdá kõõkan àti bí a śe lè mú u lò
 ÀKÓÓNÚ IŚËfún ìsõrí lítírèśõ kõõkan
 1. Kókó oro2. Śe õpõlôpõ àpççrç láti inú ìsõrí lítírèśõ kõõkan
 Àhunpõ ìtànIbùdó ìtànÊdá ìtàn àti ìfìwàwêdáÌlò èdèÌsúyô àśà abbl3. Śe àlàyé pé inú àwôn lítírèśõ tí a fi sô ìtàn nìkan ni a ti lè śe àgbéyêwò êdá ìtàn, ibùdó ìtàn àti àhunpõ ìtàn. AKËKÕÖ Tëtí sí àlàyé olùkö, kí o sì śe àkôsílê rê sínú ìwéŚe àpççrç tirê tí ó yàtõ sí ti olùkö OHUN-ÈLÒ ÌKÖNIÌwé ewì, eré-onítàn àti ìtàn àròsô
10.ÌDÁMÕOLÙKÖ
   ÀKÓÓNÚ IŚË1. Sô díê nínú oríśiríśi nýkan ní àyíká – ilé-ìwé, ilé b.a. ôwõ/ ìgbálê, àga, kíláásì, ibùsùn
 Śíśe ìdámõ oríśiríśi nýkan ní àyíká (ilé-ìwé, ilé abbl).Mímô orúkô àwôn ènìyàn àti bí wön śe jë síra wôn.Mímô díê nínú àwôn êyà araMímô orúkô àwôn çranko díê2. Dídárúkô àwôn ènìyàn àti bí wön śe jë síra wôn – ôkô, ìyàwó, bàbá, ômô.   Sô díê nínú àwôn êyà ara b.a. ojú, imú, etí.   Sô díê nínú orúkô àwôn çranko b.a. ajá, çsin, ewúrë, këtëkëtë abbl
  AKËKÕÖ
  1. Tëtí sí àlàyé olùkö
  2. Śe àpèjúwe oríśiríśi nýkan àyíká mìíràn yàtõ sí èyí tí olùkö sô.
  3. Töka sí àwôn êyà ara wôn tí olùkö mënubà àti
  iśë õkõõkan wôn.   Śe àpççrç orúkô àwôn çranko – ohun õsìn àti çranko inú igbó.Kô àwôn àpççrç tí olùkö śe sínú ìwé. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNIŚíśe àfihàn àwòrán êyà ara çni   Pípèsè ohun – èlò àrídìmú tí ó wà ní àyíká b.a. söõkì, àga, òkúta abbl
11.ÀŚÀ: Òwò ŚíśeOLÙKÖ
  1. Śe àlàyé ohun tí òwò śíśe jë
 ÀKÓÓNÚ IŚË   1. Oríkì òwò śíśe (kárà-kátà)2. Darí akëkõö láti dárúkô oríśiríśi òwò tí àwôn Yorùbá ń śe láyé àtijö àti lóde òní
 2. Ìdí tí òwò śíśe fi śe pàtàkì ní ilé Yorùbá3. Lo ìbéèrè láti mú kí àwôn akëkõö sô àpççrç ìpolówó ôjà tí wön mõ.
 3. Oríśiríśi òwò tí àwôn Yorùbá máa 
 ń śe 4. Ìpolówó ôjà ní ilê Yorùbá4. Darí akëkõö láti sô õnà tí a fi lè lo òwò śíśe láti dín àìríśë-śe àwôn õdö kù.
 5. Àìríśëśe lóde òní àti ipa tí òwòAKËKÕÖ
 śíśe lè kó.1. Tëtí sí àlàyé olùkö nípa ohun tí òwò śíśe jç.
  2. Dárúkô àwôn oríśiríśi òwò tí wön mõ láyé àtijö àti lóde òní.
  3. Śe àpççrç ìpolówó ôjà tí wön ti gbö rí
  4. Kópa nínú ìjíròrò tí olùkö darí nípa bí a ti lè lo
  òwò śíśe láti dín àìríśë-śe àwôn õdö kù lóde òní. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Àwòrán oníòwò lóríśiríśiFíìmùFídíò
12.ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ 
13.ÌDÁNWÓ 

Share this Article
Leave a comment