Yoruba Language Scheme of Work for JSS 3 Federal (All Terms)

60 Min Read
yoruba language scheme of work
yoruba language scheme of work

Education Resource Centre Federal Yoruba Language Scheme of work for JSS 3. Yoruba Teaching Scheme FCT. –Schemeofwork.com

YORÙBÁ L2 JSS 3 TÁÀMÙ KÌN-ÍN-NÍ

ÕSÊORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚÀMÚŚE IŚË  
1.ÀŚÀ: Ìśêdálê àti Ìtànkálê Ômô Yorùbá   ÀKÓÓNÚ IŚË Ìśêdálê Yorùbá láti õdõ Odùduwà Àwôn ìlú tí ó jë ti Yorùbá d.  Orúkô àwôn ômô OdùduwàOLÙKÖ a. Śe àlàyé àwôn agbègbè tí êyà Yorùbá tàn dé ní àgbáyé b. Fi ìtàn àti àwòrán máàpù śe àlàyé bí Yorùbá śe śê àti bí wôn śe dé ibi tí wôn wà báyìí.b AKËKÕÖ a. Dárúkô díê lára àwôn agbègbè tí êyà Yorùbá tàn dé. b. Tún ìtàn náà sô d. Kô kókó ìdánilëkõö sílê
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
a. Máàpù Áfíríkà àti ilê Yorùbá
b. Máàpù Nàìjíríà àti ti àgbáyé tí ó śàfihàn ìtànkálê Yorùbá.
2.FÓNËTÍÌKÌ: Ìró Èdè Yorùbá  
ÀKÓÓNÚ IŚË a. Álífábëêtì Yorùbá b. Kíka álífábëêtì láti A – Y d. Àlàyé lórí lëtà ńlá àti lëtà kékeré e. Ìsõrí álífábëêtì èdè Yorùbá (B.a. köńsónáýtì àti fáwëlì àìránmúpè àti fáwëlì àránmúpè) ç. Ìyàtõ láàrin álífábëêtì èdè Yorùbá àti èdè Gêësì.
OLÙKÖ a. Ka álífábëêtì fún àwôn akëkõö. b. Śe àlàyé lórí lëtà ńlá àti kékeré d. Pín álífábëêtì èdè Yorùbá sí ìsõrí köńsónáýtì àti fáwëlì e. Fi ìyàtõ hàn láàrin álífábëêtì èdè Yorùbá àti èdè Gêësì.
OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
a. Kádíböõdù tí a kô álífábëêtì Yorùbá sí. b. Káàdì pélébé pélébé tí a kô lëtà kõõkan sí.
3.ÀŚÀ: Ìkíni   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Ìkíni ní onírúurú ìgbà àti àkókò (B.a. àárõ, õsán, alë, òru, ìyálêta, ààjìn abbl) b. Ìkíni fún onírúurú ayçyç (Bí ìsômôlórúkô, ìgbéyàwó, ôlöjö ìbí, oyè jíjç, ìkíni fún aláboyún abbl). d. Ìkíni fún onírúurú iśë. Bí àpççrç: àgbê, ôdç, akõpç, onídìrí, aláró, awakõ, alágbêdç, babaláwo abbl.OLÙKÖ
a. Śe àlàyé ìkíni ní onírúurú ìgbà àti àkókò b. Śe àlàyé ìkíni fún onírúurú ayçyç
d. Śe àlàyé ìkíni fún onírúurú iśë
AKËKÕÖ
a. Dárúkô àkókò àti ìgbà tó wà nínú ôjö. b. Kí ènìyàn bí ó ti y
ç ní àkókò kõõkan.
d. Kí ènìyàn bí ó ti yç fún onírúurú ayçyç. e. Kí ènìyàn fún onírúurú iśë ç. Hùwà bí ó śe yç ní àsìkò ìkíni (B.a. ìkúnlê, ìdõbálê) OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI a. Pátákó tí a kô onírúurú ìkíni sí. b. Àwòrán àwôn ômô tí wôn ń kí obi wôn.
4.ÈDÈ: Àkàyé   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Kíka àwôn ìtàn kéèkèèké ôlörõ geere àti ewì. b. Títúmõ àwôn õrõ tí ó ta kókó inú àyôkà. d. Ìbéèrè àti ìdáhùn lórí àyôkà.OLÙKÖ a. Jë kí akëkõö ka àyôkà náà lëêmejì ó kéré tán. b. Tö akëkõö sönà láti lè fa kókó õrõ inú àyôkà yô. d. Béèrè ìbéèrè lórí àyôkà náà   AKËKÕÖ a. Tëtí sí olùkö b. Ka àyôkà náà ni àkàsínú – àkàsíta d. Dáhùn ìbéèrè àyôkà e. Jíròrò lórí ìtumõ õrõ pàtàkì pàtàkì àti àkànlò-èdè inú àyôkà náà, kí o sì kô ö sínú ìwé OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI a. Pátákó ìkõwé b. ìwé atúmõ èdè 
5.ÀŚÀ: Àśà Ìgbéyàwó Nílê Yorùbá   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Ìtumõ àti oríśi ìgbéyàwó b. Àwôn ìgbésê ìgbéyàwó bí i ìfojúsóde, alárinà, ìtôrô, ìjöhçn tàbí ìśíhùn, ìdána abbl d. Àwôn ohun èlò ìdána àti ìwúlò wôn.OLÙKÖ a. śe àlàyé fún àwôn akëkõö lórí ìtumõ ìgbéyàwó b. Jë kí àwôn akëkõö töka sí ìgbésê ìgbéyàwó d. Kí olùkö jë kí àwôn akëkõö dárúkô àwôn ohun èlò ìdána àti ìwúlò rê AKËKÕÖ a. Tëtí sí olùkö. b. Jíròrò nípa ìrírí rê d. Da õrõ  tí olùkö kô sí ojú pátákó kô sínú ìwé wôn. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI – Àwòrán ìgbéyàwó – Fídíò – Téèpù – Tçlifísàn
6.ÈDÈ: Àkôtö   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Àtúnyêwò álífábëêtì èdè Yorùbá b. ìtumõ àkôtö d. sípëlì àtijö àti àkôtö òde òní e. ìyàtõ láàrin sípëlì àtijö àti àkôtö òde òní. i. Fáwëlì: aiye – ayé              yio – yóò              enia – ènìyàn, abbl ii. Köńsónáýtì: Oshogbo – Òśogbo, abbl iii. Àmì ohùn: õgun – òógùn                     alãnu – aláàánú iv. Yíyán õrõ nídìí: ẹ – ç , ṣ – ś, ọ – ô v. Pípín õrõ: wipe – wí pé                  nigbati – nígbà tíOLÙKÖ a. Śe àlàyé ohun tí àkôtö jë b. kô àkôtö àtijö àti òde òní sára pátákó d. Śe àlàyé kíkún lórí ìyàtõ láàrin méjèèjì AKËKÕÖ a. Tëtí sí àlàyé olùkö b. kô àpççrç tí olùkö kô sí ojú pátákó d. Béèrè ohun tí kò bá yé ô löwö olùkö.
7.LÍTÍRÈŚÕ: Lítírèśõ Yorùbá   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Ìtumõ oríkì lítírèśõ b. Êka lítírèśõ Yorùbá i. Lítírèśõ Àpilêkô ii. Lítírèśõ Alohùn d. Ìsõrí Lítírèśõ àpilêkô i. Àpilêkô ôlörõ geere ii. àpilêkô ewì iii. àpilêkô eré-onítàn e. Ìsõrí lítírèśõ alohùn i. ôlörõ geere ii. ewì alohùn iii. eré-oníśe  OLÙKÖ a. Śe àlàyé ohun tí lítírèśõ jë b. Sô çka lítírèśõ d. pín êka kõõkan sí ìsõrí pêlú àpççrç tí ó yç e. Śe àlàyé ìyàtõ láàrin àpilêkô àti alohùn. AKËKÕÖ a. Tëtí sí àlàyé olùkö b. kô àwôn êka àti ìsõrí tí olùkö sô sílê pêlú àpççrç d. kô àpççrç mìíràn sí láti ilé OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI – Téèpù – Tçlifísàn – Rédíò – kásëëtì àti téèpù tí a gba ohùn sí – Fíìmù ìśeré lítírèśõ alohùn – ìwé tí a da lítírèśõ alohùn kô sí
8.LÍTÍRÈŚÕ: Òýkà Yorùbá   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Òýkà Õödúnrún dé irínwó (300 – 400)OLÙKÖ a. Tö akëkõö sönà láti ka òýkà láti Õödúnrún dé irínwó b. Śe àlàyé ìgbésê òýkà ní kíkún AKËKÕÖ a. ka òýkà láti Õödúnrún dé irínwó b. dá òýkà tí a kô sójú pátákó mõ ní õkõõkan d. kô òýkà tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI – Kádíböõdù tí a kô òýkà láti Õödúnrún dé irínwó – Káàdì pélébé pélébé tí a kô òýkà kõõkan sí
9.ÈDÈ: Ìsõrí Õrõ   ÀKÓÓNÚ IŚË a. õrõ-orúkô b. õrõ aröpò- orúkô/ aröpò afarajorúkô d. õrõ-ìśe e. õrõ-àpèjúwe ç. õrõ-àpönlé f. õrõ-atökùn g. õrõ-àsopõOLÙKÖ a. śe àlàyé kíkún lórí ipò àti iśë õkõõkan nínú gbólóhùn. b. śe õpõlôpõ àpççrç lórí õkõõkan fún akëkõö d. darí akëkõö láti śe àpççrç tirê AKËKÕÖ a. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí ìsõrí kõõkan b. kô àwôn àpççrç tí olùkö śe sínú ìwé d. śe àwôn àpççrç tirê lábë ìdarí olùkö. OHUN ÈLÒ ÌKÖNI a. Kádíböõdù b. Káàdì pélébé pélébé.
10.ÀŚÀ: Òwò Śíśe àti Ìpolówó Ôjà   ÀKÓÓNÚ IŚË a. ìdí tí a fi ń polówó ôjà b. bí a śe ń polówó kõõkan. Bí àpççrç; Ç fçran jêkô d. ôgbön ìpolówó ôjà láyé àtijö àti lóde òní. Bí àpççrç: ìpolówó lórí rédíò, tçlifísàn, ìwé ìròyìn, ìpàtç, ìkiri abbl.OLÙKÖ a. Tç ìpolówó ôjà tí a ti tê sórí téèpù fún àwôn akëkõö gbö. b. fún àwôn akëkõö láýfààní láti śe ìpolówó ôjà nínú kíláásì. d. kí akëkõö lô śe àbêwò sí ôjà tàbí ìdíkõ. AKËKÕÖ a. Tëtí sí téèpù tí olùkö tê b. kópa nínú śíśe ìpolówó ôjà nínú kíláásì d. śe àbêwò sí ôjà tàbí ìdíkõ OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI a. àtç b. fídíò d. êrô agbõrõsílê e. Téèpù ç. ìpolówó ôjà lóríśiríśi nínú ìwé ìròyìn
11.ÈDÈ: Ìśêdá Õrõ-Orúkô   ÀKÓÓNÚ IŚË a. kí ni õrõ-orúkô? b. oríśi õrõ-orúkô méjì: àìśêdá àti èyí tí a śêdá pêlú àpççrç. d. Àlàyé kíkún lórí oríśiríśi õnà ìśêdá õrõ-orúkô pêlú àpççrç.OLÙKÖ a. Śe àlàyé ohun tí õrõ-orúkô jë b. śe àlàyé oríśi õrõ-orúkô méjì: àìśêdá àti èyí tí a śêdá pêlú àpççrç: çja, ejò, ìyá, ôwö, êrín, adé, abö, jíjç, alaalë abbl d. śe àlàyé kíkún lórí oríśiríśi õnà ìśêdá õrõ-orúkô pêlú àpççrç. AKËKÕÖ a. Tëtí sí àlàyé olùkö b. śe àpççrç õrõ-orúkô tí a kò śêdá mìíràn d. śe àpççrç àwôn oríśiríśi õrõ-orúkô tí a śêdá mìíràn yàtõ sí èyí tí olùkö ti śe. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI a. kádíböõdù tí a kô oríśiríśi àpççrç sí.
12.ÈDÈ: Àròkô kíkô   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Àlàyé lórí àròkô kíkô b. Oríśiríśi àròkô d. ÌgbésêOLÙKÖ a. Tö akëkõö sönà láti jíròrò lórí aroko b. Töka sí onírúurú àròkô pêlú àpççrç d. śe àlàyé ìgbésê fún kíkô àròkô AKËKÕÖ a. Jíròró lórí àròkô b. Tëtí sí àlàyé olùkö d. sô àpççrç àròkô mìíràn yàtõ sí ti olùkö e. kópa nínú śíśe àlàyé ìgbésê àròkô OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI – pátákó tí a kô oríśi àròkô sí – pátákó tí a kô ìgbésê àròkô sí.
13.ÀTÚNYÊWÒ  ÊKÖ  
14.ÌDÁNWÒ  

YORÙBÁ L2 JSS 3 TÁÀMÙ KEJÌ

ÕSÊORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚÀMÚŚE IŚË  
1.FÓNËTÍÌKÌ: Àwôn êyà ara fún ìró èdè pípè   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Àwôn êyà ara tí a fi ń pe ìró b. Oríśi àfipè: i. Àwôn êyà ara tí a lè fi ojú rí ii. Àwôn êyà ara tí a kò lè fojú rí iii. Àfipè àsúnsí iv. Àfipè àkànmölêOLÙKÖ a. Śe àlàyé àwôn êyà ara tí a ń lò fún àwôn ìró èdè pípè b. Tö akëkõö sönà láti dárúkô êyà ara àfipè àti ìwúlò wôn. d. Dárúkô oríśi àfipè pêlú àlàyé kíkún AKËKÕÖ a. Tëtí sí àlàyé olùkö b. Dárúkô àwôn êyà ara tí a fi ń pe ìró têlé olùkö d. Kô ohun tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé wôn OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI – Àwòrán àwôn êyà ara tí a fi ń pe ìró tí a yà sí ara kádíböõdù – Káàdì pélébé pélébé tí a kô êyà ara ifõ kõõkan sí.
2.ÀŚÀ: Oyún níní àti ìtöjú Aláboyún   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Ìgbàgbö Yorùbá nípa àgàn, ômô bíbí àti àbíkú b. Àwôn tí oyún níní wà fún (tôkôtaya) d. Õnà tí a lè gbà dín bíbí àbíkú kù láwùjô e. oríśiríśi jënótáìpù êjê tó wà àti àwôn tó lè fëra wôn. ç. Aájò láti lè tètè lóyún – àýfààní kíkóra-çni-níjàánu nípa ìbálòpõ f. Bí a śe ń töjú aboyún látijô àti lóde òní: Àtijö; Oyún dídè, èèwõ aláboyún, àsèjç, àgbo abbl Òde òní Oúnjç aśaralóore, lílô fún ìtöjú ní ilé ìwòsàn (ìbílê/ ìjôba) abblOLÙKÖ a. Śe àlàyé ní kíkún lórí ìgbàgbö àwôn Yorùbá nípa oyún níní, ìtöjú oyún àti àsìkò tó tö láti lóyún b. Śe àlàyé onírúurú jënótáìpù êjê tí ó wà àti èyí tí ó bára mu d. Kô àwôn oúnjç aśaralóore tí aboyún lè jç sára pátákó ìkõwé e. Śe àlàyé bí a śe ń töjú aláboyún látijö àti lóde òní ç. Śe àlàyé nípa pàtàkì ìkóra-çni-ní-ìjánu sáájú ìgbéyàwó fún çni tí ó bá tètè fë ômô bí AKËKÕÖ a. Sõrõ nípa àwôn tóyún wà fún b. Sô ohun tí o mõ nípa oyún d. Sô jënótáìpù tìrç e. Dárúkô díê lára àwôn oúnjç aśaralóore ç. Dárúkô díê lára àwôn õnà tí a fi ń töjú aláboyún látijô àti lóde òní f. Tëtí sí àwôn àlàyé olùkö OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI a. Àwòrán aboyún b. Àwòrán díê lára ohun-èlò tí a fi ń töjú aláboyún ní ìlànà ti ìbílê: kòkò àgbo, ìsaasùn àśèjç, ìgbàdí abbl d. Àwòrán díê lára ohun tí a fi töjú aláboyún ní òde òní e. Àtç tí ó ń fi oúnjç aśaralóore hàn.
3.ÈDÈ: Ìdámõ   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Dídá nýkan mõ ní ilé-êkö àti inú ilé. b. Dárúkô àwôn ènìyàn àti bí wön śe jë sí ara wôn d. Dárúkô díê nínú àwôn êyà ara wa; ojú, imú, ôwö, çsê abblOLÙKÖ a. Dárúkô nýkan díê nínú ilé àti ilé-êkö b. Sô orúkô àwôn ènìyàn àti bí wön śe jë sí ara wôn. d. Töka sí orúkô àwôn çranko díê e. Sô díê nínú àwôn êyà ara wa. AKËKÕÖ a. Dárúkô àwôn nýkan díê nílé-êkö àti ní ilé yàtõ sí ti olùkö. b. Tëtí sí àlàyé olùkö d. Sô díê nínú orúkô àwôn çranko e. Töka sí êyà ara rç OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI – Àwòrán àwôn nýkan nílé-ìwé àti inú ilé – Àwòrán çranko – Àwòrán êyà ara
4.ÀŚÀ: Àkókò, ìgbà àti ojú ôjö   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Ôjö tó wà nínú õsê b. orúkô àwôn ośù nínú ôdún d. Sísô iye agogo tó lùOLÙKÖ a. Dárúkô ôjö tó wà nínú õsê àti àśà Yorùbá tó rõmö õkõõkan wôn. b. Sô orúkô àwôn ośù tó wà nínú ôdún. d. Sô iye agogo tó lù ní èdè Yorùbá pêlú õpõlôpõ àpççrç AKËKÕÖ a. Tëtí sí àlàyé olùkö b. Dárúkô ôjö tó wà nínú õsê d. Sô orúkô àwôn ośù tó wà nínú ôdún e. Sô iye agogo tó lù yàtõ sí ti olùkö. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI – kádíböõdù tí a kô orúkô ôjö àti ośù nínú ôdún sí. – Ago ara ògiri – Àwòrán ago tó ń fi onírúurú àkókò hàn.
5.ÈDÈ: Lëtà Kíkô   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Oríśi lëtà: lëtà gbêfê àti àìgbagbêfê b. Ìyàtõ àárin wôn d. ìlànà kíkô lëtà gbêfê – àdírësì, déètì, kíkô õrõ inú lëtà kí a sì pín-in sí ègé afõ bí ó ti yç. – àsôkágbá/ àgbálôgbábõ/ ìgúnlê e. ìlapa kíkô lëtà àìgbagbêfê – Àdírësì – Déètì – Àkôlé – Õrõ inú lëtà tí a pín sí ègé afõ bí ó ti yç.OLÙKÖ a. Sô oríśi lëtà kíkô méjì tí ó wà fún akëkõö b. Śe àlàyé ìyàtõ láàrin méjèèjì d. Lo ìlapa kíkô lëtà gbêfê àti àìgbêfê láti töka sí ìyàtõ wôn e. Tö akëkõö láti kô oríśi lëtà méjì AKËKÕÖ a. Tëtí sí àlàyé olùkö b. Kô ìlapa kíkô oríśi lëtà – gbêfê àti àìgbêfê bí olùkö śe àlàyé rê/ kô ö sára pátákó. d. Têlé ìtösönà olùkö láti kô oríśi lëtà méjì OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI – Pátákó çlëmõö àti kádíböõdù tí a kô ìlànà méjèèjì sí
6.LÍTÍRÈŚÕ: Ìwé Kíkà  (Àśàyàn Ìwé ìtàn àròsô ôlörõ geere)   ÀKÓÓNÚ IŚË a. Ibùdó àti ahunpõ ìtàn b. Àśà tó súyô d. Àwôn kókó õrõ tó súyô e. Êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá ç. Ônà èdè àti ìsôwölo-èdèOLÙKÖ a. Ìfáàrà lórí òýkõwé àti ohun tí êdá ìtàn dálé b. śe àlàyé ìbáyému àkóónú ìtàn náà (ìśêlê, kókó-õrõ) d. Jíròrò lórí ìwà êdá ìtàn pêlú akëkõö e. Jíròrò lórí ìlò èdè àti àśà tó súyô AKËKÕÖ a. Ka ìtàn náà kí o sì jíròrò lórí ìśêlê inú rê (àhunpõ ìtàn) b. sõrõ lórí êdá ìtàn tí wön fëràn àti èyí tí wôn kò fëràn d. śe àfàyô ìlò ônà èdè àti ìsôwölo ônà èdè e. śe àfàyô àśà tó súyô OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI a. ìwé asayan b. ìwé ìròyìn tí ìśêlê tí ó fara pë ti inú ìtàn tó wáyé wà.
7ÀŚÀ: Eré Ìdárayá   ÀKÓÓNÚ IŚË a. ìtumõ eré ìdárayá   b. Oríśiríśi eré ìdárayá i. Eré òśùpá bí i – bojúbojú, ta ló wà nínú ôgbà náà abbl ii.  Eré ojoojúmö – àlö pípa, òkòtó, àrìn títa, ayò títa   OLÙKÖ a. Śe àlàyé bí a ti ń śe díê nínú eré ìdárayá. b. Tö àwôn akëkõö sönà láti śe àwôn eré ìdárayá náà. d.  Kô àwôn orin inú eré ìdárayá náà sójú pátákó AKËKÕÖ a. Sô ohun tí o mõ nípa eré ìdárayá sáájú ìdánilëkõö. b. Dárúkô díê nínú eré ìdárayá mìíràn tí o mõ d.Tëtí sí àlàyé olùkö. e.  Kópa nínú eré ìdárayá tí olùkö darí. ç. kô eré ìdárayá tí olùkö kô sójú pátákó sínú ìwé OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Ôpön ayò Ômô ayò Òkòtó Àrìn abbl
8.ÈDÈ: Òýkà   ÀKÓÓNÚ IŚË a. kíka irínwó – êëdëgbêta ní èdè Yorùbá: bí àpççrç; okòólénírínwó – 420 ojìlénírinwó – 440 õtàlénírínwó – 460 õrìnlénírínwó – 480 abbl b. Kíka òýkà àárin wôn. Bí àpççrç: oókanlénírínwó – 401 èjìlénírínwó – 402 abblOLÙKÖ a. Kô òýkà sí ara pátákó b. Śe àlàyé ìlànà okòó, òjì, õtà, õrìn – Àwôn òýkà àárin wôn d. Śe ìdánwò akëkõö lórí àwôn òýkà náà AKËKÕÖ a. Da àwôn òýkà tí olùkö kô sí ara pátákó kô ö sí inú ìwé rç b. Tëtí sí àlàyé olùkö d. Śe ìdánwò tí olùkö pàśç ní kíláásì OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Kádíböõdù Káàdì pélébé pélébé
9.LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn Ìwé Ewì   ÀKÓÓNÚ IŚË Ewì kíkà Kókó õrõ ajçmö-õrõ-tó-ń-lô láwùjô/ lágbàáyé. Ìśêföfábo ipò obìnrinètò ôrõ-ajé ìkôlura êsìn/ àśà ìkóra-çni-ní-ìjánu nínú ìgbésí ayé õdö d. Ônà èdè àti ìsôwölo-èdèOLÙKÖ a. ka ewì sí akëkõö létí b. śe àlàyé lórí ewì tí a kà d. fa kókó õrõ jáde e. śe àlàyé ônà èdè àti ìsôwölo-èdè tó jçyô AKËKÕÖ a. Ka ewì náà sinu b. ka ewì náà síta d. fi pëńsù fàlà sí ibi tí wön ti kíyèsí kókó õrõ àti êkö tí wön rí kö e. Töka sí ônà èdè àti ìsôwölo-èdè ç. Tëtí sí àlàyé olùkö OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI a. Ìwé tí a yàn b. Àwòrán ohun tí ewì dálé d. Ìwé ìròyìn tí ó sô nípa àwôn kókó õrõ
10.ÈDÈ: Ìró Èdè Yorùbá   ÀKÓÓNÚ IŚË Àpèjúwe ìró köńsónáýtì Àpèjúwe ìró fáwëlì d. Àtç fáwëlì àti köńsónáýtìOLÙKÖ a. Töka sí õnà tí á ń gbà śàpèjúwe köńsónáýtì àti fáwëlì b. Śe àpèjúwe konsonati àti fáwëlì d. Ya àtç köńsónáýtì àti fáwëlì e. Dán àwôn akëkõö wò lórí àpèjúwe köńsónáýtì àti fáwëlì AKËKÕÖ a. Tëtí sí àlàyé olùkö b. Śàjùwé ìró köńsónáýtì àti fáwëlì d. Kô àpèjúwe tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé rç e. Śe ìdánwò tí olùkö pàśç ní kíláásì OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI a. Àtç köńsónáýtì àti fáwëlì tí a yà sínú kadiboodu b. Àwòrán êyà ara ìfõ d. Káàdì pélébé pélébé
  11.  ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ  
  12.  ÌDÁNWÒ  

YORÙBÁ L2 JSS 3 TÁÀMÙ KËTA

ÕSÊORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚÀMÚŚE IŚË  
1.ÒWE ÀTI ÀKÀNLÒ ÈDÈ KÉÈKÈÈKÉ   ÀKÓÓNÚ 1. Ìtumõ òwe 2. Àbùdá òwe 3. ìwúlò òwe: fún àlàyé, ìkìlõ, ìmõràn, ìbáwí abbl 4. Àkànlò èdè – ìtumõ 5. Oríśi àkànlò èdè pêlú àpççrçOLÙKÖ 1. Śe àlàyé owe 2. Töka sí àbùdá òwe 3. Śàlàyé ìwúlò òwe pêlú àpççrç 4. Túmõ àkànlò èdè 5. Töka sí oríśi àkànlò èdè kéèkèèké pêlú àpççrç AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö 2. Pa òwe tí olùkö kô sí ojú pátákó 3. pa òwe ti ara rç 4. Kô ohun tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé rç 5. Śàlàyé ìyàtõ láàrin òwe àti àkànlò èdè OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. kádíböõdù tí a kô òwe àti àkànlò èdè sí. 2. káàdì pélébé pélébé tí a kô òwe àti àkànlò èdè sí
2.ÈDÈ: Òýkà Yorùbá   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Àtúnyêwò òýkà láti oókan dé êëdëgbêta (1-500) 2. ka òýkà láti oókan dé êëdëgbêta 3. Da fígõ àwôn òýkà náà mõ.OLÙKÖ 1. kô òýkà sí ara pátákó 2. śe àlàyé ìlànà òýkà 3. śe ìdánwò fún akëkõö lórí òýkà náà. AKËKÕÖ 1. Da àwôn òýkà tí olùkö kô sí ara pátákó kô sínú ìwé rç 2. Tëtí sí àlàyé olùkö 3. Śe ìdánwò tí olùkö pèsè ní kíláásì OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. kádíböõdù 2. káàdì pélébé pélébé
3.ÀŚÀ: Ìtàn Ìśêdálê Yorùbá   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Ìtêsíwájú ìtàn ìśêdálê Yorùbá 2. Àwôn ômô Õkànbí 3. Àwôn ôba ilê Yorùbá àti orúkô oyè wôn 4. Êyà Yorùbá àti êka èdè wônOLÙKÖ 1. Śe àlàyé ìtàn ìśêdálê Yorùbá àti bí wôn śe tan káàkiri 2. Töka sí àwôn ôba Yorùbá àti orúkô oyè wôn 3. Dárúkô àwôn ìlú Yorùbá àti êka èdè tí wön ń sô AKËKÕÖ 1. Dárúkô díê lára àwôn agbègbè tí êyà Yorùbá tàn dé 2. Dárúkô àwôn ôba Yorùbá yàtõ sí ti olùkö 3. Sô díê lára àwôn ìlú Yorùbá àti êka èdè wôn 4. Tëtí sí àlàyé olùkö. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Máàpù ilê Áfíríkà àti ilê Marubaawa 2. Máàpù Nàìjíríà àti ilê Yorùbá
4.LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn ìwé àyôkà   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Àtúnyêwò àwôn àśàyàn ìwé ìtàn àròsô ôlörõ geere, ewì àti eré-onítàn 2. ìtàn inú ìwé ní sókí 3. Êdá ìtàn 4. Ìfìwàwêdá 5. ibùdó ìtàn 6. Àhunpõ ìtàn   7. kókó õrõ tó jçyôOLÙKÖ 1. Darí akëkõö láti sô ní sókí ìtàn náà 2. Śe àlàyé ní kíkún lórí êdá ìtàn, ìfìwàwêdá, ibùdó ìtàn, kókó õrõ 3. Darí ìjíròrò àti eré ní kíláásì AKËKÕÖ 1. Ka ìtàn àròsô 2. Tëtí sí àlàyé olùkö kí ó sì śe àkôsílê rê. 3. Béèrè ìbéèrè nípa ohun tí kò bá yé wôn 4. Sô ní sókí ohun tí  ìwé dálé lórí 5. kópa nínú ìśeré tí olùkö darí OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. ìwé tí a yàn 2. ohun èlò ìśeré 3. orí ìtàgé 4. Àwòrán àfihàn ìśêlê àti êdá ìtàn eré.
5.ÈDÈ: Ìsõrí õrõ   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Ìtêsíwájú lórí ìsõrí õrõ 2. Dárúkô àwôn ìsõrí õrõ Yorùbá: õrõ-orúkô, õrõ-àpönlé, õrõ-aröpò orúkô, õrõ-ìśe, õrõ-àpèjúwe, õrõ-atökùn, õrõ-àsopõ 3. Àlàyé kíkún lórí ipò àti iśë wôn nínú gbólóhùnOLÙKÖ 1. Śe àlàyé lórí ipò àti iśë õkõõkan nínú gbolohun 2. Śe õpõlôpõ àpççrç lórí õkõõkan fún akëkõö 3. Darí akëkõö láti śe àpççrç tirê. AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö 2. Kô àwôn àpççrç tí olùkö śe sínú ìwé 3. Śe àwôn àpççrç tìrç lábë ìdarí olùkö OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. kádíböõdù 2. káàdì pélébé pélébé
6.FÓNËTÍÌKÌ: Ìró Èdè Yorùbá   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Dárúkô àwôn ìró köńsónáýtì àti fáwëlì 2. Oríśi fáwëlì tí ó wà 3. Àpèjúwe ìró köńsónáýtì àti fáwëlì 4. Àtç köńsónáýtì àti fáwëlìOLÙKÖ 1. ka álífábëêtì Yorùbá 2. Töka sí köńsónáýtì àti fáwëlì 3. Dárúkô oríśi fáwëlì 4. Śe àpèjúwe köńsónáýtì àti fáwëlì 5. Ya àtç köńsónáýtì àti fáwëlì pêlú àlàyé. AKËKÕÖ 1. ka álífábëêtì têlé oluko 2. Ya köńsónáýtì àti fáwëlì sötõ 3. Śe àpèjúwe ìró kõõkan 4. Ya àtç köńsónáýtì àti fáwëlì 5. Tëtí sí àlàyé olùkö OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. kádíböõdù tí a ya àtç köńsónáýtì àti fáwëlì sí 2. káàdì pélébé pélébé
7.ÀŚÀ: Ìsômôlórúkô   ÀKÓÓNÚ IŚË  Ìtêsíwájú lórí: 1. Àśà Ìsômôlórúkô 2. Àwôn ohun èlò ìsômôlórúkô 3.oríśi orúkô: orúkô àbísô, àmútõrunwá, àbíkú, oríkì, ìdílé ìnagijç abblOLÙKÖ 1. Rán àwôn akëkõö létí nípa àśà ìsômôlórúkô 2. Dárúkô àwôn ohun èlò ìsômôlórúkô 3. Töka sí oríśi orúkô Yorùbá AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö 2. Dárúkô àwôn ohun èlò ìsômôlórúkô 3. Töka sí oríśi orúkô pêlú àpççrç nípa ìdarí olùkö OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Àwôn ohun èlò ìsômôlórúkô 2. Àwòrán àwôn ohun èlò ìsômôlórúkô 3. káàdì pélébé pélébé tí a kô oríśi orúkô sí
8.ÈDÈ: Akókò, ìgbà àti ojú ôjö   ÀKÓÓNÚ IŚË Ìtêsíwájú nípa: 1. Sísô àwôn àkókò tó wà nínú ôjö 2. Sísô iye agogo tó lù 3. Ìlò a.m àti p.m ní èdè Yorùbá. Bí àpççrç, Aago méje àárõ, aago kan õsán, aago méje alë abblOLÙKÖ 1. Rán akëkõö létí àkókò tó wà nínú ôjö 2. Śàlàyé agogo tó lù nípa lílo ôwö kúkurú àti gígùn 3. Töka sí õpõlôpõ àpççrç láti fi agogo tó lù hàn AKËKÕÖ 1. Dárúkô àkókò tó wà nínú ôjö 2. Sô iye agogo tó lù nípa ìdarí olùkö 3. Śe àmúlò a.m àti p.m ní èdè Yorùbá. 4. Ya àwòrán agogo tí olùkö kô sílê sínú ìwé rç. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Aago ara ògiri 2. Àwòrán agogo lóríśiríśi
9.ÈDÈ: Õrõ Àyálò   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Oríkì õrõ àyálò 2. Õnà tí õrõ àyálò gbà wônú èdè Yorùbá. Àpççrç; êsìn, ôrõ-ajé, òśèlú, õlàjú abbl. 3. Àwôn èdè tí Yorùbá ti yá õrõ lò bí i èdè Gêësì, Haúsá, Hébérù, Lárúbáwá 4. Oríśi õrõ àyálò pêlú àpççrç.OLÙKÖ 1. Śàlàyé õrõ àyálò. 2. Śàlàyé õnà tí õrõ àyálò gbà wônú èdè Yorùbá. 3. Dárúkô àwôn èdè tí Yorùbá ti yá õrõ lò. 4. Töka sí oríśi õrõ àyálò pêlú àpççrç. AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö 2. Sô àpççrç õrõ àyálò 3. Kô ohun tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé rç. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Kádíböõdù 2. Káàdì pélébé pélébé.
10.ÀŚÀ: Ìkíni   ÀKÓÓNÚ IŚË Ìtêsíwájú nípa 1. Ìkíni ní onírúurú ìgbà àti àkókò 2. Ìkíni fún onírúurú ayçyç 3. Ìkíni fún onírúurú iśë 4. Ìkíni fún çni tí õfõ sê abbl 5. Ìśesí ní àsìkò ìkíni OLÙKÖ 1. Śàlàyé oríśiríśi ìkíni 2. Jë kí àwôn akëkõö kí ara wôn nínú kíláásì 3. Tö akëkõö sönà nípa ìśesí àti ìhùwàsí ní àsìkò ìkíni AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö 2. Kí olùkö àti akëkõö bí ó ti yç 3. Hùwà bí ó śe yç ní àsìkò tí wôn bá ń kí ara wôn 4. Kô iśë tí olùkö kô sójú pátákó sílê
11.ÈDÈ: Êrô Ayára-bí-àśá (Computer)   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Àlàyé lórí èrò kõýpútà 2. Oríśi kõýpútà 3. Êyà ara kõýpútà 4. Ìwúlò kõýpútàOLÙKÖ 1. Śe àlàyé êrô ayára-bí-àśá 2. Dárúkô oríśi kõýpútà 3. Töka sí êyà ara kõýpútà àti iśë wôn 4. Śe àlàyé ìwúlò êrô kõýpútà AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö 2. Sô ìwúlò êrô kõýpútà nípa ìdarí olùkö 3. kô iśë tí olùkö kô sójú pátákó sle sínú ìwé rç. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Êrô kõýpútà 2. Àwòrán kõýpútà àti àwôn êyà ara rê.
  12.  ÀTÚNYÊWÒ IŚË   
  13.    ÌDÁNWÒ 

YORÙBÁ L1 JSS 3 TÁÀMÙ KÌN-ÍN-NÍ

ÕSÊORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚÀMÚŚE IŚË  
1.ÈDÈ: Ìsõrí Õrõ   ÀKÓÓNÚ IŚË Iśë àwôn ìsõrí õrõ nínú gbólóhùn: 1. Iśë tí õrõ-orúkô ń śe nínú gbólóhùn. 2. Iśë tí õrõ aröpò-orúkô ń śe nínú gbólóhùn 3. Iśë tí õrõ-ìśe ń śe nínú gbólóhùn 4. Iśë tí õrõ-àpönlé ń śe nínú gbólóhùnOLÙKÖ 1. Śe àlàyé kíkún lórí ipò àti iśë ìkõõkan nínú gbólóhùn 2. Śe õpõlôpõ àpççrç lórí õkõõkan fún akëkõö 3. Darí akëkõö láti śe àpççrç lórí tirê AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí iśë ìsõrí õrõ kõõkan 2. Kô àwôn àpççrç tí olùkö śe sínú ìwé 3. Śe àwôn àpççrç tìrç lábë ìdarí olùkö OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Kádíböõdù tí ó ń śàlàyé/ śe àpççrç iśë ìsõrí õrõ kõõkan
2.ÌTÊSÍWÁJÚ LÓRÍ ÊSÌN ÒDE-ÒNÍ   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Kírísítíënì 2. Mùsùlùmí 3. Çkanka 4. Buda 5. Gúrúmàrajì Ipa tí êsìn ń kó láwùjôOLÙKÖ 1. Śe àlàyé ipa tí êsìn ń kó láwùjô 2. Ìdí tí ìbõwõ fún êsìn çnìkejì śe śe pàtàkì láti dènà rògbòdìyàn àti ìjà êsìn láwùjô. AKËKÕÖ Sô ohun tí wôn gbö/ rí nípa êsìn òde òní. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Àwòrán àwôn çlësìn wõnyí níbi tí wôn ti ń jösìn sí.
3.ÒÝKÀ: Òýkà Yorùbá láti 301 – 400   ÀKÓÓNÚ IŚË Òýkà èdè Yorùbá láti 301 – 400. Sô àwôn õnà tí a ń gbà śe òýkà ní ilê Yorùbá. B.a. lé – +, dín = –OLÙKÖ 1.Tö akëkõö sönà láti ka òýkà láti oókanlélöõdúnrún dé irínwó (301-400) 2. Śe àlàyé ìgbésê òýkà ní kíkún. AKËKÕÖ 1. ka òýkà láti oókanlélöõdúnrún dé irínwó (301-400) 2. śàlàyé àwôn ìgbésê òýkà. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Kádíböõdù tí a kô òýkà láti oókanlélöõdúrún dé irínwó (301-400)
4.ÈDÈ: Àkôtö Síwájú sí i   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. ìyapa ìsùpõ köńsónáýtì 2. Àtúnśe/ àtúnkô àwôn õrõ méjì tàbí jù bëê lô tí  a ń kô papõ gëgë bí çyô kan tàbí méjì, b.a. nitorinaa – nítorí náà, biotilçjçpe – bí ó tilê jë pé abbl.OLÙKÖ 1. Fi õpõlôpõ àpççrç gbé õrõ rê lësê kí o sì tún àlàyé śe lórí àkôtö òde òní AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö. 2. Śe àkôsílê àwôn àpççrç tí olùkö śe. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Kádíböõdù tí a kô àwôn àpççrç àkôtö òde òní àti sípëlì àtijö sí.
5.LÍTÍRÈŚÕ: Ìwé Kíkà (Eré-Onítàn)   ÀKÓÓNÚ IŚË Àśàyàn ìwé lítírèśõ àpilêkô 1. Ìtàn inú ìwé tí a bá kà ní sókí 2. Êdá ìtàn 3. Ìfìwàwêdá 4. Ibùdó ìtàn 5. Àhunpõ ìtàn 6. Kókó õrõ tó jçyô/ êkö tí ìtàn kö wa: Ìbáyému õrõ tó ń lô láwùjô bí àpççrç: éèdì, ìkôlura êsìn 7. Àwôn àśà Yorùbá tó súyô 8. Ìlò èdè: (a) ônà èdè: àfiwé, òwe, àkànlò èdè  (b) Àwítúnwí, ìfìrómõrísí, ìfohùngbohùn abbl.OLÙKÖ 1. Śe ìfáàrà lórí òýkõwé àti ohun tí ìtàn dá lé lórí 2. Darí akëkõö láti tún ìtàn/ eré onítàn sô ní sókí 3. Śe àlàyé lórí àwôn kókó õrõ tó súyô àti ìbáyému wôn. 4. Śe àlàyé ní kíkún lórí êdá ìtàn, ìfìwàwêdá, ibùdó ìtàn, àhunpõ ìtàn, kókó õrõ 5. Darí ìjíròrò àti ìśeré ní kíláásì AKËKÕÖ 1. ka eré onítàn 2. Tëtí sí àlàyé olùkö, kí ó sì śe àkôsílê rê 3. Béèrè ìbéèrè nípa ohun tí kò bá yé e. 4. Śe ìsônísókí iran eré náà 5. kópa nínú ìjíròrò àti ìśeré tí olùkö darí OHUN ÈLÒ ÌKÖNI 1. Ìwé ìtàn tí a yàn 2. Ohun èlò ìśeré 3. Orí ìtàgé 4. Aśô eré 5. Àwòrán àfihàn ìśêlê àti êdá ìtàn eré 
6.ÌTÊSÍWÁJÚ LÓRÍ ÀRÒKÔ AJÇMÖ-ÌSÍPAYÁ   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Àròkô ajçmö-ìsípayá 2. Àròkô aláríyànjiyàn 3. Àpççrç àkôlé lábë oríśi àròkô kõõkan. 4. Àkôlé     5. ìlapa èrò     6. Àtúntò ìlapa èrò  7. ìfáàrà    8. ìpín afõ    9. kô õrõ inú àròkô   10. ìgúnlê/ ÀsôkágbáOLÙKÖ 1. pèsè àkôlé/ orí õrõ kõõkan 2. Tö akëkõö sönà láti jíròrò lórí àpççrç orí õrõ lábë oríśi àròkô kõõkan 3. Darí akëkõö láti śe ìlapa èrò 4. Tö akëkõö sönà láti kô àròkô nípa lílo ìlapa tí ó śe AKËKÕÖ 1. Jíròrò lórí àkôlé tí a yàn nípa títêlé ìdarí olùkö. 2. kópa nínú śíśe ìlapa èrò 3. Lo ìlapa èrò náà láti kô àròkô
7.ÈDÈ: Àpólà- Orúkô àti Iśë rê   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Ìhun Àpólà-orúkô 2. Ìsõrí õrõ tí ó máa ń wáyé nínú àpólà-orúkô 3. Iśë àpólà-orúkôOLÙKÖ 1. Kô oríśiríśi gbólóhùn 2. Töka sí àwôn ìhun àpólà-orúkô inú wôn 3. Töka sí ìsõrí õrõ tí ó máa ń wáyé nínú àpólà-orúkô 4. Sô pàtàkì àpólà-orúkô AKËKÕÖ 1. Śe àdàkô àwôn gbólóhùn tí olùkö kô. 2. Tëtí sí àlàyé olùkö nípa ìsõrí õrõ tí ó ń jçyô nínú àpólà-orúkô àti pàtàkì rê. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Kádíböõdù tí a kô àpççrç gbólóhùn tí ó ní àpólà-orúkô àti iśë rê sí.
8.LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn Ìwé Lítírèśõ Àpilêkô (Ewì)   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Ewì kíkà 2. Kókó õrõ ajçmö õrõ-tó-ń-lô láwùjô/ lágbàáyé. – ìśêtöfábo, ipò obìnrin, ètò ôrõ-ajé, ìkôlura êsìn/ àśà, ìkóra-çni-ní-ìjánu nínú ìgbésí ayé õdö abbl. 3. Ônà-èdè àti ìsôwölo-èdè.OLÙKÖ 1. ka ewì sí akëkõö létí 2. Śe àlàyé lórí ewì tí a kà 3. Fa kókó õrõ jáde 4. Śàlàyé ônà-èdè àti ìsôwölo-èdè tó jçyô. AKËKÕÖ 1. Ka ewì náà sínú 2. ka ewì náà síta 3. Fi pëńsù fàlà sí ibi tí wôn kíyèsí kókó õrõ àti êkö tí wôn ríkö 4. Töka sí ônà èdè 5. Tëtí sí àlàyé olùkö OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Ìwé tí a yàn 2. Àwòrán ohun tí ewì dálé 3. Ìwé ìròyìn tí ó sô nípa àwôn kókó õrõ
9.ÈDÈ: Àpólà-iśë àti iśë rê   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Oríśiríśi õrõ-ìśe bí i õrõ-ìśe: a. çlëlà àti aláìlëlà abbl b. agbàbõ àti aláìgbàbõ abbl 2. ìhun àpólà-ìśe 3. Pátákó àpólà-ìśeOLÙKÖ 1. Kô oríśiríśi gbólóhùn pêlú àpççrç àwôn õrõ-ìśe nínú wôn àti irú õrõ-ìśe tí wön jë 2. Śàlàyé pêlú àpççrç ìhun àpólà-ìśe 3. Sô pàtàkì àpólà-ìśe AKËKÕÖ 1. Tëtí dáradára sí àlàyé olùkö. 2. Kô àpççrç àwôn õrõ-ìśe àti irúfë èyí tí wön jë sílê 3. mënuba lára pàtàkì àpólà-ìśe OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Kádíböõdù tí ó śàlàyé léérèfé àpólà-ìśe àti iśë rê
10.ÀŚÀ: Eré Òśùpá àti Eré Ojoojúmö   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Ìtumõ eré òśùpá 2. Ìtumõ eré ojoojúmö 3. Ìgbà wo ni à ń śeré òśùpá 4. Ìgbà tí eré ojoojúmö máa ń wáyé 5. pàtàkì eré òśùpá àti eré ojoojúmöOLÙKÖ 1. Sô ìtumõ eré òśùpá àti eré ojoojúmö 2. śàlàyé ìwúlò àti pàtàkì eré òśùpá àti eré ojoojúmö 3. Darí akëkõö láti śe eré/ kô orin tí ó jçmö eré kõõkan AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö 2. Kô pàtàkì àti ìwúlò eré òśùpá àti eré ojoojúmö sílê 3. kópa nínú eré tí olùkö darí OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Ìwé pêlú àwòrán tí ó ń śe àfihàn àwôn tó ń śe eré òśùpá àti eré ojoojúmö.
11.LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn Ìwé Lítírèśõ Àpilêkô (Ìtàn àròsô ôlörõ geere)   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Ibùdó àti àhunpõ ìtàn 2. Àśà tó súyô 3. Àwôn kókó õrõ tó jçmö ìśêlê bágbàmu b.a Êtö ômô ènìyàn, ìśètòfábo, Ètò ôrõ-ajé, ìkôlura êsìn/ àśà, jíjínigbé abbl. 4. Êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá 5. Ônà èdè àti ônà ìsôwölo-èdè  OLÙKÖ 1. Ìfáàrà lórí òýkõwé àti ohun tí ìtàn náà dá lé lori 2. Śàlàyé ìbáyému àwôn àkóónú ìtàn náà (ìśêlê, kókó õrõ) 3. Jíròrò lórí ìwà êdá ìtàn pêlú akëkõö 4. Jíròrò lórí ìlò èdè àti àśà tó súyô AKËKÕÖ 1. Ka ìtàn náà yóò sì jíròrò lórí ìśêlê inú rê (àhunpõ ìtàn) 2. Sõrõ lórí êdá ìtàn tí wön fëràn àti èyí tí wôn kò fëràn 3. Töka sí ônà èdè tí ó súyô 4. Töka sí àśà tí ó súyô OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Ìwé àśàyàn. Ìwé ìròyìn tí ó ń fi ìśêlê tí ó fara pë ti inú ìtàn tó wáyé hàn.
12.ÀŚÀ: Òge Śíśe   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Oge síse 2. Ilà kíkô 3. Aśô wíwõ 4. Ìtöjú irun orí 5. Ìtöjú ara 6. Pàtàkì oge śíśe 7. Àléébù àti ewu nínú oge śíśe àśejùOLÙKÖ 1. Tëtí sí olùkö 2. Śe ìdàkô ohun tí olùkö kô sílê ní ojú pátákó 3. kópa nínú ìmënubà pàtàkì àti àléébù oge śíśe   OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Kóòmù, làálì, ôsç, ìpara, àtíke, bíléèdì omi abbl
  13.  ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ   
  14.  ÌDÁNWÒ   

Education Resource Centre Federal Yoruba Language Scheme of work for JSS 3. Yoruba Teaching Scheme FCT –Schemeofwork.com

YORÙBÁ L1 JSS 3 TÁÀMÙ KEJÌ

ÕSÊORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚÀMÚŚE IŚË  
1.ÈDÈ (FONÖLÖJÌ): Ìpàrójç àti Ìsúnkì   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Oríkì ìpàrójç àti ìsúnkì 2. pípa fáwëlì tó bêrê õrõ jç, b. a ; Adémölá – Démölá, ìkòkò – kòkò, iyàrá – yàrá 3. ìpàrójç láàrin õrõ méjì, b.a. Aya ôba – Ayaba, ojú ilé – ojúlé, ewé oko – ewéko abblOLÙKÖ 1. Śe àlàyé ohun tí ìpàrójç àti ìsúnkì jë 2. Śe àpççrç fún àwôn akëkõö 3. Darí àwôn akëkõö láti mú àpççrç ti wôn wá. AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé lórí oríkì ìpàrójç àti isunki 2. kópa nínú ìkëkõö nípa mímú àpççrç wá 3. śe àkôsílê ohun tí olùkö kô sí ojú pátákó. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Pátákó çlëmõö tí ó ń sô oríkì ìpàrójç àti ìsúnkì pêlú àpççrç 2. Orúkô àwôn akëkõö kan fún àpççrç.
2.ÀŚÀ: Çrú àti Ìwõfà   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Àlàyé lórí çni tí çrú jë. 2. Àlàyé lórí çni tí ìwõfà jë 3. Õnà tí a fi ń ní çrú, bí àpççrç mímú lójú ogun, fífi owó rà abbl 4. Õnà tí a ń gbà lo çrú 5. Õnà tí a ń gbà lo çrú àti ìwõfà (fífi yá owó) ìwõfà.OLÙKÖ 1. Śe àlàyé dáradára fún àwôn akëkõö lórí çni tí çrú jë àti çni tí ìwõfà jë 2. Sô õnà tí a fi ń ní çrú àti õnà tí a fi ń ní ìwõfà 3. Śe àlàyé lórí õnà tí a ń gbà lo çrú àti ìwõfà 4. Śe àfiwé ìkönilëkõö tí ìgbàlódé lô sí òkè-òkun fún òwò nàbì. AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö 2. Śe àfiwé ômô õdõ àti ômô mõlëbí ní õdõ àwôn òbí. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Àwòrán láti inú ìwé tí ó śàfihàn çrú àti ìwõfà.
3.ÈDÈ: Àpólà-atökùn àti iśë rê   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Ìhun àpólà-atökùn 2. Iśë àpólà-atökùn 3. Àpççrç àpólà-atökùnOLÙKÖ 1. Śe àlàyé nípa àpólà-atokun 2. Kô àpççrç àpólà-atökùn 3. Sô nípa iśë tí àpólà-atökùn ń śe nínú gbólóhùn AKËKÕÖ 1. Fi òye sí àlàyé tí olùkö śe 2. kópa nínú àfikún àpççrç 3. Śe àkôsílê ohun tí olùkö kô sí ojú pátákó OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Kádíböõdù tí ó ń śàlàyé léréèfé àpólà-atökùn pêlú àpççrç
4.LÍTÍRÈŚÕ: KíkaÌwé (Àśàyàn lítírèśõ àpilêkô)   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Ibùdó àti àhunpõ 2. Àśà tó súyô 3. Àwôn kókó õrõ tó jçmö ìśêlê bágbàmu b.a. – Ètò ômô ènìyàn – ìśêtöfábo – Ètò ôrõ-ajé – ìkôlura êsìn àti àśà – jíjínigbé abbl 4. Êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá 5. Ônà èdè àti ônà ìsôwölo-èdèOLÙKÖ 1. Ìfáàrà lórí òýkõwé àti ohun tí ìtàn dá lé lórí 2. Śe àlàyé ìbáyému àwôn ìśêlê inú ìtàn náà (ìśêlê, kókó õrõ) 3. Jíròrò lórí ìwà êdá ìtàn pêlú akëkõö 4. Àti lórí ìlò èdè àti àśà tó súyô AKËKÕÖ 1. ka ìtàn náà, yóò sì jíròrò lórí ìśêlê inú rê (àhunpõ ìtàn) 2.  sõrõ lórí êdá ìtàn tí wön fëràn àti èyí tí wôn kò fëràn 3. śe àfàyô ìlò ônà èdè àti ìsôwölo ônà èdè 4. śe àfàyô àśà tó súyô. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. ìwé àśàyàn 2. ìwé ìròyìn tí ìśêlê tí ó fara pë ti inú ìtàn tó wáyé wà.
5.Òýkà Èdè Yorùbá  400 – 500   ÀKÓÓNÚ IŚË Òýkà láti irínwó dé êëdëgbêta (400-500)OLÙKÖ 1. Tö akëkõö sönà láti ka òýkà- irínwó dé êëdëgbêta 2. Śe àlàyé ìgbésê òýkà ní kíkún. AKËKÕÖ 1. Ka òýkà láti irínwó dé êëdëgbêta (400 – 500) 2. Da òýkà tí a kô sójú pátákó mõ ní çyô kõõkan 3. Kô òýkà tí olùkö kô sójú pátákó sínú ìwé. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Káàdì pélébé pélébé tí a kô òýkà kõõkan sí.
6.ÀŚÀ: Çrú àti Ìwõfà   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Àfiwé çrú níní, ìwõfà yíyá láyé àtijö àti ômô õdõ níní láyé òde òní. 2. Kíkó õdömôkùnrin àti õdömôbìnrin lô sí òkè-òkun lô śe çrú àti òwò nàbì. 3. Àwôn ewu tí ó rõ mö wôn.OLÙKÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö 2. Śe àfikún sí àfiwé tí olùkö śe nípaśê ìrírí wôn ní ilé tàbí àdúgbò wôn. 3. Mô ewu tí ó rõ mö wôn. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Ìwé tí ó ń śàfihàn çrú àti ìwõfà.  
7.ÈDÈ: Ìtêsíwájú Lórí Sílébù Èdè Yorùbá   ÀKÓÓNÚ IŚË – Àwôn õrõ tí sílébù wôn ju méjì lô b.a. olówó, ômôdé, labalábá abbl – Ìwúlò sílébù.OLÙKÖ 1. Kö/ śe àpççrç õrõ tí sílébù wôn ju sílébù méjì lô. 2. Śe àlàyé ìwúlò sílébù èdè Yorùbá. AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö 2. Śe àfikún àpççrç tí olùkö śe 3. Śe àkôsílê ohun tí olùkö kô OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Kádíböõdù tí ó ń śe àfihàn sílébù àpççrç àti iśë rê nínú õrõ
8.LÍTÍRÈŚÕ: Ìwé Kíkà   ÀKÓÓNÚ IŚË Àśàyàn ìwé lítírèśõ àpilêkôOLÙKÖ 1. Śe ìtúpalê ìwé tí a yàn nípa títêlé ìlànà ìtúpalê ìwé AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö. 2. Śe àkôsílê ohun tí olùkö kô sí böõdù 3. Kópa nínú èdè OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Ìwé tí a yàn
9.Àròkô Aśàpèjúwe àti Oníròyìn   ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Àlàyé lórí àròkô aśàpèjúwa àti oníròyìn. 2. Àpççrç orí õrõ lábë ìsõrí àròkô kõõkan 3. Ìlapa èrò fún àròkô kõõkanOLÙKÖ 1. Śe àlàyé lórí àròkô aśàpèjúwe àti Oníròyìn 2. Kô àpççrç orí õrõ tí ó wà lábë oríśi àròkô kõõkan 3. Śe àlàyé ìlapa èrò fún àròkô kõõkan. AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí ìdánilëkõö 2. Śe àkôsílê ohun tí olùkö kô 3. Kô àpççrç àròkô oníròyìn nípa títêlé àpççrç ìlapa èrò tí olùkö sô nípa rê. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Pátákó çlëmõö tí a kô ìlànà méjèèjì sí.
10.Òwe Àkóónú iśë 1. Oríśiríśi òwe 2. Ìwúlò òwe 3. Àwôn tí wön ń pa òwe.OLÙKÖ 1. Kô àpççrç oríśiríśi òwe fún àwôn akëkõö 2. Śe àlàyé àwôn tí wôn ń pa òwe àti ìlànà tí ômôdé yóò têlé bí ó bá fë pa á. 3. Sô ìwúlò òwe AKËKÕÖ 1. Fi òye sí àlàyé tí olùkö śe. 2. Kô àpççrç oríśiríśi òwe sílê 3. Sô ìwúlò òwe OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Pátákó çlëmõö tí a kô oríśiríśi òwe sí àti ìwúlò òwe.
  11.  ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ     
  12.  ÌDÁNWÒ     

Federal Yoruba Language Scheme of work for JSS 3. Yoruba Teaching Scheme FCT –Schemeofwork.com

YORÙBÁ L1 JSS 3 TÁÀMÙ KËTA

ÕSÊORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚÀMÚŚE IŚË  
1.Àkôtö Síwájú sí i   ÀKÓÓNÚ IŚË Ìtêsíwájú lórí àkôtö 1. Ìyípadà ìsùpõ köńsónáýtì 2. Àwôn õrõ tí wön ju méjì lô tí a ń kô ní õkan.OLÙKÖ  1. Kô àwôn ìpinnu ôdún 1974 náà. 2. śe àlàyé àwôn ìpinnu náà àti àýfààní rê fún kíkô èdè Yorùbá ní àkôtö AKËKÕÖ 1. Da ìpinnu náà kô sínú ìwé rê. 2. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí àwôn ìpinnu náà lësççsç OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Kádíböõdù tí a kô àkôtö èdè Yorùbá sí.
2.Òýkà Yorùbá   ÀKÓÓNÚ IŚË Ìtêsíwájú lórí òýkà Yorùbá 1. Òýkà Yorùbá láti 301 – 350 2. 351 – 400 3. 401 – 450OLÙKÖ 1. Tö akëkõö sönà láti ka òýkà ní kíkún 2. śe àlàyé ìgbésê òýkà ní kíkún AKËKÕÖ 1. ka òýkà láti 301-350, 351 – 400, 401 – 450 2. Dá òýkà tí a kô sójú pátákó mõ ní õkõõkan. 3. kô òýkà tí olùkö kô sójú pátákó sínú ìwé. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. kádíböõdù tí a kô òýkà láti 301 – 450 sí. 2. káàdì pélébé pélébé tí a kô òýkà kõõkan sí
3.Iśë àwôn ìsõrí õrõ nínú gbólóhùn   ÀKÓÓNÚ IŚË Ìtêsíwájú lórí iśë àwôn ìsõrí õrõ nínú gbólóhùn 1. Iśë tí õrõ-orúkô ń śe nínú gbólóhùn 2. Iśë tí õrõ aröpò-orúkô ń śe nínú gbólóhùn 3. Iśë tí õrõ-ìśe ń śe nínú gbólóhùn 4. Iśë tí õrõ-êyán ń śe nínú gbólóhùn.OLÙKÖ 1. kô oríśiríśi gbólóhùn tí ó fi iśë õrõ-orúkô, õrõ-ìśe àti õrõ aröpò-orúkô hàn sójú pátákó. 2. śe àlàyé kíkún lórí wôn. AKËKÕÖ 1. śe ìdàkô àwôn gbólóhùn tí olùkö kô 2. Tëtí sí àlàyé olùkö OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Kádíböõdù tí a kô àpççrç gbólóhùn tí a ti lo õrõ-orúkô, õrõ-ìśe àti õrõ aröpò-orúkô sí
4.Àśàyàn Ìwé Eré-Onítàn   ÀKÓÓNÚ IŚË Ìtêsíwájú lórí àśàyàn ìwé eré-onítàn 1. Ibùdó ìtàn 2. Àhunpõ ìtàn 3. Àśà tó súyô 4. Kókó õrõ 5. Ìfìwàwêdá 6. Ìlò ÈdèOLÙKÖ 1. Darí akëkõö láti ka eré-onítàn náà. 2. śe ìfáàrà lórí òýkõwé àti ohun tí eré náà dálé 3. fa àwôn kókó õrõ yô 4. jíròrò lórí êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá wôn 5. śe àfiwé ìśêlê inú ìtàn pêlú õrõ tí ó ń lô láwùjô 6. śàlàyé lórí lílo èdè 7. Darí ìśeré ní kíláásì, ìbáà jë ìran kan tàbí méjì. AKËKÕÖ 1. ka eré-onítàn náà 2. jíròrò lórí ìśêlê tí wön gbö rí/ kà rí tí ó fi ara pë èyí tí wön ń kà. 3. fa êkö tí wön rí kö yô 4. töka sí oríśiríśi ìlò èdè 5. jíròrò lórí àwôn êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá wôn. 6. kópa nínú ìśeré tí olùkö darí ní kíláásì.
5.Ìtêsíwájú Lórí Êsìn Ìbílê Yorùbá   ÀKÓÓNÚ IŚË ìtêsíwájú lórí êsìn òde oni 1. Kìrìsítíënì 2. MùsùlùmíOLÙKÖ 1. śe àlàyé ipa tí êsìn ń kó láwùjô 2. ipò Olódùmarè nínú êsìn òde òní 3. àjôśe tó wà láàrin àwôn çlësìn ìbílê, Kìrìsítíënì àti Mùsùlùmí. 4. śàlàyé nípa ìjà êsìn òde òní àti bí a śe lè dëkun wôn AKËKÕÖ 1. sô ohun tí wôn mõ nípa êsìn ìbílê Yorùbá àti êsìn òde òní. 2. jíròrò àjôśe tó wà láàrin çlësìn Mùsùlùmí àti Kìrìsìtíënì 3. jíròrò lórí ìjà êsìn àti bí a śe lè dëkun rê. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Àwòrán àwôn çlësìn Kìrìsítíënì àti Mùsùlùmí níbi êsìn 2. Fídiò 3. Sínnimá
6.Àròkô Síwájú sí i   ÀKÓÓNÚ IŚË Ìtêsíwájú lórí kíkà àti kíkô àròkô Oríśiríśi àròkô: àròkô ajçmö-ìsípayá, aláríyànjiyàn, aśàpèjúweOLÙKÖ 1. pèsè àkôlé/ orí õrõ fún àròkô ajçmö-ìsípayá, aláríyànjiyàn, aśàpèjúwe. 2. tö akëkõö sönà láti jíròrò lórí õrõ náà 3. darí akëkõö láti śe ìlapa èrò 4. tö akëkõö sönà láti kô àròkô nípa lílo ìlapa tí o śe AKËKÕÖ 1. jíròrò lórí àkôlé tí a yàn nípa títêlé ìdarí olùkö 2. kópa nínú śíśe ìlapa èrò 3. lo ìlapa èrò náà láti kô àròkô OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. pátákó çlëmõö tí a kô àkôlé àwôn àròkô wõnyí sí lóríśiríśi 2. pátákó çlëmõö tí ó ń śàfihàn ìlapa èrò fún àwôn àkôlé náà
7.ÀKÀYÉ   ÀKÓÓNÚ IŚË Ìtêsíwájú lórí àkàyé: 1. Ôlörõ geere 2. Elédè EwìOLÙKÖ 1. pèsè àyôkà lórí àwôn õrõ tí ó ń lô lákòókò bágbàmu 2. pèsè ìbéèrè tí ó péye lórí àwôn kókó õrõ inú àyôkà náà. AKËKÕÖ 1. ka àyôkà tí olùkö pèsè 2. dáhùn àwôn ìbéèrè tí olùkö pèsè lórí rê OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. àyôkà oríśiríśi tí ó dálé ìśêlê õrõ tó ń lô láwùjô  2. àwòrán tó bá àyôkà náà mu.
8.Àśàyàn Ìwé Ewì   ÀKÓÓNÚ IŚË Ìtêsíwájú lórí àśàyàn ìwé ewì 1. Ìtàn inú ìwé ní sókí 2. Êdá ìtàn 3. Kókó õrõ 4. Ìfìwàwêdá 5. Ibùdó ìtàn 6. Àhunpõ ìtànOLÙKÖ 1. ka ewì sí etígbõö àwôn akëkõö 2. śe àlàyé lórí ewì tí a kà 3. kô àwôn kókó õrõ jáde 4. śe àlàyé ní kíkún lórí ônà èdè, êkö abbl 5. darí ìjíròrò nípa àwôn kókó inú êkö yìí ní kíláásì     AKËKÕÖ 1. tëtí sí bí olùkö śe ń ka ewì  2. ka ewì sí etígbõö ara wôn 3. tëtí sí àlàyé olùkö 4. kópa nínú ìjíròrò tí olùkö darí ní kíláásì OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Ìwé tí a bá yàn 2. Àwòrán àwôn ohun tí ewì dálé lórí
9.Àpólà-Orúkô àti Iśë rê   ÀKÓÓNÚ IŚË Ìtêsíwájú lórí àpólà-orúkô àti iśë rê: i. Oríkì, Ìhun àpólà-orúkô ii. iśë tí ó ń śe nínú gbólóhùn iii. ìsõrí õrõ tí ó máa ń wáyé nínú àpólà-orúkôOLÙKÖ 1. śe àlàyé kíkún lórí àpólà-orúkô àti iśë rê nínú gbólóhùn. 2. śe õpõlôpõ àpççrç lórí àpólà-orúkô àti iśë tí ó ń śe fún akëkõö. 3. darí láti śe àpççrç tirê AKËKÕÖ 1. tëtí sí àlàyé olùkö 2. kô àpççrç tí olùkö śe sínú ìwé rç 3. śe àpççrç tìrç lábë ìdarí olùkö OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. kádíböõdù tí a kô àwôn àpççrç sí.
10.Àśàyàn Ìwé Ìtàn Àròsô Ôlörõ Geere   ÀKÓÓNÚ IŚË Ìtêsíwájú lórí àśàyàn ìwé ìtàn àròsô ôlörõ geere. 1. Ìtàn inú ìwé ní sókí 2. Êdá ìtàn 3. Kókó õrõ 4. Ìfìwàwêdá 5. Ibùdó ìtàn 6. Àhunpõ ìtànOLÙKÖ 1. śe ìfáàrà lórí òýkõwé àti ohun tí ìtàn dálé 2. darí akëkõö láti tún ìtàn sô 3. śàlàyé lórí àwôn kókó õrõ tó súyô àti ìbáyému 4. śàlàyé nípa àwôn êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá wôn 5. darí ìjíròrò nípa ìlò èdè nínú ìtàn náà AKËKÕÖ 1. ka ìwé náà 2. tún ìtàn náà sô ní sókí 3. jíròrò lórí kókó õrõ inú ìwé náà àti ìbáyému wôn 4. tëtí sí àlàyé olùkö nípa êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá wôn 5 kópa nínú ìjíròrò lórí ìlò èdè OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Ìwé tí a yàn fún kíkà. 2. Àwòrán díê lára ìśêlê tó köni lëkõö nínú ìwé náà
11.Àpólà-ìśe àti Àpólà-atökùn àti Iśë wôn   ÀKÓÓNÚ IŚË Ìtêsíwájú lórí àpólà-ìśe àti àpólà-atökùn 1. Ìhun àpólà-ìśe 2. Ìhun àpólà-atökùn 3. Iśë àpólà-ìśe àti àpólà-atökùnOLÙKÖ 1. śàlàyé lórí ipò àti iśë õkõõkan wôn nínú gbólóhùn 2. śe õpõlôpõ àpççrç lórí õkõõkan fún akëkõö 3. darí akëkõö láti śe àpççrç tirê AKËKÕÖ 1.Tëtí sí àlàyé olùkö lórí ipò àti iśë õkõõkan 2. kô àwôn àpççrç tí olùkö ń śe sínú 3. śàlàyé àwôn àpççrç iśë tí õkõõkan wôn ń śe nínú gbólóhùn OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Káàdì pélébé pélébé tí a kô àpççrç iśë tí õkõõkan wôn ń śe nínú gbólóhùn sí.  
12.FONÖLÖJÌ ÈDÈ YORÙBÁ: Ìpàrójç àti Ìsúnkì   ÀKÓÓNÚ IŚË Ìtêsíwájú lórí ìpàrójç àti ìsúnkì 1. ìpàrójç ìbêrê fáwëlì, b.a. Adémölá – Démölá, Ìkõkõ – kõkõ, Iyàrá – yàrá abbl 2. ìpàrójç õrõ méjì, b.a. aya ôba – ayaba, ojú ilé – ojúlé abblOLÙKÖ 1. śe êkúnrërë àlàyé lórí ohun tí à ń pè ní ìpàrójç àti ìsúnkì. 2. kô àwôn àpççrç õrõ tí a lè pajç tàbí súnkì nínú gbólóhùn sójú pátákó. 3. darí akëkõö láti śe àpççrç tirê AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö 2. kô àwôn àpççrç wõnyí sí inú ìwé 3. śe àwôn àpççrç tìrç lábë ìdarí olùkö OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Kádíböõdù tí a kô àpççrç náà sí.
  13.  Àtúnyêwò Êkö   
  14.  Ìdánwò     

Share this Article
Leave a comment